Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,650 members, 7,955,361 topics. Date: Sunday, 22 September 2024 at 12:09 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (565192 Views)
Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (22) (23) (24) (25) (26) (27) (Reply) (Go Down)
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Writs: 2:08am On Dec 16, 2017 |
In Zenlife: |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 8:54pm On Dec 17, 2017 |
MOKI GBOGBO EYIN ENIYAN WA KUU DEDE AKOKO YIO, MOGBADUA FUN GBOGBO WA WIPE: GBOGBO IGBA KUUGBA TI YIO BAMA BAWA LAYE NI AO MAARI OPE RERE DA’O! ADEKU’IMUNRA ODUN’O, AYO ATI ALAFIA NI AO FISE’O ¬¬(AMIN) PATAKI ORO MI SI GBOGBO EYIN OLOLUFE IKANNI YI LOKUNRIN ATI LOBINRIN TI AN GBIYANJU LORI ASIRI EWE ATI EGBO LONA KAN TABI EKEJI NI WIPE: MOSE AKIESI WIPE OPO AWON ASIRI KAN WA TI AKIISE AKIESI NIPA’E, TABI KI NSO WIPE AKOKAASI PATAKI GEGE BI AWON BABA WA SE NKAASI PATAKI NIGBA TI WON. FUN APERE: AWATI OLOHUN FUN NI ANFANI LATI MON NIPATEWE’TEGBO LONA KAN TABI IKEJI, ODAJU WIPE AKOGBODO MAAFI OJU DI AWON NKAN AGBARA TABI KI AMAAFI OJU RENA AWON OGUN TABI AWON ASIRI BII: IMULE ETUTU ABEGBEPE ISOYE AFORAN AROBI ERO AWISE OHUNMO AKOYA ATI BE BE LO!! SUGBON EYI TI MOFE KI AJO JI RORO LORIE NI IMUNLE. OPO AWON ENIYAN LO MA NRO WIPE BI ABA TI NSORO TI ATI DORI IMULE YI, WON MA NRO WIPE KIA WO INU EGBE KAN TABI IKEJI NI ORO YI TUMON SI, SUGBON TI KODE RI BEE RARA, TI ABA NSORO LORI IMULE AJE WIPE ORO TI DE ORI IFA NIYEN ORUMILA BABA AGBONMIREGUN LOMA NBA AWON IYAMI ELEYE MULE NITORI IDIKAN TABI EKEJI. FUN APERE BAKANNA: ORUNMILA BABA AGBONMIREGUN LO NKI IFA OHEREMEKI LOJUDE AWON ELEYE LOJOKAN, NI AWON ELEYE BAYO SI ORUNMILA, WON NI KILODE TI ORUNMILA FI NKI IFA OHEREMEKI? ORUMILA WIPE:NITORI AWON ALABOYUN KI WONLE BA BI WERE, ATI NITORI AGAN KI OLEEBA TI OWO ALABOSUN ATI NITORI AWON OKUNRUN ILE KI OLEE BA DIDE NILE, KI SISESISE LEBA LOWO ATI KI AWON ISOWO OJA KI WONLE BA RI ERE OJA. AWON IYAMI ELEYE HA MON ORUNMILA WIPE KAI! SE IWO KOMON WIPE SISESISE TI KONI OWOLOWO ERAN WA NIISE NI? BE SINI SOWOSOWO TI KORI ERE OJA NA ERAN WA NIISE, ALABOYUN TI KOBI ERAN WA NIISE AGAN TI KORI OMOGBEPON ERAN WA NIISE OKUNRUN ILE TI KODIDE ERANWA NIISE ORUNMILA BABA AGBONMIREGUN DAHUN ONI MOMON SUGBON MOWA BAWON BEBE NI! ORUMILA BEWON TITI WON’OGBO ORUNMILA SIPE TITITI WON’OGBA ORUNMILA NI TI ONBA BEYIN TI EKOBAGBO NOKI IPONRI (…..) FUN YIN’O WON NI TI ORUNMILA BAMON KI OMA KII’O! NI ORUNMILA BA BERE SINI WI BAI PE: (…………..) AWON IYAMI ELEYE BA WIPE: ODARA AWON TI GBO! ORUNMILA NI TI EBAGBO TI OHUN WIPE TI AWON OMO OHUN NKO? NITORI AWON OMO (AWO) OHUN PO NI ODE ISALU AYE AWON IYAMI ELEYE WA SE APEJUWE AWON EWE IFA KAN FUN ORUNMILA EGE BII IPINHUN TI AMON SI IMULE WIPE TI OBADI WIPE AKOFE DA AWON OMO RE MON MON KI OMAFI SE IFA FUNWON WIPE TI AWON BATI NRI AWON NKAN WONYI WIPE GBOGBO NKAN TI AWON BATI NTANI KOKO NI AWON YIO SI MAATU! AKIESI KOKO ORO WONYI NTOKA SI PATAKI OJUSE IMULE NITORINA EYIN ENIYAN MII ODAJU WIPE> IMULE KIISE NKAN TI ENIYAN LEFI OWORO SEYIN FUN AWA TI ANI ANFANI LATI MAALO EWE ATI EGBO LONA KAN TABI EKEJI. FUN IDI EYI