₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,327,107 members, 8,429,367 topics. Date: Thursday, 18 June 2026 at 07:03 PM

Toggle theme

Yusco2000's Posts

Nairaland ForumYusco2000's ProfileYusco2000's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by Yusco2000(m): 2:14pm On Nov 23, 2017
Gbogbo ibeere wonyi tumo si wipe e kii se omo Yoruba.

Orikerike ara ni gbogbo eya ara to sepo...awon bi Ejika, Isepo Apa, Isepo Ese, orun ese, Orun owo, Igunpa ati beebe lo.

Eriru yato si Eeru...Eriru je eso ori igi, Eeru ni ajoku igi idana.

Tefa Ejiogbe tumo si wipe ka fi ika te Ifa Ejiogbe sori Iyerosun tabi Ebu Oogun.
kin lon je egungun ara iganno wall {Egungun}
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Yusco2000(m): 2:22pm On Jul 12, 2017
kadunasouth:
AJEGUN
Ki ogun lema sise lara wa daradara
Imi ayekoto pelu eyo atare mesan eru alamo ao lopo ao fi sin gbere yipo orun owo wa mejeji ati ika arin mejeji
ejo bawo ni eniyan se le ri imi ayekoto ra, to ri pe gbogbo o do elewe omo ti mon de won ni ko si ni.

1 (of 1 pages)