Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,165,134 members, 7,860,073 topics. Date: Friday, 14 June 2024 at 03:47 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ijamba Ina Sele Ni Oja Badagry (802 Views)
The Cost Of Uprooting The Ekiti Sacred Tree In Odo, Oja (Snapshot) / Watch Beautiful Rendition Of Ogbu Oja Igbo (igbo Fluitist). You Will Be Thrilled / Ooni Of Ogunwusi Visits Badagry, The First Storey Building In Nigeria (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Ijamba Ina Sele Ni Oja Badagry by SisiGbeborun(f): 2:46pm On Jul 26, 2015 |
Awon ohun ini ti o to opolopo milionu naira lo ti jona l'ana ni iso pako kan ni Badagry ni'lu Eko. A dupe pe eni kankan o ku nibi ijamba ina naa. Ina yi tun jo ile ijosin St Anthony Catholic Church kan to wa ni itosi iso pako naa. Awon panapana tete de ibi ina yi sha lati paa ni nkan bi aago mefa abo irole. Eni kan ti o ngbe itosi iso pako, Hamed, so wipe sa dede ni won ri eefin ti o n jade lati inu awon pako ti won ko jo, ti 'Thinner' si gb'ina ni eyi ti o fa ina nla yi. |
(1) (Reply)
The Tree That Survived The 1945 Hiroshima Atomic Bomb / We Know Benin History, Don’t Write It For Us - Prince Akenzua / Igbo Woman Vs Warri Family War Start
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5 |