EJEKI AJOJE ANFANI IFA IMULE TI OREMI KAN FI SE EMINA NI ANFANI KI OSE ELERI ORO NA IMULE Eyie adan,eyie onbe, atare odindi kan,a o Jo papo,ao wa ro sinu ado,lehin naa ao wa lowa Awo Sobi,Ao bu ebu yii sinu e pelu epo pupa lilo e ni ago kan oru ni ihoriho omoluabi ao fi ESE OSI ti ara ogiri ODAJU:::OFORE--BI OSO BADIN AJE NI TU NI,/ BI AJE BA DE NI OSO NI TUNI,/BI EMERE BA DE NI TOSO TAJE NI TU NI,/BI TOSO,TAJE,TEMERE,BA DE NI EYIN IYA MI OSOROGA NI TU NI SILE TO BA WA RI BEE GBOGBO IDE KU DE TI E DE EMI L OMO L KO MA TUU BAYI IBA AWO TI OFUNMI NI ASIRIYIO Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045 Ajuwase o MAJEMU LAILAI? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by castrol180(m): 8:20pm On Jan 07, 2018 |
E jowo eyin baba se a le fi gas se aseje abi ki a fi jo ise? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by castrol180(m): 8:46am On Jan 08, 2018 |
kadunasouth: E jowo eyin baba se a le fi gas se aseje abi ki a fi jo ise? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 2:52pm On Jan 10, 2018 |
AKIYESI ONA ABAYO ILE AIYEWA) opolopo isoro ti osele si eda wa lati owo kadara ati egun idile ati afi owo fa,ati awon iya osoro nga ati awon egbe orun,awon nkankan tun sele si eda ti ojepe pupo ninu re irewesi tun se pupo ninu won titoripe kosi eda ti ELEDUMARE se aburu si,apere eda tiko ni owo lowo,eda tiko ri oko tabi aya rere fe,eda tiko ni oyun tabi eniti ose aisan,osese koje owo awon iya osoronga,ejeki agbo bi ifa oheren meki se so,orunmila ji nikutu kutu owuro onkoja lojude eleiye,owa da ifa ohenren meki,awon iya osoronga sope talodafa ohenrenmeki nibe yen?orunmila sope ohun alajogun weremogun ni,won sope kilode ti ofi da ifa ohenrenmeki?orunmila sope titori alaboyun tiko bimo were kole bimo were,titoripe agan tiko towo alabosun kole towo ala bosun ni ohun se dafa ohenren meki titoripe alaboyun tiko bimo were kole bimo were,ati okurunle ti ose aisan kole towo alabosun,eniti osise tiko ni owo lowo kobale ni owolowo kolefi owo nase nkan rere ni ile aiye lohun se dafa oherenmeki,awon iya da orunmila lohun pe alaboyun tikobimo woro ati agan tiko ti owo alabosun,ati eniti osise tiko ni owolowo,ati okurubule tose aisan pe eran awon niwon je pe awon lawon wa nidi oro won,awon fiwon pase ni,orunmila sope ohun mo pe ohun wabawon bebe ni,awon iya osoronga sope awon koni gbo ebe,orunmila sope tiwon kobagbo ebe ohun apitan iyawon fun won,awon iya sope ti orunmila bamo itan awon kopa,orunmila sope olupowo oruko ti iya eyin aje nje,arihoho jedun oruko ti iya eyin aje nje,owewe lakara oruko ti iya eyin aje nje,awon iya ni oto awon tigbo ebe,pe lati onilo alaboyun tiko bimo were abimo were,agan tiko towo ala bosun atowo alabosunokunrun bule ani alafia,eniti osise ani owo lowo afi owo se ohun rere,titoripe aje kiroro koje iwin ojo,oro ti okete bale so ni ile gbo,akiyesi pataki ni eyije ki amafura si oro aiye wa gbogbo aburu ti osele si eda pupo ninu re owo awon iya osoronga ni,ejeki amalo atude ati eyonu ipese awon agba fun ona abayo,emi aimo koni ni agbara loriwa tomotomo ase Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045 Ajuwase o MAJEMU LAILAI? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Tracypacy(f): 3:32pm On Jan 10, 2018 |
