Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,160,866 members, 7,844,808 topics. Date: Thursday, 30 May 2024 at 08:06 AM

.. - Culture (89) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1832386 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (86) (87) (88) (89) (90) (91) (92) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:55am On Dec 15, 2016
Moki gbogbo eyin Omo Iya wa Nile loko lona leyin oodi
Wipe AKI'IMUNRA ODUN'OO!!!
Mo se awon aki'esi Pataki kan Lori gbogbo eyin Omo iyawa Ti eje yioruba Ti Ewa Ni Ilu okeere tabi Ti eyi kuro Nile tipe...
Opo awon call Ti moma ngba ati awon atejise to nwole lofun mi Ni akie si lopolopo Lori won wipe opo ninu won atun maarahun, elomiran tie le wipe ohun Fe pe sugbon Ko si owo card tori wipe owo Kekere Koto bawa soro, elomi ama sise sugbon bukaata tipoju, nipa bai elomi kotie ran to Ile mon nitori opo igba Ti obati ranti awon enyan re bai ironu Ni Ni gbogbo ijo na, oroyi Ni Moro Ti mofi fi awon oogun kan sile seyin iyen fun awon Ti won bale jawe tabi Sa oogun!
Opo lositi lo oogun yala Ti ose fun arare tabi Ti won fi ranse sugbon pabo lotun njaasi
Nitori Idi eyi nimose tun gbe ilana eto nipa wiwo akosejaye sile
Sugbon bai motun Fe fi awon oogun sile fun eyin Ti enpe mi lati okeere tabi fun oniru'iru isoro
Emaabawa kalo
Ajuwase o
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:02am On Dec 15, 2016
Ni bai ao fi epo obo Tele ape, ao Ko eeru alamon le Lori
AO Ko ewe ewuro oojo ati ewe eyeoba le ao bu omi totowe si ao gbe ka ori Ina Ni ago kan osan gerege, ao we Ni ago kan oru nitori Ti ide baja ona asi Ti ona basi arisiki owo awole
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:11am On Dec 15, 2016
Bakan na ao lo kafura pelebe merin ati epo obo ao fi omi Idi igbin poo, ao maawe Ni igba kan Ni odun
N.B:- ao fi oseyi si ori kan-nkan meta, ao kunle ao we ikan, ao naro ao we ikan, ao joko ao we iketa, ao ju kan'nkan na nu, ao we be Ni ekan Ni ose akoko ose keji ati iketa, eyi Ti otun Ku odi odun miran, abawon kankan koleefo Mon eniyan
Ajuwase o
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:16am On Dec 15, 2016
HMMM
eyin pepeiye mewa, eyin adie ibile mewa, a o Jo eyin mejeji sinu awo olomori funfun, ao bu iyo die si, ose lux funfun mewa, ao ha , ao ko sinu re. Ao jeki ore di ojo keji,. A o po po ninu awo yen nibe, ao ma fi we. .
N.B:- ( JOWO MASE FUN ENIA LO NINU OSE YIO ).
Re: .. by seanjizzyayo: 10:20am On Dec 17, 2016
kadunasouth:
Apagun Apa asasi APa Egun idile
Eran Malu Ekiri kan, Odidi Agban kan koko isasun ibile tuntun kekere kan ao so eran sinu isasun na ao wa lu agban yi nibi iho re ao jo omire le eran yi lori ninu koko isasun ao gbe kana to bajina ao se adua si ao so senu lekan na ao wa so agban yi sinu koko yi odi ori apata ao wa sope egun kegun ide kide airije airimu airina airilo kotu danu lara mi lati onilo ao lemole lori apata na ao malo ile ma wo eyin o!

kini itumo eran malu ekiri kan ,koyemi to ejowo elayemi

2 Likes

Re: .. by seanjizzyayo: 1:58pm On Dec 17, 2016
ALIUDAVID:
ERO MAGUN (THUNDERBOOT)
Ifun aja, igba eyo atare(200), igba obi pupa(200), igba obi ifin(200).
A o gun po a o sa yio gbe, a o fi ran onde tabi igbadi si idi wa..

