Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,852 members, 7,813,906 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 09:09 PM

.. - Culture (31) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828243 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (28) (29) (30) (31) (32) (33) (34) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by ALIUDAVID: 6:23pm On Nov 07, 2015
ERO ADAAJINA TABI TI ENIYAN BA TE OGUN MOLE.
Ti o ba wu ni, ao wa igbe abo ewure ao po pelu ori, a o mafi ra ibi ti o wu.
fun egbo ti ko jina, ao sa igbe ewure naa ti yio gbe ao ma ku si oju egbo naa.

MADARIKAN
ao fa irun ori wa ti yio dan, ao gbe ile(ground)koto, ao da irun naa si, ao wa yaa igbe le lori, ao fi odindin atare kan le igbe naa lori ao wa yepe le lori,
o kere sugbon o daju.
IBA EYIN AGBAGBA, IBA EYIN TO LAYE

4 Likes 1 Share

Re: .. by omoalade144(m): 8:39pm On Nov 07, 2015
ago onile o, moki awo moki ogberi lori ikanni yi o pe ekaale o.Baba KADUNASOUTH ati baba HEALTHFIRST modupe lopolopo lekan si fun idahun si ibere mi nipa ogun omose(aprentise) ti mobere fun ti e si dami lohun eseun odua agbe wa o.Ejowo efunwa ni ogun ti a le lo fun obirin tonse nkan osu lemeji larin osu kan.Koni baje funwa o.ASE. !!
Re: .. by rsk14rsk: 7:37am On Nov 08, 2015
kadunasouth:
Ogun iferan gbogbo aye
Ao fo eyin agiriki meji sinu igba ao se adua si ao gbe agbada kana ao da omi agban si to bati ho ao da eyin yi si ao fidin lai si iyo nibe ao koje opari
ke mi yin ogun baba! Ejo kini won pe ni eyin agiriki?
Re: .. by fbabs(m): 9:54am On Nov 08, 2015
rsk14rsk:
ke mi yin ogun baba! Ejo kini won pe ni eyin agiriki?

Eyin adiye agric. Not adiye ibile (ororo)
Re: .. by Youceemeri: 11:10am On Nov 08, 2015
Aboru bo ye oo, e jowo o ti to osu merin ti iyawo ile me ti se unkan osu keyin lati ijo ti oyun to baje ni arare ni ko ti ri mo ejowo e sa nu mi ki ni mo le lo fun Gbogbo Aye oju o gbodo ti omo awo.

Baba KADUNASOUTH ati baba HEALTHFIRST EJOWO E DA SI IBERE MI

Re: .. by Ayokunumi24(f): 1:40pm On Nov 08, 2015
e jowo baba, e jowo e fun wa ni ogun ti eyan yio fi ri visa gba

1 Like 1 Share

Re: .. by fbabs(m): 4:35pm On Nov 08, 2015
healthFirst:
OGUN TI OBINRIN KI FI KO OHUN ENIYAN
Eyin adie kan ao lu lori ao fi orii si, ao fi adi si, ao fi epo pupa sii,ao fi oruka si ao gbele ao ri mole ao loyo ni ojo keje ao ma ki bowo tia
ba fe ba obinrin soro

Se ao da tinu eyin yen nu ni abi a maa ko oruka atawon to Ku si lai da tinu eyin nu . Ejowo

2 Likes

Re: .. by Nobody: 9:30pm On Nov 08, 2015
Ok
Re: .. by omoalade144(m): 11:44pm On Nov 08, 2015
ejowo sir se ale lo igba yi fun elomi
Re: .. by Victorolami: 12:04am On Nov 10, 2015
Aboruboye ooo... Ejowo mofe ki efun mi ni ogun idi ton yoo nipase jedijedi at ogun jedi to gbona.
Re: .. by kadunasouth(m): 5:55am On Nov 10, 2015
Fun gbogbo omo ilewe lati pass Exam (secondary/university)
Eso werenjeje eyo meta eyo atare Meta ewe alupaida meta ewe atare die ao lo papo ao fi sin gbere meta si orun owo wa mejeji odaju
NB ti exam bati ku ose kan lati sin, lasiko tasin owo yio ma hunwa sugban mumara oti bere ise niye

