Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,163 members, 7,860,170 topics. Date: Friday, 14 June 2024 at 07:16 AM

Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe - Forum Games (13) - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Forum Games / Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe (98535 Views)

Raiders! Vs Bears! L.i.v.e. / Colts Vs Jaguars L-ive / Your N.l First Crush - What Drew You To Him/her (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (10) (11) (12) (13) (14) (15) (16) ... (25) (Reply) (Go Down)

Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 2:58am On Jan 29, 2009
Jcob:

Ogbeni Kola, Remi ati Ola, eku ise owe pipa. Se inu iwe ni eti wo awon owe yii abi ati ori ? Oluwa yoo bukun opolo yin.

Epari eleyi. . .Amunibuni eran Ibiye, ____________________________

Amunibuni eran Ibiye, Ibiye fo loju otun eran re foloju osi,

E pari eyi:

[b]Won fi o je eekerin ilu o un binu[/b]_________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 10:34am On Jan 29, 2009
Remii:

Amunibuni eran Ibiye, Ibiye fo loju otun eran re foloju osi,

E pari eyi:

Won fi o je eekerin ilu o un binu[/b]_________________________________

[b]Won fi o je eekerin ilu o un binu
; O fe je Olorun ni? undecided

E gba yi yewo:

Af'oju to di'ju, t'o ni oun nsun;________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 5:47pm On Jan 29, 2009
OLAAADEGBU o gbiyanju, sugbon bayi ni awon agbalagba se pari e l'oju mi ri.

Won fi e je eekerin ilu o un binu , se eyin merin lee wa nilu ni?


Af'oju to di'ju, t'o ni oun nsun, igba to laju sile kini ori.


E pari eleyi:

     [b] Ewure ko so wipe oun o se oko aguntan[/b]_________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Jcob(m): 8:25pm On Jan 29, 2009
Ewure ko so wipe oun ose oko aguntan, aguntan ni o ni gba fun

Epari eyii. . . Aifi ele kebosi _________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 11:33pm On Jan 29, 2009
Jcob:

Ewure ko so wipe oun ose oko aguntan, aguntan ni o ni gba fun

Epari eyii. . . Aifi ele kebosi _________

Ewure ko so wipe oun ose oko aguntan, aguntan lo so wipe iya oun ko bi dudu
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 11:41pm On Jan 29, 2009
Aifi ele kebosi, lai ri eni joo.


E pari eyi:

[b]Bi 'bi o te, bi 'bi o ba wo[/b]_____________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 6:23pm On Jan 31, 2009
Bi 'bi o te, bi 'bi o ba wo, eni aba l'aba ni baba, bi 'bi ba te to si wo, onikaluku a ma se baba ara e.



E pa ri eyi o:

[b]A ti je awusa[/b]________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Jcob(m): 7:02pm On Jan 31, 2009
Awon owe yin yii le die. Eba wa pari re.
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 5:41pm On Feb 01, 2009
A ti je awusa, ko to a ti mu omi sii.



[b]Eniti o sun laa ji[/b]__________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:29am On Feb 02, 2009
Remii,
O ti wa gbona ju bayi cheesy Kare omo odo agba.

Remii:

Eniti o sun laa ji[/b]__________________________

[b]Eniti o sun laa ji, a kii ji apiroro
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:30am On Feb 02, 2009
[b]Bi ina ko ba l'awo[/b]________________________- grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 4:41pm On Feb 02, 2009
kola oloye:

Bi ina ko ba l'awo[/b]________________________- grin

Bi ina ko ba l'awo, [b]koni jo goke odo.



E pari eyi:

[b]O wu eru ki o se bi omo[/b]___________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 6:31pm On Feb 02, 2009
Remii:

Bi ina ko ba l'awo, koni jo goke odo.


E pari eyi:

O wu eru ki o se bi omo[/b]___________________

[b]O wu eru ki o se bi omo
; Imale ni o je. wink


[b]Aayan fe jo;[/b]__________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 8:54pm On Feb 02, 2009
OLAADEGBU:

O wu eru ki o se bi omo; Imale ni o je. wink


Aayan fe jo;[/b]__________________________________



O wu eru ki o se bi omo [b]oruko re ni koni je.


Aayan fe jo, adie lon soo.


[b]Baa ba d'agba koja ibante oniru[/b]__________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 2:03am On Feb 03, 2009
Remii:

O wu eru ki o se bi omo oruko re ni koni je.

Aayan fe jo, adie lon soo.


Baa ba d'agba koja ibante oniru[/b]__________________

[b]Aayan fe jo
; adie ni o je wink

Aayan ati eera sigun, won ni awon nlo mu adie;____________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 7:49pm On Feb 03, 2009
OLAADEGBU:

Aayan fe jo; adie ni o je wink

Aayan ati eera sigun, won ni awon nlo mu adie;____________________________



Aayan ati eera sigun, won ni awon nlo mu adie, eni ojo iku e ba ti pe ko ni yee.