Ogun ti obirin ba nse isekuse..
Ewe ewura, ao fi nu oko nigbati a ba ba obinrin na lo po tan, ao wa odindin eko kan, ao gbo ewe ewura yen si omi to mo ti kopo ao yo omi re, ao fi foko mu ati obinrin yen...
Ti obirin yen bati ba okunrin mi lo po yi bi si okunrin yen lara.

kini a o fi ran awo yii se awo ni tabi aso abi iru awo WO .ela yemi edakun ewe amaje ooo
Re: .. by seanjizzyayo: 3:09pm On Dec 17, 2016
kadunasouth:

Agbaarin pelebe egusi inure ao lo pelu ori aparo yio kuna dada ao wa popo ma ose dudu ao fi oyin die de ose yi obirin na yio ma fi tanba toba tise kolegbadu obirin mi bi todore sugbon don't misbehave ki ogun na mabaje tori odaju gbogbo nto bafe niyio mase fune
Odaju

Mo ki yin ooo, baba wa Kadunasouth ati Baba wa healthfirst, ewe ama je ooo.
baba ejowo efumi ni ogun ti omo yahoo le Malo ti yo mari owo gba Dada lowo client, yala oruka tabi aseje tabi ose

mo si tun nilo Ogun GBOGBO IGI TI ELEGBEDE BA FOWO BA DIDUN LON DUN ejowo esanu mi konibaje fun yin agba yin adale
Re: .. by seanjizzyayo: 5:55pm On Dec 17, 2016
kadunasouth:
Asiri Owo(Asiri bibo)
Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji, eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100
Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju
Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi.
Danwo o confirm No repercursion

baba eyele yi se ale lo eyi ti oti ku tabi aye tabi ti aba ra laye aopa kato lo , atipe ewe aje yen se gbigbe ni tabi tutu, owo (money) ti eso yen se abiya eyele yii lapa otun ati osi la o fisi tabi ninu agbada ijogun lapa otun ati tosi la o fisi ati wipe se ekan ti aba Jo ebu yi ni a o lotan abi OSU melomelo la o malo , se taba lo ebu yii tan se ale matun se kamalo lo, se eni to ko ni ise owo(hand work) ti oje yahoo lonse lelo iseyi ,panbanbari re nipe se ogberi lelo atipe se agbada ti won ti fi joogun ri se mole fi Jo tabi mole Jo lodo elewe omo
edakun ESE alaye fun mi Dada Lori ibere mi
monreti idahun
Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 6:24pm On Dec 17, 2016
Baba ifankaleluya pls kindly give me Odu ifa that works for boldness"ikiya" and how to use it.isese a gbe wa ooooo...
Re: .. by Lero70: 7:31am On Dec 21, 2016
Zenlife:

You see, that's why your style isn't admirable.
Can someone who has Esu as asked be an alaimokan to ma si lo?
Dude, if you aren't posting complete, best you don't post at all. Why post it? Obviously to be contacted behind the scene or 'abe aso' as you're prone to call it, for money gains. If giving, just give. Quit teasing.

You're quick to post "Ifa ni..." But not when you really should.

Stop this practice of giving the goat and holding on to the rope, it's not honorable.

Go take a look at kadunasouth posts as an example.

May God open your heart.

Sir. Am highly disappointed with what you have posted concerning the reply of Baba Ifankaleluya, i think you are a matured man, but it seem as if your mind and your sense of reasoning are not fully matured. Aye oniimuwao, mosife keerantipe INA KOMOJU ENITODAA O. AANIIJEBI.
Re: .. by Lero70: 8:01am On Dec 21, 2016
08101646045atwp:
OGUN OWO KIA KIA TI INAWO BA KU 4 DAYS TO DAJU SAKA

Biscuits die, ashisu die, ose dudu, Schnapps, ao lo Biscuits ati ashisu papo, ao fi schnapps gas kan po mo ose dudu die ti a le lo fun ojo merin, ao maa fi we....

