Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,381,629 members, 5,312,662 topics. Date: Wednesday, 11 December 2019 at 06:48 PM

.. - Culture (4) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1574031 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (97) (Reply) (Go Down)

Re: .. by bright991: 8:26am On May 12, 2015
.
Re: .. by Nobody: 10:10am On May 12, 2015
Lionhearted:


Eseun gan ni.

Ogun la le lo fun Oral thrush ati te 'yan ba ni blocked sinuses?

Oral Trush....Ifun Enu ati Blocked Sinuses...Osi Imun ati ti Aya...A ma post won ti n ba pada de Ile.
Re: .. by Nobody: 10:14am On May 12, 2015
bright991:


Ekuse baba, ejowo njeni ogun yii lowo fun tita.

Mo mon wipe awon kan le wa ti won ko ni le se awon Oogun yi funrawon...bi e ba fe ki n ba yin se, e e-mail mi, e joo ori abala yi kii se fun ipolowo oja.

Sugbon, e gbiyanju lati se funrayin...Ipara yen dara pupo fun ebe awon agba. E lo si odo awon elewe omo, ki e beere awon eroja Oogun te ba fe se...bi e ba ra lowo won, e le be won ki won ba yin jo won papo tabi gun won po ki e to kuro nibe.

1 Like

Re: .. by Nobody: 11:03am On May 12, 2015
..

3 Likes

Re: .. by OROSUNBOLB(m): 12:03pm On May 12, 2015
E ku ise o Baba. E da kun ki ni ale lo si idi yiyo ti yio fi wole pada? E seun o.
Re: .. by Nobody: 1:22pm On May 12, 2015
...

1 Like

Re: .. by Nobody: 2:37pm On May 12, 2015
healthFirst:
21 OOGUN AWURE TO NJE BI IDAN
Oku Oga kan, ao fi ko Okun Alantakun ti yio bo lara tan patapata, ao jo pelu odindi ataare kan, a o lo kuna daada, ao wa te nifa Eji Ogbe...ao pe ofo re si:

Ofo Re: Bi idan bi idan ni Oga se n gba aso alaso wo, bi idan bi idan ni Alantakun se n ran owu tire, ire owo otun, ire owo osi, ire obinrin, ire okunri, ki won pa ori po wa ba emi lagbaja omo lakasegbe(Ao da oruko ara wa) loni.

Lehin ti a ba pe ofo si tan, ao da sinu ipara wa, ao ma fi para.

Ejoor, sehbi jankariwo ni owu alantakun? Atipe, seh oga to ti ku fun ojo pipe abi eleyi to sese ku ni kia lo?

2 Likes

Re: .. by Nobody: 2:49pm On May 12, 2015
Jadonjack:


Ejoor, sehbi jankariwo ni owu alantakun? Atipe, seh oga to ti ku fun ojo pipe abi eleyi to sese ku ni kia lo?

beeni, ijakariwo ni a n pe ni owu alantakun. ko sa ti je oku Oga

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:10pm On May 12, 2015
healthFirst:


beeni, ijakariwo ni a n pe ni owu alantakun. ko sa ti je oku Oga

Eseun

1 Like

Re: .. by ejidewa87: 8:22pm On May 12, 2015
E dakun se e le ko wa ni ogun ife
Re: .. by bright991: 9:32pm On May 12, 2015
.
Re: .. by Nobody: 11:59pm On May 12, 2015
..

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:26am On May 13, 2015
..

3 Likes

Re: .. by OROSUNBOLB(m): 2:49am On May 13, 2015
healthFirst:


OOGUN IDI YIYO
Kanfo pelebe eyo kan, koro isin eyo kan, ao lo po mon Ori...ao ma fi pa idi to yo na...yio wole pada kiakia.

E seun o baba. Ewe a ma je o.

5 Likes

Re: .. by Lionhearted: 4:53am On May 13, 2015
healthFirst:


OOGUN IFUN ENU(ORAL THRUSH)

Ewe Sayo, Eepo Olobotuje, Eepo Igi Awun, Eriru...ao se won po...yiyo mu diedie.OOGUN OSI IMUN(BLOCKED SINUSES)

Eepo Igi Obo, ao lo pelu papamilolo, ao kan Oje Igi Oro sii...ao lo won po daada, ao ma fi si imun wa.

Eseun gan ni.

Se gbogbo awon nkan won yi la le ri ra?

2 Likes

Re: .. by Nobody: 9:27am On May 13, 2015
Lionhearted:


Eseun gan ni.

Se gbogbo awon nkan won yi la le ri ra?

Beeni...opolopo ninu awon egbogi wonyi lo wa ni agbegbe wa sugbon a le ri won ra lowo awon elewe omo.

1 Like

Re: .. by scholes0(m): 10:48am On May 13, 2015
healthFirst:


Beeni...opolopo ninu awon egbogi wonyi lo wa ni agbegbe wa sugbon a le ri won ra lowo awon elewe omo.

