₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,445 members, 8,422,075 topics. Date: Sunday, 07 June 2026 at 04:18 PM

Toggle theme

.. - Culture (25) - Nairaland

Nairaland ForumNairaland GeneralCulture.. (1882372 Views)

1 2 3 ... 22 23 24 25 26 27 28 ... 99 Reply (Go Down)

Re: .. by engrkaz(m): 11:35am On Oct 03, 2015
healthFirst:
2. OOGUN OKIGBE TO DAJU

Orisirisi Oogun Okigbe lo wa; awon ti a le lo loju ogun ati awon to je wipe ti agbara won ko po pupo.

Ao ja Ewe Ewuro bi ekun owo, eyi ti ko lu rara ni ao ja, ao gbo pelu omi die, ao yo omi yen sinu ife(Cup) kan, ao bu gaari die sii, ao gbe mu. Obe tabi ada ko niran wa lehin iseju die ti a ti mun Oogun yi.

Ikilo: Eni to ba gbojule Oogun yi lati fi se ise ibi, Oogun yi ko ni sise fun lase Ajagunmole.
aboruboye o baba....se ale lo garri pupa ti a mo si garri Igbo tabi ti ijebu?? Ewe a maa je oo
Re: .. by Nobody: 12:09pm On Oct 03, 2015
enigstil:
Aboru boye o baba, edakun kini itunmo ti oju orun ba pari?
Ti Osu Oju Orun ba pari ...Osupa ni Yoruba n pe ni Osu Oju Orun....Ojo mejidinlogbon ni Ojo Osu Osupa..bi Osu yi ba pari ni ao se oogun yi.
Re: .. by Nobody: 12:12pm On Oct 03, 2015
engrkaz:
aboruboye o baba....se ale lo garri pupa ti a mo si garri Igbo tabi ti ijebu?? Ewe a maa je oo
Epo pupa ti wa lara Gaari pupa..mi o ti lo Gaari pupa fun Okigbe yi ri...sugbon e dan wo bo ba sise ke je ka gbo. Gaari ti ko ni Epo pupa ni mo ti fi danwo...o de sise.
Re: .. by Nobody: 12:20pm On Oct 03, 2015
dosht:
Se aajo yi ko lewu fun ogberi??
Rara, ko lewu
Re: .. by Nobody: 12:26pm On Oct 03, 2015
shoyemiayodeji:
E Jo mo fe mo oruko ewe yi ni Ede yoruba ati Ede gesin ( English). Ese pupo
Abamoda loruko Ewe yen...Abamoda kii so tie ko ma se.
Re: .. by sammyjay76(m): 5:00pm On Oct 03, 2015
healthFirst:
Abamoda loruko Ewe yen...Abamoda kii so tie ko ma se.
@HEALTH FIRST....
KA RA O LE O, EDAKUN OOGUN LATI WO IWORA TABI EGUNGUN ARA TI KO SE DEDE.
MO KO IWE IFIRANSE SI WHATSAPP NUMBER YIN SUGBON MI O RI ESI ATI PE EKII WA SI ORI ILA WHATSAPP NA, EJOWO E JE KI N MO TO BA JE PE E TI PARO NUMBER NI.
ESE PUPO.
Re: .. by jamiu3209(m): 6:38pm On Oct 03, 2015
Aboruboye mojuba eyin agbagba o...ejowo e fun wani Ogun IMO tabi eyi ti alefi ha nkan sori
Re: .. by Davidifa(m): 8:42pm On Oct 03, 2015
Ejo se ogun ajo yi se ao ma ri owo miran ni beni abi ba wo?
Re: .. by Davidifa(m): 8:46pm On Oct 03, 2015
Ogun adeesu ti amu si ajo, moti se fun ore mi leni to ba sise ma je ki a mo lola. Ewe a ma je oooo
Re: .. by scholes0(m):
healthFirst:
Epo pupa ti wa lara Gaari pupa..mi o ti lo Gaari pupa fun Okigbe yi ri...sugbon e dan wo bo ba sise ke je ka gbo. Gaari ti ko ni Epo pupa ni mo ti fi danwo...o de sise.
Gaari ati oje lati ewe ewuro, ni awon elo oogun ti obe tabi ada ko ni le sa wa lara?
Re: .. by scholes0(m): 9:37pm On Oct 03, 2015
Ogbeni Aareonakakanfo, mo ri yin ti e n wo itakun yii.
Nje e gbo ede abinibi wa daadaa bi?
Re: .. by Nobody: 9:40pm On Oct 03, 2015
scholes0:
Ogbeni Aareonakakanfo, mo ri yin ti e n wo itakun yii.
Nje e gbo ede abiniba wa daadaa bi?
Kilode ti mo se ni gbo ede abinibi mi la layi n se omo ale. Imo ti mo ni ni pa ede yoruba wa lara idi ti mo se mu oruko yi. aareonakakanfo
Re: .. by Nobody: 9:42pm On Oct 03, 2015
Igba mi oma n soro fun mi lati tu nkan ti awon eyan so ni bii tori pe aa kin fi ami si
Re: .. by scholes0(m): 9:45pm On Oct 03, 2015
Aareonakakanfo:
Igba mi oma n soro fun mi lati tu nkan ti awon eyan so ni bii tori pe aa kin fi ami si
Ododo oro.
ati wipe, ni igba miran- bi awon akopa itakun yii se n ko ede Yoruba won sile ko danto rara.
Bi apere, elomiran le fe so wipe:
"Ni Igba ti mo lo si Ilu Eko, mo ri omoge arewa kan"

