Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,446 members, 7,816,028 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 12:00 AM

Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju - Health (23) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (558543 Views)

Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (20) (21) (22) (23) (24) (25) (26) (Reply) (Go Down)

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by olukoya100: 10:51am On Jul 07, 2017
E karo Baba,awo ama juyin nse o.ewe a ma je, Ogun ama je oh.Baba,e jowo e ranmi lowo,ikan funfun funfun ma n jade loju ara iyawo mi ti aba jo lajosepo, ikan omokunrin mi pada sisale lara eh,o si ma run lekankan.e jowo kini o le lo ati emi naa.Olorun a ma ran yin lowo.E Jere awon omo yin.Amin.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 12:16am On Jul 09, 2017
[left][/left][i][/i][b][/b][/color]
kadunasouth:
Awan ogun lorisirisi fun itoju ara onbo lona laipe
Bi ogun gbogbonise, inu rirun , ogun iba, ito sugar, nkkan osu ti nse segesege, orififo, alakala, idi yiyo, oyun iju, isoye, airoyun ni, oko orun, ati bebelo

OOGUN INU RIRUN
Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo lo patapata lase edumare. O daju.

IDAKOLE(Amokole)
Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e, ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro.

OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE

Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...

Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.

Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo omi lasan.

OORU INU(internal heat)
Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan leemeji lojumo.

OGUN GIRI.
Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba
juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti oyinbo
ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo na.

Oogun iko to daju> Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan, alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii irole ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi talahi, ajebiidan ni. Ao nii saisan o!

ATOSI::: odindi epa ikun, odindi bara kan, ako kanhun, baka die, a o fi emu da lagbo, a o gbe pamo fun ojo meta, a o ma yo mu lehin ojo keta. Odaju

AKOKORO:: Oti oyinbo, egbo agbasa, a o ge egbo agbasa na, a o da sinu oti pelu egbo ata, didi si ereke fun iseju marun, lehin na a o tu danu. Odaju o.

EGBOGI GBOGBONISE............isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan. Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo arun.

EGBOGI JEDIJEDI (ogun jedijedi)
egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu.

[color=#000099]

EGBOGI JEDIJEDI (ogun je

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 12:37am On Jul 09, 2017

Ogun afato ao Wa egbo ogbolo tutu ati kafura pelebe ao fi oti ki ao MA yomu laro laro
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 12:42am On Jul 09, 2017

moki eyin baba mi moki eyin egbon MI awumi tie ba lefunmi ni iyonda kin matesiwaju Lori Ogun Fifi sile
Ogun osole todaju
ao wa okan elede iho meta lowa ni oju re ao ki one dollar bo oju iho kan ao ki ewe ola bo iho keji ao ki odidi atare bo iho keta ao wa Jo ni irole Mon ale ninu ikoko tuntun ninu ikoko yi nani ao ti lo ao pin si ona meta ao mafi schnapp lo ni arolaro fun ijo meta pelu kunfayakun yio ribe tested OK
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 11:04am On Jul 09, 2017

EGBOGI GBOGBONISE............isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan. Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo aru

at balogun

oata ajegun todaju
ao wa iyo obe die atapupa eyo meta oguna oju aro ao lopo ao sin ni gbere yipo orun owo mejeji
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 11:09am On Jul 09, 2017
balogun1990:
at balogun

oata ajegun todaju
ao wa iyo obe die atapupa eyo meta oguna oju aro ao lopo ao sin ni gbere yipo orun owo mejeji
ki ogun monranyan
ewe ewuro iboju igbin eyo atare meje aojo po pelu odidi atare kan aofi sin gbere yika orun owowa

1 Like 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 11:14am On Jul 09, 2017
balogun1990:
ki ogun monranyan
ewe ewuro iboju igbin eyo atare meje aojo po pelu odidi atare kan aofi sin gbere yika orun owowa
ogun arina inu onje
omonle oju eyele mesan OKO atare kan ikode kan aofi singbere round orun orun owowa ao sin kan si oju wa mejeji
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 11:19am On Jul 09, 2017
balogun1990:
ogun arina inu onje
omonle oju eyele mesan OKO atare kan ikode kan aofi singbere round orun orun owowa ao sin kan si oju wa mejeji
ose igbayi
ewe wawa ati ewe sawerepepe ati epo ogede agbagba ati alubosa elewe aogun po pelu osedudu ao Mon fi we
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 1:38pm On Jul 09, 2017
balogun1990:
at balogun

