Remii's Posts
Nairaland Forum › Remii's Profile › Remii's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 159 160 161 162 163 164 (of 164 pages)
kola oloye:Alangba ori esu, [b]t'oun t'esu lelejo. Pari asamo yi: [b]Apon tooro obe,[/b]__________________________ |
farotika:Bi a ba fa gburu, guru o fa igbo |
babsongudus:Egungun to ti jade kuro ni aiwoo. E pari owe yi: [b]Bi iya nla ba gbe ni san le[/b]_____________________________________ |
farotika:Aise alaye oro lo pa elenpe akoko, to so wipe igba wuwo ju awo lo, (Ko se alaye boya igba tutu ni tabi gbigbe) E pari owe yi: [b]Egungun to ti jade,[/b]______________________________ |
farotika:Bao ni nka agba bi ewe laari |
farotika:Farotika: Enu l'ebo, a ki je ogede kowu lereke enu lebo. Baa f'ese ko yoo san sugbon eni f'enu ko le gbabe lo. O gbagbe itan inu alawiye nipa okunrin to se igun ati adie, Oun je adie o fun awon alejo re ni igun je sugon o so fun won wipe ounje igun. Oun ni oku awon to je igun si wa laaye. Bi aye bani koo bori ti o ko b'ori sugbon too so fun won pe oti b'ori ori a gbe eo, beena ni too ba bori ti o f'enu saa ta wipe oo b'ori fun won aye ni yoo fi jamba owo ara won se eni naa. Enu l'ebo enu koni re ba wa l'ese oooo. Abo mi ree oo. |
farotika:Ota'fa s'oke yi'do b'ori, b'oba aye o rii t'orun nwo oo E pari owe yi: Bao ni nkan agba___________________________________ |
Remii:Eniyan to mu omi si awusa yoo ma pe omi koro |
Have stocks like Oceanic bought @ N24 now N10, Sterling at N10 turned N18 after their misconstruction now N2. 14, Linkage at N5.4 now 63k, FBN at N35 now N18, PhB at N17 now N8, Nascon at N17 now N5.7, Fidelity @ N13 now N4.3, Transcorpse @ N7.5 now 63k, Diamond @ N17 now N6.5, Standard alliance @ N4.4 now N1.7, Zenith @ N57 (ex bonus) now N20, UBA @ N34 (ex bonus) now N12 Japaul at N14 now N3.12 within all these lost 60.2 % of cash invested in 2008. Worse still out of cash to buy now I order to average down the cost. Had to suspend completion of personal house project since most cash are from bank overdrafts and loans of some kind. No gut to sell at the present prices either. My people, I pray and hope that 2008 would be our worst investment and financial planning year "Aani ri iru e moo Amin" ![]() |
Enu o ni pawa ooooooooh!!!!!! Agbongbon awo ode Ilore Agbayangidi awo ile Ijesa A difa fun Oloyimefun ti o bu'le Olowu r'oko Won ni ko bo eegun ile, ebo re ko ru, O bo oosa oja ebo re ko da O bori, ori pa O bo ile, ile lu Won wa ni ko bo olubobotiribo baba ebo O ni oun ma baba eni leegun ile, Oun mo iya eni loosa oja Oun mo ori l'ori, Oun si mo ile n'ile Sugobon oun ko mo olubobotiribo baba ebo Won wa so fun wipe Enu ni, Enu l'olubobotiribo baba ebo Nje ki lanbo ni Ife, Enu won la nbo n'Ife Enu won Gbogbo eni b'agbo e sora fun enu o, Enu won la nbo n'Ife. |
In fact we should rename Nairaland as "Freedom Square". |
goodass:Eni Sango toju e ja koni bawon bu olukoso. E pari owe yi: Eniyan to mu omi si awusa_______________________________ |
E pari owe yi: Agba to j'aje iw'ehin___________________________________ |
Remii:b] Afoju f'awo en'binu oun to ju awo lo ti fo lara afoju[/b] E pari eyi: Ijakumo ki rin 'de osan__________________________ |
E ku ewu ati ayo odun tuntun 2009. Odun yoo ya'bo ooh! E pari asamo yi ooh! Afoju f'awo en'binu______________________________________ |
OLAADEGBU:Ode afi fila pa erin, ojo kan ni iyi re mo [b]Baa gun'yan ni ewe[/b]___________________________ |
E pari owe o o, Ile ti afi ito mo__________________________ |
OLAADEGBU:Correct answer is Gbami gbami ko ye agba eran nle mi bo ko ye ode. Ai le ja ni a nso wipe ita baba mi kode ibiyi, odan iwaju le baba eni kii gbe ja eni Egba yi ye woo Eni egungun nle ko a roju_________________________________________________ |
Its already December 25, 2008 here in the Arabian Gulf. Merry Xmas to all expecially Nairalanders on this trend, including the expert fryers and head butters, Oju a ma rodun ooooooooooo odun ayo laa ma se o. Amin. |
Primary School- Christ Apostolic Church Primary School, Ikirun, Osun State Secondary School- Fakunle Comprehensive High School, Osogbo, Osun State. Obafemi Awolowo University, Ile Ife, Osun State. |
tkb417:Ori ti yoo ba su l'abata bi a ko ile paanu fun yoo jo loju iso. E yi nko: Gbami gbami ko ye agba__________________________________________________, |
E gbayi ye wo Ori ti yoo ba sun l'abata __________________________________ |
tkb417:Mi o kin se kofeso, yooba oh Chemical Engineer ni mi. Mo maa nwo Yoruba home video daada ni. Bi ako ba je ki odo gbe olorisa oko lo, a so wipe opelope sese efun to wa niwaju ori oun. Arise lari ka ari ka ni baba iregun. Oya gbiyanju eyi. [b] Owu iya gbon_[/b]______________________________________________ |
My take in all these Ribadu saga is that you cannot do the right thing in a wrong way. He who leaves in the glass house should not be throwing stone. If Ribadu has nothing to fear why not go defend himself. Being anti corruption commission chairman does not make one to be untouchable. He should know better, as a police officer he should that they would be watching him and any slight wrong move is in for it. You can still fight corruption in this country but follow the rule of your own appointment too and make sure your hand is clean. He who to assizes must have clean hands. On a lighter mood, Xmas 2007 - Ribadu arrested Ibori and made him spend Xmas in EFCC jail, Xmas 2008 - Ribadu lost his job - What goes around comes around. |
Remii: tkb417:Mo soore ko gbe mi, oni owo kan ika ninu ni O ya gbiyan ju eleyi wo: Bi a ko ba je ki odo gbe olorisa oko lo_________________________ |
chamotex:Onikun lo moka ajehun lo mowo pon la |
tkb417:O o gba oo. Okunkun ko nii kun koninu ma mo inu. (No matter how dark it is, you will still know your mind) E tun gba yi ye wo: Mo soore ko gbe mi____________________________ |
mukina2:Okay oo! the allied forces can suspend coalition movement oh I don retreat, no surrender sha. |
mukina2:I don run fi coffa o, the allied forces are coming!!!! |
Remii:Iice, any thing for meeeeeeeeeeeeeee!!!!!!!! |