Tabi ni odo awon ti o ba n ta "iwoshiwoshi" ni oja..... cheesy
Eni ti o ba fe ra ori tabi Iru agemo gan a ri nibe....

2 Likes

Re: .. by Nobody: 1:06pm On May 15, 2015
BELEJE

E teti beleje o,
ke gbohun tawo o gbodo se,
Awo kii paro o.
Awo kii dale awo.
Awo kii san bante awo egbe re o.
Egbe re laake o.
Eegbe re looko o.
Egbe re lola.
Tofi dele owa orangun olomo.
Oogboye o!.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 1:14pm On May 15, 2015
...

1 Like

Re: .. by Nobody: 3:40pm On May 15, 2015
Ejorwo, e maa so awon eewo ti awon ogun yi ni fun wa kia le ma kiyesara ti a ban se won

1 Like

Re: .. by Nobody: 5:20pm On May 15, 2015
Jadonjack:
Ejorwo, e maa so awon eewo ti awon ogun yi ni fun wa kia le ma kiyesara ti a ban se won


Awon eewo ti o wa nidi Oogun sise wa looto...ninu re ni wipe bi Oogun ba wa lara wa, ko dara ki a sun mo Obinrin to ba n se nkan osu lowo. Omiran ni wipe bi a ba n gun tabi jo Oogun lowo, Omo Olo ti a fi nlo Oogun yi ko gbudu duro lori Oogun na tabi Omo Odo ti a fi n gun Oogun ninu Iya Odo ko gbudo duro lori Oogun ti a n gun lowo ninu Odo.

Ao ma ko won sita ni bi a ba se ranti. E joo bi eyin na ba mon lara awon eewo wonyi, e ko sita fun wa.

Sugbon awon eewo to ro mo oogun kookan wa loto...Oogun to ni eewo tire loto, ao ko pelu re.

3 Likes

Re: .. by gawab: 2:12pm On May 16, 2015
healthFirst:


ha! inkan te beere yi lagbara pupo...ni soki, onitohun ni lati tera mo ise Ebe awon Agba kiakia....gege bi eyin na ti se alaye, ifaseyin nla ni...ayafi ki a be awon agba ki won yonu si wa.

OGUN IMULE TI AJE ATI OSO FIN JAWO LARA ENI TABI TI WON BAN DINI LOWO IRE ENI
Awo'ekun'die, Ewe'afomo'ishana'die, Eyele'dudu kan, Odidin'atare'kan, Ikoride'kan, Iye'agbe'kan, Iye'aluko'kan, Ao mu eyele'dudu yen lai ti ku, Ao ti iye agbe bo eyele yen nidi titi iye'agbe yen yio fi yo jade lenu eyele'dudu yen die , Ao wa ti iye'aluko bo oju'otun eyele yen titi yio fi jade loju'osi eyele'dudu yen die, Ao wa ti ikoride yen bo oju'osi eyele'dudu yen titi yio fi jade loju'otun eyele'dudu yen die, Ao wa jo won papo pelu awo'ekun ati ewe'afomo yen, Ao wa te ifa osa'da'meji si ori'ebu yen, Ao wa pe ofo're si, LILO'RE: Ao bora si ihoho omoluabi ninu iyara wa, Ao wa ta epo'pupa si enu ona inu iyara wa, Ao wada ebu eyele'dudu yen die si ori'epo'pupa yen, Ao wa sun sile, Ao se adura si, Ao wa fi ahon laa epo ati ebu yen, IKILO: Ahon ni ao fila.

OFO'RE
Akin'soro'3xs, Atobo'seje'idi' iya'aje'3xs, Olubeleje'idi' iya'aje'3xs, Awon meteta parapo odi ori'tameta'ele, Won kuro nibe, Odi ile omo olotu'ife, Won dele omo olotu'ife, Won ba gbogb ohun ini omo olotu ife'je, Won kuro nibe, Odi ile omo orunmila, Orunmila kigbe'tooo, Oni rara'ooo, Won ni awon yoo ma ba omo orunmila gbe ile, Orunmila ni ki won'o'bura fun owun, Akin'soro'lo'koko bura, Oni ti owun ba ba inkan ini omo orunmila je, Ki oju'otun owun kio relede owun, Ti owun koba jawo nibe, Ki oju osi owun kio relede owun, Ti owun koba jawo nibe, Ki owun ma po eje lenu titi owun yio fi po gbogbo ifun inu owun jade teje'teje, Atobo'seje idi'iya'aje na bosibe obura be fun orunmila, Olubeleje'idi'iya'aje na bosibe obura be fun orunmila, Emi omo lagbaja omo lagbaja di omo orunmila loni, Toso'taje ilu kie ma bowo fun mi, ki e mase ba ise owo mi je mo, ki e fori jimi, ki e je ki gbogbo idawole mi yori si rere ni tori modi omo orunmila loni'ooo.

