.. - Culture (32) - Nairaland
Nairaland Forum › Nairaland General › Culture › .. (1882598 Views)
1 2 3 ... 29 30 31 32 33 34 35 ... 99 Reply (Go Down)
| Re: .. by alhajialhaji(m): 2:28pm On Nov 12, 2015 |
Aburo Aboye Nile Ifa oooo.. Mo nilo iranlowo eyin baba wa ni ooo... emi omo yin Alhaji Taofeeq ni ooo..Baba Healthfirst ati Baba wa Kadunsouth.. e dakun e sanu omo Awo oooo... Gbogbo Ise Aajo ti a nse fun awo eyan ko je mo ni ooo... mio ma oun to fa ooo...e sanu mi ooo...... mio mo bi mo se le kan si yin Lori e-mail yin ni ooooo. |
| Re: .. by Aluqman(m): 8:50pm On Nov 12, 2015 |
Aboru Aboye baba o, eku ise takun takun o. Odua agbewa o. Mo nilo egbogi fun omo to sesen femahu eyin. Ko le jade ni irorun, ati Ogun akokoro fun agbalagba. Eseun o. |
| Re: .. by BookieMan: 9:56pm On Nov 12, 2015 |
avsnetbawo la se le kansi yin? O se pataki. |
| Re: .. by kadunasouth(m): 11:46pm On Nov 12, 2015 |
alhajialhaji:Egbiyanju awon igbese wonyi kia ni ayipada rere yio de 1. Ajegun ebe awon Agba Ogede omini eyokan odidi atare kan elelo atare gidi tabi atare aja eo wa bo epo atare yi eo yo gbogbo idoti arare kuro lai ni jeki okankan kojabo ninure eo fe dada eo wa dasinu tanganran funfun eo wa juba fun awon ti oloun ko aye lelowo dada eo waso bayi Ona merindinlogun lalake tiso gbo gbo igi ti elegbeje ba fowo ba didun nidun lati onilo tin ba jawe komaje tin bawa egbo komaje ti basogun komaje funmin, gbogbo aburu omo araye ati isakusa to walarami ti koje ki ogun ti mobase kojemo kotudanu lati onilo month palase nio ao wa fi ogede yi ba atare ao maje tafijetan Ewo nio okogbodo mumin fun bi wakati kan, gbogbo ori eni toba je yio gbona wa yio ma lagun wa fi owo gba eledare mun pelu iWure aje fun yin o Elekeji Egbo lapalapa ati odidi atare ao jopo ao mafi epo la lalale Eleketa egbo akese ati afoma lapalapa ati odidi atare kan ao jo idi ogun yi kogbodo kanle taba ti jotan koko na ao so si bikan ni akogbodo so kale ao mato si awon ogun tabase diedie Elekerin Ewe ata ewe alupaida 3 eyo atare meje ase oga ao gun papo gbere yipo owo wa mejeji ati gbere mesan si ika arin fun eni to nte yepe (isabi) tebase gbogbo eleyi ayipada rere deeeeeee |
| Re: .. by jades5050(m): 6:12am On Nov 13, 2015 |
kadunasouth:baba e jo sir se ekan ni won ma sin gbere yii abi gbogbo igba ti won ba ti ni Exam ni won ma ma sin si owo. ewe a ma je fun yin |
| Re: .. by tonytony208(m): 11:01am On Nov 13, 2015 |
9jacrip:Sé àwon aye mo ìtumò o thread sha! |
| Re: .. by flightz(f): 11:55am On Nov 13, 2015 |
avsnet:I appreciate your response. I will take my time to read it slowly to digest them all. @op, I'm sorry for typing in English. I communicate better in it, e fi ori jimi. |
| Re: .. by Nobody: 2:03pm On Nov 13, 2015 |
avsnet:Thanks for this explanation. Isese A Gbe Wa O! This is a deep one. My life's experience is almost similar to yours, but as the sayings goes; Ina Ile 'Lomo Ewure N'Ya gbehin. The deep can only call to the deep. |
| Re: .. by myola(m): 4:16pm On Nov 13, 2015 |
healthFirst:aboru 'boye n'ile ifà o, e jowo mo ti pe ago ko lo, beni mo tun kan s'iyin lori email naa, mi o ri esi iyen na. mo fe lati ri yin ni, ti e ba le so bi mo se le ri yin fun mi. o'gbo a'to o |
| Re: .. by Nobody: 5:08pm On Nov 13, 2015 |
myola:E send e-mail miran, i alway try to reply all my mails. |
| Re: .. by sammyjay76(m): 6:51pm On Nov 13, 2015 |