warfare for early childhood education As a war of malaria, stroke, fever, fluid, lungs, headaches, ulcers, blistering, embryo, pregnancy, abdomen, bronchitis, and bronchitis BUILDING IN AFFECTIVE LANGUAGE White beans, Baaka, Snakes, candles, and socks will last week, and we will not allow hot drinks to be dried or dried up to sensibility to add some alcohol or hot water. Drink it thoroughly and completely clean it. For sure. BACKGROUND (Short) Crocodile Colors, we can not move it slowly, we will use it slightly, we'll burn it with a burning bush. LOVE FOR ALL EQUIPMENT IN E-MAIL If people are allergic, if all of the body is suffering or physically suffers or the virus is on our skin as a thorn or any virus. The study of adults understand that blood transfusions cause these emissions. Your medicine is this ... We find the Igbo tree that Yourba calls General, it will last long and it will work well, it will be thrown into bottles or inches, and it will be less salty. Use of it: We will take it since the meditation and then after the meal. A person who has cancer (Ulcer) should not use ordinary oily fluid, so let's use only water. OORU IN (internal heat) Exotic, Cashew tree that you have picked up, cooked, we will drink in a cup twice a day. OGUN GIRI. Mouse Moisture 1, Six Monthly Diet, Moisture Moat, Taba junk, how old, old, orange, old, we will fall into the juice we will drink. And we can duplicate two cigars in the dark and we will put the baby on it. Excessive Medicine> The diagnosed immune system will be screwed into a hole and will be inserted into a plastic pot, an orange juice, a liquid, and it will not be worn as if it were cool or cold. . It's daytime and nightmare. Religious, social, and religious. And you are a psychiatrist! ATOSI ::: The whole epa belly, a whole body, cocoa, egg, pepper, and stored for three days, will be harvested after the third day. STUDENT OPERATION :: Antioxidants, diarrhea, diarrhea, cut into alcohol with peppers, freeze for five minutes, then be released. Strange it. EARN FEATURES ............ Three egg onions. The banner. Assignment. Three thumbs. A quarter. Learn more. Daylight. Three figures. Wrong. Onion onion. Hell. Poor bite bush. Three-month-olds. A little bit. Root. Effects. Red pepper. Baka. A few miles away. Rear slightly. We all burn it as a troop. It is usually burned with fire. It has been a problem for all diseases. JEDIED JUDGMENT (hostile warfare) helps prevent carbon dioxide. We go into the water and drink it. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 12:31am On Jan 12, 2018 |