Ki o si ko o bayii:

"Ni gba timolo silu Eko, mori omo ge are wa kan"
Nje eyin naa rii wipe, o ma soro fun elomiran lati ka?
Re: .. by Nobody:
scholes0:
Ododo oro.
ati wipe, ni igba miran- bi awon akopa itakun yii se n ko Yoruba won sile ko daanto rara.
Bi apere, elomiran le fo so wipe:
"Ni Igba ti mo lo si Ilu Eko, mo ri omoge arewa kan"

Ki o sii ko'o bayii:

"Ni gba timolo silu Eko, mori omo ge are wa kan"
Se eyin naa rii wipe, o ma soro fun elomiran lati ka?
Otito le so. opolopo ma n se asise yi sungbon kii se ejo wa. O di ijo ti a ba bere si fi ede Yoruba ko awon omo wa ni ile iwe ti a to le pa asise yi re
Re: .. by keyguy59(m): 12:58pm On Oct 04, 2015
EJOWO GBOGBO OMO YORUBA EJE KI A SI WHATSAPP GROUP KI A LE MA SO ORO DA DA FUN GBOGBO ENI TI O FE WA NI GROUP YI E SEND MESSAGE SI MI LO RI WHATSAPP 08133500074
Olorun o ni da arin wa ru ooooooooo
Re: .. by Davidifa(m): 9:04pm On Oct 04, 2015
Ejo mo ti se adeesu yi but oga ti mo lo ti ku moju ki lo fa
Re: .. by omoaribaba1(m): 9:33pm On Oct 05, 2015
ASEJE RIRISE
IGBIN BONU KAN EWE ALUPAIDA 11 IYERE 11 A O LO EWE PELU IYERE A O BO IGBIN YI A O YAN IGBIN LEKAN SOSO TI YO YO BO NINU IKARAHUN RE A O FI OUN TA LO SE IGBIN YI LODIDI LEPO NIYO, SADURA SI ODI JIJE: tio ba ni ibeere: omoaribaba1@gmail.com
Re: .. by omoaribaba1(m): 9:33pm On Oct 05, 2015
ASEJE RIRISE
IGBIN BONU KAN EWE ALUPAIDA 11 IYERE 11 A O LO EWE PELU IYERE A O BO IGBIN YI A O YAN IGBIN LEKAN SOSO TI YO YO BO NINU IKARAHUN RE A O FI OUN TA LO SE IGBIN YI LODIDI LEPO NIYO, SADURA SI ODI JIJE: tio ba ni ibeere: omoaribaba1@gmail.com
Re: .. by omoaribaba1(m): 9:36pm On Oct 05, 2015
ASEJE RIRISE
IGBIN BONU KAN EWE ALUPAIDA 11 IYERE 11 A O LO EWE PELU IYERE A O BO IGBIN YI A O YAN IGBIN LEKAN SOSO TI YO YO BO NINU IKARAHUN RE A O FI OUN TA LO SE IGBIN YI LODIDI LEPO NIYO, SADURA SI ODI JIJE: tio ba ni ibeere: omoaribaba1@gmail.com
Re: .. by Davidifa(m): 9:48pm On Oct 05, 2015
Ejo mo need awure obinri
Re: .. by omoaribaba1(m): 11:37pm On Oct 05, 2015
OGUN ARUN KARUN

