Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,513 members, 7,958,552 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 05:02 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842309 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (93) (94) (95) (96) (97) (98) (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Yode138: 2:35am On Nov 13, 2018 |
Moki ara iwaju o. Edakun esanu no o. Aburo mi no oko re ati iyaoko we da abilu buruku lu. Edakun egbami mi o. A ti gbiyanju sugbon pabo ni o si njasi o. SOS!!! 1 Like |
Re: .. by consato009: 10:51pm On Nov 13, 2018 |
Hello |
Re: .. by dplanner: 1:47pm On Nov 16, 2018 |
MO KI GBOGBO ILE OOO, A KU OLA JIMOH ONI , ASIRI KAN NBE TO LAGBARA FUN GBOGBO EYAN TO BA NWA IPO OSELU NI TABI IPO TO KO JE , TO JASI TI A BA PARI RE WALLAHI GBOGBO AWON TO N BA WA DU IPO NINU PARTY ABI PARTY TO KU NI WON O NI GBO RA WON YE MO , TI NKAN MA FI DARU TI YI O SI JE TI TI ENI NA, LAPEJUWE OWO ISE ENI TO N WA IPO COUNCILLOR YATO SI GOVERNOR ATI BE BE LO , WALLAHI ASIRI NBE LODO AWON AGBALAGBA TO DAJU . PE 07067796292, 07055595911 TO BA NI FE SI KA SORO . MA SUN KO LE BA SUN SI WAJU , AYE KO SE WO LASAN OOOOOO |
Re: .. by Yode138: 9:39am On Nov 21, 2018 |
OGUN TI WON KI FI DA EYAN DURO NI IBI ISE: ori ako alangba kan ati ase re, atare eyo kan. Ao Ki ase yen ati atare kan yen si lenu, Ao sa gbe. Ao WA we ni aso waji, Ao fi owu dudu ati funfun we. Odi awo(re re) ni ao fi ran. Ao wa ibikan ninu ile ise yen fi ise yi pamo si. Opari. O le my kuro nijo ti oba wun e lati fi ile ise na sile. Iba gbogbo eyin agba. Iba Iyanda, Omo Olowu oduru. |
Re: .. by biometrics: 7:50pm On Nov 27, 2018 |
Canme4u: Aboru boye... Eyin agbalagba itakun yi, se eni to ba wani igbekun, le tura re sile fun rare pelu ogun itude tabi atuwo ati eni toba bii ni ninu irawo eran {leo} lelo ninu awon atude to wa ninu ikan yi? |
Re: .. by biometrics: 7:56pm On Nov 27, 2018 |
08101646045atwp: Aboru boye... Eyin agbalagba itakun yi, se eni to ba wani igbekun, le tura re sile fun rare pelu ogun itude tabi atuwo ati eni toba bii ni ninu irawo ina {leo -fire} lelo ninu awon atude to wa ninu ikan yi? 2 Likes |
Re: .. by biometrics: 9:15am On Nov 30, 2018 |
why the silence on this thread. Are there no more elder? To, iba akoda, iba aseda, iba olukosi, iba olukotun, iba awon orisa, iba awon agbalagba t'olorun ko ile aye si lowo. Iba arawaju, iba ero eyin o, iba awon agba to wa ni ikan yi, iba awon agba tosi ni ikan yi mo. Ki iba mi ose o, Iba! iba!! iba!!! Aboru boye.... 1 Like |
Re: .. by biometrics: 9:07pm On Nov 30, 2018 |
Aboru boye....?