Ofo e: Bi oku ba ku, a gbowo lowo ara, a gbowo lowo ebi, oku a gbowo lowo okunrin, a gbowo lowo obirin, ti ekun, ti eje loku fin gboowo lowo omo e, tori ipakupa ni igbo npa eni to mun igbo ko to na owo owo e tan, itikuti ni oti nti oloti ko to fi owo owo e tore, inawo ti mo fe se ni ojo bayi bayi, bii eni mun igbo, bii eni mun oti ni ki o maa lo ti gbogbo awon enyan to lowo gidi lowo gboongboon ki won maa wa ko owo owo won wa fun mi, ki wo maa wa da owo owo won sile fun mi, ki emi fi bo asiri ara mi oooo. Ase!!!...Tested ok.. o confirm baje... ai mo ye igba la ti lo fun ianwo... e test e wo, ki e fun wa labo...

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o

ejowo kilonje ashisu?
Re: .. by Zenlife: 11:32am On Dec 21, 2016
Lero70:

Sir. Am highly disappointed with what you have posted concerning the reply of Baba Ifankaleluya, i think you are a matured man, but it seem as if your mind and your sense of reasoning are not fully matured. Aye oniimuwao, mosife keerantipe INA KOMOJU ENITODAA O. AANIIJEBI.

You're not appointed.

Opinions are like arseholes, everyone has one.

Re: .. by Nobody: 8:42am On Dec 26, 2016
Ejowo, awure wo lonje "awure dalu te?? ".
Re: .. by Ifankaleluya: 1:35pm On Dec 29, 2016
Ayomidegbenga1:
Baba ifankaleluya pls kindly give me Odu ifa that works for boldness"ikiya" and how to use it.isese a gbe wa ooooo...

IFA ILAYA OLODI-MEJI

1. Yangi Oju-ona

2. Ikujebu

3. Eresile ewe-idi

4. Yangi esu

Ao lo papo, ao wa te ni odu-ifa odi-meji.

ifa re; Olukimolaya, ayamudindi kimolaya, ayamu didi ni ti kujebu, ayamu didi ni tesu, yangi oju-ona kiije ji aya ona o ja, ewe-idi ni ko di emi lagbaja omo lagbaja laya. odi-meji iwo ni ko di emi lagbaja omo lagbaja laya. eewo ni, aya esu liija nigba kookan. ao ma fi fo eko tutu mu.

Aboru, Aboye, Abo-sise.

2 Likes 2 Shares

Re: .. by ademotech: 6:41pm On Jan 03, 2017
baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi
Re: .. by ademotech: 6:42pm On Jan 03, 2017
Ifankaleluya:

IFA ILAYA OLODI-MEJI

1. Yangi Oju-ona

2. Ikujebu

3. Eresile ewe-idi

4. Yangi esu

Ao lo papo, ao wa te ni odu-ifa odi-meji.

ifa re; Olukimolaya, ayamudindi kimolaya, ayamu didi ni ti kujebu, ayamu didi ni tesu, yangi oju-ona kiije ji aya ona o ja, ewe-idi ni ko di emi lagbaja omo lagbaja laya. odi-meji iwo ni ko di emi lagbaja omo lagbaja laya. eewo ni, aya esu liija nigba kookan. ao ma fi fo eko tutu mu.

