Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,200,610 members, 7,975,374 topics. Date: Tuesday, 15 October 2024 at 12:36 AM |
Nairaland Forum / SisiGbeborun's Profile / SisiGbeborun's Posts
Politics / Re: Why Sen. Gbenga Obadara Is Begging Bola Tinubu by SisiGbeborun(f): 6:28am On Mar 02, 2017 |
...And yet when people he's owing salaries of up to 7 months resign from his radio station in Abeokuta (sweet fm), he removes their names from the payroll without any explanations and justification. He just looks the other way and pretend they never existed. BAD! |
Music/Radio / Re: What Music Are You Listening To Right Now? by SisiGbeborun(f): 5:13pm On Feb 25, 2017 |
Smile For Me - Simi |
Investment / Re: Mine Altcoin On Your Regular PC And Convert To Bitcoin Easily. by SisiGbeborun(f): 9:37pm On Dec 22, 2016 |
Must we do everything through that link? Why do I think this might be shady. I hope people won't be mining into your bitcoin wallet at the end of the day..... Anyway, thanks for sharing the tips. Quite useful |
Business / Re: Help! ATM Card Trapped At Gtbank Ikota by SisiGbeborun(f): 8:56am On Dec 21, 2016 |
What kind of human being is this? MMM don turn to Gtb abi? Why do I have a feeling you just cooked up something for cheap publicity....smh. Get a life! |
Investment / Re: Am Seeing Wonders Its Keeps Coming To My Btc Wallet Hourly by SisiGbeborun(f): 4:44pm On Nov 26, 2016 |
bunmi.fadah@gmail.com |
Investment / Re: Put Your Bitcoins To Work And Get Paid Per Hour by SisiGbeborun(f): 1:06pm On Nov 25, 2016 |
bunmi.fadah@gmail.com |
Investment / Re: Bitcoin Investment (screen Shot) by SisiGbeborun(f): 12:52pm On Nov 25, 2016 |
bunmi.fadah@gmail.com |
Culture / O Ma Se O... Eya Ara Eeyan Ree Loju Titi L'abuja Yii by SisiGbeborun(f): 1:15pm On Oct 03, 2015 |
Ado oloro meji to bu gbamu ni'lu Abuja l'anaa ti se'ku pa opolopo awon eeyan ni agbegbe Nyanya ati Kuje, koda, se ni won n ri eya ara eeyan kaakiri oju popo. Ado oloro kan dun nigba ti omobinrin kan n gbee lo si ago olopa kan ni agbegbe Kuje, ti ado oloro onibeji imii si dun ni ibudoko Jikwoyi ni Nyanya, l'oju ona marose Abuja si Keffi. http://www.sisigbeborun.com/2015/10/o-ma-se-o-eya-ara-eeyan-ree-loju-titi.html |
Culture / Iku Mama HID Lo Gbe Mi Jade Ni'bi Ti Mo F'ara Pamo Si - Goodluck Jonathan by SisiGbeborun(f): 9:13am On Sep 24, 2015 |
Aare ana ni Naijiria, Omowe Goodluck Jonathan pelu awon eeyan pataki to lo si Ikenne lati lo ba awon ebi Awolowo k'edun lori iku Mama HID Awolowo to sun ninu Oluwa ni ojo Satide to koja. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/iku-mama-hid-lo-gbe-mi-jade-nibi-ti-mo.html |
Culture / Sisigbeborun N Ki Gbogbo Mumini Ati Mumina Ododo Ku Odun O by SisiGbeborun(f): 9:03am On Sep 24, 2015 |
Won ni b'odun ba ba ni l'aye, ope lo ye ka maa da. Mo n fi asiko yi ki gbogbo awon omo iya wa ninu esin Islam ati paapa gbogbo ololufee SisiGbeborun ku odun oni o. Emi wa a se pupo re laye ati laaye wa. Adura mi ni wipe ki odun y'abo fun gbogbo wa, eyi ti oju wa de ti ri yi naa, ayo, idunnu ati ore-ofe Allah ni ka fi se, Amin! E ma wa gbagbe, ti e ba fe fi eran odun mi ranse, eyin e sa ti fi ranse si ori ero ayelujara wa - gbeborunsisi@gmail.com..(hehehe). http://www.sisigbeborun.com/2015/09/sisigbeborun-n-ki-gbogbo-mumini-ati.html |
