Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,159,355 members, 7,839,636 topics. Date: Saturday, 25 May 2024 at 04:49 AM

Primate7's Posts

Nairaland Forum / Primate7's Profile / Primate7's Posts

(1) (2) (3) (4) (5) (of 5 pages)

Religion / Tani Jesu Nse? - Iranse Ikola Nitori Otito Olorun by Primate7: 11:05pm On Aug 22, 2019
TANI JESU NSE?
IRANSE IKOLA NITORI OTITO OLORUN
EPISTELI TI PAULU APOSTELI SI AWON ARA ROMU, ORI IKEDOGUN, ESE KEJO ATI IKESAN SO WIPE: 8. Mo si wipe, a ti fi Jesu Kristi se iranse ikola nitori otito Olorun, ki o ba le mu awon ileri na duro ti a ti se fun awon baba, 9. Ati ki awon keferi ki o le yin Olorun logo nitori anu re; gege bi a ti ko o pe, Nitori eyi li emi o se yin o larin awon Keferi, emi o si korin si oruko re.
LATI INU BIBELI MIMO
(22/08/2019)
Religion / Who Is Jesus? - Blessed Is The Fruit(jesus) Of Your Womb! by Primate7: 10:27am On Aug 15, 2019
WHO IS JESUS?
BLESSED IS THE FRUIT(JESUS) OF YOUR WOMB!
THE GOSPEL ACCORDING TO LUKE , CHAPTER 1 VERSE 41 AND 42 SAY THAT: 41. When Elizabeth heard Mary greetings, her baby leaped in her womb; and Elizabeth was filled with the Holy Spirit and empowered by Him. 42. And she exclaimed loudly, "Blessed [worthy to be praised] are you among women, and blessed is the fruit of your womb!
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 14/08/2019.
Religion / Tani Jesu Nse? - Alabukun - Fun Si Ni Fun Omo (jesu) Inu Re by Primate7: 10:22pm On Aug 14, 2019
TANI JESU NSE?
ALABUKUN - FUN SI NI FUN OMO (JESU) INU RE*
IHINRERE TI LUKU, ORI KINNI, ESE IKANKANLELOGOJI ATI IKEJILELOGOJI SO WIPE: 41. O si se, nigbati Elisabeti gbo kiki Maria, ole so ninu re; Elizabeti si kun fun Emi Mimo: 42. O si ke li ohun rara, o si wipe, Alabukun - fun ni iwo ninu awon obinrin, alabukun - fun si ni fun omo inu re.
LATI INU BIBELI MIMO
(14/08/2019)
Religion / Who Is Jesus? - Jesus' Death Reconciled Us To God by Primate7: 8:31pm On Aug 07, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS' DEATH RECONCILED US TO GOD
THE LETTER OF PAUL TO THE ROMANS, CHAPTER 5 VERSE 10 AND 11 SAY THAT: 10. For if while we were enemies we were reconciled to God through the death of His Son, it is much more certain, having been reconciled, that we will be saved [from the consequences of sins] by His life [that is, we will be saved because Christ lives today]. 11. Not only that, but we also rejoice in God [rejoicing in His love and perfection] through our Lord Jesus Christ, through whom we have now received and enjoy our reconciliation [with God]. [Jer 9:24]
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 07/08/2019.
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Mu Wa Ba Olorun Laja Nipa Iku Re. by Primate7: 8:21pm On Aug 07, 2019
TANI JESU NSE?
JESU MU WA BA OLORUN LAJA NIPA IKU RE.
EPISTELI TI PAULU APOSTELI SI AWON ARA ROMU , ORI KARUN, ESE KEWA ATI IKANKANLA SO WIPE: 10. Nje bi, nigbati awa wa li ota, a mu wa ba Olorun laja nipa iku Omo re, melomelo, nigbati a la wa ni ija tan, li a o gba wa la nipa iye re. 11. Ki si ise be nikan, sugbon awa nsogo ninu Olorun nipa Oluwa wa Jesu Kristi, nipase eniti awa ti ri ilaja gba nisisiyi.
LATI INU BIBELI MIMO
(07/08/2019)
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Adamu Ikehin Emi Isonidaye by Primate7: 11:15pm On Aug 01, 2019
TANI JESU NSE?
JESU NI ADAMU IKEHIN EMI ISONIDAYE.
EPISTELI KINNI TI PAULU APOSTELI SI AWON ARA KORINTI, ORI IKEDOGUN, ESE IKARUNDINLADOTA SO WIPE: Beli a si ko o pe, Adamu okunrin isaju, alaye okan li a da a; Adamu ikehin emi isonidaye.
LATI INU BIBELI MIMO
(31/07/2019)
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The Last Adam, Became A Life - Giving Spirit by Primate7: 9:33pm On Aug 01, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE LAST ADAM, BECAME A LIFE - GIVING SPIRIT
THE FIRST LETTER OF PAUL TO THE CORINTHIANS, CHAPTER 15 VERSE 45 SAYS THAT: So it is written [in Scripture], "The first MAN, Adam, BECAME A LIVING SOUL (an individual);" the last Adam (Christ) _became_ a life - giving spirit [restoring the dead to life]. [Gen 2:7]
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 31/07/2019.
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The Firstborn Of All Creation by Primate7: 10:13pm On Jul 24, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE FIRSTBORN OF ALL CREATION
THE LETTER OF PAUL TO THE COLOSSIANS CHAPTER 1 VERSE 15 SAYS THAT: He is the exact living image [the essential manifestation] of the unseen God [the visible representation of the invisible], the firstborn [the preeminence one, the sovereign, and the originator] of all creation.
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 24/07/2019.