oata ajegun todaju
ao wa iyo obe die atapupa eyo meta oguna oju aro ao lopo ao sin ni gbere yipo orun owo mejeji
ogun eyonu todaju
ao wa ewe botuje funfun (lapalapa)ao fi tele ikoko ao GBE orimusu le ao fi ikode ha ori musu yi lenu ao wa GBE atare kan ti legbe ao wa da ewe ewuro lelori ao wa ko opolopo ewe orijin lelori ao Jo po ao Mon fi ogere epopupa loni alale tia ba ti fesun ti ani jade lobi kankan mon
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 1:54pm On Jul 09, 2017
balogun1990:
ogun eyonu todaju
ao wa ewe botuje funfun (lapalapa)ao fi tele ikoko ao GBE orimusu le ao fi ikode ha ori musu yi lenu ao wa GBE atare kan ti legbe ao wa da ewe ewuro lelori ao wa ko opolopo ewe orijin lelori ao Jo po ao Mon fi ogere epopupa loni alale tia ba ti fesun ti ani jade lobi kankan mon
ogun aseje osole owo todaju
ao wa ewe Anu, ewe ola, ewe orijin, eweaje, ewe ajeobale, alubosa funfun, ogagbigbe, ao lotio kun na ao fise eyele funfun kan je ao gesi mesan omi okun ati omi osa lao fi se tio ba jina ao fi aso funfun opakan se osuka ibe lao so obeyi, aso funfun lao WO ti ao fi je obe yi ao gbadura si Dada kia toje
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 1:59pm On Jul 09, 2017
balogun1990:
ogun eyonu todaju
ao wa ewe botuje funfun (lapalapa)ao fi tele ikoko ao GBE orimusu le ao fi ikode ha ori musu yi lenu ao wa GBE atare kan ti legbe ao wa da ewe ewuro lelori ao wa ko opolopo ewe orijin lelori ao Jo po ao Mon fi ogere epopupa loni alale tia ba ti fesun ti ani jade lobi kankan mon
ogun aseje osole owo todaju
ao wa ewe Anu, ewe ola, ewe orijin, eweaje, ewe ajeobale, alubosa funfun, ogagbigbe, ao lotio kun na ao fise eyele funfun kan je ao gesi mesan omi okun ati omi osa lao fi se tio ba jina ao fi aso funfun opakan se osuka ibe lao so obeyilelori, aso funfun lao WO ti ao fi je obe yi ao gbadura si Dada kia toje,

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 7:31pm On Jul 09, 2017
balogun1990:
ogun aseje osole owo todaju
ao wa ewe Anu, ewe ola, ewe orijin, eweaje, ewe ajeobale, alubosa funfun, ogagbigbe, ao lotio kun na ao fise eyele funfun kan je ao gesi mesan omi okun ati omi osa lao fi se tio ba jina ao fi aso funfun opakan se osuka ibe lao so obeyilelori, aso funfun lao WO ti ao fi je obe yi ao gbadura si Dada kia toje,
ogun ito sugar tabi ti arabawu
ao wa oroagogo oroadete enuopiye ao se lagbo enina yio mamu diedie ni gbigbona /die ni ao mamun ooo tori pe omaun yayan ni igbe ooooo

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 7:43pm On Jul 09, 2017
balogun1990:
ogun ito sugar tabi ti arabawu
ao wa oroagogo oroadete enuopiye ao se lagbo enina yio mamu diedie ni gbigbona /die ni ao mamun ooo tori pe omaun yayan ni igbe ooooo
Ogun atude
ao lo egbo tude tio kuna dada ao wa eyin ibile ti Adie baye lojoo ao wa fo sinu about kan ao wa da egbo tude yi si ao wa ro papo ao mo fi pa gbogbo ara wa tio ba to iseju marun ao lofi ose we danu ,.....ose ti ao fi we niiii....oa loja ewe lapalapa funfun meta pupa mata ao gun pomon epo obo ao fi we danu otanj