healthFirst:E jowo fi ero iba ni soro yin ranse si sajolive6@gmail.com Eseun. |
| Re: .. by omoalade144(m): 9:05pm On Nov 13, 2015 |
aboru aboye ooooo!!!.Ejoo iru awo ewo lonje Tangaran |
| Re: .. by keyguy59(m): 11:14pm On Nov 13, 2015 |
ORO IKILO orunmila ni ko ko ifa,ki won le mo ifa da,,,won ko won ko ifa won o si mo ifa daa,,...won ni ko ko ewe ki won le ba mo ewe ja won ko won ko ewe mi mo,,,won o si mo ewe ja..won ni ko ko ohun jiju won ko won ko ko ohun jiju.....iba agbagba.........eyi so fun wape bi ologun ba se ni ke sa ni ke se sa oooooo.......iba healthfirst oo, |
| Re: .. by kadunasouth(m): 3:12am On Nov 14, 2015 |
OGUN AWURE TO NSI ONA NI TIPATIPA Ako alangba gbigbe kan,ewe firiganmu,Eru alamo ,Imi ojo, ao gun gbogbo re po,aofi ase joo dada ,nigbati aba joo tan ,ao gbon eyi ti oba kunna yen ao po mo ose dudu,sawasawa toku ni ,ao fi ma fi turari ni ale ojo Aje ,ao ma we ose yen ni ojo Aje ati Ojobo ,ao ma sope ki ona si fun mi lona kona o tan. |
| Re: .. by ALIUDAVID: 5:07pm On Nov 14, 2015 |
Oriki Iyami
Iba Olodunmare
Iba Akoda
Iba Aseda
Iba Esu Lalu Ogiri Oko Iba Ogun Lakaiye
Iba Sango Olukoso Lalu
Iba Osun Ramu Ofide Wemo
Iba Eyin Iya mi o
Eyin Lajapa Jori O
Eyin Latifun Joronro Obalanta Omi tutu ni o temu Eja Bo
Oro tutu ni o tenu mi bo
Ki irawo Mi ma rele
Giga Giga Lan Bojo
Oke Oke Lolawa Yio ma re
Oke Oke Lolawa Iyo ma re Eyin Iya Eni Ki ma Su Sepo
Mo su sepo E O bami Wi Rara
Eni Kin Ma To Sala
Mo to Sala E O Ba Mi Wi Rara
Eni kin mafi Ikodide nudi
Mo fi ikodide nudi e o bami wi rara Eyin Iya Ke Je O ju Mi Se
Ase ti Eledunmare
Olodunmare Ase |
| Re: .. by ALIUDAVID: 5:12pm On Nov 14, 2015 |
kadunasouth:baba ki lo nje 'imi ojo' se ti eniyan ni. |
| Re: .. by ALIUDAVID: 5:38pm On Nov 14, 2015 |
IBA EYIN IYAMI OSORONGA. Ilè mopue o ! Ìyàmì Òsòróngà Mopue o ! Òdu-Logboje Ibá o ! Ibá Òsa-iyeku kibí odu Ìyàmì Òsòróngà Mojubá Obinrin Lode Olo Gèlèdè Ibà Ìyàmì o ! Ohun abáwi fun Agbà Ni agbà Ngbo Ohun awí fun Agbà Ni agbà Ngbá Ohun timowí loníjé osé Ohun mofé kose loní Je kori be e Ní orunkò éhiyn Ìyàmì Òsòróngà Olo hun Òla ! Olo kun Òla ! Ójó ojú ómó , baféfó Aki gbe pue Òòrúnmìlà Ko gbehun Agbe Asè o ! |
| Re: .. by myola(m): 7:22pm On Nov 14, 2015 |
healthFirst:aboru 'boye o. ifa ori mi re o, ifa iya mi re o. mo fi email miran ranse. email mi ni : olayede@gmail.com |
| Re: .. by STAREWEALTH: 9:07pm On Nov 14, 2015 |
E JOWO TA NI O MO PHN HEALTHFIRST KI WON FI RANSE SI (alaooluwatosin1@gmail.com)e jowo oodua agbe wa o ase |
| Re: .. by Ayokunumi24(f): 9:34pm On Nov 14, 2015 |
BABA E DAKUN E FUN WA NI OGUN TI ENIYAN TO SANRA YIO FI JO, NITORI AWON AISAN TO RO MO SISANRA |
| Re: .. by STAREWEALTH: 9:58pm On Nov 14, 2015 |
E JOWO E FUN WA NI OGUN TI ENIYAN FI MA N PO AFUNJE IFE TI IYAWO FUN OKO JE TI O FI SOKO RE DI DINDINRIN |
| Re: .. by Nobody: 1:38am On Nov 15, 2015 |
baami healthfirst e dakun ki ni won lo ewe pandoro fun? |
| Re: .. by STAREWEALTH: 4:34pm On Nov 15, 2015 |
EJOWO GBO ILE, SE EWE WEREPE NI WON N PE NI EWE INA? |
| Re: .. by Snowealth: 12:00am On Nov 16, 2015 |
Mo ki gbogbo ile o, pataki julo baba wa healthfirst ati Kaduna south , Olorun a ma fun yin se o, e o pe fun wa lase Edumare. Mo ti ko eko lorisiri lori fanran yii. Ile ati ona yin ati ti gbogbo awon omo egbe ko ni daru o. |
| Re: .. by Nobody: 6:08am On Nov 16, 2015 |
