Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,461 members, 7,819,681 topics. Date: Monday, 06 May 2024 at 08:45 PM

Asiri Gbigba Adua - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Asiri Gbigba Adua (51860 Views)

Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re / Asiri Nla Loju Ona Sufi (2) (3) (4)

(1) (2) (Reply) (Go Down)

Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 5:02pm On Jun 21, 2015
Bere Adua re Pelu opolopo asalatu sise fun alaye lorun anabi Muhammad S.A.W

Maha bere si ko awan adua tan fi nbo ninu gbogbo ide ati aburu ni ilana ti oloun yonu si

For your spritua help bad dream istihara solution to ur prob and more info
(fun gbogbo isoro ati atunse si oro igbese ayere kansimi )
contact me
08028358926a@gmail.com
09090305775

1 Like 1 Share

Re: Asiri Gbigba Adua by Hardetutu01(m): 5:09pm On Jun 21, 2015
more pls
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 6:34pm On Jun 21, 2015
kadunasouth:
Bere Adua re Pelu opolopo asalatu sise fun alaye lorun anabi Muhammad S.A.W

Maha bere si ko awan adua tan fi nbo ninu gbogbo ide ati aburu ni ilana ti oloun yonu si

Ti isoro badoju ko o,
Alauma soli ala muhammadi wasalim 100
Bismillahi rahmani rahim 1
Ao daniyan isoro na
Ao tun wase
Bismillahi rahmani rahim 786
Alauma soli ala muhammadi wasalim 100

Sarare dawa agolokan agbado agolo kan iyo sibikan sugar sibi meji omin toma sibi meje fun obinrin sibi mesan fun okunrin ao da gbogbore papo ao daniyan si ao gbe sinule ti omina yio fi gbe man lara bi wakati mefa ao wa fan sita tabi kalore dasi ori atan abi kadafun adie adura na yio gba larin ojo meta

5 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 7:36pm On Jun 21, 2015
Ti isoro badoju ko o,
Alauma soli ala muhammadi wasalim 100
Bismillahi rahmani rahim 1
Ao daniyan isoro na
Ao tun wase
Bismillahi rahmani rahim 786
Alauma soli ala muhammadi wasalim 100

Sarare dawa agolokan agbado agolo kan iyo sibikan sugar sibi meji omin toma sibi meje fun obinrin sibi mesan fun okunrin ao da gbogbore papo ao daniyan si ao gbe sinule ti omina yio fi gbe man lara bi wakati mefa ao wa fan sita tabi kalore dasi ori atan abi kadafun adie adura na yio gba larin ojo meta
(

3 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by Hardetutu01(m): 10:06pm On Jun 21, 2015
kadunasouth:
Ti isoro badoju ko o,
Alauma soli ala muhammadi wasalim 100
Bismillahi rahmani rahim 1
Ao daniyan isoro na
Ao tun wase
Bismillahi rahmani rahim 786
Alauma soli ala muhammadi wasalim 100

Sarare dawa agolokan agbado agolo kan iyo sibikan sugar sibi meji omin toma sibi meje fun obinrin sibi mesan fun okunrin ao da gbogbore papo ao daniyan si ao gbe sinule ti omina yio fi gbe man lara bi wakati mefa ao wa fan sita tabi kalore dasi ori atan abi kadafun adie adura na yio gba larin ojo meta
(
jaza kumu laha kaeran

1 Like 1 Share

Re: Asiri Gbigba Adua by Hardetutu01(m): 10:28pm On Jun 21, 2015
agolo kan....se agolo milk tabi agolo de rica?
sugar sibi meji right?
omi tio ba mo sibi meje fun obinrin ati sibi mesan fun okunrin?

pls help to clarify it......
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 10:42pm On Jun 21, 2015
Hardetutu01:
agolo kan....se agolo milk tabi agolo de rica?
sugar sibi meji right?
omi tio ba mo sibi meje fun obinrin ati sibi mesan fun okunrin?

pls help to clarify it......

