Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 12:13pm On Nov 01, 2025 |
Ayínrin — Neon Yellow
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 7:56am On Nov 01, 2025 |
OBAJESU: Opolopo na lo mo awo yi ni 'Ayinrin', abi bee'ko? Bẹẹni ṣhugbọn àwọ̀ òfèhèfè ni orishirishi (Shades) Èyí tí ó ùn tàn Yòò ninu àwọn (Shades of Yellow) yi ni a ùn pè ní ayínrín Yellow — Òfèhèfè Neon Yellow — Ayínrín |
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 7:47am On Nov 01, 2025*. Modified: 12:12pm On Nov 01, 2025 |
Waji — Light blue
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 7:45am On Nov 01, 2025*. Modified: 12:11pm On Nov 01, 2025 |
Saró — Sky blue
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 8:51pm On Oct 31, 2025*. Modified: 12:09pm On Nov 01, 2025 |
Posò — Olive
|
Politics › Re: Bayelsa: Governor Douye Diri To Join APC On Monday by Raydos(m): 3:57pm On Oct 31, 2025 |
I hope you guys get this fixed sir/ma Your bots keeps banning me and removing my post without breaking any rules Please help me restore my post, This thread is to educate people, I don't know why I keep getting banned Dominique Lalasticlala Myndd44 This is the thread https://www.nairaland.com/8551135/oruko-awon-awo-pelu-aworan |
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 3:56pm On Oct 31, 2025*. Modified: 12:08pm On Nov 01, 2025 |
Kése — Teal
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 3:55pm On Oct 31, 2025*. Modified: 8:53pm On Oct 31, 2025 |
Fàdákà — Silver
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 2:19pm On Oct 31, 2025*. Modified: 8:52pm On Oct 31, 2025 |
Rẹ́sú — Mauve
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 2:17pm On Oct 31, 2025*. Modified: 4:13pm On Oct 31, 2025 |
Ọ̀gàn — Lavender
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:31pm On Oct 31, 2025 |
Rínrin — Lemon
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:29pm On Oct 31, 2025 |
Shúro — Navy blue
Ìsùnkì Àti ipàrójẹ wà nínú òrùkọ yìí Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ orúkọ yi gangan ni (Shú—Aró) Ni èyí tí o tunmọ sí Aró ti ó shú (Shú as in Dark)
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:25pm On Oct 31, 2025 |
Lenbe — Coral
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:21pm On Oct 31, 2025 |
Sányán — Tan
Àwọ̀ Asho-òkè Sányán ni ó she àtinúda fún sísọ Àwọ̀ yi li orúkọ yi
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:16pm On Oct 31, 2025 |
Àlárì — Maroon
O ní ìkan lára àwọn Adẹ́rìnpọ̀shónú L'órí tiktok ti o ùn lo "Àlàrí" gégébí inagijẹ rẹ, Púpọ lára wa lè ti ba fónrán rẹ pàdé rí (Kidbaby) — Shugbọ́n Njẹ ẹ mo wípé orúkọ "Àlàrí" yi jẹyọ latara Asho-òkè kan ti àwọ̀ rẹ̀ fi ará jọ Àwọ̀ (Maroon)
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 1:11pm On Oct 31, 2025 |
Wúrà — Gold
Mo lérò wípé gbogbo wa pata ni a ti ri àwọ̀ wúrà rí
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 12:13pm On Oct 31, 2025 |
Èfì — Cream
Àwọ̀ eléyìí jẹ ìkan lára àwọn àwọ̀ ti mo fẹràn jù
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 10:44am On Oct 31, 2025*. Modified: 12:12pm On Oct 31, 2025 |
Pupayòò — Scarlet
|
|
Foreign Affairs › Re: 16-year-old Terrorist Released In Gaza Deal Arrested For Plotting Terror Attack by Raydos(m): 10:38am On Oct 31, 2025 |
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 10:37am On Oct 31, 2025*. Modified: 12:11pm On Oct 31, 2025 |
Pupadú — Burgundy
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:39am On Oct 31, 2025 |
Ìtuná — Pink
A tún lè pèé ní"Gbúre
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:37am On Oct 31, 2025 |
Ọsànwọ̀ — Orange
Orúkọ yi wáyé látàrì àpapọ Ọsàn ati Àwọ̀
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:34am On Oct 31, 2025 |
Ọlọ́yẹ́ — Grey
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:33am On Oct 31, 2025 |
Lúkúsù — Peach
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:32am On Oct 31, 2025 |
Arówé — Cyan
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:30am On Oct 31, 2025 |
Ẹ̀lù — Indigo
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:28am On Oct 31, 2025 |
Èsè-Àlùkò — Violet
@ScienceInyoruba ni ó sọ àwọ̀ yi ni orúkọ
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:25am On Oct 31, 2025*. Modified: 12:17pm On Nov 01, 2025 |
Èsèèdú — Purple
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 9:21am On Oct 31, 2025 |
Ewéyòò — Neon green
Tí a bá fẹ she atúpalẹ̀ "Ewéyòò" , Nkan ti o tunmọ̀ sì ni wípé "Ewé tí o tàn Yòò"
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 8:44am On Oct 31, 2025 |
Sọwé — Emerald
|
Culture › Re: Orúkọ Àwọn Àwọ̀ Pẹ̀lú Àwòrán Wọn Ní Yorùbá by Raydos(op): 8:43am On Oct 31, 2025 |
Aró — Blue
|