Wam24's Posts
Nairaland Forum › Wam24's Profile › Wam24's Posts
1 (of 1 pages)
ajinde ara yio maa je ooo.aye oni pa yin ti bi aso to ti gbo ooo.ejo baba kadunasouth.mo ti ni aru ulcer ati iba lati nkan bi last may.ko si nkan ti mi o ti lo amo pabo loun jasi.bi ki ori ma fomi legbe kan ati eyin ju .ara atun ma gbona laro kutu.o ma n re mi ni gbogbo igba.ejo kini ero pe oun se mi ati kini mo le lo.e seun oooo[/quote][right][quote author=Kollyk11 post=43119530]ajinde ara yio maa je ooo.aye oni pa yin ti bi aso to ti gbo ooo.ejo baba kadunasouth.mo ti ni aru ulcer ati iba lati nkan bi last may.ko si nkan ti mi o ti lo amo pabo loun jasi.bi ki ori ma fomi legbe kan ati eyin ju .ara atun ma gbona laro kutu.o ma n re mi ni gbogbo igba.ejo kini ero pe oun se mi ati kini mo le lo.e seun ooo |
ASERO KI OYUN LE DURO (ANTI-MISCARRIAGE). ASEJE ASERO. Ewe laali pelu omi agbon ni ao fise eja aro ... ni owuro ojo keji ti o pari nkan osu. |
E ku ikale ninu yara yio |
*OGUN TI AFI WO AISAN WARAPA KAN RE,* odidi omo aja kan ti ko ti laju,eru ti ko ba la enu,siri, iyere kan, obu otoyo,ao lo gbogbo re papo ao ge aja yen si mesan,adi eyan ni ao fi se obe yi,yio ma la eran yi ati omi obe na yio ma je eran na ni okokan ✍� *adejorin Michael a k a iyamah iyamah* |
*Emi woli Adejorin Michael a k a iyamah iyamah fi awon ise yi ki awon musulumi to wa larin wa pe a ku imunra sile awe tonbo lona yio bawa ninu alafia ati ifokanbale lase edumare.* OOGUN INU RIRUN Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo lo patapata lase edumare. O daju. IDAKOLE(Amokole) Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e, ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro. OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi... Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si. Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo omi lasan. OORU INU(internal heat) Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan leemeji lojumo. OGUN GIRI. Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti oyinbo ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo na. OOGUN IKO TO DAJU Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan, alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii irole ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi talahi, ajebiidan ni. Ao nii saisan o! ATOSI::: odindi epa ikun, odindi bara kan, ako kanhun, baka die, a o fi emu da lagbo, a o gbe pamo fun ojo meta, a o ma yo mu lehin ojo keta. Odaju AKOKORO:: Oti oyinbo, egbo agbasa, a o ge egbo agbasa na, a o da sinu oti pelu egbo ata, didi si ereke fun iseju marun, lehin na a o tu danu. Odaju o. EGBOGI GBOGBONISE............ isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan. Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo arun. EGBOGI JEDIJEDI (ogun jedijedi) egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu. ✍� *WOLI ADEJORIN MICHAEL a k a iyamah iyamah* |
OOGUN INU RIRUN Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo lo patapata lase edumare. O daju. IDAKOLE(Amokole) Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e, ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro. OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi... Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si. Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo omi lasan. OORU INU(internal heat) Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan leemeji lojumo. OGUN GIRI. Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti oyinbo ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo na. Oogun iko to daju> Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan, alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii irole ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi talahi, ajebiidan ni. Ao nii saisan o! ATOSI::: odindi epa ikun, odindi bara kan, ako kanhun, baka die, a o fi emu da lagbo, a o gbe pamo fun ojo meta, a o ma yo mu lehin ojo keta. Odaju AKOKORO:: Oti oyinbo, egbo agbasa, a o ge egbo agbasa na, a o da sinu oti pelu egbo ata, didi si ereke fun iseju marun, lehin na a o tu danu. Odaju o. EGBOGI GBOGBONISE............isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan. Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo arun. EGBOGI JEDIJEDI (ogun jedijedi) egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu. |
A ku dede asiko yio gbogbo eniyan |
Yara yi wa fun iwosan nikan, ogun iwosan lo je wa LOGUN ninu yara yi |
1 (of 1 pages)