Agolo miliki

1 Like 1 Share

Re: Asiri Gbigba Adua by Hardetutu01(m): 10:46pm On Jun 21, 2015
kadunasouth:

Agolo miliki
is it sugar sibi meji and omi tio ba mo sibi meje fun obinrin nd sibi mesan fun okunrin?
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 10:48pm On Jun 21, 2015
Hardetutu01:
jaza kumu laha kaeran
Ameen
Adura na wulo pupo ale fi wa owo tabi igbega lenu ise tabi onise owo kia kia ni iyipada si rere yio de pelu ase oloun oba
Re: Asiri Gbigba Adua by thesource(m): 11:31pm On Jun 21, 2015
Inu mi dun pupo lati ri musulumi ododo bi ti yin ti o le maa ba awon eeyan wa iyanju si isoro aye won latara adua, e seun gan, olorun yio san yin lesan daada. Ti e basi tu ri awon eto adua mi to tu le se wa lanfani, ki e tu ba wa ko sibi yi, e seun pupo, olorun yio gbo adua gbogbo wa ( Ameen)

2 Likes

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 3:49am On Jun 22, 2015
thesource:
Inu mi dun pupo lati ri musulumi ododo bi ti yin ti o le maa ba awon eeyan wa iyanju si isoro aye won latara adua, e seun gan, olorun yio san yin lesan daada. Ti e basi tu ri awon eto adua mi to tu le se wa lanfani, ki e tu ba wa ko sibi yi, e seun pupo, olorun yio gbo adua gbogbo wa ( Ameen)
Ameen
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 6:30am On Jun 22, 2015
Hardetutu01:
is it sugar sibi meji and omi tio ba mo sibi meje fun obinrin nd sibi mesan fun okunrin?
Beni egbiyanjure kie funmi labo eo ripe ayipada rere yio de ni kia kia

1 Like

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 12:48pm On Jun 26, 2015
ADUA ARISIKI LONA TI AKO LERO
Ao dojuko ibuyo orun ni ago mesan aro ao se
Bismillahi rahmani rahim 300 Times
Allahuma sali ala muhammadi wa alihi wasalim 200 times

Esekese tobati pari wa wa 20 Naira 14 wa fise sara fun oni bara ti agbara re kobaka sarayi fi 20 Naira eyokan se sara ijona ladure yio gba alubarika Anabi salallau Alai wasalam

8 Likes 1 Share

Re: Asiri Gbigba Adua by vistaprint: 4:13pm On Jun 26, 2015
kadunasouth:
ADUA ARISIKI LONA TI AKO LERO
Ao dojuko ibuyo orun ni ago mesan aro ao se
Bismillahi rahmani rahim 300 Times
Allahuma sali ala muhammadi wa alihi wasalim 200 times

Esekese tobati pari wa wa 20 Naira 14 wa fise sara fun oni bara ti agbara re kobaka sarayi fi 20 Naira eyokan se sara ijona ladure yio gba alubarika Anabi salallau Alai wasalam
E seun gan Ustaz, olorun yio bawa lora emi yin, olorun yio gba adua ti yin na. Jazakumu lahu khairan.

3 Likes 1 Share

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 4:42pm On Jun 26, 2015
vistaprint:
E seun gan Ustaz, olorun yio bawa lora emi yin, olorun yio gba adua ti yin na. Jazakumu lahu khairan.

Amin suma Amin Adura gbogbowa yio gba Amin

1 Like

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 1:34pm On Jun 27, 2015
Atunse Fun Eniti Ayare Nja tikoma nkan to nja laya
Ki iru enibeye lore ra omin samsam tabi omi ojo ofurufu tikobari nkan kan ninu omi wonyi kolo swan water koka Ayatul Kursiyu 66 fatia 1 sinu omin komun pelu ogo oloun ayare koni jama
Otun sise fun eni to nla alakala.
Aduaa wa yio gba Alubarika Anabi (s.a.w)

2 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by vistaprint: 5:29pm On Jun 28, 2015
kadunasouth:
Atunse Fun Eniti Ayare Nja tikoma nkan to nja laya
Ki iru enibeye lore ra omin samsam tabi omi ojo ofurufu tikobari nkan kan ninu omi wonyi kolo swan water koka Ayatul Kursiyu 66 fatia 1 sinu omin komun pelu ogo oloun ayare koni jama
Otun sise fun eni to nla alakala.
Aduaa wa yio gba Alubarika Anabi (s.a.w)
Ustaz eo nitawona, adua yin o gba, olorun o ni fi yin le ni gba kookan, e seun gan fun gbogbo awon asiri gbigba adua ten ju le fun wa lofe yi, to ba se pelomi ni yi o ni ka wa ri oun tabi ki a san nkankan. Mo mo riri gbogbo adua yi pupo, olorun yi o bawa lora emi yin.

