Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,824 members, 7,956,115 topics. Date: Monday, 23 September 2024 at 02:59 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842124 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Nobody: 11:32am On Apr 15, 2015 |
..... 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 11:58am On Apr 15, 2015 |
.. 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:29pm On Apr 15, 2015 |
.. 4 Likes |
Re: .. by Nobody: 3:31pm On Apr 15, 2015 |
Eku seh ooooo. Ejoor, Oogun wo lafi le da majele moo tia ba gbe dani? Boya ninu ounje abi ninu oti |
Re: .. by Nobody: 3:37pm On Apr 15, 2015 |
healthFirst: Ejoor, seh eleyi ni agbara re kopo abi fun igba wo ni eleyi lee siseh di? 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 3:55pm On Apr 15, 2015 |
Jadonjack: Beeni, agbara eleyi ko po pupo ati wipe lehin ojo die, yio kuro lara wa. Sugbon dan wo...Okigbe to daju ni. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 4:23pm On Apr 15, 2015 |
healthFirst: Odaa, eseun. Ee ti bami daun ibeere mi akoko ooo 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:36pm On Apr 15, 2015 |
Jadonjack: .. 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 4:40pm On Apr 15, 2015 |
healthFirst: Eseun. Yio tunbo dara fun yin 3 Likes |
Re: .. by Ewuro4: 5:07pm On Apr 15, 2015 |
healthFirst: Okay sir. |
Re: .. by absoluteSuccess: 10:04pm On Apr 15, 2015 |
Jadonjack:Moremo l'Agege, hunhun. Wo, apala koni jiya to e nijo ti ewe okigbe yi ba sunko. Ooni fe se konge igbaju-igbamu ti kerikeri mbarode. Sori, to ba raye ja, wa sare kababa pelu igbonse gbigbona ati hilahilo. Ng o nii gbagbe ikilo baba to bimi l'omo: 'ogun lo lojokan iponju, ori eni lo l'ojo gbogbo'. Too eni ori yo odile. Oku nibon nro. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by scholes0(m): 1:03am On Apr 16, 2015 |
healthFirst: Hhahahhaahha Eleyii pa mi lerin pupo. E joo, ki ni o maa sele ti okurin naa ba ti fi pa oko ba iyawo e sun ?? 1 Like 2 Shares |
Re: .. by Nobody: 5:57am On Apr 16, 2015 |
absoluteSuccess: Oseun 1 Like |
Re: .. by absoluteSuccess: 6:54am On Apr 16, 2015 |
Jadonjack:Emi naa dupe, Aku ojumo rere. |
Re: .. by Nobody: 9:40am On Apr 16, 2015 |
scholes0: Yes, bo se ma n ri niyen...we deride whatever we don't understand but it doesn't remove or change it's efficacy. ko si nkan to ma se Oko obinrin na sugbon enikeni yato si eni to fi ewe yen nudi to ba make attempt lati ba obinrin ni ajosepo, yio kabamo. 3 Likes |
Re: .. by scholes0(m): 12:10pm On Apr 16, 2015 |
healthFirst: E maa binu o, ko ri be rara, mi o fi yin se yeye, oro naa kan n pa mi lerin die lasan ni. Amma kilode ti e n se asopo, ati ajopo ede geesi ati ede abinibi? Ko joju rara. Ti a ba fe ko ede Yoruba ki a ko o, ki o danto, ti a ba si fe ko ede Geesi, ki a se be pelu. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 1:30pm On Apr 16, 2015 |
scholes0: Hun, otito loro te so...sugbon yio fun awon eeyan miran laye lati ba wa da si eto yi...sugbon awon Oogun wonye ni mo lero wipe ko ye ki a ko ni ede Oyinbo...idi ni wi pe, ao fe ki awon omo atohun rin wa mon nipa awon Oogun wonyi. 3 Likes |
Re: .. by gawab: 9:47am On Apr 18, 2015 |
Yara lo si www.itanyoruba.com fun ekunrere awon itan ile yoruba lorisirisi. |
Re: .. by absoluteSuccess: 10:35pm On Apr 19, 2015 |
Ago o, mo ki tewetagba lori ikanni yi o, eku oro iwosan ati ilera lori ewe ati egbo o. Inu mi dun lati so nipa egbogi ajebiidan kan ti mo sese pile re. Mo pe oruko egbogi naa ni 'Allicin Pride', ah, egbogi naa dara yeye! Pupo awon ara mi ti won ti too wo ni won'gboriyin fun iwulo Allicin Pride gege bii immune booster tabi 'awogba-arun'. Lowo yi, mo ni obinrin kan ti mo nlo Oogun naa fun lati wo 'iko fee'. Ogun ti a wi yi mumi feran lati wa imo sii lori bi a tile fi ewe ati egbo Ile Ibi Wa se iwosan fun koowa. Sombo ati beebeelo wa ninu oun ti a fi pelo Allicin Pride. Akoja ewe mi re o, Ki Eleduwa o je ki egbogi naa di ilumooka. Aye wa a dara, ewe a maa je funwa o, Ase. Looking back in time, all I can say is, To God be the glory. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:19pm On Apr 21, 2015 |
.. 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 4:38pm On Apr 21, 2015 |
.. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 4:50pm On Apr 21, 2015 |
... 1 Like |
Re: .. by Nobody: 12:39am On Apr 22, 2015 |
... 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 11:39am On Apr 24, 2015 |
... 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 12:51pm On Apr 24, 2015 |
,,, 1 Like |
Re: .. by Nobody: 5:43pm On Apr 28, 2015 |
... 2 Likes |
Re: .. by Redoil: 9:49pm On Apr 28, 2015 |
healthFirst:wicked and wow. Better you hid it in ur native language 1 Like |
Re: .. by Redoil: 9:54pm On Apr 28, 2015 |
healthFirst:i agree with you on this. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 10:53pm On Apr 28, 2015 |
E FUN WA NI OOGUN AYETA ATI AFEERI |
Re: .. by Nobody: 7:46am On Apr 30, 2015 |
walexy30: Ayeta, Tidi jo, Asaki Ibon, Afobon, Afeeri, Egbe, Isuju to daju daada wa sugbon ao le fi sile lori afefe nitori awon eni ibi igara olosa...e ma binu. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 11:28am On Apr 30, 2015 |
... |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 26 |