1 Like 1 Share

Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Akobi Gbogbo Eda by Primate7: 9:55pm On Jul 24, 2019
TANI JESU NSE?
JESU NI AKOBI GBOGBO EDA.
EPISTELI TI PAULU APOSTELI SI AWON ARA KOLOSSE , ORI KINNI , ESE IKEDOGUN SO WIPE: Eniti ise aworan Olorun ti a ko ri, akobi gbogbo eda:
LATI INU BIBELI MIMO
(24/07/2019)
Religion / Re: Have You Praised Him Yet, Today? by Primate7: 7:38pm On Jul 18, 2019
Thanks to RABBONI, REPROACH CRUSHER.
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Irawo Owuro Ti Ntan. by Primate7: 7:36pm On Jul 18, 2019
TANI JESU NSE?
JESU NI IRAWO OWURO TI NTAN.
IFIHAN (ISIPAYA) TI JOHANNU, ORI KEJILELOGUN, ESE IKERIDINLOGUN SO WIPE: Emi Jesu li o ran angeli mi lati jeri nkan wonyi fun nyin niti awon ijo. Emi ni gbongbo ati iru - omo Dafidi, ati irawo owuro ti ntan.
LATI INU BIBELI MIMO
(17/07/2019)
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The Bright Morning Star by Primate7: 9:14am On Jul 18, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE BRIGHT MORNING STAR
THE REVELATION TO JOHN, CHAPTER 22 VERSE 16 SAYS THAT: "I, Jesus, have sent My angel to testify to you _and_ to give you assurance of these things for the churches. I am the Root (the Source, the Life) and the Offspring of David, the radiant _and_ bright Morning Star." [Num 24:17; Is 11:1,10]
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 17/07/2019.
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Irawo Owuro Ti Ntan. by Primate7: 10:28pm On Jul 17, 2019
TANI JESU NSE?
JESU NI IRAWO OWURO TI NTAN.
IFIHAN (ISIPAYA) TI JOHANNU, ORI KEJILELOGUN, ESE IKERIDINLOGUN SO WIPE: Emi Jesu li o ran angeli mi lati jeri nkan wonyi fun nyin niti awon ijo. Emi ni gbongbo ati iru - omo Dafidi, ati irawo owuro ti ntan.
LATI INU BIBELI MIMO
(17/07/2019)
Religion / Who Is Jesus? - Jesus ,the Holy One, The True One, Has The Key by Primate7: 6:29am On Jul 11, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE HOLY ONE, THE TRUE ONE, HE WHO HAS THE KEY TO THE HOUSE OF DAVID
THE REVELATION TO JOHN, CHAPTER 3 VERSE 7 SAYS THAT: "And to the angel (divine Messenger) of the church in *Philadelphia write: "These are the words of the Holy One, the True One, He who has the key [to the house] of David, He who opens and no one will [be able to] shut, and He who shuts and no one opens: [Is 22:22]
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 10/07/2019.
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Je Eni Mimo, Oloto Ati Eniti O Ni Kokoro Dafidi by Primate7: 8:39pm On Jul 10, 2019
TANI JESU NSE?
JESU JE ENI MIMO, OLOTO ATI ENITI O NI KOKORO DAFIDI
IFIHAN (ISIPAYA) TI JOHANNU, ORI KETA, ESE KEJE SO WIPE: Ati si angeli ijo ni Filadelfia kowe: Nkan wonyi li eniti o je mimo ni wi, eniti ise oloto, eniti o ni kokoro Dafidi, eniti o si, ti ko si eniti yio ti; eniti o si ti, ti ko si eniti yio si.
LATI INU BIBELI MIMO
(10/07/2019)
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Eleri Oloto by Primate7: 9:49am On Jul 06, 2019
TANI JESU NSE?
JESU NI ELERI OLOTO.
IFIHAN (ISIPAYA) TI JOHANNU, ORI KINNI, ESE KERIN ATI APA KINNI ESE KARUN SO WIPE: 4 JOHANNU si ijo meje ti mbe ni Asia; Ore - ofe fun nyin, ati alafia, lati odo eniti o mbe, ti o si ti wa, ti o si mbowa; ati lati odo awon Emi meje ti mbe niwaju ite re; 5A. Ati lati odo Jesu Kristi, eleri oloto,
