Yode138's Posts
Nairaland Forum › Yode138's Profile › Yode138's Posts
1 (of 1 pages)
biometrics: biometrics:Aboru boye baba... E bawa repost ise Imule asefijin na. Isese agbeyin o. |
Ago Aleko ati Moko Tobi learnt from this thread tode shaprapra. Pandora tutu, odidi atare kan to gbe dada, eru alamo, eru awonka. Ao wa gbogbo re sinu pot, ao bu omi si ao se ni agbo. Idaji stainless cup. Mimu ni aro ati ale. NB: You must warm it before you drink. Tested and confirmed! camobri: |
"thank God today is December 1st Eni ni ojo akoko osun titun December. Let those that have used any charm here that has worked for him or her come forth and share any particular charm rhat works out on this 'itakun'. I have used Imule Asefijin and it works. Any other person to testify to any other medicine on this thread" Dplanner, ejowo e repost ise Imule Asefijin na. Eseun. |
Ejowo e post Imule Asefijin yen pada. biometrics: |
OGUN TI WON KI FI DA EYAN DURO NI IBI ISE: ori ako alangba kan ati ase re, atare eyo kan. Ao Ki ase yen ati atare kan yen si lenu, Ao sa gbe. Ao WA we ni aso waji, Ao fi owu dudu ati funfun we. Odi awo(re re) ni ao fi ran. Ao wa ibikan ninu ile ise yen fi ise yi pamo si. Opari. O le my kuro nijo ti oba wun e lati fi ile ise na sile. Iba gbogbo eyin agba. Iba Iyanda, Omo Olowu oduru. |
Moki ara iwaju o. Edakun esanu no o. Aburo mi no oko re ati iyaoko we da abilu buruku lu. Edakun egbami mi o. A ti gbiyanju sugbon pabo ni o si njasi o. SOS!!! |
Ifankaleluya: |
What is the current price of onion in Aliero market in Kebbi? What is also the cost of transporting? |
Planning on buying a brand new one... |
Pls what do you think about Suzuki Kizachi 2010 model? |
1 (of 1 pages)