Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,288 members, 7,957,742 topics. Date: Tuesday, 24 September 2024 at 06:55 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842236 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (90) (91) (92) (93) (94) (95) (96) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by mercysamuelson(m): 11:57pm On Jul 12, 2017 |
Omo owo wo ni a ma ki bo ki si ni ero re? sammyjay76: |
Re: .. by Divinedew: 4:12pm On Jul 14, 2017 |
Ago onile o, e jowo kini Yoruba un pe ni OJU WOWO. E se pupo. |
Re: .. by Alibaba1981: 10:08am On Jul 16, 2017 |
moki gbogbo eyi baba alubarika pe aku ojumo ejo mo need ( Ogun asiri bibo fun inawo) |
Re: .. by skysky05: 5:29pm On Jul 16, 2017 |
Ogbó ató oo. Ewe aje, egbo afò fun gbogbo jawe jawe rere ooo. E jowo mo nilo ogun ti eyan fi mu oti sugbon ti oti koni pa rara |
Re: .. by Nobody: 6:15am On Jul 20, 2017 |
hello, this thread is for lovers of nature when it comes to health and other areas of our lives. This thread is also strictly for the Yorubas and those who can read and understand as the language here is going to be pure Yoruba and no translation will be allowed. Reason is that we are going to be revealing some Yoruba secret knowledge of the application of leaves and roots and we intend to preserve and guard these wisdom of our ancestors. Am Yoruba but I can't really read and understand Yoruba and I really really need ur assistance medically because I've some medical issues and i need medical attentions. how can I contact you on this? thanks looking forward for ur reply. |
Re: .. by adeyenuwo: 9:46am On Jul 21, 2017 |
[/color] janle:[color=#990000] janle: janle:ki lo nje abaweku ati wipe se owo eyo ni kudi ti e mean |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 11:02am On Jul 29, 2017 |
OSOLE OWO TODAJU FUN CONTRACTOR ATI OMO YAHOO :-Okan maalu nla kan, iho merin lo nbe ni ara re, iho ti aarin ao ki ori eye osin kan si, iho keji oba owo tuntun kan ao bu ewe ola si ninu a o wee papo ao kibo iho keji, iho keta odindi atare kan la o ki bo, iho kerin eran NLA tutu ekiri kan la o ki bo. Ao gbe si inu ape tuntun odi jijo ti aba joo tan ao ro sinu ado ide nla ti yio gba gbogbo ebu yen, a o wa mu akuko adie pupa to ti gbo daada ao pa, ao ro eje re si ara ado ide yen, a o fi iye re le ado ide yen lara. a o wa se adie yen toritese re, lepo niyo niru, ti o ba jina!! EEWO REE:- Akogbodo to obe yi woo.... ETUTU RE:- Ao fi ewe iyalode meta tele inu awo ipese nla ti o le gba gbogbo obe yen ao daa sinu awo ipese yi, ao se adua si daada bi a ti se nfe, a o gbe losi ikorita meta lagogo mokanla oru, fun awon iya mi osoronga. Ti o ba di ojo keji a o lo mu awo yen LILO RE:- To ba di agogo kan oru ao ma fi oti schnapp original lo ebu yen lati inu ado ide yen. ao lo lojoojumo for 21days EWO RE:- Ako gbodo sunmo obinrin fun 21days ti a fi loo'o lowo ba de!!! Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: .. by lhordspy: 6:55pm On Jul 29, 2017 |
Ejo kini eyan lelo fun eyan to ni staph infection to ti pe lara |
Re: .. by Sebiotife: 7:28am On Aug 07, 2017 |
[color=#990000][/color] Redoil: |
Re: .. by adebayo111: 7:13am On Aug 09, 2017 |
kini mo le lo fun obinrin tio je wipe okunrin ti poju fun ( iyawo to nyan ale) |
Re: .. by woletaiwo: 9:05am On Aug 10, 2017 |
Saw this in your write up itose l’o l’Oyo, onibode l’o ni aafin’ Please, what is the meaning. Thanks |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 7:39am On Aug 13, 2017 |
Moki gbogbo ile wipe ototo meta'o Mofi asiri yi sile fun awon ti won wadi Ola, sugbon ti won ti kolu eewo towa ninu'e, ti won wa nba inu fuu'aya fuu kaakiri, Ema bami kalo! Ti aba seso ola ti asije eewo ti won ka ni eewo ni awon baba wa ma nse iseyi, Ni akoko ao akoko se ado gbekude ti ao mu:- Igba ewe ape, igba obi abata, igba orogbo, igba atare, pelu ori akalamagbo kan. adi jijo pelu omo'owu toti sise lagbede daada ohun ni ao maafi ro Lori INA, nigbati abajo tan, ao ro sinu ado, kekere kosi iye ado ti akole rosi Ao fi iye idi akalamagbo ha lenu tobaje Fifi korun ni afese,tobaje gbi gbe mi ni aofi ewe ape di lenu aogbe ado kekere na mi. Ni elekeji Ewe ayajo IFA ewe atibirokun, abamoda, alupaida, ewe roro, eku eliri kan, aojo ao po mose Ao we fun IJO meje pelu ewe awede ! Iketa ni etutu inu ogbe irete! Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: .. by mercysamuelson(m): 12:30pm On Aug 14, 2017 |