Ema bami ka lo... |
Re: .. by biometrics: 8:14pm On Dec 01, 2018 |
thank God today is December 1st Eni ni ojo akoko osun titun December. Let those that have used any charm here that has worked for him or her come forth and share any particular charm rhat works out on this 'itakun'. I have used Imule Asefijin and it works. Any other person to testify to any other medicine on this thread? 1 Like |
Re: .. by biometrics: 8:01am On Dec 02, 2018 |
Atude/Atuwo/Ebe Agba ¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤¤ Ao fi ogede omini 3 ti o pon dada, atare odindi 7, ao bo ogede omini yi, ao wa yo omo atare yen si bi kan. Ao wa ma fi ogede omini yi fiba atare yen ni gbogbo ara re. Ao she ogede 3 yen be. Ti a ba ti se tan, ao wa fi odo ti won fingun iyan bo ogede omini/atare yen mole di ojo keji. Ao wa k'ogede 3 pelu atare yi sinu agbada, ao wa jo. Ta ba ti jo tan, ao wa lo kunaa dada. Awa da sinu igo funfun. Lilo re: Ao ma busi eyin owo wa, ao ma fi owo gba y'o si ma wole pelu ase olohun. Ki e to lo ise kankan fun alaisan, e o koko se ise yi fun eni na. Ti e ba fun eni na lomi mu lasan pe kolo yio sise fun. Edanwo! |
Re: .. by biometrics: 1:49pm On Jan 04, 2019 |
Happy New Year to you all. Eku odun titun o. |
Re: .. by Nobody: 9:05pm On Jan 04, 2019 |
biometrics:Does pandoro and ori amo work for enlargment of breast and penis? |
Re: .. by Fm007: 11:22am On Jan 05, 2019 |
Ejowo kini je ijoka adie |
Re: .. by Yode138: 1:46am On Jan 10, 2019 |
Ejowo e post Imule Asefijin yen pada. biometrics: |
Re: .. by Yode138: 1:50am On Jan 10, 2019 |
"thank God today is December 1st Eni ni ojo akoko osun titun December. Let those that have used any charm here that has worked for him or her come forth and share any particular charm rhat works out on this 'itakun'. I have used Imule Asefijin and it works. Any other person to testify to any other medicine on this thread" Dplanner, ejowo e repost ise Imule Asefijin na. Eseun. |
Re: .. by Yode138: 2:10am On Jan 10, 2019 |
Ago Aleko ati Moko Tobi learnt from this thread tode shaprapra. Pandora tutu, odidi atare kan to gbe dada, eru alamo, eru awonka. Ao wa gbogbo re sinu pot, ao bu omi si ao se ni agbo. Idaji stainless cup. Mimu ni aro ati ale. NB: You must warm it before you drink. Tested and confirmed! camobri: 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Funmiladey(m): 6:22am On Jan 11, 2019 |
E jowo, se ise yii ni ma mu ki oko tobi si, ati wipe ojo melo ni eniyan yoo fi loo ki ato da owo re duro? Yode138: 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:29pm On Jan 12, 2019 |
Yode138:odidi Pandoro ni a yio lo abi a yio ge? Ejowo, nibo ni motile ri Eru alamo ati eru awonka ra? |
Re: .. by dplanner: 7:42am On Jan 17, 2019 |
EYIN TI WA , MO KI YIN PE AKU ODUN TUNTUN EMI YI O SE PUPO RE ASE OLORUN OBA ,ISE PO NI E FI RI OWO MI LATI OJO DIE ,EYI TI MO TUN MY WA NI YI OOO OLUGBOHUN RIRISE TO CONFIRM TESTED AND TRUSED KO SI ISE TI ALE LO FUN , ISE NA LO BAYI EWE INA, EWE ESINSIN , EWE ARAGBA , EWE OLOYIN , A O GUN PO MO OSE DUDU, A O FI EMU AILA PELU OGURO AILA PO PAPO PELU OTI SCHNAPP PO PAPO DADA, A O FI OGA AYE ATI EJA OJIJI AYE KAN TELE TELE IHO MALU YEN , A O WA KO OSE YEN LELORI , A O FI ASO PUPA BO LORI , A O WE MO LARA , A O MA SI ASO PUPA YEN LOJU TI A BA FE LO , GBOGBO ENI TO BA NIFE SI KO PE , 07067796292 TABI KO WHATSAPP MI LORI NUMBER YEN NA, NKAN TO FA TI MI FI SO ISE NA KALE TAN, TORI ISE TONI AGBARA NI, KI AWON EYAN MA LO MA SI LO FUN NKAN MI , AMO ENI TO BA PE MI TABI WHATSAPP TI MO RI PE LO OTO O NEED FUN KO LE MA RISE GBA DADA , MA FUN PELU MAJEMU TORIPE OF DAJU PUPO . FUN PIPE TABI WHATSAPP 07067796292. |
