Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,380,047 members, 5,306,919 topics. Date: Sunday, 08 December 2019 at 03:13 PM

.. - Culture (3) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1573178 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (97) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Nobody: 9:46pm On Apr 30, 2015
E seun gan fun idaun yin.
Re: .. by Nobody: 7:44am On May 02, 2015
...

1 Like 1 Share

Re: .. by Nobody: 10:36am On May 02, 2015
...

3 Likes

Re: .. by Nobody: 12:27pm On May 02, 2015
Ewe ati egbo yi o ma je.

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:54pm On May 02, 2015
walexy30:
Ewe ati egbo yi o ma je.

Ase Wa!
Re: .. by absoluteSuccess: 7:34pm On May 02, 2015
healthFirst:


Ayeta, Tidi jo, Asaki Ibon, Afobon, Afeeri, Egbe, Isuju to daju daada wa sugbon ao le fi sile lori afefe nitori awon eni ibi igara olosa...e ma binu.

awon eniyan buburu ti ba eniyan rere je, o se.
Re: .. by Nobody: 11:29am On May 03, 2015
Ejoor, seh e ni oogun afose?
Re: .. by Nobody: 7:20pm On May 03, 2015
Jadonjack:
Ejoor, seh e ni oogun afose?


Beeni...o wa lorisirisi sugbon ki le fe lo fun?
Re: .. by Nobody: 3:19pm On May 04, 2015
...

3 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 6:14pm On May 04, 2015
healthFirst:Beeni...o wa lorisirisi sugbon ki le fe lo fun?

Mo kan leero pe oye kamoo nooni oo. Sugbon tie ba lero pe koye ke fi sori afefe, ema fisi ooo
Re: .. by Nobody: 9:00pm On May 04, 2015
Jadonjack:


Mo kan leero pe oye kamoo nooni oo. Sugbon tie ba lero pe koye ke fi sori afefe, ema fisi ooo

O da...a ma fi sita laipe
Re: .. by Nobody: 4:28pm On May 06, 2015
Ejowo, mo nilo ogun ikiya.. Aya mi man tete jah ju
Re: .. by Nobody: 10:35am On May 07, 2015
E JOWO, TI OWU ALANTAKUN BA NKO ENIYAN LOJU ATI OWO NI GBAGEDE, IRU IPA WO LO NKO NI IGBESI AIYE ENIYAN ATI WIPE KINI ONA ABAYO.

NITORI MO GBO WIPE O NI NKAN TI AWON BABA WA MA NSE LAIYE IJOUN SI IRU NKAN BAYI.

E JOWO , E BA WA SE IWADI LORI RE, NITORI EYI NFA IFASEYIN FUN OPOLOPO ENIYAN. E SE.
Re: .. by Nobody: 10:03pm On May 07, 2015
...

1 Like

Re: .. by Nobody: 10:56pm On May 07, 2015
...

3 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 8:04am On May 08, 2015
[quote author=healthFirst post=33411411]19 IFUNPA YI SISE FUN OWO O TUN SISE FUN TI OPO ENIYAN BA FE BA WA JA

Ipe Oore meje ori ikun nla kan akisa. Ori ataan odidi ataare kan. Ao so akisan na si inu omi ao jo awon eroja yoku ti o ba ti fe jo tan, ao yo akisa na, ao ju si inu ogun na... ti o ba wa jo tan ao bu si inu aso funfun, ao di ni owu dudu ati funfun ao wa lo ran ni odi awo funfun ni ifunpa... ogun yi sise fun owo, amo ti won ba fe ba wa ja ao ma fi owo yi ifunpa yi ao ma pe ofore si.... ikun loni ki apa okun yin. Oore loni ki oore yin wesi. Bi akisa ba bo somi wesi nire. Won a kan ma wo booo ni, won koni le se ikankan fun wa titi ao fi koja !!!
[/edakun se gbo gbo ebuyi lamalo fun iyokan abi abu die nibe ni

6 Likes 1 Share

Re: .. by kadunasouth(m): 8:17am On May 08, 2015
Mokiyin pupo
Edakun se gbogbo ebuyi lamalotan lekan soso abi ale budie ninure tamafi ebu kan se si bi ona meta
Re: .. by Nobody: 2:15pm On May 08, 2015
healthFirst:


OGUN IKIYA FUN ENI TI AYA RE N JA-
Oko sango, a o fi sinu ina. Ti o ba gbona daada a o ju sinu epo pupa die. To ba tutu, a o yo ninu epo yen. A a wa da epo yen sinu ekuru ti a ti fo, ao po mo, a. A wa je e.