Aboru, Aboye, Abo-sise.
. baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi

1 Like

Re: .. by 08101646045atwp(m): 11:29am On Jan 04, 2017
ademotech:
. baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi

Bi otile je wipe:- nti okoju si enikan, eyin lokoju si fun elomiran!
Sugbon gege bi eti la alayi!
Eyi ntumon bai wipe:- tobaje wipe awon Ti oyi yin kayi baje aon Ti edamon eyin tumon si wipe bi iku Ile koba pani tode kii pani
Ti osi nsalaye bai wipe olowo kan laarin otosi otosi Ni gbogbo won, Ni odunyi aseyori wa ninu afoju sun yin yen daada!
Sugbon enilati se imule ati ebe awon agba Ti ma nje Ki omo'osowo Lai jere!
Nitori wipe Oni sowo Ti Ko se ase jere ifa ohere meki wipe eran awon Iya Ni nse!
Nitori na esun Mon awon agba daada.
Ekoni ri ija kule'o
Re: .. by 08101646045atwp(m): 12:09pm On Jan 04, 2017
OSOLE=Ti o ma n mun EYAN Mon AWON nlanla nileyi ati okere.(OMO-YAHOO LELO KOSI LABURU)
Eiye kannakanna tutu kan,ao fi biscuit okin si labiya otun, ao fi Odidi atare kan si labiya OSI,Ao wa ka iye re mejeji Mon Lara ki awon nkan wonyi maba bole.....ao wa ko eyin ororo meta tele ape tuntun, ao wa GBE eiye kannakanna yen le monle.....ao wa ko ewe ekuya tutu pelu sawerepepe tutu die bo monle....odi jijo.......ao lo kuna Dada,ao wa ma fi 1000naira tuntun kan ko ebu yen sinu oti ST-REMMY....Ao wa GBE si igun yara wa,ao fi 1000naira yen si legbe.
Ao wa sope:---------Owo timofi dao loko owo re ooo,kio lo ma bami WO olowo nlanla, olooro,okunrin, obinrin tiowa fun emi l omo l ni owo nlanla wasi odo mi.ADURA....
Ao ma mun diedie laro laro.
N/B******

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: .. by Nobody: 12:28pm On Jan 04, 2017
Baba ejowo... ose awure wo lonje " awure dalute ". Ejowo kini iwulo re atipe bawo lose ma n sise.

Inu mi Ma dun ti e ba dahun ibeere mi. cool
Re: .. by 08101646045atwp(m): 7:47am On Jan 05, 2017
CallmePROF:
Baba ejowo... ose awure wo lonje " awure dalute ". Ejowo kini iwulo re atipe bawo lose ma n sise.

Inu mi Ma dun ti e ba dahun ibeere mi. cool

Awure Ti won npe Ni dalute Ni awure agbalu
Enikan soso Ni ma nlo ninu Ilu kan!
Osi a nsise bii apede Ni
Ajuwase o

1 Like

Re: .. by Nobody: 9:17am On Jan 05, 2017
08101646045atwp:

Awure Ti won npe Ni dalute Ni awure agbalu Enikan soso Ni ma nlo ninu Ilu kan! Osi a nsise bii apede Ni Ajuwase o
Baba ejowc...moni lo Ise eyonu nla
Re: .. by Nobody: 5:38pm On Jan 05, 2017
08101646045atwp:

Awure Ti won npe Ni dalute Ni awure agbalu
Enikan soso Ni ma nlo ninu Ilu kan!
Osi a nsise bii apede Ni
Ajuwase o

Eshe modupe baba, a maa juyin se o.
Re: .. by Nobody: 5:39pm On Jan 05, 2017
08101646045atwp:

Awure Ti won npe Ni dalute Ni awure agbalu
Enikan soso Ni ma nlo ninu Ilu kan!
Osi a nsise bii apede Ni
Ajuwase o

E seun modupe baba, a maa juyin se o.
Re: .. by ademotech: 7:52pm On Jan 05, 2017
08101646045atwp:

