Remii's Posts
Nairaland Forum › Remii's Profile › Remii's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 158 159 160 161 162 163 164 (of 164 pages)
Simpson - Adult swimmer |
Aifi ele kebosi, lai ri eni joo. E pari eyi: [b]Bi 'bi o te, bi 'bi o ba wo[/b]_____________________________ |
Jcob:Ewure ko so wipe oun ose oko aguntan, aguntan lo so wipe iya oun ko bi dudu |
OLAAADEGBU o gbiyanju, sugbon bayi ni awon agbalagba se pari e l'oju mi ri. Won fi e je eekerin ilu o un binu , se eyin merin lee wa nilu ni? Af'oju to di'ju, t'o ni oun nsun, igba to laju sile kini ori. E pari eleyi: [b] Ewure ko so wipe oun o se oko aguntan[/b]_________________________________ |
Jcob:Amunibuni eran Ibiye, Ibiye fo loju otun eran re foloju osi, E pari eyi: [b]Won fi o je eekerin ilu o un binu[/b]_________________________________ |
A ki i bo sinu omi tan; ka maa kigbe otutu E pari eyi: [b]Won fi o je eekerin ilu o un binu[/b]_________________________________ |
Won mu Agba'je, o ni oun kii se ole, kini oruko eni to ba gbe owo Adaba np'ogede, o ro pe eyele o gbo; eyele gbo ti tiiri lon tiri. E pari eyi: [b]Ai pe ipade iya[/b]______________________________ |
Inna lilahi wahi na lilah rajihun, from God we came and to him is our return. May his soul rest in peace. May God protect those left behind including us too till our own time. |
farotika:Agunleyinju ni oooooo! Boya maa wa wa Afunleyinju kan nisisiyi, iyen a je oloju waa se waa se , abi. Same naa ni now. |
OLAADEGBU:Were dun un wo loja[b] ko see bi l'omo. [/b] E pari eyi: Won mu Agba'je, o ni oun kii se ole, ____________________ |
farotika:farotika, e ku ise opolo. Emi ro wipe Agunleyinju ni dipo Afunleyinju se e le se alaye iyato boya yoruba egbe lemi gbo ![]() |
tkb417:Eyi tumo si wipe Agbado inu igo ti di awomaju fun adie. [i][/i] |
allboyz:Yersterday! When last did you pray for Nigeria's progress and prosperity. |
Since two of you must marry by hook or crook, do the following. Two of you should open "anticipated children medical bills" account and start making deposits. If you happen to have an SS baby, the cash would come handy if not, the cash would used for better life. ![]() |
Bi Oke Ibadan ba gba maalu, enu alagbaro ko lo ye ka ti gbo. E pari eyi: Won mu Agba'je, o ni oun kii se ole, ___________________________________ |
Oko ba ra e enu e obo. (you have implicated yourself, you are not able to keep your mouth shut) |
kola oloye:O see. O ya bami gbiyanju eleyi: [b]Bi Oke Ibadan ba gba maalu[/b]______________________________________ |
Melo laa do ninu obo, taa so wipe ki ile o ma mo Koju mora bi oloko nla Ashawo say make una no rush the abuuna go go round all |
kola oloye:Sako laa sin'to bi ito ba yi layi ju odi kelebe. E pari owe "now" [b]Bi Oke Ibadan ba gba maalu[/b]______________________________________ |
epi:epi can not spell "blue" |
kola oloye:Yoo daa fun Kola Oloye, emi naa ro bee o sugbon kosi eni to mo ede ayan bi eni to mi gongo e lowo, eni nlu omele lo mon to mele nso lo je ki dake. |
Horror! |
Agba ofifo ni npariwo;_________________________________ [quote][/quote]Agba ofifo ni npariwo eyi to lomi ninu kii dun. E pari eleyi: Bi Oke Ibadan ba gba maalu[b][/b]______________________________________ |
goodass:Oro kii to bi titi kafi obe buu enu naa loa fi so. Epari eleyi: [b]Opolo so wipe inu oun ko dara[/b]____________________________________ |
kola oloye:Aifeso ke iboosi lai r'eni joo E pari owe yi: [b]Omo kii ba ipele iya re[/b]__________________________ |
Okanran:Oka ko ki nje oka ohun to nje oka l'oka nje. Pari owe yi: [b]Ohun to pa oloko lekun[/b]____________________ |
E pari owe yi: [b]Egungun ti o ba koko jo[/b]__________________________________ |
goodass:Mo ti gbo bayi ri 1. Alangba ori esi t'oun t'esu le l'ejo 2. Agbeni ko l'uni alangba ori esu 3. Alangba ori esu nii mu ni soko lu orisa Ewo ni idahun to ba ero okan re mu. |
kola oloye:Apon tooro obe l'ofi ma iye ta ra ila. (Apon ko iti ni iyawo. When a bachelor begs for stew often he would be told the cost of ingredients). E pari owe yi: Ojo to pa alapa[/b]__________________________ hollandis:_________________________-Koro ti nje efo ara efo lowa. ogiri awoku ile lonje alapa (partially fallen hose wal) |
kola oloye:Apon tooro obe l'ofi ma iye ta ra ila. (Apon ko iti ni iyawo. When a bachelor begs for stew often he would be told the cost of ingredients). E pari owe yi: [b]Ojo to pa alapa[/b]__________________________ |
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 158 159 160 161 162 163 164 (of 164 pages)
Jowo gbe simi leti 