Re: .. by dplanner: 11:29am On Jan 17, 2019 |
FUN AWON ALFA ATI AWA OMO KEU ELEYI NI OSE ISEGUN , ASINA TIAFIRIAYESE TO KA JUE A o gun ori oka pelu epo obo ati kafura pelebe mo ose dudu , a o Han suratul masad tamo si tabatiyada 71 , a o fi omi die fo, ohun la o fi po ose yen pelu oronro malu ati lofinda bintu , a o ma we laro ki orun o to yo tabi lale ta ni jade mo .Fun ibere 07067796292 tabi ki e whatsapp mi lori number yen na . |
Re: .. by biometrics: 4:48am On Jan 27, 2019 |
This Imule Asefijin reposted; dominicson: 2 Likes |
Re: .. by dplanner: 11:44am On Feb 01, 2019 |
AKU OLA JIMOH ONI , EMI YI O SE PUPO RE , ELEYI NI , AWURE OWO ATI ONFA NEW CLIENTS FUN ENIKENI : Ako alangba kan , abo alangba kan , a o la mejeji laya , a o yo ifun won jade sori olo , a o lo pomo ose , a o fi eyin agric po ose na dada bi ose yen base posi ni ase malo eyin na , alelo eyin meji tabi meta ko sa ti dun ose na dada , a o wa ko ose na sinu ike funfun , a o ma we laro kutu kutu , awon alangba tayo ifun re , a o fi obi ipa sinu ako , a o fi obi ifin sinu abo , a o wa da aya mejeji korawon ninu ape , a o fi odindi atare kan si legbe , a o wa ko ewe sawerepepe bo mole ti ko ni Han Sita mo , a o jo po lai yipada , a o ma oti schnapp tabi oyin gidi lo , ti a ba ti we ose de lati ilewe, o daju ooo.Fun ibere tabi Nipa akosejaye ati irawo aye ko mo ibi to n lo whatsapp mi lori 07067796292 |
Re: .. by dplanner: 9:17am On Feb 02, 2019 |
MO KI GBOGBO ILE , A O NI DAMU LAYE WA O OOO AMIN , ETO YE RA RE WO TO NLO LOWO NI MONI KI N FI TO LE . FUN AYEWO AKOSEJAYE ATI IRAWO RE KO LE MO SE TO BA O LARA MU, ATI GBOGBO NKAN TO ROMO AYE RE, TORIPE ELOMI TI LO OGUN DUDU TI KO SISE FUN, TO JA SI WIPE ADUA ATI SARA LASAN LORO GBA, ELOMI NKAN FUNFUN NI SOLUTION AYE RE , O TI WA LO ORISISI ISE , KO WA JE FUN , ELOMI IDIWO LO FA , TI ISE KO FI DAHUN, AYAFI KI KO FI NKAN MU IDIWO NA KURO PELU ADURA ATI SARA KI ISE TO LE MA JE FUN ATI BE BE LO , IWO TO BA FE JE ANFANI NI YI, PROMO NLO LOWO BAYI LATI YE RA RE WO PELU 3K PERE , TORIPE TELE 5K NI , AMA PROMO TI BERE LATI 31 DECEMBER 2018 TO MA PARI NI 311ST MARCH, 2019 LEYIN NA YI O PADA SI 5K RE PADA , IWO TO BA NIFE SI ,KAN SI MI NI WHATSAPP NUMBER 07067796292 , PELU ORUKO RE ATI AWON OBI RE MEJEJI PELU OJO IBI RE , PELU OGO OLORUN GBOGBO NKAN LO GBO LEKUN RERE NI PA GBOGBO NKAN TO ROMO AYE. WHATSAPP NUMBER 07067796292 . |
Re: .. by dplanner: 5:31pm On Feb 10, 2019 |
FUN ANJO OMO BIBI TO CONFIRM INSHALLAH, WHATSAPP 07067796292 |
Re: .. by biometrics: 8:39am On Mar 06, 2019 |
Happy new month - March. God let the good of life begin in our life, amin. AWORO - ABOMOLE TO DAJU. ===================== Eyin ororo 8 Alabahun nla 1 Iyo isebe Ao wa gbele lenu ona shop wa ti yo gba odidi alabahun naa. Ao koko fi omi tutu won inu iho ti a gbe yen. Ao wa bu iyo si. Ao wa gbe ijapa naa lelori, ao wa tun bu iyo si ti yo bo gbogbo ara ijapa yen mole. Ao wa to eyin ororo yen bi wipe atefa ejiogbe si ori iyo ti a bu si eyin alabahun naa ibi sonso eyin yen la fi gun o. Ao wa tun bu iyo si lori eyin naa ti eyin ko ni han sita. Ao wa fi hunkan bomole pako tabi pannu, ao wa ro yee pe bomole dada. O tan. Lesekese ni yoo bere ise o daju pupo o. |
Re: .. by ayogabriel: 7:21pm On Mar 19, 2019 |
