Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,195 members, 7,822,035 topics. Date: Thursday, 09 May 2024 at 03:08 AM

╚►Ibere !◄╝ - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / ╚►Ibere !◄╝ (1721 Views)

(2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

╚►Ibere !◄╝ by sima(f): 3:53am On Sep 30, 2008
ask a question in yoruba n' d next person replys in yoruba . . grin grin
[size=4pt]am not jobless. . it's condition[/size] tongue
Re: ╚►Ibere !◄╝ by sima(f): 3:54am On Sep 30, 2008
bawo ni grin
Re: ╚►Ibere !◄╝ by minute(f): 12:26pm On Sep 30, 2008
daadaa ni sugbon oju yii kore lowo die sad sad sad
mofe lowa nkan je,oyii nko mi.

Talo bimi lere ejo gan?

talo mo ibi tiwo npe ni LALUPON ni Oyo?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by Pataki: 4:17pm On Sep 30, 2008
LALUPON, emi ko mo ibi ti o wa o ninu ilu Ibadan. So mo wipe Ibadan tobi gan sha.

Kini itumo abala thread yii gangan?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by sima(f): 5:35pm On Sep 30, 2008
abala thread keh. . kilon jebe undecided
Re: ╚►Ibere !◄╝ by Pataki: 5:40pm On Sep 30, 2008
Ibeere Pataki lo beere yen o.

Ta lo le bami da lohun?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by sima(f): 7:02pm On Sep 30, 2008
iwo ole dami loun abi. . ?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by Pataki: 7:43pm On Sep 30, 2008
Kilode ti ma se da e lohun? Se dandan ni?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by timbabng(m): 9:57pm On Sep 30, 2008
ise lo ye ki o da lohun, gege bi omo yoruba ijinle grin
Re: ╚►Ibere !◄╝ by sima(f): 1:02am On Oct 01, 2008
abi oO. . ori so jare timba grin
@pataki. . kilode ti iwo ole dami loun ? she ikan buruku ni ??
Re: ╚►Ibere !◄╝ by Pataki: 8:19am On Oct 01, 2008
Kilode to fe je ki da lohun? Se dandan ni?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by toba1909(m): 1:07pm On Oct 01, 2008
Dandan ko o!

Aku odun itunu awe ati ojo ibi orile-ede wa
Emi wa yoo se pupo o

Omo ilu wo ni iwo?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by abdurrazaq(m): 2:55pm On Oct 01, 2008
Omo bibi Ile Yoruba ni mi. A ku poposese Odun lorisirisi yii oo, emi wa a se pupo iru re l'aye ati l'aye wa o - Aamin.

Ta ni eni naa ti o n bere itumo abala thread yi lekan rii?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by Pataki: 3:00pm On Oct 01, 2008
So ni gbolohun lati so si ibeere yen ni?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by sima(f): 7:18pm On Oct 01, 2008
she emi loun ba sori? ?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by ayomifull(f): 3:48pm On Oct 02, 2008
oti iwo ko ni mo nba soro eniti o wa ni egbe mi nibi ni, se o gbo oun ti mo so fun ni?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by bigfather(m): 3:59pm On Oct 02, 2008
Ewo lon tun je AGBALA THREAD O ? undecided
Re: ╚►Ibere !◄╝ by tollu: 4:03pm On Oct 02, 2008
he he he he he. Yeeparipa, nse ni Ayomifull gbe Sima ni agbele/ela pelu ogbon sha.
Tee heee heeee

Ki wa ni itumo abala o? Ibeere yen lo si ori ero 'akowegbesi' Pataki ati abdurrazaq.
Re: ╚►Ibere !◄╝ by Moyola(f): 9:57am On Oct 03, 2008
Kin maà fí oro gùn, "Àbàlà thread" tunmo sí Thread. . . . abi? undecided

Tà lo ní ìbérè?
Re: ╚►Ibere !◄╝ by sima(f): 5:29pm On Oct 03, 2008
ki loun je Àbàlà thread ?? undecided
Re: ╚►Ibere !◄╝ by Pataki: 5:44pm On Oct 03, 2008
Se e si wa lenu ibeere yi na? undecided
Re: ╚►Ibere !◄╝ by sima(f): 5:45pm On Oct 03, 2008
oda bee. . . abi seh inko buruku ni??
Re: ╚►Ibere !◄╝ by tRoOE(f): 6:16pm On Oct 03, 2008
[size=13pt]i suck in yoruba but i will trueTa ni buruku, e mi abi[/size]
Re: ╚►Ibere !◄╝ by abdurrazaq(m): 12:06pm On Oct 04, 2008
Abala thread tumo si GBAGEDE tabi AAYE ti a ti n soro lowo yii. Tani ko ye ki o nowo re s'oke ki Oluko yin to lo? cheesy
Re: ╚►Ibere !◄╝ by RibaduFan(m): 9:21pm On Oct 04, 2008
eleyi ga gani o.O da bi a se n gbe ede wa laruge. E je ki amura si o. Olorun ama buku wa o.
Re: ╚►Ibere !◄╝ by tamme: 11:27pm On Jul 15, 2009
nice thread
Re: ╚►Ibere !◄╝ by bintab(f): 9:13am On Jul 25, 2009
tamme:

nice thread
(write it in yoruba)Gagede yi dara.
Ibere=Idahun.

(1) (Reply)

7 Bizarre Cultural Practices You Didn't Know About !! - (PICS) / The Origin Of Iyawo (yoruba Word For Wife) / Origin Of The Igbos

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 12
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.