Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,165,924 members, 7,863,254 topics. Date: Monday, 17 June 2024 at 01:51 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Asiri Gbigba Adua (52036 Views)
Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re / Asiri Nla Loju Ona Sufi (2) (3) (4)
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 6:35pm On Mar 02, 2016 |
aktab:Ko pan dan dan kase aluwala, alese aluwala, asi lese lai se aluwala obinrin ti konirun kole se iseyi tabi okunrin ti jenaba wa larare konilese tabasi ti soro siyan ao le sema otun di ojomiran |
Re: Asiri Gbigba Adua by talktofemi: 7:24am On Mar 16, 2016 |
kadunasouth: se eniti kiise musulumi le se ise ati bawo ni yio se se. |
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 10:09pm On Mar 18, 2016 |
talktofemi:Rara o! Abala yi wa fun elesin Islam, (musulumi) ti eni ti kokin se musulumi bani ifesi iru enibe ni latiwe si islam, igbayi loto le ni anfani ati se Ese pupo fun ibere yin |
Re: Asiri Gbigba Adua by niphmmy(f): 10:33am On Mar 30, 2016 |
Ejowo ustaz, eran mi lowo. Efun mi ni adura ti mole fi wase(job) alalubarika, ki aanu Olorun wa miri. Esaanu mi sir. 1 Like |
Re: Asiri Gbigba Adua by suledes(m): 12:11pm On Apr 08, 2016 |
Salamu Alaikum Alfa, Eku igbiyanju si ona esin Islam. Allah atunbo sanyi lesan. Eyin le o jeki atoju bole, opolopo Alfa lo wa lode oni. Tio je wipe awon asiri ti won ni, won nfi sahun si awon musulumi nitori owo, nitori be won nku pelu asiri won. won gbagbe wipe Allah sope gbogbo nkan ni yoo tan, afi oun Allah. Gbogbo nkan ti eniyan bani ko mafi sahun somo lakeji Ejowo ebawa post awon Hatimi (Hontu) to daju fun awa omo ilekewu yin. Maa salm 1 Like |
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 9:16am On Aug 05, 2016 |
ADUA BIBIA BUKATA Astagafurullahi 70 Alhamdulilahi rabil Alamina 100 Fatia 4 ao fitoro Alekun ike ati ige fun Anabi Muhammad (s.a.w) Fatia 2 fun gbogbo awan waliyi oloun Jaoratul kamal 65 Ao toro nkan ti anfe. Ao se Adua yi fun ojo meji Sara re Ao lora akara. Tabi kiwan bawa din si 92 ao toro wipe ki oloun bawa bia bukata na kiojo meje otope lola Alubarika ati ife tonisi Anabi muhammad s.a.w Pelu ogo oloun bukatana yio bia botiselewu kio tobi to odaju NB kariwipe irun wakati marunwa npe dada Mase dite eniyan tobati kolu ofinyin osese kadua gba ni ijo keji ti kobaribe ojokeje kogbodo jubelo tiko bawa ribe ye arare wo |
Re: Asiri Gbigba Adua by uaolayiwola(m): 9:01am On Aug 23, 2016 |
ese_pupo_baba |
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 2:52am On May 20, 2020 |
Allauma soli wasalim ala sayidina wana biyina Muhammad Alasi ma wulida mislahu fil hujudi walam yukhladi mislahu kotu Asalamu Alaikun waramatullahi wabarakatu Gbogbo ile mo nkiyin o RAMADAN MUBARAK, WA LAILATUL KODIR, am doing today Barkallahu fihi |
Adeboye Frowns At Pastors Growing Beards / Pastor Chris Oyakhilome Buys A Car For Ada Ehi (Photos) / I Wantr To Know More About The Pyrates Confraternity Aka Seadog
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 17 |