Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,457 members, 7,816,066 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 01:55 AM

.. - Culture (68) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828636 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (65) (66) (67) (68) (69) (70) (71) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by dominicson: 6:06am On Mar 20, 2016
Lero70:
@Dominicson Ejowo efunmi ni phone no. Ati email add yin




08145802864. 08121751389. benige4@gmail.com

2 Likes

Re: .. by dominicson: 6:09am On Mar 20, 2016
wale259:
E se sir,Agba yin o ni baje

Ase n'Ife!
Re: .. by Lero70: 10:01am On Mar 20, 2016
dominicson:







Yes, a o gbe etutu yii jina si ibi ti a n gbe. Ekuru meje ti a jo pelu atare kan ni a o fi te odu osa eleye ti a o fi won(bu si ori) ipese yii. Ti o ba se e se, oru ojo yii gan ni odara ki a se ikeji(the second part) ti o lo bayi:


Ebu.

Oromodie (a chick) ati atare kan, a o jo, a o da ebu yii si inu igba olomori kekere kan. A o tun jo alapandede ati atare kan, a o da sinu igba kekere miran. A o jo eye ega kan ati atare kan, a o da sinu igba olomori keta. Ti o ba di agogo kan oru, a o te aso funfun si ile ni gbangba abe sanmo. A o joko le lori ni ihoho. A o wa akara elepo meta. A o fi akara kan je ebu inu igba kan. So, akara meta, igba meta. Ki a to je, a o so wipe:

Eyin alaye, mo ba yin mule loni o. Emi o ba yin fi omo mi mule o. Emi o ba yin mule a n pa ara eni l'aya, l'omo... Emi wa ba yin mule kin le la, kin n le lu, ki n le ri owo se fuja. Ti eran ba n wu yin je, awon ota mi ni ki e ma mu pa je lokokan o.
ejowo Alagba se ki ato kunle sidi ipese yi lati ka psalm re sii ni aoti fi ebu ti atenifa awon maami wonan ni abi leyin ti atigbe de ibiti aol gbee kale si. Esee pupo
Re: .. by Lero70: 10:22am On Mar 20, 2016
dominicson:



Eko tutu la a fi lo. Owuro kutukutu la a lo. Aaye ologinni nla la a lo. Ti a ba ti pe gbolohun si ki a to ro sinu ato, o ti daa.

edakun aaye ologinni, se ti ao sesepa funrawa abi ti ao gbe sinu agbada laaye? Ejoo ebawatanmonle sii Moseba Agba o.
Re: .. by dominicson: 11:01am On Mar 20, 2016
Lero70:


edakun aaye ologinni, se ti ao sesepa funrawa abi ti ao gbe sinu agbada laaye? Ejoo ebawatanmonle sii Moseba Agba o.

Ti e ba se n pa tan ni e o gbe sinu agbada, kii se laaye o. Nitoripe ologinni kii se eran be o!

3 Likes

Re: .. by dominicson: 11:13am On Mar 20, 2016
Lero70:

ejowo Alagba se ki ato kunle sidi ipese yi lati ka psalm re sii ni aoti fi ebu ti atenifa awon maami wonan ni abi leyin ti atigbe de ibiti aol gbee kale si. Esee pupo


Ninu iyewu yin ni e o gbe ipese naa si, e o te ifa si egbe re, e o kun le ti (a bi se eyin o le kunle fun awon mami ni?) Ti e ba ti ka psalm yen si tan, e o da ifa naa si ori ipese naa, e o wa gbe jade lo si ibi ti e fe gbe si. Kan ni awon baba mi ni, awon a maa le(bi opele/ifa) ibi ti won ti fe pade yin. But never to worry, just take it at least a bit far to your place. If you have a car, put it in your car and drive to a convenient place to place it! If you don't (Awon ti Olorun fi se opo/pillar aye yoo pese fun yin), just put it in a 'poly bag', stroll out, or take bike if need be, and drop it off! Regards.

