Raydos's Posts
Nairaland Forum › Raydos's Profile › Raydos's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 238 pages)
Èsè-Àlùkò — Violet @ScienceInyoruba ni ó sọ àwọ̀ yi ni orúkọ
|
Èsèèdú — Purple
|
Ewéyòò — Neon green Tí a bá fẹ she atúpalẹ̀ "Ewéyòò" , Nkan ti o tunmọ̀ sì ni wípé "Ewé tí o tàn Yòò"
|
Sọwé — Emerald
|
Aró — Blue
|
Please my post was removed by the bot and I was banned unjustly without breaking any rules - I am just trying to document my research and works here, but the bots are making it hard for me Please restore my post Dominique, Lalasticlala myndd44 This is the link to the thread: https://www.nairaland.com/8551135/oruko-awon-awo-pelu-aworan |
Òfèhèfè — Yellow
|
Ẹ̀pọ́nrúsú — Brown
|
Ọ̀bẹdọ̀ — Green Ní ọ̀pọ̀ ìgbà ni a ma ùn pe (Green) ni àwọ̀ ewé - Shugbọ́n nínú ishẹ́ ìwádìí mi, Mo She alabapade orúkọ yi (Ọ̀bẹdọ̀) nínú ìwé Àjàyí crowther fun Àwọ̀ ewé
|
Pupa — Red Àwọ̀ Pupa ti wà ní èdè Yorùbá tẹlẹ rí
|
Funfun — White Àwọ̀ Funfun ballau ni yoruba
|
Mo shí abala yi láti She àfihàn onírúurú Àwọ̀ ní Yorùbá pẹ̀lú àwọn àwòrán wọn kí o lè rọrùn fún wa láti dá wọn mọ̀ Awọn míràn nínú àwọn awọ̀ yí tí ni orúkọ tẹlẹ rí, Shugbọ́n awọn míràn wà tí o jẹ wípé awa ni a sh fún wọn ní orúkọ Titun Ọpẹ pàtàkì fún @Science_in_yoruba ati @Agbarotede Ti wọn fún púpọ nínú àwọn awọ̀ yí ni orúkọ Titun Dúdú — Black
|
In a world of Face ID and Fingerprints sensor If they can't unlock it, then they're dumb |
This phone has been Sold ✅ |
Neatly used iphone 11 pro for sale Name: iphone 11 pro ROM: 64gb RAM: 4gb No crack or anything, No issue! I am selling because i upgraded to 13 If interested, contact me on: 07062030911 I am in abeokuta Price: 320k
|
A beautiful sight, So many beautiful places wasting away in nigeria I think for things to work in this country, we need to break it |