2 Likes

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 10:04pm On Jun 28, 2015
vistaprint:
Ustaz eo nitawona, adua yin o gba, olorun o ni fi yin le ni gba kookan, e seun gan fun gbogbo awon asiri gbigba adua ten ju le fun wa lofe yi, to ba se pelomi ni yi o ni ka wa ri oun tabi ki a san nkankan. Mo mo riri gbogbo adua yi pupo, olorun yi o bawa lora emi yin.
Amin o Adua gbogbo wa ni yio gba Alubarika Anabi (s.a.w)

1 Like

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 7:56pm On Jul 29, 2015
Adua Bibo Ninu Isoro Ati Ifa ore wole
Astagafurullahi 100
Laila ila llahu. 100
Alauma soli ala Muhammadi wasalim 100
Alhamdu lillahi 100
Hasbunallahu wanimal wakil 450
Aniyan
Fatia 2
Ao se Adua yi fun ojo Meje
Fi nkan ti oba wuo se sara Adua re yio gba Alubarika Anabi

2 Likes

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 7:55am On Jul 31, 2015
ADUA Ki ABURO ATI OLE MALE WOLE TAFE KOSI

Ki ato ko si ile tun tun ti agba abi ile tako funrawa
Ao se Hasbunallahu wanimal wakil 450 si origun mererin ile na lori naro ni watise Adua yi yio je 450 lona merin niye wawa joko wa toro nto nba tun fe wa wa ka suratu yasin kan ati suratu muliku kan ti oko bamo awan surayi waka fatia kan kurisiyu 66 fi ropo re fi agban meta se sara lodidi
Adua yi dara pupo ti obalo ogorun odun ninu ilena Aburu kan kan ko niwo Alubarika Anabi salallau alai wasalam

5 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 9:27pm On Aug 05, 2015
Adua wibe jebe Ni kia kia
Nafila raka meji
Fatia 1
Kuli uwallau dele 6 lori iduro kokan
Iforikanle to kan in raka elekeji ao wa sope
Robi masani duri wa anta ar amu rahimina 99 times
Wawa toro nkan to nbafe wawa salama
MUJARABA NI

2 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 3:41pm On Aug 07, 2015
Adura Isoye
Fatia 2
Sanukurihuka fala tansa 313
Man ka sinu omi ojo ko mamu
Osi tun dara fun awan omo keke ta nba se funwan ti wan mun wan yio ma iwe wan daradara ati ima alkurani

2 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 10:49am On Sep 09, 2015
Adura Ore ati Ifokan Bale
Wala aola wala kuwata ila billah 313
Ya Aliyu Ya Azeemu99

Sarare
Ogi Agbado tutu oni 70naira ati 20 naira se sara
Adua wa yio gba

2 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 11:35am On Oct 01, 2015
ADUA IFERAN GBOGBO AYE
Ya wadud 1000
Wa alqaitu alaika muhibatu minni 313
Rahufu rahimu fain tawalao fakuli hasbiyyah llau laila ila uwa alai taWakalitu wa uwa rabul arizil azeem 7times
Sarare iyo idi meta

3 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 3:49pm On Oct 01, 2015
Adua ki result le dara leyin Exam
Every day(ojojuma)
Wa ina jundana lahumuligalibuna 1111 times

3 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 9:02pm On Oct 01, 2015
ADUA Fun Enito ba Feri Alayelorun Anabi Muhammadu s.a.w Loju orun
Wa se aluwala yan Nafila raka meji fatia kan ina ataina (suratul kaosara 7) lori iduro kokan wasalama
Asalatu 100
Suratul kaosara 1000 times
Ao wa lore sun sibi toma ti egbin kosi nibe pelu ase oloun walala ri Onise nla Anabi Muhammadu s.a.w
Eleyi Daju Pupo