1 Like 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 7:44pm On Jul 09, 2017
balogun1990:
ogun ito sugar tabi ti arabawu
ao wa oroagogo oroadete enuopiye ao se lagbo enina yio mamu diedie ni gbigbona /die ni ao mamun ooo tori pe omaun yayan ni igbe ooooo
Ogun atude
ao lo egbo tude tio kuna dada ao wa eyin ibile ti Adie baye lojoo ao wa fo sinu abo kan ao wa da egbo tude yi si ao wa ro papo ao mo fi pa gbogbo ara wa tio ba to iseju marun ao lofi ose we danu ,.....ose ti ao fi we niiii....oa loja ewe lapalapa funfun meta pupa mata ao gun pomon epo obo ao fi we danu otan
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 7:53pm On Jul 09, 2017
balogun1990:
Ogun atude
ao lo egbo tude tio kuna dada ao wa eyin ibile ti Adie baye lojoo ao wa fo sinu abo kan ao wa da egbo tude yi si ao wa ro papo ao mo fi pa gbogbo ara wa tio ba to iseju marun ao lofi ose we danu ,.....ose ti ao fi we niiii....oa loja ewe lapalapa funfun meta pupa mata ao gun pomon epo obo ao fi we danu otan
ogun asina
ao wa omi agbon ao tu sinu koko aoju omoatare kan sinure ao wa jo tititio fi di ogun(edu)ao bo eyin agric/ibile ao wa mafi kan ebuyi ao maje tia baje tan ao lofi agbon yi se sara
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by qolam: 11:40pm On Jul 09, 2017
Thanks a whole lot @ balogun1990 for all your wonderful posts on this forum, you're such a blessing to everyone on Nairaland just like Baba Kaduna South, may God continue to enrich you in wisdom and knowlegde. 1. Pls, i need a favour from you, my wife to be has some kind of womb infections according to the doctor's report which has been making difficult for her to conceive all this while and she has actually tried some medicines to no avail, pls what can we do?
2. I'm a printer, and since i opened my small makeshift shop, i always sit down in the shop from morning till evening without anything, i don't get jobs at all, i'll just sit down counting the number of vehicles on the road from morning till evening, pls help me. Iru Ogun wo ni mo lese fun isoro mejeeji yi sir, inu mi a si dun pupo ti e ba le ran mi lowo, e seun pupo gaan ni sir.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Yusco2000(m): 2:22pm On Jul 12, 2017
kadunasouth:
AJEGUN
Ki ogun lema sise lara wa daradara
Imi ayekoto pelu eyo atare mesan eru alamo ao lopo ao fi sin gbere yipo orun owo wa mejeji ati ika arin mejeji
ejo bawo ni eniyan se le ri imi ayekoto ra, to ri pe gbogbo o do elewe omo ti mon de won ni ko si ni.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by mercysamuelson(m): 11:43pm On Jul 12, 2017
Kadunasouth: Baba, e jowo mo si nduro de esi yin Lori nkan ti mo le lo nigba interview fun visa. Ma maa reti yin o, Ese.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 4:08pm On Jul 19, 2017
mercysamuelson:
Kadunasouth: Baba, e jowo mo si nduro de esi yin Lori nkan ti mo le lo nigba interview fun visa. Ma maa reti yin o, Ese.
@balogun/ogun aworo
ao wa eyin ti adie baye loojo ao wa ewe akoko tutu abi gbigbe tio po dada ao lo kuna ao gbe koto si iwaju sobu wa ao wa da ewe akoko yi si inu iho yi ao wa gbe eyin sinure ao wa da oyin lelori ao wa da ewe akoko tio ku lelori ao tun wa da iyo lelori ao wa se opolopo adura ero pupo si ao wa dayepe bo monle /ale ni agbodo se ise yio bere lati ago mokanla ale
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by tjmc: 4:11pm On Jul 19, 2017
Please where can I find herbs market that is close to satellite town