Culture / Oba Orin Juju Pe Omo Odun Mokandinlaadorin (69 Years) Lonii by SisiGbeborun(f): 10:13pm On Sep 22, 2015 |
Oni l'ojo ibi oba orin Juju ni Naijiria, Sunday Adeniyi eni ti gbogbo eeyan mo si King Sunny Ade tabi KSA. A bi King Sunny Ade si'nu ebi oba alade ni ilu Ondo. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/oba-orin-juju-pe-omo-odun.html |
Culture / Oba Orin Juju Pe Omo Odun Mokandinlaadorin (69 Years) Lonii by SisiGbeborun(f): 2:54pm On Sep 22, 2015 |
Oni l'ojo ibi oba orin Juju ni Naijiria, Sunday Adeniyi eni ti gbogbo eeyan mo si King Sunny Ade tabi KSA. A bi King Sunny Ade si'nu ebi oba alade ni ilu Ondo. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/oba-orin-juju-pe-omo-odun.html |
Culture / Awon To Ji Olu Falae Gbe N Beere Ogorun Milionu Naira by SisiGbeborun(f): 1:43pm On Sep 22, 2015 |
Ojo to ye ko je ojo idunnu ati ayo, lo ti ja si ojo ibanuje bayi fun agba oje oloselu ati oludije fun ipo aare tele ri labe asia egbe oselu AD l'odun 1999, oloye Olu Falae, eni to tun ti fi igba kan ri je akowe fun ijoba apapo ile wa. Olu Falae la gbo pe awon kan ti won fura si pe Fulani daran-daran ji gbe salo lojo ti o n se ayeye ojo ibi re. Oko Falae to wa ni Ilado, l'oju ona Igbatoro l'Akure ni awon ajinigbe lo ka mo, ti won si ji gbe salo. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/awon-to-ji-olu-falae-gbe-n-beere-ogorun.html |
Culture / Oluwa Mi, Emi O Jebi O....Ni Orin Ti Saraki Fi S'enu Ni Ile Igbejo by SisiGbeborun(f): 12:48pm On Sep 22, 2015 |
Ni nkan bii deede aago mokanla koja iseju meedogbon laaro yi ni Bukola Saraki wo inu ibi iduro ni ile igbejo to ti n dahun si awon esun onigun metala ti won fi kan-an. O wo inu ibi iduro leyin ti agbejoro e, Joseph Daudu ku'na lati ri ogbon e da, ko ma baa wo'be. Loro kan sa, Saraki ti be'be pe oun o jebi si awon esun ti won fi kan oun o. E fo'ju so'na. Gbogbo bi o ba se n lo ni SisiGbeborun a maa fi to yin l'eti... http://www.sisigbeborun.com/2015/09/oluwa-mi-emi-o-jebi-oni-orin-ti-saraki.html |
Culture / Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa by SisiGbeborun(f): 9:27pm On Sep 19, 2015 |
Won ni oja l'aye, gbogbo wa naa bayi la de wa na oja naa, bope boya, onikaluku a pada re'le naa ni. Mama, Oloye Hannah Idowu Dideolu Awolowo (HID) ti r'orun alakeji. Omo odun mokandinlogorun (99 years) ni mama n se ki olojo to de, ko da, osu meji pere lo ku ki mama HID pe omo ogorun odun. Iroyin ti a ri gbo ni wipe nkan bii wakati die seyin ni mama dake. Ireti wa ni wipe laipe, awon molebi a fi oro sita, lati se ikede iku mama. |
Politics / Mama H.I.D Awolowo Ti Lo Sun Ninu Oluwa by SisiGbeborun(f): 9:04pm On Sep 19, 2015 |
