Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! - Culture - Nairaland
Nairaland Forum › Nairaland General › Culture › Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! (1565 Views)
| Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! by Aipete2(op): 8:27am On Jul 17, 2015 |
OMO YORUBA OH!!! Oya e jade kawa gbe ASA wa laruge. Foruko sile nibi ti o ba je OMO ODUDUWA rere, maje ki oju ilu e ti e. 'Iyanuoluwa loruko mi, lati Osi Ekiti' omo yoruba rere ni mi |
| Re: Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! by Nobody: 8:32am On Jul 17, 2015 |
Awa omo oodua gbudo le fi imo wa sokan, bi mo se nwo yi ko si irepo to dan moran larin wa, o ye ka le pe aroo ati odofin inu wa, ko ye ki ale maa se eru eya yoku. Yoruba Ronu Ooo |
| Re: Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! by Aipete2(op): 8:44am On Jul 17, 2015 |
elijah2u:eru eya yoku lona wo? Cos, mi o gbo ri mi o de ri ri |
| Re: Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! by PenSniper: 8:20pm On Jul 17, 2015 |
E ooo, omo Oodua gangan at Pataki lemi lati Ile Ijebu ninu eya oloriire ile Yoruba. E se ti e si eto ifarahan at ipejopo ofurufu yi fun eya wa. Yoruba ki ise, beni ako ni se eru enikeni. Ayoleke ni oruko temi. |
| Re: Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! by Aipete2(op): 8:31pm On Jul 17, 2015 |
PenSniper:ehn? Huh? Lol, okay okay okay, ayoleke ayote mi gan ti leke |
| Re: Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! by PenSniper: 8:56pm On Jul 17, 2015 |
Aipete2:Correction: Ayo temi gan ti leke. Lol. Se daadaa lewa o. Omo iya mi. |
| Re: Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! by Aipete2(op): 9:12pm On Jul 17, 2015 |
PenSniper:Lol, beeni mo wa daadaa, eyin na nko? |
| Re: Omo Oduduwa Oh!!! Omo Yoruba Rere Oh!!! by PenSniper: 10:42pm On Jul 17, 2015 |
Aipete2:A ndupe lowo Olorun rere. |
Oluwo Rasheed Akanbi Welcomes Son, Names Him "Oduduwa" • Oduduwa Is Your Father, Not Jesus - Ooni Of Ife Told By A Nigerian • "Ooni Of Ife, Ogunwusi, Ascended Our Father Oduduwa's Throne" - Olu Of Warri • 2 • 3 • 4
What Has The Black Race Contributed To Humanity? • Is Black Magic Real Or Just Made Up To Scare People? • Young Hausa Lady Getting Married To A 60 Years Old Man - Photo