₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,328,195 members, 8,434,567 topics. Date: Friday, 26 June 2026 at 09:18 PM

Toggle theme

Skamoh74's Posts

Nairaland ForumSkamoh74's ProfileSkamoh74's Posts

1 (of 1 pages)

HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 6:27pm On Nov 01, 2016
skamoh74:
thanks again Sir pls sir I need ILAMU.
thanks
pls sir I need ILAMU abi isoye TODAJU fun omo university
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 8:29am On Nov 01, 2016
kadunasouth:
OSE ERO ATI ITURA
ogede omini tio pon meta aogun tepotepo ati ewe bomubomu ao po mo ose dudu ao ko sinu ike green ao ma fi we ao ra aso green opa meta ao mafi nura
NB ose yiwa fun eni tara ni ti ota koje kori alanu, ero loje fun asasi ati ifokanbale ati asina
thanks again Sir
pls sir I need ILAMU.

thanks
HealthRe: Ewe Nje Oogun Nje- Oogun Ti Ko Je, Ewe Re Lo Kukan by skamoh74: 2:16pm On Oct 28, 2016
Aareago1:
OOGUN IDI YIYO EYI TI YORUBA NPE NI OROBO(DO DO RE)

Ewe guava tutu. A o gboo pelu omi tutu to mo daadaa. A o fi ase see (sieve it properly). Mimu laaro ati lale bi a se fe. Idi naa yo wole pada pelu ase Olorun.


OOGUN TI ENIYAN BA N YAGBE EJE

Ogede agbagba dudu, a o so sinu ina ti yoo jona bii eedu, a o loo kuna daadaa. A o maa fi fo eko tutu elewe fomu ninu igba tabi aha kekere laaro ati lale. Ise to daju ni. Danwo.


AMUDO TO NJE BII IDAN
Ewe amunimuye
Oruka irin
Itakun isirigun
Ewe aluro

A o lo won papo, ao koo si inu eyikeyi iwe adie
tutu, aofi aso waji we daada, aolo boo mo idi amun ti
omi kiitan ninure, fun Odidi ojo 9, ao lo ko o, ti
abafelo, aofisowo, alefidimu, sugbon eyi
ti o maa n tete sise ni wipe ki a maa fi romance obinrin naa. ,Ko ni pe iseju meji ti ido re yoo fi maa dide.,
SUGBON BERU OLORUN, TI O BA FI YAN OBINRIN JE,
OLORUN KONIJEKI OSISE.
Eseun pupo Sir. Ibere mi lori amudo yi nipe kini ale fi dipo Amu fun awa ti angbe EKO
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 10:29pm On Oct 23, 2016
08101646045atwp:
Ise ti afi nwa nkan ti ole bajilo!
Ewe Ina ati ewe esisi ati ako alangba ao gun papo, ao Sa ti yio gbe.
Lilore: Ao wa eyin na sinu akufo ikoko ni dede ago mokanla, ao maafin Lai nije Ki o fin si Awa na Lara
Pelu gbogbo bai wipe gbogbo iyeju awon ti ogbe nkan baibai lo tabi iyeju awon ti ogbe nkan lagbaja Ki ara maani komaroju raaye Ile aye re mon'o!
Afi tobada pada
Ao Sa bee ni ijo kini ikeji ati ijo keta!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Eseun yio ma juyin se oo

e add mi mo Egbe naa
08085632313
08058212821
CultureRe: .. by skamoh74: 6:44am On Oct 09, 2016
08101646045atwp:
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o


Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Kajolasepe'o
. please add me
08085632313

thanks
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 1:33pm On Oct 06, 2016
08101646045atwp:
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o


Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Kajolasepe'o
eseun pupo. Oluwa yio ma so agbara dotun . mo Fe darapo mo MAJEMU LAILAI

08085632313

. eseun
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 2:59pm On Sep 05, 2016
Salam alaikum Baba, eku ipalemo Odun Ileya Sir. Olohun ajeki odun naa bawa laye.

Baba mo fe Ogun OLE fun ninu ile ati fun OKO.

e seun sir
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 5:56pm On May 25, 2016
kadunasouth:
Osun yoba ao lo loto, efun ado ao lo loto eedu ao lo loto ose dudu ao ti fi omi de ti yio ro dada igba olomori ao bu sibi kan osun sinu igba yi ao wa bu sibi kan efun sinu igba ao bere si mape ofore si ao ropo ao tun bu sibi kan eedu si ao tun ropo ao wa mu ose tati gun toti de dada ao jusi ao ma fi owo po dada ao wa fi sile bi iseju marun ao lo epo obo die kuna ao te ifa osa meji si ao da si leyin tati se opolopo adua ao tun popo dada ao de idire kogbodo kanle man leyin taba ti setan tati gbe kuro ni ile toba jabo nibi tagbesi ao lore jusi ori atan nio ise yi daju ti ona badi ti araye nkorira re fi epo rara koto lore we kosi fi igo epo kan se sara ona yio si lesekese
thanks very much. I don't know what to say جزاك الله خيرا

