Culture › Re: .. by wale259(m): 9:46pm On Nov 30, 2015 |
kadunasouth: OGUN ISOYE Ewe akoko 16 ori akuko adie togbo dada odidi atare kan aojo ao ma fi oyin la Sir,se omo odun meta le lo ogun isoye yii? |
Culture › Re: .. by wale259(m): 7:34pm On Nov 30, 2015 |
healthFirst: 104 EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9 Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua. E dan wo ke fun mi labo. Sir,se lepo,niyo ni atipe ale ja taba fe bere si je...se koni hutuba bi Oun |
Culture › Re: .. by wale259(m): 7:29pm On Nov 30, 2015 |
kadunasouth: Ogun Fun Eni To nse Ise Isegun ti kokinri customer dada Eso ewe oyo lopolopo, Ewe taba ao jo papo ma odidi atare kan ao mala pelu oyin lararo Sir,se eni to nse ise clearing and forwarding na le lo ko le ri ise gba abi onisegun nikan lo wa fun? |
Culture › Re: .. by wale259(m): 7:26pm On Nov 30, 2015 |
kadunasouth: Ogun fun eni ti aye ban dalamu ewe lapalapa pupa pelu ewe agogogun, ebo obo ao gun mo ose dudu ao ko sinu igba olomori ao eedu eyokan ao kibo ose na larin ao ma fiwe. Wan atuwo lorore Baba kaduna,Ejo kini oruko miran fun ewe agogogun abi oroagogo ni e n so ni.ese sir |
Culture › Re: .. by wale259(m): 5:16pm On Nov 30, 2015 |
Iba Akoda,Iba Aseda,Iba Gbo Eyin Agbalagba Lokunrin,Lobirin....E jo mo fe iranlowo eyin Awo lori ise ti mo n se ki le rise gba rowo gba....Clearing and forwarding ni Apapa....mo n sun mo nji ni lai rise gba....E sanu mi ooo |