E pari eyi:

[b]Baa ba d'agba koja ibante oniru[/b]__________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 1:01am On Feb 04, 2009
Remii:

Aayan ati eera sigun, won ni awon nlo mu adie, eni ojo iku e ba ti pe ko ni yee.

E pari eyi:

Baa ba d'agba koja ibante oniru[/b]__________________


[b]Rara o, o ku ka a to.
  wink

Aayan ati eera sigun, won ni awon nlo mu adie; alo l'ari, a o r'abo


[b]A mba'ni  mu adie a nf'orukun bo;[/b]________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by FunmyKemmy(f): 5:13pm On Feb 04, 2009
Ka ma ba fun ni je ni.

Ibi ko ju ibi ,
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 5:59pm On Feb 04, 2009
(a). Baa ba d'agba koja ibante oniru, omo eni laa boo fun.


(b). Ibi ko ju ibi, bi a ti bi eru laa bi omo.

E pari eyi:

       Ai fi eni pe eni, ai fi eniyan pe eniyan,___________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Lami05(m): 7:37am On Feb 05, 2009
Ti n mu ara oko san bante wolu.
A n kii, a n saa, ._____
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:42am On Feb 05, 2009
Lami05:

Ti n mu ara oko san bante wolu.
A n kii, a n saa, ._____
A n kii, a n saa, o loun o mo eni t'oku  cheesy

O dara na , e gbaa:
[b]kan gbongbon -kan gbongbon[/b]_________________ grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 8:47am On Feb 05, 2009
OLAADEGBU:


[b]A mba'ni mu adie a nf'orukun bo;[/b]________________________________
A mba'ni mu adie a nf'orukun bo;Ti a o ba mu ideregbe nko? grin
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 4:25pm On Feb 05, 2009
E pari eyi:

  Aare npe o o un da ifa,_____________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by kolaoloye(m): 4:30pm On Feb 05, 2009
Remii:


E pari eyi:

Aare npe o o un da ifa,_____________________
Aare npe o o un da ifa, bi ifa ba fore ti Aare o fore nko? grin

kan gbongbon -kan gbongbon__________________-
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 5:01pm On Feb 05, 2009
FunmyKemmy:

Ka ma ba fun ni je ni.
kola oloye:

A mba'ni mu adie a nf'orukun bo;Ti a o ba mu ideregbe nko? grin

Oti o.

A mba'ni mu adie a nf'orukun bo; b'owo ba ba okoko, a o fun aladie bi?
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 5:07pm On Feb 05, 2009
kola oloye:

Aare npe o o un da ifa, bi ifa ba fore ti Aare o fore nko? grin

kan gbongbon -kan gbongbon__________________-

kan gbongbon -kan gbongbon; aku-warapa lo nkangun s'orun

Eyele fi esin re pamo;_________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 5:38pm On Feb 05, 2009
Eyele fi esin re pamo; o nse eleya adie

E pari eyi:

Ai ni ora ogongo,________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by FunmyKemmy(f): 10:14am On Feb 06, 2009
A ko le fi we ti adigbonanku


A fi ase gbe ojo, ,
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 3:59pm On Feb 06, 2009
FunmyKemmy:

A ko le fi we ti adigbonanku


A fi ase gbe ojo, ,

A fi ase gbe ojo, ntan ara e je.


Bi asedanu ko ba ti nii po ju,____________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 8:51pm On Feb 07, 2009
Bi asedanu ko ba ti nii po ju, eni a un soore fun ko ni moo. (Your losses would be minimal if the recipent is an ingrate).

E pa ri eyi:

Igbe ko ni egungun,___________________________ (Shit no get bone)
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by OLAADEGBU(m): 11:36am On Feb 10, 2009
Remii:

Bi asedanu ko ba ti nii po ju, eni a un soore fun ko ni moo. (Your losses would be minimal if the recipent is an ingrate).

E pa ri eyi:

Igbe ko ni egungun,___________________________ (Shit no get bone)

Igbe ko ni egungun; Ki onigbe ma gbe igbe re

Ko si eni ti Olorun o se fun;_________________________________________
Re: Owe L' Esin Oro, Oro L'esin Owe by Remii(m): 5:36pm On Feb 10, 2009
OLAADEGBU:

Igbe ko ni egungun; Ki onigbe ma gbe igbe re

Ko si eni ti Olorun o se fun;_________________________________________



Igbe ko ni egungun, sugbon eni ba tee mo le yoo tiro, (Shit no get bone but if you step on it you would limp)

Ko si eni ti Olorun o se fun, a ya fi eni ba ni t'oun ko to.
Epari eyi:

[b]Eniyan meji kii p'adanu iro[/b]_______________________

(1) (2) (3) ... (10) (11) (12) (13) (14) (15) (16) ... (25) (Reply)

Lovely Pictures / Match 2 Personalities 2 Make A Couple / Who Are You Missing Today?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 32
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.