ATUDE OSE" ewe lapa funfun mesan, ewe ewuro ojoo mesan, ewe efinrin mesan, ewe ajaobale mesan, yerupe ago kan osan ati toru, ao gun mose, ao fiwe fun ojo meta pere lori ni ago kan oru ni wiwe re o, ti abatiwe ose ye pari, ao tu kanhinkanhin yeka, ao sonu ni o. Odaju ITUWO ATUDE- aowa ewe ajeobale, epo igi ajeobale, egbo ajeobale, aolopo mose aopin ose na si ona meje, ti abafe we aowa ajadi apere kan aoko sinu re aowa we ose mejeje na lekan na telera won ninu apere yi kain kain meje ni aofi we ooo, AKIYESI, ti aba nwe lowo aogbodo soro, aosi gbodo siju le afi ti aba wekan tan ti atun fewe imin ATUDE TODAJU Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri Ike oloun ola oloun komaba alayelorun NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu dada ao dasi ao waje EYONU AWON AGBA TODAJU Ao wa Opolopo ewe imi esu ao japo ma ododo ati itanara ao jo po ma atare odidi kan ao mafi la epo pupa lalale pelu adua odara pupo atude ni pelu odaju EYONU¤ Ewe Akoko ati Itanna re, epo ati egbo re ao jo pelu odindi ataare kan, ao maa fi epo la ki a to sun... Ti o baa di ojo keje ti a lo ise yii ao fi Akara elepo se sara fun enia meta pere odaju EYONU¤ Eru oju aro, epo obo ao lo kuna daadaa ao mo mo ose Lux ao maa fi we lalale.... Odaju EYONU AWON IYAMI TURARI NI O¤ Eku asin meta, Epo Obo, Epo Igi nla, Korowu ao gun papo, ao daa sinu try kan ao waa daa adin gidi si ao ro papo daadaa, ao saa si ategun, ao maa fin ni alale ki a to sun.... Awon Agba won yi maa yonu siwa EYONU ASINA TIPATIPA¤ Ao gun ewe Afelorun kuna daadaa, ao waa po pelu Ose dudu, ao te Ifa Eji Ogbe si ori iyere Osun, ao se Adura Isina si daadaa ao waa po pelu ose yen ao ko sinu igba Olomori, ao maa fi we ni gbogbo igba..... Walahi Odaju EBE/IMULE AWON AGBA TODAJU Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise EYONU Oga3,asin3,opolo3,eso ido,eso werenjeje,ewe ajeobale, ewe orijin,ewe kileofimise,odindi atare 3,ao Jo po ao ma fi epo ogere la ninu fitila oloju kan. Tested ok IMULE AGBA Akara elepo16,eran menu,ao to akara yi round ninu ape ao fi eran sarin re ati odindi atare kan ao Jo po ama fi otin lo lalale Eyonu ,ogede omini ati epo obo ati igbo mimu ao gun papo mo ose ,odaju Etutu awon eleye kan reo:- alubosa funfun ao fi din eran namo tikoiti womi tiagesi ona merindinlogun, ao jo ako alangba kan pomo odidi atare kan ao lokuna ao da sori ipese na ao da epopupa lelori ao daniyan si ao gbelo sorita loru oganjo, odaju Tour! Eyin isoro ope eyin nikiee bawa toroyise'o Tori eku Ni awon ko nko nfilele awa'omon Kaye omo olufe lebaagun gege nio Kiya maba jomo'olufe nio Edakun edabo efiye denu'o Etanti imule'o Bawobapawo ile loda'o... Moseba agba.. Mowari faye'ooo Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045 Ajuwase o MAJEMU LAILAI? 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by chiefboomite204(f): 7:35pm On Jan 16, 2018 |
E se sir 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Abdulmujeeb1995: 6:16pm On Jan 19, 2018 |
baba ejowo kinni ogun fibroid? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by olaewe13(m): 4:09am On Jan 20, 2018 |
Salaam alaikum ooo eyin agbaagba, aani waayin Ti o lase edunmare. Edakun ona wo Ni elegba ranwa lowo Lori awon nkan etutu to daju bii: Onipasan owere ati beebee lo Ti ale fi tin irin ajo itusile tabi ebe awon agba? Eseun ewe ati egbo amaaje o |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by olaewe13(m): 12:02pm On Jan 20, 2018 |