tjmc:
Pls where can I find a herb market in Lagos I stay in satellite town, ijegun to be precised
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 4:15pm On Jul 19, 2017
mercysamuelson:
Kadunasouth: Baba, e jowo mo si nduro de esi yin Lori nkan ti mo le lo nigba interview fun visa. Ma maa reti yin o, Ese.
@balogun/ogun aworo
ao wa eyin ti adie baye loojo ao wa ewe akoko tutu abi gbigbe tio po dada ao lo kuna ao gbe koto si iwaju sobu wa ao wa da ewe akoko yi si inu iho yi ao wa gbe eyin sinure ao wa da oyin lelori ao wa da ewe akoko tio ku lelori ao tun wa da iyo lelori ao wa se opolopo adura ero pupo si ao wa dayepe bo monle /ale ni agbodo se ise yio bere lati ago mokanla ale iseyi dara pupo yio je fun yin lola awon tio ni ile aiye aseeee
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 4:31pm On Jul 19, 2017
balogun1990:
@balogun/ogun aworo
ao wa eyin ti adie baye loojo ao wa ewe akoko tutu abi gbigbe tio po dada ao lo kuna ao gbe koto si iwaju sobu wa ao wa da ewe akoko yi si inu iho yi ao wa gbe eyin sinure ao wa da oyin lelori ao wa da ewe akoko tio ku lelori ao tun wa da iyo lelori ao wa se opolopo adura ero pupo si ao wa dayepe bo monle /ale ni agbodo se ise yio bere lati ago mokanla ale iseyi dara pupo yio je fun yin lola awon tio ni ile aiye aseeee
emabinu si mi owu mi pupo lati ma fi awon orisirisi ogun kalee sugbon card ni man sojoro fun min sugbon mo fin dayin loju pe gbogbo ise kokan ti mobanju kale mobura pelu olohun to dami ise gidini ise ti mo si ti se fun yan ri tio confarm ni

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by balogun1990: 4:39pm On Jul 19, 2017
balogun1990:
@balogun/ogun aworo
ao wa eyin ti adie baye loojo ao wa ewe akoko tutu abi gbigbe tio po dada ao lo kuna ao gbe koto si iwaju sobu wa ao wa da ewe akoko yi si inu iho yi ao wa gbe eyin sinure ao wa da oyin lelori ao wa da ewe akoko tio ku lelori ao tun wa da iyo lelori ao wa se opolopo adura ero pupo si ao wa dayepe bo monle /ale ni agbodo se ise yio bere lati ago mokanla ale iseyi dara pupo yio je fun yin lola awon tio ni ile aiye aseeee
@balogun
emabinu si mi owu mi pupo lati ma fi awon orisirisi ogun kalee sugbon card ni man sojoro fun min sugbon mo fin dayin loju pe gbogbo ise kokan ti mobanju kale mobura pelu olohun to dami ise gidini ise ti mo si ti se fun yan ri tio confarm ni @

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by AKINS005: 3:38am On Jul 22, 2017
Mo Je omo adaota odun, mo Je odo omode oni-isegun ibile, saa dede ni mori pe orun-ese mejeeji wu de ibi isu-ese ati pe okan mi maa dun pipipi. Mo wa lori awon DOKITA OYINBO won ni pe, mo ni Eje ruru tin da okan mi lamu, sugbon won ko ogun fun mi, sugbon ogun naa maa mu mi ru. Mi o de tun ri iyato re.. Ni itori eyi ni mo ke to eyin baba me, nitori mo mo pe Ewe ati Egbo n'be... Ese mo dupe maa maa reti esi yin, baba mi ooooo.........
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by AKINS005: 3:40am On Jul 22, 2017
[quote author=AKINS005 post=58705525]Mo Je omo adaota odun, mo Je odo omode oni-isegun ibile, saa dede ni mori pe orun-ese mejeeji wu de ibi isu-ese ati pe okan mi maa dun pipipi. Mo wa lori awon DOKITA OYINBO won ni pe, mo ni Eje ruru tin da okan mi lamu, sugbon won ko ogun fun mi, sugbon ogun naa maa mu mi ru. Mi o de tun ri iyato re.. Ni itori eyi ni mo ke to eyin baba me, nitori mo mo pe Ewe ati Egbo n'be... Ese mo dupe maa maa reti esi yin, baba mi ooooo......... kadunasouth e jowo no fe iranlowo yin..
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by adeyenuwo: 8:12pm On Jul 27, 2017
kadunasouth:
Aseje Arisiki Owo lona irorun
Ewe sawerepepe ,ewe ola, ewe efo gure, ewe tanagbowo, ewe ela, iyere ao lo papo ao fise edo malu tage si 16 je pelu isasun tuntun lepo niyo, yio je funyin lase awan toni ile aye