Sugbon Ikilo kan wa...Bi Oogun yi ba wa lara wa, Oogun Egbe ko ni sise nitoripe bi aya wa ko ba ja nigbati ohun eru ba sele, Oogun Egbe ko ni sise.

Ese pupo. Ejoor, bi odun melo ni o ma lo lara eeyan ko to baje, ati pe kin tun ni ohun to le ba oogun yi je lara eeyan? Atipe, bawo ni mo sele ri okuta sango? Emi gangan ni mo fee lo oogun yi. Ejoor e ran mi lowo. ESE GAN!!!

2 Likes

Re: .. by Nobody: 9:03pm On May 08, 2015
healthFirst:


ha! inkan te beere yi lagbara pupo...ni soki, onitohun ni lati tera mo ise Ebe awon Agba kiakia....gege bi eyin na ti se alaye, ifaseyin nla ni...ayafi ki a be awon agba ki won yonu si wa.

OGUN IMULE TI AJE ATI OSO FIN JAWO LARA ENI TABI TI WON BAN DINI LOWO IRE ENI
Awo'ekun'die, Ewe'afomo'ishana'die, Eyele'dudu kan, Odidin'atare'kan, Ikoride'kan, Iye'agbe'kan, Iye'aluko'kan, Ao mu eyele'dudu yen lai ti ku, Ao ti iye agbe bo eyele yen nidi titi iye'agbe yen yio fi yo jade lenu eyele'dudu yen die , Ao wa ti iye'aluko bo oju'otun eyele yen titi yio fi jade loju'osi eyele'dudu yen die, Ao wa ti ikoride yen bo oju'osi eyele'dudu yen titi yio fi jade loju'otun eyele'dudu yen die, Ao wa jo won papo pelu awo'ekun ati ewe'afomo yen, Ao wa te ifa osa'da'meji si ori'ebu yen, Ao wa pe ofo're si, LILO'RE: Ao bora si ihoho omoluabi ninu iyara wa, Ao wa ta epo'pupa si enu ona inu iyara wa, Ao wada ebu eyele'dudu yen die si ori'epo'pupa yen, Ao wa sun sile, Ao se adura si, Ao wa fi ahon laa epo ati ebu yen, IKILO: Ahon ni ao fila.

OFO'RE
Akin'soro'3xs, Atobo'seje'idi' iya'aje'3xs, Olubeleje'idi' iya'aje'3xs, Awon meteta parapo odi ori'tameta'ele, Won kuro nibe, Odi ile omo olotu'ife, Won dele omo olotu'ife, Won ba gbogb ohun ini omo olotu ife'je, Won kuro nibe, Odi ile omo orunmila, Orunmila kigbe'tooo, Oni rara'ooo, Won ni awon yoo ma ba omo orunmila gbe ile, Orunmila ni ki won'o'bura fun owun, Akin'soro'lo'koko bura, Oni ti owun ba ba inkan ini omo orunmila je, Ki oju'otun owun kio relede owun, Ti owun koba jawo nibe, Ki oju osi owun kio relede owun, Ti owun koba jawo nibe, Ki owun ma po eje lenu titi owun yio fi po gbogbo ifun inu owun jade teje'teje, Atobo'seje idi'iya'aje na bosibe obura be fun orunmila, Olubeleje'idi'iya'aje na bosibe obura be fun orunmila, Emi omo lagbaja omo lagbaja di omo orunmila loni, Toso'taje ilu kie ma bowo fun mi, ki e mase ba ise owo mi je mo, ki e fori jimi, ki e je ki gbogbo idawole mi yori si rere ni tori modi omo orunmila loni'ooo.

NB ODU IFA OSA LOWO OTUN ATI NI OWO OSI. NI WON PENI ODU OSA TOWA LONA MEJI! LAN PENI OSA'DA'SI'MEJI.

E SE PUPO

3 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 12:08pm On May 09, 2015
Jadonjack:


Ese pupo. Ejoor, bi odun melo ni o ma lo lara eeyan ko to baje, ati pe kin tun ni ohun to le ba oogun yi je lara eeyan? Atipe, bawo ni mo sele ri okuta sango? Emi gangan ni mo fee lo oogun yi. Ejoor e ran mi lowo. ESE GAN!!!