Won ni oja l'aye, gbogbo wa naa bayi la de wa na oja naa, bope boya, onikaluku a pada re'le naa ni. Mama, Oloye Hannah Idowu Dideolu Awolowo (HID) ti r'orun alakeji. Omo odun mokandinlogorun (99 years) ni mama n se ki olojo to de, ko da, osu meji pere lo ku ki mama HID pe omo ogorun odun. Iroyin ti a ri gbo ni wipe nkan bii wakati die seyin ni mama dake. Ireti wa ni wipe laipe, awon molebi a fi oro sita, lati se ikede iku mama. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/mama-hid-awolowo-ti-lo-sun-ninu-oluwa.html |
Culture / Innocent "Tuface" Idibia Ti Pe Omo Ogoji Odun Lonii by SisiGbeborun(f): 8:18am On Sep 18, 2015 |
Olorin igbalode to tun je ilumooka ninu ka gbe awon awo orin to m'ogbon wa jade Tuface Idibia ti awon ololufe re kookan gan a tun pe ni "Tubaba" ti pe omo ogoji odun loni ti n se ojo kejidinlogun, osu kesan, odun 2015. Tuface wa lati ipinle Benue sugbon... http://www.sisigbeborun.com/2015/09/innocent-tuface-idibia-ti-pe-omo-ogoji.html |
Culture / Odun Kan Gbako Ni Awon Olori Ooni Ile-ife To W’aja Maa Fi S’ofo by SisiGbeborun(f): 7:46am On Sep 18, 2015 |
Lati fi han pe won b’owo fun Alayeluwa, Oba Okunade Sijuade ti Ile-ife to w’aja ni ojo kejidinlogbon osu keje, odun yii, igbagbo wa wipe odindi odun kan gbako ni awon olori oba maraarun-un ti baba fi sile saye lo maa fi wa ninu aso opo. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/odun-kan-gbako-ni-awon-olori-ooni-ile.html |
Culture / Esi Idanwo WAEC Awon Akeeko Ghana Lo Dara Ju Lati Bii Odun Meta Seyin by SisiGbeborun(f): 5:28pm On Sep 17, 2015 |
Ajo to n ri si eto idanwo awon akeeko jade girama nile adulawo, West African Examination Council (WAEC) ti fi oro sita pe orile ede Ghana ni awon esi idanwo naa to dara ju lo ti maa n wa lati bii odun meta seyin. Oga patapata fun olu ile ise WAEC ni Naijiria, Ogbeni Charles Eguridu sipaya oro yi nibi asa'le apeje kan pelu awon oniroyin ni ilu Abuja lanaa ojoru. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/esi-idanwo-waec-awon-akeeko-ghana-lo.html |
Culture / Oni Ni Ojo Ibi Asa by SisiGbeborun(f): 5:03pm On Sep 17, 2015 |
Olojo Ibi fun toni ni ASA! Ojo ketadinlogun, Osu kesan, odun 1982 ni won bi omobinrin olohun iyo ti gbogbo aye mo si Asa. A le pe e ni omo Naijiria, a de tun le pe e ni omo ile Faranse. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/oni-ni-ojo-ibi-asa.html |
Culture / Ope O! Ijoba Ipinle Osun Ti F'owo Si Sisan Owo Awon Osise by SisiGbeborun(f): 10:45am On Sep 17, 2015 |
Se won ni b'ekun ba pe dale kan, ayo n bo l'owuro. Nkan ti n senu're f'awon osise ijoba n'ipinle Osun bayi gegebi iroyin to te wa lowo. Won ni gomina ipinle naa, Ogbeni Rauf Aregbesola ti f'owo si sisan owo ti ijoba ti je awon osise ipinle naa lati bii odun to koja. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/ope-o-ijoba-ipinle-osun-ti-fowo-si.html |
Culture / Oko Ayokele Merinlelogun Ni Gomina Ana Ni'pinle Plateau Nikan Ko Salo by SisiGbeborun(f): 11:13am On Sep 16, 2015 |
Gomina ippinle Plateau Simon Lalong ti fesun kan Jonah Jang, eni to je gomina ana ni ipinle naa wipe gbogbo oko ayokele to ko salo to merinlelogun. Gegebi awon iroyin kan to jeyo lati inu iwe iroyin PUNCH, akowe fun ijoba ipinle, ogbeni Rufus Bature to je asoju fun gomina Lalong so wipe Jang ati iyawo e ni eto si oko ayokele mesan, sugbon nigba ti o maa fi pari saa isakoso e, oko merinlelogun lo gbese le, http://www.sisigbeborun.com/2015/09/oko-ayokele-merinlelogun-ni-gomina-ana.html 2 Likes |