Ayokunumi24; Please, did you receive any help concerning the visa stuff? e jowo baba, e jowo e fun wa ni ogun ti eyan yio fi ri visa gba? |
Re: .. by Ayokunumi24(f): 11:39am On Aug 15, 2017 |
mercysamuelson: No |
Re: .. by Nobody: 2:19pm On Aug 18, 2017 |
08101646045atwp: E jowo Kini itumo eran NLA tutu ekiri kan? Tabi ka nipe iru eran wo gan ni? Abi eyi ti mo nro ni!! |
Re: .. by horlakunmy: 8:05pm On Aug 19, 2017 |
osole owo NLA kan reooo koni ipalara rara . foroforo olokun ,eyele funfun,ESO baka,ewe aje ewe sawerepepe,omi agbon,igba olomori tuntun ,ao gun gbogbo awon nkan wanyi papo pelu eyele ,ako gbogbo gun APA eyele mejeji man wan,APA eyele mejeji lao fi tele igba ti afe ko ose si,ao pa eje eyiele yen si ara igba ,aofi iye eyiele Le ara igba yen,omj agbon laofipo ose yen ,ako gbodo fi omi Miran po ose nan ,osole yi damiloju pupo ,fun alaye epemi sori number MI ,07087774041 or 08091466676 owo akoko ti osole yi ba gbewa ,aofi die se Sara nibe .iba olohun..iba a won to koko jawe ,iba awon iyami osoronga |
Re: .. by horlakunmy: 8:28pm On Aug 19, 2017 |
Osole akeesu ,ojojumo ni ao man mu owo tuntun ni apo WA ,gbogbo igbati aba ti nilo owo ni aoma mu owo ninu apo WA,mofi olohun bura,eni toba se ise odi dandan kodi olowo ni, afoman botuje,afoman Lara ,afoman igi mangoro,pelu oga oye ,owo 1000 tuntun pelu ,gbogbo awon kini wanyi gungun nio ,koise jijo,ao koko pa eje oga yen sori a won nkan eroja toku ,ao koko jeki oga yen GBA awo owo 1000 yen ,ti aba gun tan ,ao Sa tiyio GBE ,ao ri wipe ori lubulubu bi elubo ,ao da si ona meji ,toba di ojo alaruba , ao sofun a won alfa Oni hantu kiwanbawa han ayayi si ona meji ototo. aya na niyi انما امره اذا اراد شيءا ان يقول له كن فيكون 70 times ao hansi ona meji ototo toba wadi oru ale Wednesday eyi tinse oru majuma Thursday ago kan ,ao mu hantu alakoko Peru did a idakan Ogun ti apinsi ona meji sinu hantu na ,ao gbemu toba tunwa di ago kan osan Thursday ao tun fo hantu ikeji pelu dida Ogun kan toku sinu ohun na .. akiyesi, omi ojo laofi fo hantu na ,aso funfun ni aowo ni ojo Thursday... osole yi damiloju pupo ,fun alaye epemi sori number MI ,07087774041 or 08091466676 owo akoko ti osole yi ba gbewa ,aofi die se Sara nibe .iba olohun..iba a won to koko jawe ,iba awon iyami osoronga osole owo NLA kan reooo koni ipalara rara . foroforo olokun ,eyele funfun,ESO baka,ewe aje ewe sawerepepe,omi agbon,igba olomori tuntun ,ao gun gbogbo awon nkan wanyi papo pelu eyele ,ako gbogbo gun APA eyele mejeji man wan,APA eyele mejeji lao fi tele igba ti afe ko ose si,ao pa eje eyiele yen si ara igba ,aofi iye eyiele Le ara igba yen,omj agbon laofipo ose yen ,ako gbodo fi omi Miran po ose nan ,osole yi damiloju pupo ,fun alaye epemi sori number MI ,07087774041 or 08091466676 owo akoko ti osole yi ba gbewa ,aofi die se Sara nibe .iba olohun..iba a won to koko jawe ,iba awon iyami osoronga |
Re: .. by horlakunmy: 8:30pm On Aug 19, 2017 |
Osole akeesu ,ojojumo ni ao man mu owo tuntun
ni apo WA ,gbogbo igbati aba ti nilo owo ni aoma
mu owo ninu apo WA,mofi olohun bura,eni toba
se ise odi dandan kodi olowo ni,
afoman botuje,afoman Lara ,afoman igi
mangoro,pelu oga oye ,owo 1000 tuntun pelu
,gbogbo awon kini wanyi gungun nio ,koise jijo,ao
koko pa eje oga yen sori a won nkan eroja toku
,ao koko jeki oga yen GBA awo owo 1000 yen ,ti
aba gun tan ,ao Sa tiyio GBE ,ao ri wipe ori
lubulubu bi elubo ,ao da si ona meji ,toba di ojo
alaruba , ao sofun a won alfa Oni hantu
kiwanbawa han ayayi si ona meji ototo.
