₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,002 members, 8,419,876 topics. Date: Thursday, 04 June 2026 at 06:05 AM

Toggle theme

Snowealth's Posts

Nairaland ForumSnowealth's ProfileSnowealth's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by Snowealth: 2:10pm On Dec 29, 2015
ayokomi1010:
OGUN ONMO NLA
odidi eye karo kan,ori olongbo kan,egungun eye akala die,eja ojiji kan,odidi imo ope kan,odidi atare kan,ikode meta,ao jopo gbere kan si igbayawa,iyoku Ogede omini pupa la o mafi koje,kosi oun kan ti o sokunkun siwa koda won a tunma kowa ni OGUN loju orun pelu.odaju iba eledumare o
E ku ise takuntakun Baba, oluwa a ma ran yin lowo. E jowo, onmo yii, se ti onmo oju orun ni tabi ti iriran ti eniyan fi n mo ohun to ti sele ri, ati ohun to tun nbo wa sele lola? E seun , modupe, odun a ba wa layo.
CultureRe: .. by Snowealth: 9:53pm On Dec 13, 2015
E kaale Baba healthfirst ati Baba KadunaSouth, mo se ba eyin agbagba ati omo awo patapata yi o ma ju wa se o. A o si ni te oju ile mole, mo ki yin wipe eku ise takuntakun, eledua yi o ma wa pelu yin. A seye lalakan n se epo, aseye la o se o. Ase .
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by Snowealth: 8:11pm On Dec 05, 2015
ayokomi1010:
OGun AJEGUN.
ao toju oga aye kan,ao fi ako Okuta ge iru oga na ni aye,ao lo pelu omo atare mesan,ao fi si gbere yipo owo mejeji. o daju.
E kaale Baba, e jowo to ba se wipe obinrin ni o fe lo ise yii, se atare mesan naa lo ma lo ni tabi meje. E jowo, e la mi lo ye. Mo dupe o. Eledua a ma ran yin lowo o.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by Snowealth: 9:34am On Dec 05, 2015
ayokomi1010:
oruka bi meta tabi Meje lama lo fun Ogun na
E seun pupo, mo dupe o.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by Snowealth: 10:47pm On Dec 04, 2015
ayokomi1010:
OGUN IWOSAN AYE
ewe ela,ewe alupayida odidi atare kan, ao jo po ao da sinu omori isaasun ao wa ko oruka irin si,ao wa da epo pupa si ao ro po, ao wa fa Ogun yan si enu akuko adie,ni emeta,ao ma fi oruka ni si lenu ni okokan yio ma gbemi,ti o bawa di OJO keje ao pa adie na,ao lainure ao Ba awon oruka na,ao ko ao ma fun eniti Asian ba nse yio fi bowo re,aisan re yio San ni OJO na ase eledunmare ni,iba eyin agba o aiye mojuba o,mowole mo pa igbunmo o,mofori bale fun gbogbo ajunilo.
E jowo baba, oruka melo ni a ma lo? A ju yin se o.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by Snowealth: 10:42pm On Dec 04, 2015
E ku ise baba, Eledumare a tun bo ma fun yin se o.
CultureRe: .. by Snowealth: 7:46pm On Nov 30, 2015
wale259:
Baba kaduna,Ejo kini oruko miran fun ewe agogogun abi oroagogo ni e n so ni.ese sir
E jowo se a le ko ose naa si inu ike Funfun olomori abi dandan ni ko je pe inu igba ni a ma ko si. E seun o, agba ko ni tan lorile.
CultureRe: .. by Snowealth: 7:35pm On Nov 27, 2015
E jowo mo ni lo atuwo to lagbara fun eniyan ti aye n da laamu, to be ti ise re daru. E jowo e fi ran mi lowo.
CultureRe: .. by Snowealth: 12:00am On Nov 16, 2015
Mo ki gbogbo ile o, pataki julo baba wa healthfirst ati Kaduna south , Olorun a ma fun yin se o, e o pe fun wa lase Edumare. Mo ti ko eko lorisiri lori fanran yii. Ile ati ona yin ati ti gbogbo awon omo egbe ko ni daru o.

1 (of 1 pages)