LATI INU BIBELI MIMO
(03/07/2019)
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The Faithful And Trustworthy Witness by Primate7: 10:19pm On Jul 04, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE FAITHFUL AND TRUSTWORTHY WITNESS
THE REVELATION TO JOHN, CHAPTER 1 VERSES 4 AND 5A SAY THAT: 4*John, to the seven churches that are in [the province of] *Asia: * Grace [be granted] to you and peace [inner calm and spiritual well - being], from Him Who is [existing forever ] and Who was [ continually existing in the past] and Who is to come, and from *the seven Spirit that are before His throne, [Is 11:2] 5A and from Jesus Christ, the *faithful _and_ trustworthy Witness,
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 03/07/2019.
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Bisopu Okan Nyin by Primate7: 9:52am On Jun 28, 2019
TANI JESU NSE?
JESU NI BISOPU OKAN NYIN.
EPISTELI IKINI TI PETERU SI ENIA GBOGBO, ORI KEJI, ESE IKEDOGBO SO WIPE: Nitori enyin ti nsako lo bi agutan, sugbon nisisiyi enyin pada si odo Oluso - agutan ati Bisopu okan nyin.
LATI INU BIBELI MIMO
(26/06/2019)
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The Guardian Of Your Soul. by Primate7: 6:32pm On Jun 27, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE GUARDIAN OF YOUR SOUL.
THE FIRST LETTER OF PETER CHAPTER 2 VERSE 25 SAYS THAT: For you were continually wandering like [so many] sheep, but now you have come back to the Shepherd and Guardian of your souls. [Is 53:5, 6]
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 26/06/2019.
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The Guardian Of Your Soul. by Primate7: 5:31pm On Jun 27, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE GUARDIAN OF YOUR SOUL.
THE FIRST LETTER OF PETER CHAPTER 2 VERSE 25 SAYS THAT: For you were continually wandering like [so many] sheep, but now you have come back to the Shepherd and Guardian of your souls. [Is 53:5, 6]
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 26/06/2019.
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The Guardian Of Your Soul. by Primate7: 5:24pm On Jun 27, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE GUARDIAN OF YOUR SOUL.
THE FIRST LETTER OF PETER CHAPTER 2 VERSE 25 SAYS THAT: For you were continually wandering like [so many] sheep, but now you have come back to the Shepherd and Guardian of your souls. [Is 53:5, 6]
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 26/06/2019.
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Nse Itoju Wa. by Primate7: 3:53pm On Jun 22, 2019
TANI JESU NSE?
JESU NSE ITOJU WA.
EPISTELI IKINI TI PETERU SI ENIA GBOGBO, ORI KARUN, ESE KEJE SO WIPE: E ma ko gbogbo aniyan nyin le e; nitoriti on nse itoju nyin.
LATI INU BIBELI MIMO
(19/06/2019)
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Cares And Watches Over Us Very Carefully. by Primate7: 8:34pm On Jun 20, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS CARES AND WATCHES OVER US VERY CAREFULLY.
THE FIRST LETTER OF PETER CHAPTER 5 VERSE 7 SAYS THAT: casting all your cares [all your anxieties, all your worries, and all your concerns, once and for all ] on Him, for He cares about you [with deepest affection, and watches over you very carefully]. [Ps 55:22]
culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 19/06/2019.