NB ODU IFA OSA LOWO OTUN ATI NI OWO OSI. NI WON PENI ODU OSA TOWA LONA MEJI! LAN PENI OSA'DA'SI'MEJI.
E jowo asiko ni enia le lo egbogi yi?
Se enia le lo losan?
Se gbogbo ebu ti a jo ni a o lo lekan na?

1 Like

Re: .. by Nobody: 2:43pm On May 16, 2015
healthFirst:Awon eewo ti o wa nidi Oogun sise wa looto...ninu re ni wipe bi Oogun ba wa lara wa, ko dara ki a sun mo Obinrin to ba n se nkan osu lowo. Omiran ni wipe bi a ba n gun tabi jo Oogun lowo, Omo Olo ti a fi nlo Oogun yi ko gbudu duro lori Oogun na tabi Omo Odo ti a fi n gun Oogun ninu Iya Odo ko gbudo duro lori Oogun ti a n gun lowo ninu Odo.

Ao ma ko won sita ni bi a ba se ranti. E joo bi eyin na ba mon lara awon eewo wonyi, e ko sita fun wa.

Sugbon awon eewo to ro mo oogun kookan wa loto...Oogun to ni eewo tire loto, ao ko pelu re.

Oda, eseun

2 Likes

Re: .. by nisai: 3:36pm On May 17, 2015
Kepe baba.Ejowo se ele fun mi ni aparun ati apagun?
Re: .. by gawab: 9:27am On May 18, 2015
gawab:
E jowo asiko wo ni enia le lo egbogi yi? Se enia le lo losan? Se gbogbo ebu ti a jo ni a o lo lekan na?
Re: .. by Nobody: 10:27am On May 18, 2015
healthFirst:Awon eewo ti o wa nidi Oogun sise wa looto...ninu re ni wipe bi Oogun ba wa lara wa, ko dara ki a sun mo Obinrin to ba n se nkan osu lowo. Omiran ni wipe bi a ba n gun tabi jo Oogun lowo, Omo Olo ti a fi nlo Oogun yi ko gbudu duro lori Oogun na tabi Omo Odo ti a fi n gun Oogun ninu Iya Odo ko gbudo duro lori Oogun ti a n gun lowo ninu Odo.

Ao ma ko won sita ni bi a ba se ranti. E joo bi eyin na ba mon lara awon eewo wonyi, e ko sita fun wa.

Sugbon awon eewo to ro mo oogun kookan wa loto...Oogun to ni eewo tire loto, ao ko pelu re.

Eruwadaji!

Eku ise, Olodumare a ma ro yin l'agbara.

Ni afikun si awon eewo ti eti ko won yi:

1. A ko gbudo ni ibalopo rara ti a ba fe gun, jo tabi lo oogub (boya ni nkan osu tabi mimora).

2. Obinrin to ba nse nkan osu ko gbudo fi pwo kan eroja ogun kan kan tabi nkan ti a ba fe fi gun, ge tabi lor. Kosi tun gbudo fi owo or ara kan oogun taba ti pese tan.

Ni tootor, oogun kankan ni eewo re ti a ban ja ewe re, ti aba fe gun, jo tabi lor, ati eewo lilo naa. Boya ki eku ma fi awon eewo si ese awon oogun ti e kor si ori ibibi.

3 Likes

Re: .. by Nobody: 11:43am On May 18, 2015
gawab:

E jowo asiko ni enia le lo egbogi yi?
Se enia le lo losan?
Se gbogbo ebu ti a jo ni a o lo lekan na?

Asiko to ba wun wa la le se Oogun yi sugbon bi ba se nise temi ni, Oru Oganjo ni o dara ju.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 4:05pm On May 18, 2015
..

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:13pm On May 18, 2015
..

6 Likes 2 Shares

Re: .. by mhicrotee: 5:19pm On May 18, 2015
E jowo mo nilo iranlowo yin,ara ile mi kan nse aare(she is sick),mo de waa funra pe ti mo ba daa ina tan yio waa mu eyin ina(hot charcoal) ti mo fi dana kuu,e jowo se ko si ewu nibe(Am I safe)? e jowo e dahun Kia kia
Re: .. by scholes0(m): 5:56pm On May 18, 2015
healthFirst:
AWON OJU ODU MERINDINLOGUN(THE PRINCIPAL OJU ODU)

Haa!! Imo ati asa Yoruba leke, O ta gbogbo awon iyoku yo.
Re: .. by scholes0(m): 6:00pm On May 18, 2015
mhicrotee:
E jowo mo nilo iranlowo yin,ara ile mi kan nse aare ,mo de waa funra pe ti mo ba daa ina tan yio waa mu eyin ina ti mo fi dana kuu,e jowo se ko si ewu nibe(Am I safe)? e jowo e dahun Kia kia

shocked shocked

1 Like

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (97) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2019 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 127
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.