Sidiq80's Posts
Nairaland Forum › Sidiq80's Profile › Sidiq80's Posts
1 (of 1 pages)
Hi lady comfort,how r u doing?can i have ur number or email address.i need to discuss sth wt u.u can add m on whatsap 08076503605 thanks |
Baba ifakaleluya eku ise o,number mi ni yi o (08076503605)mo nilo ogun yi .ese o |
Baba healthfirst,ama juse fun yin o.ise isegun ota yi ni afa mi kan fun mi ni ibadan,ko ti e yato si ara won.eleyi fi han wipe baba health first olododo eniyan ni yin.mojuba ooo.motun nife si iwe iwulo ewe ati egbo na o.iba eyin agbalagba IFA ISEGUN OTA TO N DINA RERE MO ENIYAN Ao fi iyerosun te Ifa Otura-Gbe, Otura lotun Ogbe losi, a o wa pe ofo yi sii- Oruko ikujuwon(re mi do mi) omo aje aforanmoje be esu(re do do do mi (3*)mo ni mofe lowo, won ni mi o gbodo lowo, mo ni mo fe laya rere,won ni mio gbodo laya rere, mo ni mo fe bimo rere, won ni mio gbodo bimo rere, mo ni mo fe kole,won ni mi o gbodo kole, nje toba ribe, otura kio ko fun won, ki odi eru buburu le won lori, ki nraye se temi, ao fi ogede omini pupa ba ifa naa je, ao se nigba meje lodun, gbogbo ota wa lao segun lagbara eledumare. A le te odu yi sinu opon ifa, tabi oun toba perese, ogede omini lao fi koje.[/quote] |
Ise aseta ti odaju re o:eso ewe imi esu 9 ati atare mesan,a o da senu jije.ise yi kere sugbon odaju.iba olorun,iba awon agbagba o,iba baba healthfirst,iba baba kaduna south.mojuba yin o |
Baba healthfirst eku ise takun o,eledua agbe yin,ejo moni fesi iwa na .ejo elo ni owo re |
healthFirst: |
1 (of 1 pages)