6 Likes 2 Shares

Re: .. by kadunasouth(m): 6:00am On Nov 10, 2015
Ose Awure
Ewe tagiri ewe sawerepepe ewe imi esu ao gun ao fi ori popo man ose dudu ao ma fi we

2
Omunu ewuro ewe orijin tutu epo obo ori ose dudu ao gun papo ao ma fiwe

3 Likes 1 Share

Re: .. by kadunasouth(m): 6:03am On Nov 10, 2015
Eyonu
Eru oju aro epo obo ao lopo ma ose lux ao ma fiwe lalale odaju

1 Like

Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 8:14am On Nov 10, 2015
kadunasouth:
Eyonu Eru oju aro epo obo ao lopo ma ose lux ao ma fiwe lalale odaju
E jowo sir, kin ni won n pe ni Eru oju aro.Ewe a maa je fun yin oooooooooo

1 Like

Re: .. by Youceemeri: 11:05am On Nov 10, 2015
Aboru bo ye oo, e jowo o ti to osu merin ti iyawo ile me ti se unkan osu keyin lati ijo ti oyun to baje ni arare ni ko ti ri mo ejowo e sa nu mi ki ni mo le lo fun Gbogbo Aye oju o gbodo ti omo awo.

Baba KADUNASOUTH ati baba HEALTHFIRST EJOWO E DA SI IBERE MI

EJO WO OOOOOO
Re: .. by Victorolami: 3:39pm On Nov 10, 2015
Aboruboye ooo... Ejowo mofe ki efun mi ni ogun idi ton yoo nipase jedijedi at ogun jedi ti oo daju.
Re: .. by Nobody: 5:15pm On Nov 10, 2015
Good
Re: .. by kadunasouth(m): 10:02pm On Nov 10, 2015
Youceemeri:
Aboru bo ye oo, e jowo o ti to osu merin ti iyawo ile me ti se unkan osu keyin lati ijo ti oyun to baje ni arare ni ko ti ri mo ejowo e sa nu mi ki ni mo le lo fun Gbogbo Aye oju o gbodo ti omo awo.

Baba KADUNASOUTH ati baba HEALTHFIRST EJOWO E DA SI IBERE MI

EJO WO OOOOOO

Ogun Obinrin ti kori nkan osure Tabi orun tabi onse Segesege
Egbo paran pupa ati paran funfun ati bara nla kan ati enu opiye ose dudu bi oni 100 naira tabi 50naira babase fe kiopo si ni ati kanhun bilala epo osan wewe tabi kage osan wewe si meji meji ao jo papo yio month fi omin oronbo wewe mu ogun yi daju saka
Otun sise fun atosi, Aremo ati obinrin ti inu ma nrun lasiko to nse nkan osure odaju odaju

2 Likes 2 Shares

Re: .. by flightz(f): 10:41pm On Nov 10, 2015
Was this thread put on front page? I'm amazed by the number of views.... This thread got me thinking; does doing things stated here make one fetish? Eshe
Re: .. by Bostilo: 10:44pm On Nov 10, 2015
Ejowo kini ogun teyan lelo fun oko eniyan ti kofi nile se sina mo. E gbami o tori arun karun towa nita. Ewe a ma je funyin sir o.

1 Like 1 Share

Re: .. by Nobody: 10:49pm On Nov 10, 2015
ALIUDAVID:
ERO ADAAJINA TABI TI ENIYAN BA TE OGUN MOLE.
Ti o ba wu ni, ao wa igbe abo ewure ao po pelu ori, a o mafi ra ibi ti o wu.
fun egbo ti ko jina, ao sa igbe ewure naa ti yio gbe ao ma ku si oju egbo naa.

MADARIKAN
ao fa irun ori wa ti yio dan, ao gbe ile(ground)koto, ao da irun naa si, ao wa yaa igbe le lori, ao fi odindin atare kan le igbe naa lori ao wa yepe le lori,
o kere sugbon o daju.
IBA EYIN AGBAGBA, IBA EYIN TO LAYE

i need it so much...for my mum. d wound is 3yrs plus naw...we've spend alot to know avail.

pls help

1 Like

Re: .. by Nobody: 10:50pm On Nov 10, 2015
kadunasouth:
Ose Awure
Ewe tagiri ewe sawerepepe ewe imi esu ao gun ao fi ori popo man ose dudu ao ma fi we