1 Like

Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The King Of Kings, And Lord Of Lords. by Primate7: 2:43pm On Jun 13, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS THE KING OF KINGS, AND LORD OF LORDS.
THE REVELATION TO JOHN, CHAPTER 19 VERSE 16 SAYS THAT: And on His robe and on His thigh He has a name inscribed, "KING OF KINGS, AND LORD OF LORDS." [Deut 10:17]
*Culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 12/06/2019

1 Like

Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Ti Ru Ebo Kan Soso Ti O To Fun Ese Araye by Primate7: 8:43am On May 30, 2019
TANI JESU NSE?
JESU TI RU EBO KAN SOSO TI O TO FUN ESE ARAYE
EPISTELI SI AWON ARA HEBERU, ORI KEWA, ESE KEJILA ATI IKETALA SO WIPE: 12. Sugbon on, lehin igbati o ti ru ebo kan fun ese titi lai, o joko li owo otun Olorun; 13. Lati igba na lo, o nreti titi a o fi fi awon ota re se apoti itise re.
LATI INU BIBELI MIMO
29/05/2019
Religion / Who Is Jesus? - Jesus' Once Sacrifice Is Sufficient. by Primate7: 8:35pm On May 29, 2019
WHO IS JESUS? JESUS' ONCE SACRIFICE IS SUFFICIENT
THE LETTER TO THE HEBREW CHAPTER 10 VERSE 12 and 13 SAYS: 12.whereas Christ, having offered the one sacrifice [the all - sufficient sacrifice of Himself] for sins for all time, SAT DOWN [signifying the completion of atonement for sin] AT THE RIGHT HAND OF GOD [the position of honor]. 13. waiting from that time onward UNTIL HIS ENEMIES ARE MADE A FOOTSTOOL FOR HIS FEET. [Ps 110:1]
Culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 29/05/2019
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is The Mediator Of A New Covenant. by Primate7: 10:55am On May 23, 2019
WHO IS JESUS? JESUS IS THE MEDIATOR OF A NEW COVENANT.
THE LETTER TO THE HEBREW CHAPTER 12 VERSE 24 SAYS: and to Jesus, the Mediator of a new covenant [uniting God and man], and to the sprinkled blood, which speaks [of mercy], a better and nobler and more gracious message than the blood of Abel [which cried out for vengeance]. [Gen 4:10]
Culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 22/05/2019
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Baptizes With The Holy Spirit by Primate7: 11:51pm On May 15, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS BAPTIZES WITH THE HOLY SPIRIT
THE GOSPEL ACCORDING TO JOHN CHAPTER 1 VERSE 33 SAYS THAT: "I did not recognize Him [as the Messiah], but He who sent me to baptize *in water said to me, 'He upon whom you see the Spirit descend and remain, this One is He who baptizes with the Holy Spirit.'
Culled from Amplified Holy Bible, Large Print. 15/05/2019

1 Like

Religion / Who Is Jesus? - Jesus Foretold The End Of The Age. by Primate7: 9:43pm On May 08, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS FORETOLD THE END OF THE AGE
THE GOSPEL ACCORDING TO MATTHEW CHAPTER 24 VERSE 14 SAYS THAT:
“This good news of the kingdom [the gospel] will be preached throughout the whole world as a testimony to all the nations, and then the end [of the age] will come.
Culled from Amplified Holy Bible, Large Print.
08/05/2019
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu So Asotele Opin Aye by Primate7: 9:26pm On May 08, 2019
TANI JESU NSE?
JESU SO ASOTELE OPIN AYE
IHINRERE TI MATTEU ORI KERINLELOGUN ESE KERINLA SO WIPE
A o si wasu ihinrere ijoba yi ni gbogbo aiye lati se eri fun gbogbo orile – ede; nigbana li opin yio si de.
LATI INU BIBELI MIMO
08/05/2019
Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Je Onise Iyanu (jesu Rin Lori Omi) by Primate7: 5:25pm On May 02, 2019
TANI JESU NSE?
JESU JE ONISE IYANU (JESU RIN LORI OMI)
IHINRERE TI MATTEU ORI KERINLA ESE IKEJILELOGUN TITI DE IKEDOGBON SO WIPE:
22. Lojukanna Jesu si ro awon omo-ehin re lati bo sinu oko, ki nwon ki o siwaju re lo si apakeji, nigbati on tu ijo enia ka.
23. Nigbati o si tu ijo enia ka tan, o gun ori oke lo, on nikan, lati gbadura: nigbati ale si le, on nikan wa nibe.
24. Sugbon nigbana li oko wa larin adagun, ti irumi nti i , siwa sehin: nitoriti afefe se owo odi si won.
25 Nigbati o di iso kerin oru, Jesu to won lo, o nrin lori okun.
LATI INU BIBELI
01/05/2019
Religion / Who Is Jesus? - Jesus Is A Miracle Worker (he Walks On Water) by Primate7: 10:48pm On May 01, 2019
WHO IS JESUS?
JESUS IS A MIRACLE WORKER (HE WALKS ON THE WATER)
THE GOSPEL ACCORDING TO MATTHEW CHAPTER 14 VERSES 22-25 SAY THAT:
22. Immediately He directed the disciples to get into the boat and go ahead of Him to the other side [of the Sea of Galilee], while He sent the crowds away. [Mark 6:45-52; John 6: 15-21]
23. After He had dismissed the crowds, He went up on the mountain by Himself to pray. When it was evening, He was there alone.
24. But the boat [by this time] was already a *long distance from land, tossed and battered by the waves; for the wind was against them.
25. And in the fourth watch of the night (3.00-6.00a.m.) Jesus came to them, walking on the sea. [Mark 6:48; John 6:19]
Culled from Amplified Holy Bible, Large Print.
01/05/2019

(1) (2) (3) (4) (5) (of 5 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 47
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.