وطول الله عمرك بكل خير و سعادة

آمين آمين لا أرض بواحدة حتى أضيف لها مليون آمين .
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 4:11am On May 24, 2016
salam ala ahlu l haqqi
Baba e ko mi ni ise yii tan , bawo ni lilore gan :-


AYAJO AWEBI, AWE-OGUN IDILE AWE-EPE etc Efun ni baye osun je Osun ni baye efun je Atefun Atosun edu ni baye awon mejeji je. Gbogbo asasi, edi, offa, aisan, epe, idiwo, arun, owo kowo, airi je, airi mu tin be lara oni kaluku wa koba je, kopa ibi da, koso dire, ki ona owo nlala ati arisiki kio la kan mi ati gbogbo ololufe Nairalanders!!! Ase odumare
CultureRe: .. by skamoh74: 7:21am On May 23, 2016
Ifankaleluya:
Ero-ifa ni e le se, sugbon esu re ti e o ma bo ni o dara ju!
e seun sir. may live long sir in peace and prosperity
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 6:24am On May 23, 2016
skamoh74:
salam
may Allah continue to bless you abundantly bijahi M.T.N

sir, what can I use for a brother of mine so that he will grant my request. l want him to finance my business but he doesn't want to turn up at all . I have sent many of his close friends to him but still nothing.

what can I do sir.


thanks again
am still waiting for this sir or shall I contact you privately
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 6:00am On May 23, 2016
kadunasouth:
Asin tan pa lojo ao gun saka saka ao da sinu adi eyan ao ma mun sibi meji meji lojo juma ao tun mafi para

Elekeji Asin tanpa lojo epo obo odidi atare kan ao jo ao da si meji epo idakan ma ose iwe eo mu idakan toku eo dasi inu adin eo mala, ele se die ku ninu ebu yi kie po ma epo pupa toba denu epo pupa owo (money) lowa fun ao la

Eleketa emaje orogbo eyo kokan lojo kie wa ma mun epo sibi kan lelori

Adua wa yio gba Alubarika Anabi s.a.w
Mojuba awan agbagba
Allah the Alfa and Omega will protect you and your family for ever in this life and the hereafter bijahi M.T.N

e seun pupo sir.
CultureRe: .. by skamoh74: 4:17pm On May 22, 2016
baba wa Ifankaleluya Eledua a jeki e pe fun. Apada saburu ko ni bayin tomotomo.
e jowo mofe Ogun ERO fun gbogbo asasi.
e seun
stay blessed sir
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 4:03pm On May 22, 2016
salam
may Allah continue to bless you abundantly bijahi M.T.N

sir, what can I use for a brother of mine so that he will grant my request. l want him to finance my business but he doesn't want to turn up at all . I have sent many of his close friends to him but still nothing.

what can I do sir.


thanks again
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by skamoh74: 3:56pm On May 22, 2016
kadunasouth:
ASINA ATUDE
Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin kogbodo kan ao ko sinu roba fun fun ao wa so ori niwan ba si ao gbe sinu orun toba yo ao tun po papo ma ose yi taba tipo tan idire ko gbodo kanle mon ao ma fiwe ni ojo merin larin ose sunday monday tuesday thusday ti aba lo ose yi yato si awan ojo wonyi koni sise mon, taba si fe se ose yi arin ojo mererin yi lalese tabase yato si ojo mererin yi koni sise odaju
salam aleykum
E seun pupo ao ma RI yin ba lase Almighty Allah ati atileyin Anobi Muhammed S.A.W.

Baba e Jo mofe Ogun ERO against any asasi.

thanks and stay blessed
IslamRe: Sufism In Islam. Share Your Opinions With Us. by skamoh74: 7:16pm On Sep 16, 2014
My believe is that we must 1st understand d word ''BIDIA'' according to the hadith. That is when we can determine if sufism or solatul fatihi is bidia or nt?

Wa sharrul Umoori Muhdathaatuhaa, Wa kulla Bid'atin dhaialah, wa kulla dhalatin fin-naar" Al-Hadith (Sahih Muslim). Translation of the above Hadith: ''Every innovation is a misguidance and every misguidance goes to Hell fire.''

1- what is the meaning of inovation in the above hadith?
2- In which hadith is inovation defined as what the prophet and khalefas didn't do?
3- what are the yardsticks 4 determination of bidia by the kalefas?

1 (of 1 pages)