Bi otile je wipe:- nti okoju si enikan, eyin lokoju si fun elomiran!
Sugbon gege bi eti la alayi!
Eyi ntumon bai wipe:- tobaje wipe awon Ti oyi yin kayi baje aon Ti edamon eyin tumon si wipe bi iku Ile koba pani tode kii pani
Ti osi nsalaye bai wipe olowo kan laarin otosi otosi Ni gbogbo won, Ni odunyi aseyori wa ninu afoju sun yin yen daada!
Sugbon enilati se imule ati ebe awon agba Ti ma nje Ki omo'osowo Lai jere!
Nitori wipe Oni sowo Ti Ko se ase jere ifa ohere meki wipe eran awon Iya Ni nse!
Nitori na esun Mon awon agba daada.
Ekoni ri ija kule'o
ejor imule ati ebe awon agba wo ni mo lese
Re: .. by Ifankaleluya: 11:32pm On Jan 05, 2017
ademotech:
. baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi

Hnmmmmmmm.........!

Baba, emi o mo bi a ti n tan(deceives) ni. Ala ti e la ko dara rara. Iseda yin o ni gba abode pelu ogo-olohun......Amin! N o ni so ju bayen lo.....!
Re: .. by Ifankaleluya: 11:42pm On Jan 05, 2017
CallmePROF:
Baba ejowo... ose awure wo lonje " awure dalute ". Ejowo kini iwulo re atipe bawo lose ma n sise.

Inu mi Ma dun ti e ba dahun ibeere mi. cool

Baba, e ma je ka tan ara wa je. EMI o gbagbo ninu Awure ti e n toka si yen. Gege bi Apere, ki eniyan kan ni ohun fe ma lo awure dalute ni ilu eko, e dakun nibo ni alujonnu awon to se alujonnu owo ma lo? E dakun, nibo ni alujonnu awon to n lo OSOLE-GBIGBONA ma lo? E ma je ka tan ara wa je, ALUJONNU ju ara won lo. won si ma n da ara won lona gege bi ole ti ma n da eniyan lona! Won da pe fun yin ni, o ni loruko miran, gbogbo n kan to ba je mo bayen gbodo ni owo awon iyami(AJE) ninu,

4 Likes

Re: .. by Ifankaleluya: 11:56pm On Jan 05, 2017
EBE AWON AGBA TO DAJU

1. EPO-OBO TI IGI RE KU FUN RA RE

2. ASO-AGBA MOKANLELOGUN(21)

3. EWE-AJE-OBALE TUTU TO JE TOOJO

4. EPO-IGI NLA

5. EWE-EGELE TUTU TO JE TOOJO

ao gun awon eroja yi papo mo ose, lai si aso-agba ati epo-nla yen nibe. ao ko ose yen sinu isasun titun kan to ni ideri, ao wa lo epo-igi nla yen,ao ku si ose yen lori bi elubo, ao wa fi aso-agba yen gun ose yen lori ni eyo kookan. ao de isasun yen pa. ao gbe sinu ora kan, ao so, ao lo bo mole lorita meta fun ojo meje. ao lo wu leyin ojo keje, ao ma fiwe ki a to sun lale.

ABORU, ABOYE, ABO-SISE.

1 Like 1 Share

Re: .. by ademotech: 12:53pm On Jan 06, 2017
Ifankaleluya:

Hnmmmmmmm.........!

Baba, emi o mo bi a ti n tan(deceives) ni. Ala ti e la ko dara rara. Iseda yin o ni gba abode pelu ogo-olohun......Amin! N o ni so ju bayen lo.....!
ejor kini molese
Re: .. by Ifankaleluya: 1:24pm On Jan 06, 2017
ademotech:
ejor kini molese