aya na niyi
ﺍﻧﻤﺎ ﺍﻣﺮﻩ ﺍﺫﺍ ﺍﺭﺍﺩ ﺷﻲﺀﺍ ﺍﻥ ﻳﻘﻮﻝ ﻟﻪ ﻛﻦ ﻓﻴﻜﻮﻥ 70
times
ao hansi ona meji ototo
toba wadi oru ale Wednesday eyi tinse oru
majuma Thursday ago kan ,ao mu hantu alakoko
Peru did a idakan Ogun ti apinsi ona meji sinu
hantu na ,ao gbemu toba tunwa di ago kan osan
Thursday ao tun fo hantu ikeji pelu dida Ogun
kan toku sinu ohun na ..
akiyesi, omi ojo laofi fo hantu na ,aso funfun ni
aowo ni ojo Thursday...
osole yi damiloju pupo ,fun
alaye epemi sori number MI ,07087774041 or
08091466676
owo akoko ti osole yi ba gbewa ,aofi die se Sara
nibe .iba olohun..iba a won to koko jawe ,iba
awon iyami osoronga |
Re: .. by horlakunmy: 8:26am On Aug 23, 2017 |
Ogun owo tikoni ipalara ,ewe owu akese oojo ,ESO Lara pupa,ao gun man ose dudu ,sosorobia ni aofi po ose na ,ao GBE eja ojiji aye tele igba ti ao ko ose na si ,so bere si we ose na leyin 16days ,eje ako eyeiele funfun laopasi ara igba ose na,,,,,fun ekunrere alaya pemi sori number yi......07087774041 or 08140444773.
|
Re: .. by dplanner: 8:49am On Aug 23, 2017 |
Osole owo nla fun enikeni to daju gan......... A o han suratul yasin lona 9, eye onbe 9, okan malu ti ko womi kan, a o lo eye onbe yi lubulubu, a o fi omi ojo fo hantu yi ti a o fi okan malu yi je lepo niyo ise to daju ni iwo to ba Fe se ise yi kan si mi ni ori ero ibani soro 07067796292, 07055595911. |
Re: .. by horlakunmy: 8:57am On Aug 23, 2017 |
Ogun eniti oro re ko lojutu ,asina tipatipa,ewe ajeobale to rele 16,omudun re 16,eyi tofe jabo tiko kanle 16,iyere 16,Ata ijosi 16,eyin adie mefa,isasun tuntun,aseje ,ojo Thursday tabi Tuesday or Monday or Sunday. call me 07087774041 or 08140444773.
|
Re: .. by horlakunmy: 8:59am On Aug 23, 2017 |
if u have red or white liquid MECURY contact me 07087774041... |
Re: .. by horlakunmy: 9:00am On Aug 23, 2017 |
to change your red or white liquid MECURY contact 07087774041 |
Re: .. by horlakunmy: 9:03am On Aug 23, 2017 |
for your red or white liquid MECURY ,we don't sell oo ,contact 07087774041 |
Re: .. by horlakunmy: 9:04am On Aug 23, 2017 |
need operator for red and white liquid MECURY..07087774041 |
Re: .. by horlakunmy: 9:06am On Aug 23, 2017 |
did u have red and white MECURY ?08087774041. no play oo |
Re: .. by horlakunmy: 4:06pm On Aug 24, 2017 |
Ogun owo gbewa to dami loju gidi ,,eja ojiji aye meji ,afoman laali,afoman Lara,afoman obi abata ,ewe aje tutu,ewe owu akese , lofinda Bintu Sudan original,Ao gun gbogbo kiniyi papo pelu eja ojiji kan ,ao kowan man ose funfun,lofinda yen laofipo ose yan,eja keji laotele igba taoko ose si ,ao pa akuko funfun kan fun ose na,aofi adie nase Sara,eni tiyiolo ise kogbodo lo nibe ,leyin ojo meje laofi bere sifi ose yi,,,call me if u have any question , 07087774041....08091466676 |
Re: .. by dplanner: 11:30am On Aug 27, 2017 |
ise fatiah fun iso ati arisiki ti a mo bo mole to daju o n bo lona laipe . |
Re: .. by fredo360(m): 9:02pm On Sep 01, 2017 |
ekun deede asiko yi o oruko mi no Taye eejo kini eniyan le lo ti nkan omokunrin ba kere ju ojo orie lo. ejowo mo fe kii edami lohun ki oju maba timi oooh |
Re: .. by Opeexy(m): 11:54pm On Sep 17, 2017 |
Baba ejowo kini itumo lilopo ti a o fi pa eyin adie na lara |
Re: .. by Whitty1992: 9:38am On Sep 24, 2017 |
Harjibode: |
Re: .. by fatus2210: 3:17pm On Oct 03, 2017 |
tundebadmus:ejo ewo WO ni ise yi ni |
(1) (2) (3) ... (90) (91) (92) (93) (94) (95) (96) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 60 |