Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,781 members, 7,955,989 topics. Date: Sunday, 22 September 2024 at 08:40 PM |
Nairaland Forum / Entertainment / Jokes Etc / Tommorrow's Yoruba Examination Expo (waec)... (2418 Views)
10 Places People Hide Expo In Examination Hall / June/July WAEC Examination Questions / I,m Getting Married Tommorrow, Hurray! (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Tommorrow's Yoruba Examination Expo (waec)... by Laitesmart(m): 12:50pm On Apr 09, 2013 |
TOMMORROW'S YORUBA EXAMINATION EXPO (WAEC)... Dahun ibeere mewa ni ipin yii... 1. Awon wo ni yoruba n pe ni AARE ONA KAKANFO? 10mrks 2. Daruko ohun mewa ti a le ba pade loju ogun. 10mrks. 3. Kinni oruko miiran fun EWEDU?10mrks 4. Tani eni akoko to koko gun keke rally ni ile yoruba??10mrks 5. Daruko eewo akonilogbon marun ti o ba mo?10mrks 6. Salaye lekunrere awon ami ti a fi n da ogidi were mo..10mrks. 7. So iyato kan pato ti o wa laarin were ibo, were hausa ati were yoruba.10mrks 8. Bi won ba n ta moin-moin kan ni pon-un marundinlogun. Eelo ni won maa ta moin?10mrks 9. Tani eni akoko to koko din akara ta? Ilu wo si ni won ti din?10mrks 10. Pari owe yii... AKOBANI IYAWO KASUMU...10mrks 11. Pari owe yii... SAKATAPARA LA A SINTO...10mrks 12. Pari owe yii... PATAPATA LA A FOJU..10mrks. 13. Ta ni okunrin akoko ti o koko wu irungbon?10mrks 14. Se apejuwe oro oruko mewa ti o ni ami ohun "MI MI MI".10mrks 15. Bi oko ba je ole, ti iyawo je aje... Tani yio maa bawon so ile loru? 10mrks |
(1) (Reply)
Short Stories With Moral Lessons / Funny Quotes Made By Robert Mugabe / 7 Steps On How To Cross The Road In Naija
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9 |