ASINA OWO 2- eso ose iyekiye aojoo pelu odidi atare 1, ao loo Kuna aoroo sinu eso ose imii ao ma wipe: Ti abafi igba bonugba aarowona, Ti abafi igba bonu gba aaraye se, Ti abafi igba bonu igba aarigbalo. Motifi igba bonu gba kin rowo naa .......... Ao mafi nkan loo laaro laaro. Odaju o |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by mercysamuelson(m): 10:31am On Feb 06, 2018 |
kadunasouth E jowo, mo nilo Ogun ape obinrin ti o wa ni ilu oyinbo to daju. Maa ma reti esi yin. Email; anuoluwapo.shodunke@gmail.com |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by newdawn79(m): 10:42pm On Feb 07, 2018 |
ejowo baba ama ju yin se oooo, mofe Ogun teyan n fi bo ninu ide emere |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Kemade2007(f): 9:48am On Feb 08, 2018 |
E jowo sir, Kini a le lo fun ara yiyun,isaka ati lapalapa ni ara 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Titilayooni(f): 11:14pm On Feb 08, 2018 |
E kaale sir....E jo kini a le lo fun aisan to n mu symptoms kidney failure wa.....ara yiyun ,eyin didun,ito to pon, inu rirun,owo ati ese fe maa wu nigbaami. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by newdawn79(m): 5:09pm On Feb 09, 2018 |
Baba ejowo mo nilo Ogun ti mo le fi ta dukia ti mi o nilo mo . ESE pupo. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by newdawn79(m): 11:30pm On Feb 10, 2018 |
Baba ESE pupo fun agbakale yin , ile yin ati aye yin koni daru. Ejowo ile Egbon mi kan daru lowolowo bayi , iyawo egbon mi kii jeki Egbon mi ba ohun lasepo Dada Egbon mi si kundun ohun tan wi yii Dada , ejowo se Ogun ta le se wa to jewipe iyawo egbon mi gangan ni yio ma wa ki Egbon mi ba ohun sun nigbogbo igba. ESE pupo. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 7:53am On Mar 20, 2018 |
pe awon number yi 07067796292, 07055595911, whatsapp 09062199194 fun awon asiri gidi bere lati osole to daju, awise, ariran to daju gbagada fun awon pastors, alfa ati onisegun, ati agbara ti afi wo gbogbo iwosan to daju ati bebelo iwo kan si wa Lori ago fun nkan to ba nwa oku ku wa sugbon oni majemu oooo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Writs: 10:21pm On May 04, 2018 |
Zenlife: |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Wam24(m): 4:30am On May 09, 2018 |
ajinde ara yio maa je ooo.aye oni pa yin ti bi aso to ti gbo ooo.ejo baba kadunasouth.mo ti ni aru ulcer ati iba lati nkan bi last may.ko si nkan ti mi o ti lo amo pabo loun jasi.bi ki ori ma fomi legbe kan ati eyin ju .ara atun ma gbona laro kutu.o ma n re mi ni gbogbo igba.ejo kini ero pe oun se mi ati kini mo le lo.e seun oooo[/quote][right][quote author=Kollyk11 post=43119530]ajinde ara yio maa je ooo.aye oni pa yin ti bi aso to ti gbo ooo.ejo baba kadunasouth.mo ti ni aru ulcer ati iba lati nkan bi last may.ko si nkan ti mi o ti lo amo pabo loun jasi.bi ki ori ma fomi legbe kan ati eyin ju .ara atun ma gbona laro kutu.o ma n re mi ni gbogbo igba.ejo kini ero pe oun se mi ati kini mo le lo.e seun ooo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 3:09pm On May 09, 2018 |
Ibere se pataki fun gbogbo nkan to ba n se eda ki oluwa le mo ibiti problem ti wa ati solution re, iwo to ba se tan ati bere nipa nkankan o le pemi si ori ero ibanisoro mi 07067796292, 07055595911, tabi whatsapp number 09062199194.emi ki se ibere lofe oooo toripe owo na lafi ko, to si daju. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Writs: 10:38am On May 10, 2018 |