ogbo ato baba ejo se koni ata ijosi ninu
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 6:46pm On Jul 28, 2017
OSOLE TODAJU FUN CONNECTION TABI FUN CONTRACT OMO YAHOO NASILELO LAI SEWU
ยค (1) Oga aaye. (2) Aso egungun die ati #1,000. (3) Igbo mimu. (4) Ewe ela. Ao fi owo #1,000 si aso egungun(ao fi tele). Ao tun wa fi igbo, ewe ela, ati biscuits okin die,ati atare odidi kan sori aso egungun naa, ao waa di gbogbo re papo. Ao waa kii si enu oga naa. Ao waa joo. Ao maa fi oti SEAMAN SCHNAPP lo lararo.
Hmmm
Edanwo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 11:00am On Jul 29, 2017
OSOLE OWO TODAJU FUN CONTRACTOR ATI OMO YAHOO
:-Okan maalu nla kan, iho merin lo nbe ni ara re, iho ti aarin ao ki ori eye osin kan si, iho keji oba owo tuntun kan ao bu ewe ola si ninu a o wee papo ao kibo iho keji, iho keta odindi atare kan la o ki bo, iho kerin eran NLA tutu ekiri kan la o ki bo.
Ao gbe si inu ape tuntun odi jijo ti aba joo tan ao ro sinu ado ide nla ti yio gba gbogbo ebu yen, a o wa mu akuko adie pupa to ti gbo daada ao pa, ao ro eje re si ara ado ide yen, a o fi iye re le ado ide yen lara.
a o wa se adie yen toritese re, lepo niyo niru, ti o ba jina!!

EEWO REE:- Akogbodo to obe yi woo....

ETUTU RE:- Ao fi ewe iyalode meta tele inu awo ipese nla ti o le gba gbogbo obe yen ao daa sinu awo ipese yi, ao se adua si daada bi a ti se nfe, a o gbe losi ikorita meta lagogo mokanla oru, fun awon iya mi osoronga.
Ti o ba di ojo keji a o lo mu awo yen

LILO RE:- To ba di agogo kan oru ao ma fi oti schnapp original lo ebu yen lati inu ado ide yen.
ao lo lojoojumo for 21days

EWO RE:- Ako gbodo sunmo obinrin fun 21days ti a fi loo'o lowo ba de!!!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by KolaBELIEVE: 4:04am On Aug 03, 2017
kadunasouth:
Aseje Arisiki Owo lona irorun
Ewe sawerepepe ,ewe ola, ewe efo gure, ewe tanagbowo, ewe ela, iyere ao lo papo ao fise edo malu tage si 16 je pelu isasun tuntun lepo niyo, yio je funyin lase awan toni ile aye
. baba Kaduna south eku use ooo.ejowo se ewe ela na lo n je ewe laa( pupa tabi fun fun) ?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 7:31am On Aug 13, 2017
Moki gbogbo ile wipe ototo meta'o
Mofi asiri yi sile fun awon ti won wadi Ola, sugbon ti won ti kolu eewo towa ninu'e, ti won wa nba inu fuu'aya fuu kaakiri,
Ema bami kalo!
Ti aba seso ola ti asije eewo ti won ka ni eewo ni awon baba wa ma nse iseyi,
Ni akoko ao akoko se ado gbekude ti ao mu:- Igba ewe ape, igba obi abata, igba orogbo, igba atare, pelu ori akalamagbo kan. adi jijo pelu omo'owu toti sise lagbede daada ohun ni ao maafi ro Lori INA, nigbati abajo tan, ao ro sinu ado, kekere kosi iye ado ti akole rosi
Ao fi iye idi akalamagbo ha lenu tobaje Fifi korun ni afese,tobaje gbi gbe mi ni aofi ewe ape di lenu aogbe ado kekere na mi.

Ni elekeji
Ewe ayajo IFA ewe atibirokun, abamoda, alupaida, ewe roro, eku eliri kan, aojo ao po mose
Ao we fun IJO meje pelu ewe awede !

Iketa ni etutu inu ogbe irete!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by mercysamuelson(m): 1:21pm On Aug 14, 2017
Benjamite01 Please, I will like to confirm if you received any help concerning what we can use to the embassy for visa interview. Please, don't hesitate to post details here.
Thanks in advance.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by memime: 4:54pm On Aug 16, 2017
For the very first time my eyes have been opened to the fact that the LORD ALMIGHTY indeed blessed our fathers with great research and wisdom.

God bless you KADUNASOUTH and all AWOs on this thread.

A ma ju yin se o.

(1) (2) (3) ... (20) (21) (22) (23) (24) (25) (26) (Reply)

Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 156
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.