SisiGbeborun's Posts
Nairaland Forum › SisiGbeborun's Profile › SisiGbeborun's Posts
Kate Henshaw, gbajugbaja osere Nollywood ti gba awon ololufe e niyanju lati ma je ki lilo awon awujo ori ero ayelujara bii Facebook, Twitter, Instagram, ati bee bee lo dari igbesi aye won. O so eleyi di mimo nigbati o n salaye nkan ti oju oun ri leyin ti awon kan fesun kan pe o se afihan awon nkan to lodi si ofin ati ilana oju ewe awujo ero ayelujara kan ti won si tii jade nibe. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/mi-o-le-wa-je-ki-awujo-ero-ayelujara-ma.html |
Rogbodiyan to n lo lori eni to ni Centre for Black Culture and International Understanding ti gbile si bayi. Lojo Jimoh ni Omowe Wole Soyinka se apejuwe gomina ipinle Osun nigba kan ri, Omoba Olagunsoye Oyinlola gegebi opuro. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/wole-soyinka-deruba-oyinlola-pe-oun-maa.html |
Before nko? Who wan die naaa ![]() |
Se won ni ko si bi obo se sori ti inaki o se... awon egbe kan ti ni ki Aare Buhari ya gbe'ja fun Babatunde Fashola naa. Won ti fi iwe ebe kan siwaju EFCC pe awon owo kan wa ti Fashola na nigba to wa lori aleefa. won si gbodo se iwadi e http://www.sisigbeborun..com/2015/08/awon-onigbeja-ti-wo-fasola-lo-si-efcc.html?m=1 |
Awon omo UNILAG yi kala gan o. Nitori shandi, won fo gilaasi moto Reekado Banks.... http://www.sisigbeborun..com/2015/08/awon-ololufe-reekado-banks-koluu-leyin.html?m=1 |
O ku oriire o, omo olojo ibi. Igba odun, odun kan. www.sisigbeborun..com
|
O le ni eeyan egberun lo'na egberun to ti f'emi s'ofo ni awon apa ibi kan ni guusu Asia latari omiyale to n ba won finra.....o ma se o. www.sisigbeborun..com
|
www.sisigbeborun..com lo n ki gbogbo yin k'aabo s'inu osu kejo, loni ti n se ojo kini, gbogbo nnkan ti a ba dawo le ninu osu yi ati ti odun yi a fi pari, lo ma ja si rere o. AMIN... A ku isinmi opin ose. |
It's quite unfortunate that a lot of ladies nowadays find it hard to cut down on junks and fatty foods....(and you now say your bobo is avoiding you). No matter how big a guy's "amusement park" is....forget about six-packs, you'll discover that such a guy would always crave for a woman with a considerable level of flat tummy. I don't blame them, after all, it's guys that woo the ladies(African mentality). All I see these days is ladies with round protruding tummy....ogini? Please ladies, let's try as much as possible to shed some of these unwanted tummy fat so that, the special man in your life will also see you as his special woman. |
Ki olorun te baba s'afefe rere. E ka iroyin yi ati awon miin ni ede Yoruba nibi - www.sisigbeborun..com |
Beautiful submission @Jollyjoy, but you started out on a wrong note. Did u really have to insult d writer? Let's grow up please...and thanks for dropping by. |
Who do you think stays more committed in a relationship, the male or the female? What do you think? |
Fred is on the verge of losing it right now. He's been married for close to 3 years but after their wedding night, his wife has since moved to the guest room and that's where she's been sleeping. All efforts to get her to occupy her side of the bed in the master bedroom proved abortive. She maintained that she needs her privacy by all means. Even when they have to make love, Fred will have to go and meet her in the guest room. It seems the situation is getting out of hand now. Please advise.... |