2
Omunu ewuro ewe orijin tutu epo obo ori ose dudu ao gun papo ao ma fiwe

Pls I Need Your Email Asap.. Thanks
Re: .. by afoami(m): 10:55pm On Nov 10, 2015
iba arawajuo! ejowo baba healthfirst; mo se akiyesi wipe king sunny ade (ninu awon orinwon), prof. wole soyinka ati eyinfunrarayi(esp) ni abala ikinikabo thread yi. eso wipe eti di omo awon agba. wipe won gbodo fi owo tiyi woyin;pe won koni diyin lowo ati mu kadara yin te wa fulfil laye se.ejowo emina oloye(wisdom and intellectual) nla nimi, be moni great dream tole yi orile edeyi pada si rere. mofi edumare (eleruniyi) beyin. ewa ran mi lowo kojo tolo; ke wa gbemi se imule awo agba. email mi{afolamiadenlolu@yahoo.com}
Re: .. by Nobody: 11:33pm On Nov 10, 2015
kadunasouth:
Aseje osole (awure owo)
Ewe onitikuti to lale wu (ewe timati) ao fi owo lu lemeta pelu gboloun onitikuti ti olowo olola wa bami pelu owo lowo 4times
Ao wa ja aolo pelu ata ijosi 16 ao wa lora eja aro ao gesi ona merin ao fiseje ninu koko isasun ibile lepo niyo
Aje funyin lagbara eledua Oba odumare

Tomato ryt?
Re: .. by Bostilo: 11:50pm On Nov 10, 2015
Ejowo kini ogun teyan lelo fun oko eniyan ti kofi nile se sina mo. E gbami o tori arun karun towa nita. Ewe a ma je funyin sir o.

Pls am waitin 4 my reply.
Re: .. by avsnet: 9:01pm On Nov 11, 2015
flightz:
Was this thread put on front page? I'm amazed by the number of views.... This thread got me thinking; does doing things stated here make one fetish? Eshe

I pray that 'healthfirst' should permit me to reply 'flightz' in english as I will not be revealing any inner code of which such revelation must be in Yoruba. Having said that here is my response to your question - 'fetish'

What is FETISH:
1. It is a charm superstitiously believed to
embody magical powers
2. excessive or irrational devotion to some activity
3. a form of sexual desire in which gratification depends to an abnormal degree on some object or item of clothing or part of the body

Having shown the above, I want to state categorically without mixing words that we are in the era of mental slavery, I will also explain this later.

As for all you found being discussed here, it is what define us from any other tribe or culture all over the world. It is our ORAL tradition, our own KABALAH.

I used to tell people around me that: A solution is the right solution to a problem until proved otherwise. And this is the basis of the development of science. It did not get to where it is today on one jump. It was sequenced bit by bit, add some removing some.

What authority do I have to say all the little I have said above? Here it is;
1. I grew up in the village
2. I hate anything charm while growing up.
3. I'm a keen researcher of why nature works in the way it works.
4. I face an unusual life situation, and have to start testing what works for ME!
5. Part of what works for me is this you call fetish.

Now to some simple story about those points above.

1. Sometimes in 2003, I was faced with a serious challenge that will involve being jailed, and having my uncle deported from the US cos, my accuser wrote about me to the national assembly and some ministries. I ran first to the christian clerics, the Pastor and Prophets said 'work' must be done and the work entails dropping 50k, went to muslim cleric same. Fast forward, my business partner dust his fathers archive, we spent 5naira and it is only if the farm produced planted with salt grows that the matter can come up again.

2. In 2006, I experience extreme poverty, such that any coloured paper appears like money to me. (Who has been there before?). However, in 2004, one uncle from US in Nigeria gave me a sheet of paper and on that paper is written 'Asiri Nla'. Why did he give it to me, because as he said, he told me I'm the only one among our peers who always say 'I will never use a left hand to describe my fathers house' that I always say I'm a typical Yoruba Village Boy living in the City.
Now that sheet of paper was what I carried out its experiment, and within 3week, I got a job that has made me travel to SA, Tanzania, Liberia, France and still counting.
3. Since 2006, I have traverse over 30states of the federation, and if not by air by road, and if by road or air, I only need to imprint Ika Meji on the ground, give the word, rub it off and be on my way. I have never encounter turbulence, robbery or the like.