healthFirst:Ejoor sir, e bami tun email address yin ko sibi. I'm findin it difficult check from the begining cos of my phone. I hav a serious problem that I need your help on. Pls reply me as soon as possible. This as to do with stroke. Its an emergency |
| Re: .. by kadunasouth(m): 7:47am On Nov 16, 2015 |
Ogun fun eni ti aye ban dalamu ewe lapalapa pupa pelu ewe agogogun, ebo obo ao gun mo ose dudu ao ko sinu igba olomori ao eedu eyokan ao kibo ose na larin ao ma fiwe. Wan atuwo lorore |
| Re: .. by alhajialhaji(m): 9:44am On Nov 16, 2015 |
E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo.. Olohun a maa tun bo wa pelu yin... Eo pe ju bi mope tinpe lo.. wonyi kia ni ayipada rere yio de 1. Ajegun ebe awon Agba Ogede omini eyokan odidi atare kan elelo atare gidi tabi atare aja eo wa bo epo atare yi eo yo gbogbo idoti arare kuro lai ni jeki okankan kojabo ninure eo fe dada eo wa dasinu tanganran funfun eo wa juba fun awon ti oloun ko aye lelowo dada eo waso bayi Ona merindinlogun lalake tiso gbo gbo igi ti elegbeje ba fowo ba didun nidun lati onilo tin ba jawe komaje tin bawa egbo komaje ti basogun komaje funmin, gbogbo aburu omo araye ati isakusa to walarami ti koje ki ogun ti mobase kojemo kotudanu lati onilo month palase nio ao wa fi ogede yi ba atare ao maje tafijetan Ewo nio okogbodo mumin fun bi wakati kan, gbogbo ori eni toba je yio gbona wa yio ma lagun wa fi owo gba eledare mun pelu iWure aje fun yin o Elekeji Egbo lapalapa ati odidi atare ao jopo ao mafi epo la lalale Eleketa egbo akese ati afoma lapalapa ati odidi atare kan ao jo idi ogun yi kogbodo kanle taba ti jotan koko na ao so si bikan ni akogbodo so kale ao mato si awon ogun tabase diedie Elekerin Ewe ata ewe alupaida 3 eyo atare meje ase oga ao gun papo gbere yipo owo wa mejeji ati gbere mesan si ika arin fun eni to nte yepe (isabi) tebase gbogbo eleyi ayipada rere deeeeeee[/quote] |
| Re: .. by alhajialhaji(m): 10:08am On Nov 16, 2015 |
alhajialhaji: |
| Re: .. by alhajialhaji(m): 10:11am On Nov 16, 2015 |
kadunasouth:. E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo.. Olohun a maa tun bo wa pelu yin... Eo pe ju bi mope tinpe lo.. Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo to gbona gidi,ounmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa. Efu mi ni phone number yin...email mi ni yi. taofeeqyeqeen@yahoo.com. |
| Re: .. by alhajialhaji(m): 10:12am On Nov 16, 2015 |
[quote author=alhajialhaji post=40073071][/quote]E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo.. Olohun a maa tun bo wa pelu yin... Eo pe ju bi mope tinpe lo.. Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo to gbona gidi,ounmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa. Efu mi ni phone number yin...email mi ni yi. taofeeqyeqeen@yahoo.com. |
| Re: .. by alhajialhaji(m): 10:16am On Nov 16, 2015 |
rsk14rsk:Emi Alhaji Taofeeq Oladapo ti e fun ni Ajegun ni sir... E se mo dupe pupo lowo yin ooooooooo.. Olohun a maa tun bo wa pelu yin... Eo pe ju bi mope tinpe lo.. Ma fun yin ni esi bi o ba se ri.... E jo! mo fe onmo to gbona gidi,ounmo ti a fin wo iyepe, ati onmo kamo oun ti oni jalabi ba babawa. Efu mi ni phone number yin...email mi ni yi. taofeeqyeqeen@yahoo.com. Ejo e Funmi ni email yiin..... |
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana • How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? • Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re • 2 • 3 • 4