2 Likes

Re: .. by Tevez83839: 12:22pm On Mar 20, 2016
Aboruboyeooo Baba Edakun omo gidi nimi. Won n yan mi je lori tori mio le jaa .ejowo mo nilo oruka agbefuye/ anasare todaju kiwon le mo pe mo ni baba nigbejo.Ibaoooo

1 Like 1 Share

Re: .. by Lero70: 9:36pm On Mar 20, 2016
skamo74:

Haba! Sir sorry for saying this I think it's now clear you are not on this forum for the good of it. what are you really teaching people here? Are you using style to sell yourself as the biggest Babalawo? it seems you have a lot of power you want to use or test.

awon agba bo won ni " Igberaga ni siwaju iparun" ati pe " Agba to ba lomi ninu kin pariwo".

Sir can't you start your own forum on IFA or what ever. Everybody has been pleading with you but you still want to pick fight with Baba heartfirst.

sir, since you came on this forum you've managed to create a lot of confusions for us who are learning. the simple truth is that Baba healthfirst and Baba kadunasourh and others has help us alot. we tested what they teaches us and we conformed it to be true.

sir, if you have some just teach and stop urging for war.


sorry my view


hmm! Hmm!!, Awon agba bo wonni binaobalawo, kiijo goke-odo. Alagba skamo74 se owe enikan lenje ni abi adaje ise arayin? Tobajepe owe tiwonbeyin lenje, yio dara pupo teebale fi tomo je ise-eru tiwonbeyin o nitori aimoseeko niipeshin logun o, tobasijepe adaje ise arayin lenje, molerope bi igbati eeyan tun moomo tapo si ina aawo totinkulo ni oroyin je, osidunmi wipe ekofiye ba ohun tonsele laarin awon agba mejeeji ati gbogbo awon agbalagba toti dasii lo, tabikojepe ekiise olufe alaafia. Sugbon mogbosuba fun ogbon agba atiwa-agba ti Alagba Ifankaleluya hu, nitori awon agba bo wonni BAATITO NIKIIJE KABINU, BIWON OSEMO NIKIIJE KIWON MOWAAHU. atipe FORISIKUNBIAGBA FIGBIGBO SALAIGBO.
nobody is perfect, so let us tolerate ourselves.
Healthfirst turn to Nobody, i've discovered most of ur post has bn deleted is it because of ds issue or other things, i dnt tnk its ought to b so.
Ifankaleluya, i perceive u've stop postn y? I dnt tnk its ought to b so, eyinmejeeji emajeki nkankan tiotonkan sepalara fun atijenkan tiyin.
Eniti mobase koforijimio IBA AGBA.
Re: .. by fxopen(m): 9:39pm On Mar 20, 2016
Ifankaleluya:



@fxopen..!

R u a forex-trader? If you're one, what are d indicators you're using?

Concerning wht you asked. Asiri bibo keekeke ni awon yen now,so ko ni eewo or whteva kankan.

Awon alujon-nu ti n wa owo(money) fun awon eeyan po lode(mi re).

So.....Oloju awon-asiri bibo to le sise(re mi).

Emi kan n woran ni....Nigbati mo ri awon kan ti won post oso-owo olojo-meje to gbona pe ke lo fi isu dandan je.

Kosi wahala kankan ore mi(my 5rnd)!

E seun, ewe a maa je oo, emi o ki n se ferex trader oo, mo kan lo oruko yen gegebi inagije lati wole sori ikanni yii ni, mo moriri idahun yin..
Re: .. by whykay77: 7:03am On Mar 21, 2016
@healthfirst I want to believe after all we discuss here about you and @ ifankaleluya rifts that it is over between you and the thread will work together for the growth of we watchers and partakers. Let's help to lift up the glory of yoruba high. E jebu re eyin mejeeji. Eje ka jo ma bara se. An se oloun on dari jinni ambosi awa eniyan eleran ara wa.
Re: .. by Nobody: 7:40am On Mar 21, 2016
whykay77:
@healthfirst I want to believe after all we discuss here about you and @ ifankaleluya rifts that it is over between you and the thread will work together for the growth of we watchers and partakers. Let's help to lift up the glory of yoruba high. E jebu re eyin mejeeji. Eje ka jo ma bara se. An se oloun on dari jinni ambosi awa eniyan eleran ara wa.

I have envisaged the death of this thread and it has finally happened. Its original objective has since been grossly abused as a result of disobedience and power play.