Zenlife: |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Sweetvenom(m): 10:16am On May 15, 2018 |
kadunasouth:"akara ori atan" means what |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Sweetvenom(m): 10:33am On May 15, 2018 |
Kemade2007:go to chemist ask for G DERM |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Sweetvenom(m): 10:35am On May 15, 2018 |
chiefboomite204:se ise egbe tabi ti oko orun fun lase Olson yio loyun, Ki o WA wadi ti ko ba ni Arun Lara. For more contact me 08062282643 |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Emizone100: 5:53pm On Jul 09, 2018 |
mo fi towotowo kiyin baba o, ki e pe fun wa . Ogun WO ni mole lo fun idakole ati Ato sisan |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Nobody: 2:26pm On Jul 10, 2018 |
eku ise oo kini MO le Lo fun Aran inu tiki jeki Oyun duro Lara obirin edakun |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by KolaBELIEVE: 5:06pm On Jul 21, 2018 |
baba Kadunasouth
ejowo Eranmilowo pelu aworo owo fun ile iwe tikolewu tabi eewo. eseun |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by aygafsam11(m): 6:49pm On Jul 21, 2018 |
se mole ri ogun idi yiyo (pile) eseun |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 3:54pm On Jul 25, 2018 |
Iwo to ba n wa omo, ipo, aworo, riirise gidi, afose ati bebe lo tabi o Fe se ibere Lori oro aye re pe number yi 07055595911, 07067796292 , no flashing oooo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 8:51am On Aug 12, 2018 |
Eyonu oshole tako tabo to daju taara Ako alangba 16, abo na 16, egbo tude ti won di si ona 16, opolopo eso yerepe, opolopo ewe ewuro oojo, atare odindi 16, akuko adire totobi kan, abo adire to ti bimo ri kan, alelo alangba tutu tabi gbigbe kosi wahala ,a o ko sinu ape tuntun kan, a o ko egbo tude si, a o ko eso yerepe si, a o ko ewe ewuro si, atare a o ko si , a o ma jo taba jo tan , a o lo to yi ooo kuna dada, a o pin si ona meji , a o po idakan mo ose dudu , eje abo adire yen lama fi po ose yen a o ko sinu ise funfun , a o wa sere ado kan, a o ro idakeji ogun yen si, ao pa eje akuko adire yen si, ao le iyere mo sere yen lara , ao gbe mejeji si aye owo , a o ma fi ose yen we lararo kutukutu , a o si ma fi ebu yen fo eko tutu mu leyin re .Akiyesi ti olorun ba fun yin ni iyonda iseyi se, kosora pupo toripe o ma ko obinrin wa pupo ju, to ba tinlo iseyi , ti ara ba tin hun wa, a o gba alejo toni owo lowo niyen, akogbudo hun ara na, teyan ba hun ara na, alejo ma wa sugbon koni mu owo wa, iseyi daju pupo ninu awon oshole to n je lowa. Awon adire mejeji yen a o fi se sara fun enikeni, sugbon enitoni ise kogbudo je nibe .07067796292 fun anything . |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 9:02am On Aug 12, 2018 |
Aran Inu ti ki je ki obinrin o tete loyun, egbo tude ,konukoho , kafura pelebe, a o gun po, a o po mo ori , a o ma bu si inu eko gbona die ,die .07067796292 fun anything . |
(1) (2) (3) ... (22) (23) (24) (25) (26) (27) (Reply)
Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 84 |