Mo ki gbogbo ile. E Jọwọ e ṣe iranlọwọ fun mi, oga mi oyinbo fe damidiro Leui ise. O san fu n HR manager wa pe, ni Friday o ma damidiro. O Fe gbe eyan ti ti e wole. Ejo, ajo wo mo le se? |
Re: .. by dplanner: 8:13pm On Mar 29, 2019 |
ASIRI TI A FI NKO ILE MEFA LARIN ODUN KAN TESTED AND CONFIRMED Omo eye ega meji , ti o wa ninu Ile loke , a o ja won tile tile , ewe esisi ojoo lopolopo, a o su losuka, lona meje , a o gbe agbada kana, a o to osuka meta , sori ara won ninu , a o wa ko awon omo eye ega na le lori tile tile , a o tun wa gbe ewe osuka to seku le lori , a o wa jo po ,a o lo kuna dada , a o ro ebu na sinu ado ide tuntun Kan, a o wa fi igi orijin ati Ikode kan di ado na Lenu pa , ti a ba ti wa pari ise na, a o gbe ado na sinu apoti lesekese , a o fon ekuru funfun si idi ise na fun ojo meta gbako , leyin ojo keta yi , a o lo aso awon agba meta, a o da sinu ise yi leyin igba ti a ti fon ekuru yen , a o wa fi ideri re de pada . LILORE A o din akara elepo nla kan , a o lu akara na ni iho (a o da lu ) a o da ebu inu ado yi sinu akara na , a o si je lesekese lobatan . Daju daju a o ko odindi ile kookan lona mefa larin ODUN KAN , to daju ti o si iyemeji nbe. EWO RE EWO meta nibe fun ise yi ,Akoko , a o gbudo fi enu kan akara elepo mo laelae , ekeji a o gbudo ko ile ju mefa na lo , bi o se gbogbo re ni yi o wo loju aye wa , te o si ni ko ile mo Titi , e o fije olorun ni pe , eketa , a o gbudo su mo obinrin fun osu meta gbako . AKIYESI PATAKI E se akiyesi, ti ise na ba bere ise , eye kan Ma ke ninu ikun wa, sugbon , a o gbudo beru , ko si wahala kankan o ti bere ise niyen . T I A BA FE BA ISE NA JE Leyin igba ti a ti kole tan , a o lo ewe ekuku tutu , a o fi se igbin agbonu nla kan je, a o lo ya igbe si ori akitan , a o si fi oju wa mejeji ri eye funfun kan ti yi o fo jade nibe , ogun ti baje ni yen ooo. IWO TO BA FE SE ISE YI GBIYANJU KO KAN SI MI LORI WHATSAPP 07067796292 TABI KO PE KA LE SORO , TO RI OKU LEYIN LEYIN NI IBON N RO, O OOO. |
Re: .. by biometrics: 1:35am On Apr 09, 2019 |
Aku new month moni aku osu titun olohun ada wa si o. |
Re: .. by biometrics: 7:57am On Apr 09, 2019 |
IFERAN ATINUDENU FUN OBINRIN TODAJU ==================== Tobadi ago 12am oru -midnight- ni ao se ise yi o. Ekuru elewe kan ati iyereosun. Ao da iyereosun sori opon ifa, white paper tabi white plate kan ao te ni ejiogbe. Ao pe ofore si. ========== Gbolohun re ========== Okara 3x, okooro 3x, ifa iwo loko somo niye, lo ko ife emi lagbaja omo lagbaja si iye lagbaja omo lagbaja. Nitoripe ni ojo ti elekuru bakiri ekuru ni fobore tore fomo araye oni ibonbo ekuru. Ki lagbaja omo lagbaja fobore tore fun emi lagbaja omo lagbaja. Ko di iyawo mi loni, ko male sun ko male wo, bio ba joko ko ma ranti mi, ohun kohun toba nse koma ranti mi, iyereosun loni kio male sun. Ejiogbe oba lorun lo bami gbe ife emi lagbaja omo lagbaja si okan lagbaja omo lagbaja loni. Ao da iyereosun naa sori ekuru naa ao ko je. Iree o. |
Re: .. by biometrics: 4:59pm On May 04, 2019 |
Happy New month - May. Ajeogun ====<= Ao ra ewe esisi, ewe ina, eyin ina - ao mu ogun ina. Ao sare so si pelu atare mesan. Ao lo. Ao wa fin singbere si owo ati ese wa. Ire o |
Re: .. by Nobody: 2:40pm On May 17, 2019 |
dominicson: Hello please can you drop your whatsapp nunber let's talk privately? 1 Like |
Re: .. by dominicson: 11:17pm On May 17, 2019 |
1 Like |
(1) (2) (3) ... (93) (94) (95) (96) (97) (98) (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 62 |