Unfortunately, the person who conceived the idea close to a year ago lost the exclusive power to control and moderate postings on the thread due to its invasion by those who claimed to have ''best'', corrective knowledge and ideas. Where are they now? A leper can not squiz cheese, but can waste it!

Oba to laye ati Orun yoo saanu fun gbogbo wa. I really gained a lot since I stumbled on this thread about four months ago and I have no regrets learning Yoruba Science in full and varieties. I am everly grateful to those who had contributed positively notably Baba KadunaSouth, Baba Healthfirst and a host of others, in assisting the less-privileged to tap from their wealth of knowledge and experience.

People will remember you for two things:
1. What you have done successfully.
2.What you failed to do.

Let us purge ourselves and think of our impacts on those we come across in life. There is reward for everything we do. Kind regards to all.

1 Like

Re: .. by Lionhearted: 9:30am On Mar 21, 2016
.
Re: .. by rawe45: 9:42am On Mar 21, 2016
E wo email yin baba
dominicson:



Ninu iyewu yin ni e o gbe ipese naa si, e o te ifa si egbe re, e o kun le ti (a bi se eyin o le kunle fun awon mami ni?) Ti e ba ti ka psalm yen si tan, e o da ifa naa si ori ipese naa, e o wa gbe jade lo si ibi ti e fe gbe si. Kan ni awon baba mi ni, awon a maa le(bi opele/ifa) ibi ti won ti fe pade yin. But never to worry, just take it at least a bit far to your place. If you have a car, put it in your car and drive to a convenient place to place it! If you don't (Awon ti Olorun fi se opo/pillar aye yoo pese fun yin), just put it in a 'poly bag', stroll out, or take bike if need be, and drop it off! Regards.
Re: .. by Aareago1: 11:56am On Mar 21, 2016
Lionhearted:
I have tried many of healthfirst Ooguns and they all worked. I am grateful to him for that.

Having said that, we also have to understand where Ifankaleluya is coming from. Some of the Ooguns here doesn't corresponds to the purpose and the ofos mentioned with them. How do I know this? In January I was opportuned to meet an Alfa in a bus travelling to Ibadan. The said Alfa was reading a book that is exclusively full of Ooguns, their uses and taboos.

I showed the Alfa this thread. He said I should seek a second opinion because some of the Ooguns here are wrong. Curiously he endorsed all of kadunasouth's saying 'this is someone that know what he is doing'.

An incomplete or wrong Oogun is capable of wrecking a great havoc in a human's life hence the need for caution.

Healthfirst has a wealth of information concerning African Science no doubt, but a misrepresentation of one is or not isn't good.

Ifankaleluya, we know you are a babalawo but we will appreciate it more if you can be posted what will be beneficial to us all.

Btw healthfirst, all the Ooguns you posted here are saved by me in a doc file. Thanks.

It is a big shame you are revealing your findings after the thread has been expunged. That is the problem with people. It was a fundamental issue raised by that alfa you had an encounter with. The noble thing you could have done is to contact Healthfirst privately either via whatsapp or e-mail and tell him of someone's observation regarding some of his postings. This is the same thing Ifankaleluya failed to do that led to the deletion of the thread.

Even if a student knows more than the teacher, there must be dignity, honour and respect in not only pointing to errors, but giving corrections where necessary and constructively too. I did not see it anywhere and here particularly where Healthfirst paraded himself as a priest, and if he opens up privately to someone, that secrecy must be preserved. If we see errors, we are duti-bound to call the attention of the author and give our own objective and express opinion. If you say something is fake, then show us the real original thing.

Conclusively, Yoruba science is far and wide, just like any other science. No one knows it all. The use of one item that I know, could be very different from the use that you know of. Don't forget that before most of these charms were documented, their efficacy were tried, tested and confirmed okay- that is the same process a research goes through. Anybody can invent a charm; get two or three ingredients, grind or burn them together and use it, if it works, fine- you claim the copyright ownership. We should not be lazy; let us think and do things on our own. Where we have no time or grace to do that, we need to appreciate those who do it. If they give it out freely, let us be grateful, and if they decide to charge a token, let us oblige or if we cannot afford it, let us try our luck elsewhere. Nothing is free nowadays, not even in Freetown.

1 Like

Re: .. by Lionhearted: 12:11pm On Mar 21, 2016
^ Your point is noted.