A le ri Okuta Sango ni leele a si tun le ri ra lodo awon elewe omo. E le maa se Oogun yi ni bi Odun meta meta.

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:09pm On May 09, 2015
kadunasouth:
Mokiyin pupo
Edakun se gbogbo ebuyi lamalotan lekan soso abi ale budie ninure tamafi ebu kan se si bi ona meta

Beeni, gbogbo e la nilati lo leekan

2 Likes

Re: .. by Nobody: 11:08pm On May 09, 2015
kadunasouth:
Iyonu Odaju

Enu opiye alubosa elewe eru alamo oko atare kan ao gun po aso egun ori adi epo ao fi orun yo ao fi aso egun tele konjo (idi konjo na kogbodo kanle alegbesi inu roba ao mafi para).

OFORE
Ojoti adi bafi oju kan orun ojona ni oro inure yo, ojoti epo ori bafi ojukan orun ojona ni oro inure yo Atewe Atagba ni teriba fun Egun ki omode ati Agbalagba ki wan o ma teriba fun emi (L omo L).
Contact[s] [/s]

Rara o, ao fe aago lori ibi o. e jowo e yo ero ibanisoro yen kuro kiakia.

3 Likes

Re: .. by Nobody: 6:28am On May 11, 2015
healthFirst:


A le ri Okuta Sango ni leele a si tun le ri ra lodo awon elewe omo. E le maa se Oogun yi ni bi Odun meta meta.

Eseun gan
Re: .. by Nobody: 9:41am On May 11, 2015
[quote author=kadunasouth post=33578685]Iyonu Odaju

Enu opiye alubosa elewe eru alamo oko atare kan ao gun po aso egun ori adi epo ao fi orun yo ao fi aso egun tele konjo (idi konjo na kogbodo kanle alegbesi inu roba ao mafi para).

OFORE
Ojoti adi bafi oju kan orun ojona ni oro inure yo, ojoti epo ori bafi ojukan orun ojona ni oro inure yo Atewe Atagba ni teriba fun Egun ki omode ati Agbalagba ki wan o ma teriba fun emi (L omo L).
Contact [/quo
E joo e ba wa yo ero ibanisoro yi kuro tabi ki n fi ejo yin sun awon oludari

3 Likes

Re: .. by Lionhearted: 4:30pm On May 11, 2015
Eku ise o.
Ki le yan le lo toba ni yeast infection/candida to tipe lara?
Re: .. by OROSUNBOLB(m): 10:27pm On May 11, 2015
Mo gbadun abala yi gan ni o! Odua afewonro yio gbe wa o! E da kun e ma je ki o re yin o. Opolopo anfani ni a ti ri je ninun e. Yi o si tun je ki imon ewe ati egbo ki o kun si. Aboru,boye o Baba!
Re: .. by Nobody: 12:33am On May 12, 2015
...

2 Likes

Re: .. by Nobody: 12:35am On May 12, 2015
OROSUNBOLB:
Mo gbadun abala yi gan ni o! Odua afewonro yio gbe wa o! E da kun e ma je ki o re yin o. Opolopo anfani ni a ti ri je ninun e. Yi o si tun je ki imon ewe ati egbo ki o kun si. Aboru,boye o Baba!

Aboru Bo sise. E seun o.
Re: .. by Nobody: 12:51am On May 12, 2015
..

1 Like

Re: .. by Nobody: 1:21am On May 12, 2015
..

1 Like

Re: .. by Lionhearted: 3:28am On May 12, 2015
healthFirst:


OOGUN ARUN OJU ARA OBINRIN(candida/yeast infection)
Ao wa Ewe Urere ati Ewe Abamoda...Ao gun won po daada, ao fun omi re pelu adin...ao maa fi pa oju abe wa titi ti arun na yio fi lo.

Ki Obinrin na kiyesara nipa lilo ile salanga to je ti gbogbo eniyan ati beebe lo.

Eseun gan ni.

Ogun la le lo fun Oral thrush ati te 'yan ba ni blocked sinuses?

2 Likes

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (97) (Reply)

Viewing this topic: 2 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2019 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 86
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.