Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,166,922 members, 7,866,497 topics. Date: Thursday, 20 June 2024 at 06:44 PM

Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe - Forum Games (17) - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Forum Games / Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe (98664 Views)

Raiders! Vs Bears! L.i.v.e. / Colts Vs Jaguars L-ive / Your N.l First Crush - What Drew You To Him/her (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (14) (15) (16) (17) (18) (19) (20) ... (25) (Reply) (Go Down)

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 5:59pm On Apr 06, 2009
Igba wo ni Maku o ni ku, O fi aimo awo o nbu opa, ofi aimowe o kan lu'do.



Eniti oju re ko ba ri oran ri,______________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 12:58pm On Apr 07, 2009
Eniti oju re ko ba ri oran ri e je o wi
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Moyola(f): 1:07pm On Apr 07, 2009
E pari owe yii

Itakun toni ki erin ma lo loke odo ____________ tongue
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 1:11pm On Apr 07, 2009
Itakun toni ki erin ma lo loke odo ayefele tohun ti erin ni o jo lo
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Moyola(f): 1:13pm On Apr 07, 2009
Oooooooo! was it dhat obvious?! angry grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 2:26pm On Apr 07, 2009
romade:

Eniti oju re ko ba ri oran ri e je o wi


romade you are correct, there are other conclusions as follows:

1. Eniti oju re ko ba ri oran ri, eje ko fi omo orogun fun oko.
2. Eniti oju re ko ba ri oran ri nii so wipe oun yoo ko ajo kehin



Oran ko ba ojugun_______________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 4:46pm On Apr 08, 2009
Oran ko ba ojugun, o lo hun ni ara eran
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 6:00pm On Apr 08, 2009
romade: soo ti ri wipe omo odo agba ni gbogbo wa bayi:

E pari gbolohun yi:



O ba esu l'orita o ni ko ko ile fun o,____________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Amigoz(f): 6:16pm On Apr 08, 2009
I knew one day it will hunt me not studying yoruba until SS1 undecided sad
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by MrCrackles(m): 6:22pm On Apr 08, 2009
Topic
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 6:34pm On Apr 11, 2009
O ba esu l'orita o ni ko ko ile fun o, laalu iba le da ile ko amaa gbe ita gbangba.


Aparo kan ko ga ju 'kan lo,_____________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 10:01am On Apr 14, 2009
Remii:

O ba esu l'orita o ni ko ko ile fun o, laalu iba le da ile ko amaa gbe ita gbangba.


Aparo kan ko ga ju 'kan lo,_____________________
Aparo kan ko ga ju 'kan lo, a fi eyiti o ba gun ori ebe grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 10:03am On Apr 14, 2009
[b]A ni ki Gambari o ta okiti,o ni ile le[/b]_____________________- cheesy
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 10:08am On Apr 14, 2009
u already completed it
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 10:14am On Apr 14, 2009
romade:

u already completed it

rara ko iti pari grin
se daada lo wa
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 10:15am On Apr 14, 2009
cool
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 10:35am On Apr 14, 2009
[b]A ni ki Gambari o ta okiti,o ni ile le[/b]_____________________-
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 12:21pm On Apr 14, 2009
A ni ki Gambari o ta okiti,o ni ile le, se ata'ye laa pe okiti naa

(Who cares if or not he survives the acrobatic display)


[b]Osupa le eni ko gun rege[/b]_______________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 1:17pm On Apr 16, 2009
Osupa le eni ko gun rege, eni ki baba nla eni na lo yi dada
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 3:51pm On Apr 17, 2009
Remii:

A ni ki Gambari o ta okiti,o ni ile le, se ata'ye laa pe okiti naa

(Who cares if or not he survives the acrobatic display)


Osupa le eni ko gun rege[/b]_______________________


[b]Osupa le eni ko gun rege
; eni t'owo re ba to ko tun se.

[b]Pasan ti a fi na iyanle;[/b]___________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 4:23pm On Apr 17, 2009
Pasan ti a fi na iyanle; o n be laja fun iyawo
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 9:10pm On Apr 17, 2009
Didun lo dun ta nba ore je eko,___________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 9:23am On Apr 22, 2009
Remii:

Didun lo dun ta nba ore je eko,___________________
Didun lo dun ta nba ore je eko,ti ile oge to'ge je grin

[b]Ti apa ba ko sisan[/b]________________________--
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 9:05pm On Apr 22, 2009
Ti apa ba ko sisan, a kaa le ori



Omo ko gbon a ni ko ma ku,__________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by jamace(m): 6:43pm On Apr 25, 2009
Yeeeepaaaaa!
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 2:52pm On Apr 28, 2009
complete the proverb & stop makin noise jo'o
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by wunmilyn(f): 3:41pm On Apr 28, 2009
oya e pari owo yi,

omode o le mo eko je ,
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 4:30pm On Apr 28, 2009
omode o le mo eko je, ko ma raa ni owo



Omo ko gbon a ni ko ma ku,__________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 4:32pm On Apr 28, 2009
Remi pls answer dat one and give me a simpler one
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 4:46pm On Apr 28, 2009
Omo ko gbon a ni ko ma ku, ki lon pa 'ni bi aigbon.


Yio san ko nii san,_________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 12:07pm On May 06, 2009
Remii:

Omo ko gbon a ni ko ma ku, ki lon pa 'ni bi aigbon.


Yio san ko nii san, Olorun ma fi were dan wa wo


[b]

Omo Oba ti nje alakan, [/b]___________________________ (A prince that is eating crab)
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by romsky: 11:53am On May 12, 2009
wia are u all now?

(1) (2) (3) ... (14) (15) (16) (17) (18) (19) (20) ... (25) (Reply)

Lovely Pictures / Match 2 Personalities 2 Make A Couple / Who Are You Missing Today?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 21
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.