EWE AWOGBA-ARUN,
EGBO AWOGBA-ARUN,
EGUN-EIYE KANAKANA
EGUN-AKALA
EWE TABA GIDI
IDARO ALAGBEDE
KANHUN-BILALA
ODIDI ATARE KAN
EGBO EWE OWO
EWE ARUNYANYAN
ERU ALAMON
AIDAN
ATA-IJOSIN
A O JO PO
A O MA FI OTI LO
LOBATAN
ARUN KO NI SEWA: ti koba yeo; mail mi ni:omoaribaba1@gmail.com
Re: .. by enigstil(m): 5:57am On Oct 06, 2015
Ogbeni Davidifa, moti n she akiyesi yin lori ikanni yi, mori wipe gbogbo nkan ti ema n bere fun koboju mu, ti eyin na ba se akiyesi ema ri wipe eki n ri enikeni da yin lohun.Ejowo mo ro yin ni, ema beere fun awon nkan ti o le se yin lanfanni.
Davidifa:
Ejo mo need awure obinri
Re: .. by omoaribaba1(m):
Mr Difa, ogun awure ti emi mon ti mon ro wipe odaaju ni ki okunrin tepa monse owo re, ema je kin tonyin, tie ba se bimose wi yi,ti owo de tan, tie ko ba pe obirin......obirin ma pe yin, Odami loju ju ada lo....... Saabi oloogun ti ni oolo.
Re: .. by Lionhearted: 6:47am On Oct 06, 2015
Ejowo mo ni ibere kan. Se ti eniyan ba nlo eyonu awon agba ko gbodo sunmo obirin?
Re: .. by kadunasouth(m): 8:03am On Oct 06, 2015
Olubinkin3 osanyin bikin3 olubinkin lokoko jawe, osan in binkin lokoko wa egbo, Aji gbe apo ogun ko eyin lekoko ji gbe apo ogun ko,Orinrin lo nsawo wan lode egba orinrin lo nsawo wan lode orinrin, bo se je fun akoda lo nje fun aseda ki ewe ati egbo koma je fun gbo gbo wa o
Toripe awise ntifa afose ntorun mila kosekose niti ilakose sango kan ki koun orogbo orisa kan wan kogbo do koun obi aba ti alagemo bada lorisa oke gba abamoda koni datie komase oro ti okete baso nile gbo ase kidigba ti nbe ni iru oka enu loti nfi soro eyi mowi yi aro ti roma ase odumare





Moju ba eyin agbagba eje osanmi si rere o!
Re: .. by Davidifa(m): 12:47pm On Oct 06, 2015
E se popo ooooo mo ni ise lowo mo to ni owo lowo.omo oni ifa to ni mi mokan fe mo boya ogun wa ni
Re: .. by Davidifa(m): 12:51pm On Oct 06, 2015
Ti a ba fe mope omo oni ifa todaju ni a se ise mi yi
Re: .. by Davidifa(m): 12:55pm On Oct 06, 2015
Awure eyonu Ewe oriji,lmin ewure,lmin aguntan,ori olongbo ao jo po,ao po mo ose ao ma wee
Re: .. by Davidifa(m): 1:06pm On Oct 06, 2015
Awure ti enia fi ma nwu obinrin).... Irun ori afin,ori ako okere,ewe iroko,irun abe obinrin,ao jo gbogbo re po ao po mose,ao ma fi we ofo re: finfin ni afin to nfi ara re fun orisa eyin obinrin e wa fi ara yin fun mi,gbogbo igi ni o dari jo jin igi iroko,ema fi gbogbo ara yin jin mi,eun okere ni okere fi npe ode enia efi enu yin pe mi,ki e ma fe mi teru tomo ni obo nwu.
Re: .. by Davidifa(m): 1:08pm On Oct 06, 2015
Eyi todaju be apo ekan si mi ni email mi.Aleburudavid6@gmail.com
Re: .. by scholes0(m): 1:26pm On Oct 06, 2015
Davidifa:
Awure ti enia fi ma nwu obinrin).... Irun ori afin ,ori ako okere,ewe iroko,irun abe obinrin,ao jo gbogbo re po ao po mose,ao ma fi we ofo re: finfin ni afin to nfi ara re fun orisa eyin obinrin e wa fi ara yin fun mi,gbogbo igi ni o dari jo jin igi iroko,ema fi gbogbo ara yin jin mi,eun okere ni okere fi npe ode enia efi enu yin pe mi,ki e ma fe mi teru tomo ni obo nwu.
shocked shocked shocked !!
1 2 3 ... 22 23 24 25 26 27 28 ... 99 Reply

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From GhanaHow Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo?Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re234

Viewing this topic: 1 guest(s)