2 Likes 2 Shares

Re: Asiri Gbigba Adua by Ousmaf(m): 6:24pm On Oct 11, 2015
kadunasouth:
Atunse Fun Eniti Ayare Nja tikoma nkan to nja laya
Ki iru enibeye lore ra omin samsam tabi omi ojo ofurufu tikobari nkan kan ninu omi wonyi kolo swan water koka Ayatul Kursiyu 66 fatia 1 sinu omin komun pelu ogo oloun ayare koni jama
Otun sise fun eni to nla alakala.
Aduaa wa yio gba Alubarika Anabi (s.a.w)
Ejo Ustaz, mo nilo adua ti eyan le fi se ISTIHARA fun ara eni tio fi mon ohun ti nsele si igbesi aye re, eseun Olohun o lora emi yin fun wa ola Anabi wa Muhamad (SAW)
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 8:17pm On Oct 12, 2015
Istihara
Ao wa omi toma dada bi omi ojo tabi omi kanga tabi bohol ao fi se aluwala alelo omi tap na sugbon omi ojo lodaraju tabi bohol
Taba se aluwala tan eyi toku ninu omi yi wada sinu cup toma te aso funfun opakan sile joko lelori ka Bismillahi rahmoni rahim19 fatia 2 salatul fatihi 100
Alama li insana ma lamu yalamu 102 watoro lodo oloun nkan tofema wawa se asalatu ogorun iru eyi toba wuo wawa beto sinu omiyi diedie wa gbemu
Wawa dide pelu nafila raka meji fatia 1 kuli uwallahu 6 lori iduro mejeji wa salama
Astagafurullah 100
Laila ilallah 100
Alhamdulillah 100
Yah khabiru 99 Aniyan nkan tofema
Fatia1 salatul fatih 1 losun kedere niwa ri nto bere fun Alubarika Anabi s.a.w
NB ri wipe kosi egbin ni ayika ibi ti oma sun si
Maha salam
Re: Asiri Gbigba Adua by kadunasouth(m): 3:40pm On Oct 24, 2015
Adua Isegun Ota (Asete)
Tabaji nidaji kutu kato lo kirun Asuba lai ti soro si eni kan kan
Ika arin owo alafia wa ao beto die si ao wa fi kan amuje wa pelu kika lakadi jakun 66
Tobadi aro kutu hai wawa lore fi akara elepo se sara ti otare koba jawo lati man sa sio yio kudanu gba gbo agbara towu koleni
Eleyi daju
Olohun nikan lala gbara julo to se farati

1 Like

Re: Asiri Gbigba Adua by suledes(m): 10:34am On Nov 16, 2015
Salamu alykum, eku igbijanju lori awa omo iya yin ninu esin Islam, Allah yoo tunbo lora emi yin o. Amiiin. Jazakallah airan. Mofe beyin lori adua ti eniyan fi nwa ise, ati ri ise alalubarika, ati adua ti eniyan fi nwa, ati ri iyawo daada. Maa salam
Re: Asiri Gbigba Adua by Herbdursalam(m): 6:39pm On Feb 20, 2016
kadunasouth:
Adua wibe jebe Ni kia kia Nafila raka meji Fatia 1 Kuli uwallau dele 6 lori iduro kokan Iforikanle to kan in raka elekeji ao wa sope Robi masani duri wa anta ar amu rahimina 99 times Wawa toro nkan to nbafe wawa salama MUJARABA NI
Re: Asiri Gbigba Adua by aktab: 11:28pm On Feb 22, 2016
Salam alaekun Uztadz e ku igbiyanju,e jowo se pelu aluwala la o se adua yi tabi ko need aluwala ki a to se,elekeji ibeere mi ni wipe se mo le din akara elepo fun rara mi ni ile tabi ki n ra lo dara ju.
Ma salam
kadunasouth:
Adua Isegun Ota (Asete)
Tabaji nidaji kutu kato lo kirun Asuba lai ti soro si eni kan kan
Ika arin owo alafia wa ao beto die si ao wa fi kan amuje wa pelu kika lakadi jakun 66
Tobadi aro kutu hai wawa lore fi akara elepo se sara ti otare koba jawo lati man sa sio yio kudanu gba gbo agbara towu koleni
Eleyi daju
Olohun nikan lala gbara julo to se farati

(1) (2) (Reply)

Primate Ayodele's 2017 Prophesies On Politics, Economy, Sports, Others / 7 Year Old Girl Brings Warnings From Jesus To Top Nigeria Pastors & Their Wives / 8 false Teachings by Churches And The Biblical Truths Concerning them.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 49
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.