Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,194,120 members, 7,953,457 topics. Date: Thursday, 19 September 2024 at 04:36 PM

Oro Po Ninu Iwe Kobo - Family - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Family / Oro Po Ninu Iwe Kobo (5388 Views)

Before You Say "I Do", My 2 Kobo (2) (3) (4)

(1) (2) (Reply) (Go Down)

Oro Po Ninu Iwe Kobo by tpia1: 8:38pm On Sep 15, 2014
this is a family proverb which used to be commonly said.

it means something about deep i should think.

ie there is no end to endless deep.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:24pm On Sep 15, 2014
What's this?

Is this the culture or language section? You are the one who always complain of silly topics here and imagine this nonsense from you.

Be careful o ki o towo omo e bo aso
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:25pm On Sep 15, 2014
adolfebad: What's this?

.

i need to be careful o ki mo towo omo mi bo aso

1 Like

Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:25pm On Sep 15, 2014
no d.umb comments, thanks.

1 Like

Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:26pm On Sep 15, 2014
Ati kekere lati npeka Iroko.....
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:30pm On Sep 15, 2014
temigracie: Ati kekere ni ti temi ti ma peka Iroko.....


true that dear
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:31pm On Sep 15, 2014
more, thanks.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:34pm On Sep 15, 2014
itstpia1:


true that dear


hehehehehehe....

Oun bo, Oun bo....Ode la nde de....
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:36pm On Sep 15, 2014
temigracie:


hehehehehehe....

Mo nbo, Mon nbo....Ode la nde de....
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:36pm On Sep 15, 2014
[quote author=itstpia1][/quote]


Ok o. You will eat your pounded yam as yam.

Oya translate that if you know the popular proverb.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:36pm On Sep 15, 2014
keep it coming folks.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:37pm On Sep 15, 2014
adolfebad:


Ok o. I will eat stones as pounded yam


good one bro, post more.

1 Like

Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:39pm On Sep 15, 2014
itstpia1:

good one bro, post more.

You are a funny lady. So you don't even know your yoruba doju ami.

For your info, the translation is waa je iyan e nisu.

Simple.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:41pm On Sep 15, 2014
[quote author=itstpia1][/quote]

hehehehehehe...

Agbalagba kii se langba langba...
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:44pm On Sep 15, 2014
temigracie:

hehehehehehe...

Agbalagba kii se langba langba...


Okere ti yoo gun igi iroko, ekana re yoo mu sa sa
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:45pm On Sep 15, 2014
adolfebad:



For your info, the translation is ma je iyan mi lokuta.

Simple.


we are saying the same thing bro.

no need to get upset.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:45pm On Sep 15, 2014
adolfebad:


Okere ti yoo gun igi iroko, ekana re yoo mu sa sa

I dont know how to translate that to English......am not that good in Yoruba....


Oro kekere la nso fun omoluabi...To ba de inu re yo di odidi....
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:45pm On Sep 15, 2014
temigracie:

hehehehehehe...

Agbalagba temi kii se langba langba...
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:46pm On Sep 15, 2014
adolfebad:


Keregbe to fo deyin lehin odo, emi oloriburuku yoo pada lehin re
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:47pm On Sep 15, 2014
more, my peeps
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:50pm On Sep 15, 2014
temigracie:



Oro okunkun inu elede bi temi lon gbe.

can you finish that proverb dear.

1 Like

Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 9:51pm On Sep 15, 2014
back to topic!
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:53pm On Sep 15, 2014
[quote author=itstpia1][/quote]

Iponri aja kan kii je ifun okete. Ajakaja to ba danwo a ya digbolugi.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:54pm On Sep 15, 2014
...Ai gbo Ifa la nwo oke..
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 9:55pm On Sep 15, 2014
itstpia1:

can you finish that proverb dear.

hanhan...I offend you before ni??

1 Like

Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Tymax(m): 9:56pm On Sep 15, 2014
temigracie:

I dont know how to translate that to English......am not that good in Yoruba....


Oro kekere aabo la nso fun omoluabi...To ba de inu re yo di odidi....
cool
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 10:02pm On Sep 15, 2014
Tymax: cool
...lol....Tnks alot, sir....
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 10:04pm On Sep 15, 2014
Bi omode ba n ge igi ninu igbo, agba lo ma mo ibi to ma wo si.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by CAMNEWTON4PRES: 10:11pm On Sep 15, 2014
Translation please
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by spanzed(m): 10:46pm On Sep 15, 2014
Bi su eni ba ta an fi owo bo je ni.. tongue
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 2:58am On Sep 16, 2014
adolfebad:

Ai si'nle ologbo, lon mu eku shako.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 3:01am On Sep 16, 2014
adolfebad: Ki eegun to de lalagbaa ti nfolele jeko

(1) (2) (Reply)

Please Help Me - I Am Going To End My Miserable Life / Help Me With The Right Food Processor/blender / Must I Wear Our Wedding Ring?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 15
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.