4. Now the big one was, I was always short on money, until during research I came across a book that details the whole 16Odus, and another with the 256Odus, with the method of checking them out with ordinary ludo dice, I tried it, only to start reading exactly the messages that has been given to me by both Pastor/Prophet/Imam/Alfa/Babalawo since 1982 after secondary school. However, knowing fully well that taboo might just be the reason why some of us experience hardship, I went straight to read the taboos and what interest and change my status may surprise you. The taboo says, in all situation, I must not lament, it says every morning I must greet and thank my ORI, it says I must not allow rain to drain my head. I decided to comply and breakthrough has been the word.

For your information, science today was magic of yesterday. All of them involve using specimen A, B, C, mixed in a predefined manner to give a particular result whether the practitioner believe in it or not.

For your information, all of life is energy in motion, all religion is an attempt to manipulate this energy.

For the Jews, they use Kabbalah, for the Arabs they use their own form of Kabbalah, for the Christians their own Kabbalah too, and for the Yoruba their own Kabbalah, which was bastadised by own own Bishop Crowther when he interpreted the Christian Devil to mean the Yoruba Esu. (Which is not the same thing). Kabbalah for avoidance of doubt means ORAL TRADITION.

It is this ORAL Tradition that all initiates used to lord it over their subjects.
I will like to pause here as some of what I'm telling here are coming up in my little book - The Owners Manual.

I hope I have been of help.

11 Likes 1 Share

Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 8:27am On Nov 12, 2015
avsnet:

please kindly give me this "ASIRI NLA" so that my life can be turned around for good like you.

1 Like

Re: .. by jades5050(m): 12:23pm On Nov 12, 2015

Re: .. by jades5050(m): 12:25pm On Nov 12, 2015

Aha I so like this many people forget and abandon their culture and their tradition while following the religion of not their own , you do mention of the GOLDEN DAWN KABBALAH , you must have study the KABBALAH , well that's not what I want to state here , I just want the people following this thread to know that the YORUBA 16 ODUs was so divine and is connected with the celestial world , the day I come across , I was so surprise, and it put more interest in me for further research on it , beside it makes me come back to culture and the Tradition I'm not saying this just for joke or for fun but to let the people know about the YORUBA science and to back you up with your post . Firsthealth e ma binu si mi because I have breach the rule of this thread , as in no other language is allow except our YORUBA language ODUA o gbe wa oooooooooo ase EDUMARE

1 Like

Re: .. by alhajialhaji(m): 2:07pm On Nov 12, 2015
Aburo Aboye Nile Ifa oooo.. Mo nilo iranlowo eyin baba wa ni ooo... emi omo yin Alhaji Taofeeq ni ooo..Baba Healthfirst ati Baba wa Kadunsouth.. e dakun e sanu omo Awo oooo...

Gbogbo Ise Aajo ti a nse fun awo eyan ko je mo ni ooo... mio ma oun to fa ooo...e sanu mi ooo...
Re: .. by alhajialhaji(m): 2:16pm On Nov 12, 2015
healthFirst:
hello, this thread is for lovers of nature when it comes to health and other areas of our lives. This thread is also strictly for the Yorubas and those who can read and understand as the language here is going to be pure Yoruba and no translation will be allowed. Reason is that we are going to be revealing some Yoruba secret knowledge of the application of leaves and roots and we intend to preserve and guard these wisdom of our ancestors.

Please do not ask further question regarding my reason to keep this as a Yoruba affairs, it's my choice...but if you refused to respect this, I shall only dignify you with silence.

Aye wa fun o lati beere fun iru Oogun to ba fe sugbon ao ma ko awon orisirisi Oogun sita. Awon Oogun fun itoju aisan, akoya, ati awon Oogun fun isora/isori, awure, aworo, ati beebe lo. Sugbon kii se gbogbo Oogun ni a le fi sita lofe, awon eyi to ba ni agbara gan ni ao so wipe ki e kan siwa lori apo ifiwe ranse wa binaryteck@gmail.com fun ekun rere alaye.

E le dara po mo wa lori whatsapp pelu ero ibanisoro yi...08148398067...e fi gbogbo ibeere yin ranse, ao da yin lohun

Bi a ba ri inkan ti ko ye wa, e je ki a beere ibeere pelu alaye, ao si gbiyanju lati se alaye lekun rere.