But I didn't in anyway said his ooguns are fake. I actually tried some and they all work.

I just want people to be cautious of doing ooguns anyhow. Well, since my post is apparently construed kindly edit your quote.
Re: .. by Ifankaleluya: 5:16pm On Mar 21, 2016
Stop exchanging words on a dead issue. No rifts,or whatever between anyone here.


In fact, I & Healthfirst had a chat late yest9t.

You av not c my post here again because am a busy type.

I only like adding value whenever I see people talking about Yoruba culture,our gods & tradition.

Beeing an ifa-priest does not means my earnings for living was from that source.(i.e. Some governors are ifa-priest,&also some musicians)

I only like to shed-light about Ifa anywhere the needed be.

I hope Healthfirst w b back,& I also w alys contributes anytime I wish & @leisure to do so.

2 Likes

Re: .. by fxopen(m): 7:19pm On Mar 21, 2016
kadunasouth:

Aseta todaju

Igbin to pinu 3 ewe kasan eru alamo odidi atare kan ao jo papo ao rosibi kan tiaba felo ao bu die nibe ao te ifa obara eka si ao wa pe ofore si ao fi omi gbigbona lo tabi eko gbigbona

Kowe leye aye agbigbo leye ode orun ton bari hihihi amako awon agbagba sanko sanko losode orun, ese oba taye lape obara eka, obara eka bamika Awon otami lese losi ode orun, owo mowo ibiwon lewon lori eru maru ibiwon da siwon lara , ti igbin ba fa ikarahun re atele, gbogbo aburu ti awon ota baro simi komon tele won leyin

e jowo, ofo yen ko ye mi daadaa, koowe l'eye aye agbigbo l'eye ode orun...next word ko ye mi ...TON BARI HIHIHI AMAKO AWON AGBAAGBA SANKO LOSODE ORUN, ESE OBA TAYE LAPE ...... awon to seku ye mi E JOWO KINNI AWON ORO TI MO KO NI LETA GADAGBA NINU APAKAN OFO YII , E JOWO KOO KO YE MI ....THANKS

1 Like

Re: .. by Aareago1: 8:23pm On Mar 21, 2016
Lionhearted:
^ Your point is noted.

But I didn't in anyway said his ooguns are fake. I actually tried some and they all work.

I just want people to be cautious of doing ooguns anyhow. Well, since my post is apparently construed kindly edit your quote.

@Lionhearted The points in my posts are divided into 2:
1. When we observe a mistake or errors, we should
point it out without condemnation, not after an
irredeemable damage has been done.
2. We need to appreciate others who share their
secret knowledge. Several others protect their
own jealousy.

I never quoted you out of context. I stand by my opinion.

2 Likes

Re: .. by Pingballsearch: 10:03pm On Mar 21, 2016
Baba E pe fun wao mo ni lo ise yi 07057210628
Re: .. by AyeMoJuba: 11:42pm On Mar 21, 2016
Re: .. by wale259(m): 9:28am On Mar 22, 2016
Sir,e fun mi idi isoye yi...
dominicson:




Akii ka owo ki a gbagbe eni
Orisa kii gbagbe ati ko ila owo(hand)
Omo irunla kii so loko (at farm) ko mala
Gbogbo eko ti mo ba ti nko, ki o ma la si mi lokan!

1 Like

Re: .. by fxopen(m): 12:14pm On Mar 22, 2016
alhajialhaji:
Ifankaleluya, E jo e fun mi ni ise yi pe ooooo... 070529055775...Alhaji [img][/img]Taofeeq.

e jowo e fun mi ni ise yii pe ooo..oluwolelove@gmail.com
Re: .. by wale259(m): 1:35pm On Mar 22, 2016
WE RENDER OUR CUTTING-EGDE SERVICES TO OUR CLIENTS IN THE FOLLOWING WAYS THEY NEED US:
(1)SHIPPING AND PORT SERVICES
(2)CLEARING AND FREIGHT FORWARDING
(3)AIR FREIGHT FORWARDING
PLS:DO CONTACT ME IF U NEED OUR PARTNERSHIP IN ANY OF THE ABOVE SERVICES:08184357512 OR 08038864811...waleadewale2002@yahoo.com
THANK U FOR YOUR POSITIVE CONSIDERATION.
Re: .. by dominicson: 3:50pm On Mar 22, 2016
wale259:
Sir,e fun mi idi isoye yi...