Culture / Ni Ipinle Oyo, Owo Awon Olopa Ti Ba Awon Afurasi L'ebo-l'oogun Merin by SisiGbeborun(f): 11:03am On Sep 16, 2015 |
Ile ise olopa ipinle Oyo ti safihan awon afurasi l'ebo-l'oogun merin kan ni ilu Ibadan lana ode yi. Oga olopa yaanyan ni'pinle naa, Ogbeni Leye Oyebade so fun awon oniroyin pe awon afurasi wonyi ni owo te ninu ile kan ti won o tii ko pari l'agbegbe Owode. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/ni-ipinle-oyo-owo-awon-olopa-ti-ba-awon.html 1 Like |
Culture / Aarun Ebola Tun Ti Pada Si Orile Ede Sierra Leone by SisiGbeborun(f): 10:55am On Sep 16, 2015 |
Awon osise eleto ilera ti ya awon eeyan to le ni ogorun meje soto ni apa ariwa Sierra Leone ni ojo aje leyin ti omobinrin kan ti oruko re nje Kadiatu Thulla ti ojo ori re o ju merindinlogun lo gbemi mi l'ojoo Isinmi to koja lo, latari aarun Ebola to kagbako lati ara ibalopo. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/arun-ebola-tun-ti-pada-si-orile-ede.html |
Politics / Re: Ongoing Fight At Alaba International Market? by SisiGbeborun(f): 3:53pm On Sep 15, 2015 |
vivalavida:I simply hope they won't start killing one another. May God save this country |
Pets / Re: What Is This Life Turning Into!!!(photo) by SisiGbeborun(f): 7:40am On Sep 15, 2015 |
Like seriously? Shows how even animals can be more caring than some humans Femiblacky: |
Culture / Obasanjo Ni Oun Fi (n287bn) Owo Ti Abacha Ji Sile Ninu Apo Ijoba Ni O! by SisiGbeborun(f): 6:17pm On Sep 14, 2015 |
Aare ana lorile ede Naijiria, Oloye Olusegun Obasanjo ti pariwo sita pe gbogbo owo ti Sani Abacha ji ko ni oun fi sile sinu apo owo ijoba o. Owo ti a n soro e yi ma po gidi gaan ni, N287bn http://www.sisigbeborun.com/2015/09/obasanjo-ni-oun-fi-n287bn-owo-ti-abacha.html |
Culture / Awon Olorin Naijiria O Ni Agbekale Ohun To Yato - Paul Play Dairo by SisiGbeborun(f): 5:57pm On Sep 14, 2015 |
O ti se die ta ti gburo Paul Play Dairo lagbo orin sugbon pelu pe o ti tadi meyin die ninu ise orin, o si mo bi gbogbo nkan se n lo pelu awon to si wa loju ise. O fe jo pe inu Paul Play o dun si bi nkan se ri lagbo awon olorin ode oni latari bi won se n wo aago ara won sise dipo ki won ronu se nkan tuntun. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/awon-olorin-naijiria-o-ni-agbekale-ohun.html |
Culture / Eedris Abdulkareem Ni Akoni Oun Tooto Ni Omowe Goodluck Jonathan by SisiGbeborun(f): 5:33pm On Sep 14, 2015 |
Olorin taka sufe labe egbe orin Kennis Music nigba kan ri, Eedris Abdulkareem tun ti ri nkan so bayi o. Ti e ba ranti, Eedris se awo orin kan fun eto ipolongo ibo sipo Aare nipa awon ise rere ti omowe Goodluck Jonathan se nigba to wa lori aleefa, sugbon sa ti nkan o senu're fun Jona lati pada sori oye. http://www.sisigbeborun.com/2015/09/eedris-abdulkareem-ni-akoni-oun-tooto.html 1 Like 1 Share |
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 51 |