Visionary... www.sisigbeborun..com |
Ti e ba fe ka awon iroyin to make sense ni ede Yoruba, e ma lo jina rara... Sisi Gbeborun ti wa ni sepe fun yin. E lo taara si www.sisigbeborun..com. O ta l'enu gaan |
Jollyjoy:Telemundo is the definition of romance...ok? |
grad2012:Repeat episode tinzz |
Please I'll like to find out if there are Telemundo addicts in the house...which of the telenovelas is your favourite? I'll start, mine will always be Forbidden Passions... |
Hehehe, King Sunny Ade ti pinnu lati si Music&Culture radio station. O ni ki odun yi to pari, igb'ohun s'afefe maa bere ati pe ile ise radio ma je akoko eleyi to maa ma gbe asa(culture) ati orin Naija l'aruge. www.sisigbeborun..com |
O se'ni laanu gidi gidi wipe omo kan soso ti Whitney Houston fi s'aye lo ti je olorun ni'pe leyin bii osu mefa to ti wa ni ese kan aye, ese kan orun. O ma se o. Ki olorun f'orun ke, Amin. |
Won ti ni ki Snoop Dogg maa lo l'alaafia leyin ti awon olopa mu ni ilu Sweden.....e ka nkan to se - www.sisigbeborun..com |
O kere tan, eeyan mefa lo ti p'adanu emi won nibi isele buruku to sele ni Mogadishu, olu ilu Somalia....... www.sisigbeborun..com |
Awon ohun ini ti o to opolopo milionu naira lo ti jona l'ana ni iso pako kan ni Badagry ni'lu Eko. A dupe pe eni kankan o ku nibi ijamba ina naa. Ina yi tun jo ile ijosin St Anthony Catholic Church kan to wa ni itosi iso pako naa. Awon panapana tete de ibi ina yi sha lati paa ni nkan bi aago mefa abo irole. Eni kan ti o ngbe itosi iso pako, Hamed, so wipe sa dede ni won ri eefin ti o n jade lati inu awon pako ti won ko jo, ti 'Thinner' si gb'ina ni eyi ti o fa ina nla yi. |
A dupe l'owo Olorun fun anfaani to fun wa lati ri ojo isinmi to gbeyin ninu osu keje, odun 2015. Eyin Nairalanders, Sisigbeborun lo n ki yin wipe, ose titun yi a san wa s'owo, a san wa s'omo, a san wa is aiku baale oro.... E ku isinmi oni o. www.sisigbeborun..com |
A dupe l'owo Olorun fun anfaani to fun wa lati ri ojo isinmi to gbeyin ninu osu keje, odun 2015. Eyin Nairalanders, Sisigbeborun lo n ki yin wipe, ose titun yi a san wa s'owo, a san wa s'omo, a san wa is aiku baale oro.... E ku isinmi oni o. www.sisigbeborun..com |
O ti wa n di lemo lemo fun JAMB bayi o...kini ka ti pe eleyi ti won tu n so bayi? #shoro niyen? **** nje e ti e ti ri awon aso omode ti MAVINS sese ran fun awon omo tuntun.....o fine baje...hehehe - www.sisigbeborun..com |
E lo si www.sisigbeborun..com lati ka awon koko inu iwe iroyin gbogbo to jade loni. Punch, Vanguard....ati bee bee lo. |
Ti e k'aabo ba je, welcome ni ede oyinbo, e jowo kini eku'le ni ede oyinbo? Ta lo mo? |
Hmm, omode n se bobo yi sa... Davido ma ti pe gbogbo akorin egbe re t'oku. O ni ki won ma ko owo won bo wa si ilu Amerika....fun kini? www.sisigbeborun..com |
A dupe ooo....ija ti pari laarin Omo Baba Olowo(Davido) ati Wizkid leyin ti a gbo wipe awon mejeeji jo ya foto papo ni MAMA2015 to wa'ye ni South Africa. Inu mi dun lati je ko ye yin wipe awon mejeeji ti wo ile agbara orin bayi lati se collabo to l'agbara. Lambogini ni akole orin ti won se l'owo ti orin na de ma jabo ninu osu t'ombo yi. ***okay nau... a ku oju lona |

nje e ti e ti ri awon aso omode ti MAVINS sese ran fun awon omo tuntun.....o fine baje...hehehe -