Irunla, that is ila(okra/okro) ti o gbe/dry si ori iya e, owo eyo kan (eyi ti ko lu), oko atare kan, a o gun papo, ao fi fo eko tutu kan mu.

2 Likes

Re: .. by Lero70: 4:35pm On Mar 22, 2016
dominicson:





08145802864. 08121751389. benige4@gmail.com
Alagba Dominicson, email address teefisita yi, motigbiyaju lati kole ranse sinu re, sugbon esi tiwon ndapada funmi nipe wonkodaamo ( address is not recognized ) eranmilowo. Eseepupo.
Re: .. by dominicson: 6:50pm On Mar 22, 2016
Lero70:

Alagba Dominicson, email address teefisita yi, motigbiyaju lati kole ranse sinu re, sugbon esi tiwon ndapada funmi nipe wonkodaamo ( address is not recognized ) eranmilowo. Eseepupo.


benige4@gmail.com

1 Like

Re: .. by Ifankaleluya: 8:23pm On Mar 22, 2016
Olori(re mi mi) niyanri

Ogberi(do do do) o gbodo gba obi pa lowo babalawo

Adifa fun ose(do mi) nijo ti n lo re rugba ise(do mi) sigbo, ebo won ni ko se

Ogbebo nibe o si sebo

Oru tesu o si tu

kiipe kii jina,ka wa ba ni ni ijebutu ire(re re)

Ijebutu ire la b ni lese(mi do) obarisa.



Ela-boru,Ela-boye, Ela-bosise.
Re: .. by Ifankaleluya: 8:28pm On Mar 22, 2016
FUN ENITI N LA ALA-KALA

Ewe-ajeobale mokanlelogun

Omi-agbon to po daa daa.

Omi-agbon yi ni ao fi gbo ewe-ajeobale yen,ao mu die ti a ba fe sun,ao si ji mu iyoku ni aro kutu-kutu.

Bayi ni ao se ma se ti adura wa yio fi gba.

3 Likes

Re: .. by Ifankaleluya: 8:38pm On Mar 22, 2016
EYONU AWON AJE
Elo re wa eso-laara to po daadaa
Odidi-atare kan
Ao jo won papo ni
Ao wa lo(re) sugar mo
Ao ma da senu pelu adura ni alaale ati aro.

Aboru,Aboye.

3 Likes

Re: .. by wale259(m): 8:49pm On Mar 22, 2016
wale259:
Sir,e fun mi idi isoye yi...

Akii ka owo ki a gbagbe eni
Orisa kii gbagbe ati ko ila owo(hand)
Omo irunla kii so loko (at farm) ko mala
Gbogbo eko ti mo ba ti nko, ki o ma la si mi lokan!

Akii ka owo(hand/money)ki a gbagbe eni

Se a ma se nigba gbogbo ni abi ekan pere?
Se ale se fun omo kekere bi odun meta
Re: .. by wale259(m): 8:55pm On Mar 22, 2016
Ni gba gbogbo ni sise re abi bawo,nitori wipe Ala temi ko clear si mi bi osu melo kan seyin titi di asiko yi,ati wipe se ka to soro si eniyan laro ni mu laro.
Ifankaleluya:
FUN ENITI N LA ALA-KALA

Ewe-ajeobale mokanlelogun

Omi-agbon to po daa daa.

Omi-agbon yi ni ao fi gbo ewe-ajeobale yen,ao mu die ti a ba fe sun,ao si ji mu iyoku ni aro kutu-kutu.

Bayi ni ao se ma se ti adura wa yio fi gba.
Re: .. by wale259(m): 9:00pm On Mar 22, 2016
Sugar melo la ma lomo?
Ifankaleluya:
EYONU AWON AJE

Elo re wa eso-laara to po daadaa

Odidi-atare kan

Ao jo won papo ni

Ao wa lo(re) sugar mo

Ao ma da senu pelu adura ni alaale ati aro.


Aboru,Aboye.

2 Likes

(1) (2) (3) ... (65) (66) (67) (68) (69) (70) (71) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 70
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.