Gbogbo Oogun ti a ba ko sita la ti dan wo, to de ni idaniloju wipe yio se ise ti a ba ran.

Too, mo seba awon agbalagba awo ile aye, mo seba awon awo ode orun, mo seba awon Iya mi abeni...e juba o se o.

Iba, iba, iba

Akoda iba

Aseda iba

Ile ogere a foko yeri

Alapo Iku

Olona ola, iba

Esu odara, iba

Irunmale olukotun

Igba imale olukosin

Iba gbogbo yin o

Ero osaju, ero eyin, iba

Adase ni ni wun omode

Iba ki wun ni o

Eyin to ni aye

E je sise mi o san mi

Emi lomo agba

E je owo a maa je fun mi o

Ada ki nmu, ki o ge eku idi e

Omo eni ki nburu,

Ki a gbe fun ekun pa je

E dari jimi, ki e fi owo mi wo mi

Emi lomo aie fepo we

Osoronga opiki elese osun

Ajefun jedo

Oriri aye

Ebo aye ni a ru o

Osoronga ni nba ni gbele aye

Aje ni npa eni

Osoronga gbigbe ni o gbe mi o

Aje ma pa mi lomo
Lomi ki o somo mi

Iya mi agba opiki elese osun

A woni maye

A woni loju re orun

Eje lepo ekuru won

Iya-mi aye elekuru pupa foo

O gberita jagun

O gbe origi ke kanran kanran

Fori jimi bi mo ba se

Fi owo re wo mi

Na ke kanran wonu ile mi

Iya-mogun alara

Bi igun jebo

Aje gbe ni nje

Bi akala jebo

Aje gbe ni nje

Gbogbo eyi a ba se

Asegben ni e je o je

Iya-agba alapo iku

Olokiki oru

Ki nfo o fara pa

Onile origi ki njebo

Ki ebo naa ma gun rege

A agba ki nfi abo bo eni

Ki Omo ara aye ma ri ami won Lara eni

A jefun jedo

Ki nje tire tan

Ki o ma fio na han eni

Iya mi toto aye

Fio na han mi

Bi o ba gbe ori igi ke

Ma ke ao mi

Bi o gbe orita ke

Ma ke pa mi

Kike ni ki o fi ike re ke mi

Omidan eleye oloju owiwi

A ri eni ko to pe eni

Omoran ologbon

Linmo riro ati w ri eda

Alapo iku olona ola

Iku ti nba nro nile mi

Re danu,Opiri eleye moran bi afefe

Arun ti nba nro nile mi

Ro danu

Iya-mi omoran eleye

A pani ma yoda

A mubo ti nbe laye mi

Re danu o

Eyin ti o ni aye

E fa mi mora

Aje eleye e fa mi mora o

Aburo Aboye Nile Ifa oooo.. Mo nilo iranlowo eyin baba wa ni ooo... emi omo yin Alhaji Taofeeq ni ooo..Baba Healthfirst ati Baba wa Kadunsouth.. e dakun e sanu omo Awo oooo...

Gbogbo Ise Aajo ti a nse fun awo eyan ko je mo ni ooo... mio ma oun to fa ooo...e sanu mi ooo...
Re: .. by alhajialhaji(m): 2:23pm On Nov 12, 2015
kadunasouth:
Fun gbogbo omo ilewe lati pass Exam (secondary/university)
Eso werenjeje eyo meta eyo atare Meta ewe alupaida meta ewe atare die ao lo papo ao fi sin gbere meta si orun owo wa mejeji odaju
NB ti exam bati ku ose kan lati sin, lasiko tasin owo yio ma hunwa sugban mumara oti bere ise niye

Aburo Aboye Nile Ifa oooo.. Mo nilo iranlowo eyin baba wa ni ooo... emi omo yin Alhaji Taofeeq ni ooo..Baba Healthfirst ati Baba wa Kadunsouth.. e dakun e sanu omo Awo oooo...

Gbogbo Ise Aajo ti a nse fun awo eyan ko je mo ni ooo... mio ma oun to fa ooo...e sanu mi ooo...... mio mo bi mo se le kan si yin Lori e-mail yin ni ooooo.

(1) (2) (3) ... (28) (29) (30) (31) (32) (33) (34) ... (99) (Reply)

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 112
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.