E lo re wa EWE-AJABO(eku gogoro ni a n pe bayen). e gbo ninu omi ti e le fi we ni e kan soso ni aro kutukutu, ki e wa ju epo igi-nla di e sinu omi yen ki e gba omi yen si ibi ti o tile ri sanmo lati aro yen di ale. ki e wa ra AJAPE eran oruko, ki e ko sinu awo-abokadale, ki e bu epo pupa si lori, ki e wa se adura si wipe Oso lo ba fe bayin ja ni, aje lo ba fe ba yin ja ni gbogbo ajogun kajogun to ba fe koju ija si yin lati de yin mole lona kan tabi lona miran, odidi eran ni e ti pa fun won yi, ki won jowo ki won yonda yin. eo ti wa efun ati osun sile, eo lo papo, eo fi omi di e po, eo wa fi pa ese yin lati orunkun da atelese, eo wa lo gbe ipese yi si orita-meta lale ti gbogbo eniyan ba wole sun tan. pi pada ti e ba pada wo inu ile ni eo wa fi omi ti e ti gbo ewe-ajabo ninu re yen sin gbogbo ara yin ti eo si wole sun.

NB; Ti ile ba mo laro ojo-keji, e gbiyanju lati se saara fun afoju meje.

Pelu ogo-olohun, eo si ja Ajabo ninu odun yi, e ki yio ri ohun ti yio da yin gunle tabi ogun atimo(do do mi). Ase!

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:41pm On Jan 06, 2017
Ifankaleluya:

Baba, e ma je ka tan ara wa je. EMI o gbagbo ninu Awure ti e n toka si yen. Gege bi Apere, ki eniyan kan ni ohun fe ma lo awure dalute ni ilu eko, e dakun nibo ni alujonnu awon to se alujonnu owo ma lo? E dakun, nibo ni alujonnu awon to n lo OSOLE-GBIGBONA ma lo? E ma je ka tan ara wa je, ALUJONNU ju ara won lo. won si ma n da ara won lona gege bi ole ti ma n da eniyan lona! Won da pe fun yin ni, o ni loruko miran, gbogbo n kan to ba je mo bayen gbodo ni owo awon iyami(AJE) ninu,

E se pupo, won o dape fun mi rara. Mo ri awure dalute na ninu awon iwe grandpa ko fun mi, sugbon emi ko mo iwulo re... to rire ni mo se bere. Awon eroja ise nah Le lati ri pupo!....sugbon mole dan wo ti mo ba ri awon eroja re pe cheesy. Eyin agba leso wipe "Oju orun to eye fo laifi ara kan arawon". danwo lobi iya okere grin thanks sir.
Re: .. by belatoxx: 6:40pm On Jan 06, 2017
Baba 08101646045atwp(m) ko si akole kan kan lo ri ise yi ejowo e fi akole si

Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:02am On Dec 15, 2016
Ni bai ao fi epo obo Tele ape, ao Ko eeru alamon le Lori
AO Ko ewe ewuro oojo ati ewe eyeoba le ao bu omi totowe si ao gbe ka ori Ina Ni ago kan osan gerege, ao we Ni ago kan oru nitori Ti ide baja ona asi Ti ona basi arisiki owo awole
(Quote) (Report) (Like) (Share)

Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:11am On Dec 15, 2016
Bakan na ao lo kafura pelebe merin ati epo obo ao fi omi Idi igbin poo, ao maawe Ni igba kan Ni odun
N.B:- ao fi oseyi si ori kan-nkan meta, ao kunle ao we ikan, ao naro ao we ikan, ao joko ao we iketa, ao ju kan'nkan na nu, ao we be Ni ekan Ni ose akoko ose keji ati iketa, eyi Ti otun Ku odi odun miran, abawon kankan koleefo Mon eniyan
Ajuwase o
(Quote) (Report) (Like) (Share)

Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:16am On Dec 15, 2016
HMMM
eyin pepeiye mewa, eyin adie ibile mewa, a o Jo eyin mejeji sinu awo olomori funfun, ao bu iyo die si, ose lux funfun mewa, ao ha , ao ko sinu re. Ao jeki ore di ojo keji,. A o po po ninu awo yen nibe, ao ma fi we. .
N.B:- ( JOWO MASE FUN ENIA LO NINU OSE YIO ).

(1) (2) (3) ... (86) (87) (88) (89) (90) (91) (92) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 71
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.