.. - Culture (6) - Nairaland
Nairaland Forum › Nairaland General › Culture › .. (1882841 Views)
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 ... 99 Reply (Go Down)
| Re: .. by scholes0(m): 1:22pm On May 20, 2015 |
Bmark:Alaye aisan ti e se yii jo eleyii ti awon elede geesi maa n pe ni "Anaemia", ti o maa n waye ti eje eniyan ba dinku ninu seeli eje funfun. E je ki eni yen pada lo si odo dokita onisegun oyinbo fun ayewo ara titun. Imoran mi niyen. Ki alaare naa si tun maa fi oogun ibile tele iwosan re naa leyin. |
| Re: .. by Bmark: 6:17pm On May 20, 2015 |
healthFirst:ese gan.nkan ti mo tun fe moniwipe shey ofa ni oogun yen shishe fun ni tori ati lo ogun oyinbo titi ti ko shishe rara |
| Re: .. by Nobody: 6:21pm On May 20, 2015 |
Bmark:E se alaye lekun rere bi aisan na se n se eni na. |
| Re: .. by Bmark: 8:04pm On May 20, 2015 |
healthFirst:gbogbo ara e weak,,oti lo oogun eje titi ko ri iyipada ojo ti aisan yii ma a bere o ni odab ti won ju nkan lu oun laya lojiji.lati ojo naa loti bere to ba ti rin irin die a maa laaguin gidigan.aa ni okan re oun ni. |
| Re: .. by sammyjay76(m): 8:13pm On May 20, 2015 |
Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo... |
| Re: .. by sammyjay76(m): 8:16pm On May 20, 2015 |
Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo... |
| Re: .. by Nobody: 8:28pm On May 20, 2015 |
sammyjay76:Ibeere ti o dara ni e bere. KI a maa reti baba fun idahun. |
| Re: .. by Kulrunner: 11:31pm On May 20, 2015 |
ejo kini ale lo fun eni ti koma n se nkan osu lai loyun. |
| Re: .. by Mayorz200: 6:25am On May 21, 2015*. Modified: 9:00am On May 21, 2015 |
Ejowo baba---se mo le salaye funyin ni bokele idi ti mo fe ti oniyepe subu. Ejowo baba |
| Re: .. by scholes0(m): 8:07am On May 21, 2015*. Modified: 8:24am On May 21, 2015 |
Mayorz200:E fe so fun wa wipe e mo awon oro Yoruba fun: Pls: ( E jòwó) Private: (Ìkòkò tàbí Gbònkélé) Month (Osù) need: (Nílò) |
| Re: .. by Lionhearted: 8:15am On May 21, 2015*. Modified: 10:25am On Jun 30, 2015 |
? |
| Re: .. by scholes0(m): 8:19am On May 21, 2015 |
Lionhearted:E ni suuru die, e je ki baba Onisegun ibile wa o pada de, o da mi loju wipe won ni egbogi pato, fun isoro ti eni yii n dojuko. |
| Re: .. by bolorunfem(f): 12:26pm On May 21, 2015 |
Baba, e ku ise iwosan, Olodumare a pin yin ni ere o. Ase. E jowo e fun wa ni oogun iju olojo-pipe, oogun eda ati aran latanlatan. E seun mo dupe. |
| Re: .. by Nobody: 2:35pm On May 21, 2015 |
E joo...mo lo irin ajo ranpe ni o. Bi n ba pada sile lola, ng o dahun gbogbo ibeere yin. |
| Re: .. by Nobody: 4:08pm On May 21, 2015 |
Bmark:E je ki eni na pada lo si Ile Iwosan alayewo, ki won se ayewo Okan eni na..Alaye yin jo ti eni to ni aisan Okan oni pajawiri...bi o se ma n bere niyen. Sugbon lehin ayewo, bi awon dokita ba tun so wipe awon o ri inkankan, ki e pada fun wa labo. |
| Re: .. by Nobody: 4:46pm On May 21, 2015*. Modified: 10:18pm On Mar 17, 2016 |
.. |
| Re: .. by Nobody: 5:00pm On May 21, 2015 |
Mayorz200:O ya, e se alaye ni bonkele. |
| Re: .. by sammyjay76(m): 8:07pm On May 21, 2015 |
healthFirst:Eseun fun dahun yi....... Ejowo se dan dan ni o gbodo je. Pe eegun itan adie ni won yio ma fi mu ni? Se a o toju eegun adie naa ti a o ma fi mu ni igba de igba ni abi ekan soso naa nbi yio fi mu eko abi, ao ma pa adie ni gbogbo igba ti a ba fe fi oogun yi mu eko ni? E dakun e se alaye naa daradara fun wa. |
| Re: .. by Mayorz200: 7:07am On May 22, 2015*. Modified: 6:12am On May 23, 2015 |
. |
| Re: .. by Nobody: 9:48am On May 22, 2015 |
sammyjay76:Rara o eegun itan kan ti e ba ti fi bere na leo maa lo |
| Re: .. by Nobody: 9:50am On May 22, 2015*. Modified: 7:31pm On May 22, 2015 |
Mayorz200:E fi ranse si binaryteck@gmail.com |
| Re: .. by Nobody: 10:00am On May 22, 2015*. Modified: 10:19pm On Mar 17, 2016 |
.. |
| Re: .. by Nobody: 12:57pm On May 22, 2015*. Modified: 10:19pm On Mar 17, 2016 |
.. |
| Re: .. by Lionhearted: 1:29pm On May 22, 2015 |
healthFirst:Eni na ti se ayewo. Esi re ni Sinusitis ati systemic yeast infection. |
| Re: .. by Nobody: 2:27pm On May 22, 2015 |
all dis igbo fools self |
| Re: .. by Nobody: 2:32pm On May 22, 2015 |
Lionhearted:E je ki eni na lo Gbogbonise yen...ng o tun fi omiran sita fun yin. |
| Re: .. by bolorunfem(f): 4:23pm On May 22, 2015 |
healthFirst:Mo dupe, e seun o, baba. Ewe a maa je o. Olorun a se gbogbo ise yin ni asepe. |
| Re: .. by Nobody: 6:12pm On May 22, 2015*. Modified: 10:21pm On Mar 17, 2016 |
.. |
| Re: .. by Nobody: 6:47pm On May 22, 2015 |
healthFirst:E seun gan Baba fun idahun yi. Bi otileje pe ko si ogun oyinbo fun arun yi, Ogun ibile wa fun foniku-foladide (sickle cell). |
| Re: .. by Nobody: 7:15pm On May 22, 2015 |
walexy30:beeni |
| Re: .. by Nobody: 7:27pm On May 22, 2015 |
walexy30:Oogun re wa daada sugbon mo fi eleyi sita nitoripe a ti lo ri to sise daada. |
| Re: .. by talktofemi: 4:46am On May 23, 2015 |
Eku ise o, Nje ogun wa fun eniti ki gboran daadaa? Eniyan mi kan ni lo re, |
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana • How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? • Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re • 2 • 3 • 4