Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,153,551 members, 7,819,957 topics. Date: Tuesday, 07 May 2024 at 07:25 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (197871 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (38) (39) (40) (41) (42) (43) (44) ... (100) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 10:46pm On Jul 18, 2009 |
IFELEKE: O see jare, eniyan mi, opin ose nflenjo, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:03pm On Jul 18, 2009 |
IFELEKE:LOL. P.A e koti de bi o. Nitori e ni mo fin nlo si diner. As to the YIM, sure. Leave your thingy in your profile, I'll let you know when I get it |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:00am On Jul 20, 2009 |
IFELEKE: Iro lo pa joo. Kini e o tii le di omo Nitorinaa emi ni mo ni oyun |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:09am On Jul 20, 2009 |
PERVERT9: Eyin ara mi ninu tireedi yi, ti mo ba so fun yin pe ina njo nibi kan, e ni ki nko eeru e wa. Nigba ti mo so fun yin ni ijo kinni ana pe ifeleke ti ni iyawo (bi o tile je pe kole fun un loyun nitoripe epon e o tii gbo ) e ro pe iro ni mo npa. Se o tan abi ko tan Imoran fun ore mi Ifeleke: Ma se je ki toyin tan e. Bi mo se n te kiboodu yi, toyin ti ngbe ninu ile temi. Iba san ti o ba le lo ba SIKIRATU BEBEDI nitoripe o feran re tokan tokan. Ko si ni dara ki o padanu iru ife nla yi ati awon akitiyan ti o ti se lati rii pe fe omo naa Ire o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 9:24am On Jul 20, 2009 |
debosky: Ohun ko o Emi ni mo ni oyun yen o. Je ki nwa so kini kan fun o, obinrin meji ni o wa ninu toyin bi a se nsoro yii. Emi ni mo mo nkan ti mo to sibe nau . Bi a se nsoro yi, mo se je iyan akanilaya kan ti toyin gun fun mi laaro yi ni. Se ewa rii pe ifeleke kan nse lasan ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 11:27am On Jul 20, 2009 |
PERVERT9:pafati, tope-lobi ni ko'o dari leta e yen si. Emi o kin le awon omo kekeeke kiri bi ore mi tope Nipa kini abe e to n yun e, lo fi ose soda fo ko de fi acid we'e. topsy25:Ogbeni tope, awe ja'wo l'apon ti o yo, ko'o lo gb'o mi ila kana!. Kete rin o n lori tireedi yi mo fo aya mi ni toyin' i' se,on mo fo oyun mi le'e ninu toyin, kuo ye'e dorare laimu!. Gbogbo kuru-kere ti owo ati bobo oni demerol(pafati) yi n se ni mori sugbon ko le da'arin emi ati toyin mi ru. lo gba oyun risika, ye toju bo iyawo oni yawo kiri adugbo! topsy25:se loju ala? abi we'e sun ni? FL Gators:Ehen! P.A mi o ti de odo e ke? I am going to fire him right away! pele bawo ni? se wahala yen o poju fun iwo ati awon babies sha? on YIM,I removed it from my profile when i started getting ridiculous mails and messages from fraudsters. . .its luv4real003 . @gbogbo ile(tope,debo.pafati,toyin,tubabie,remii,dami-re,ajenti et al) Eku ojumo oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:48am On Jul 21, 2009 |
IFELEKE:Okiez Dokiez, got it. But who are you loffing for real? @topsy topsy, o ri mi, o si ki mi. se bee ni in un okirin Ondo se n se si olufe wan? o ti ko mi fun omoge ye, se bee le se ri? [my oh my, I'm so proud of myself. IFELEKE, that last 2 sent to topsy was good right! ] *clap clap* |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:42am On Jul 21, 2009 |
FL Gators: Tani o ro pe ifeleke nife e bikose Sikiratu Bebedi FL Gators: Adumaradan temi nikan, Bawo ni mi o se ni ki e Sebi odo mi ni o sun moju ana Nkan ti o je ki nki e niyen o, nigbati o jepe a sun ti ara wa moju a tun fi enu ko enu laaro ana, ki lo tun ku Sugbon, bi o ba je pe mo ti se o nipa pe mi o ki e lori tireedi, jowo ma binu si mi. Se iwo o mo pe ekuro mi ni alabaku ewa e ni Yooba ni bi igbin ba fa ikaraun a telee; ibi ti oloomi ba koju si nibe gan an ni ona mi gba lo Se iwo ti gbagbe ni, pe ife eyele ni mo ni si e, kii se ti adaba rara. Eyin oju mi lo je o, bi enikeni ba fowo kan o (eeyan bi ifelepon), yio ru igi oyin ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:59am On Jul 21, 2009 |
Eyin ara mi ninu tireedi yi, e bami dupe lowo Eledumare o nitoripe oro mi ti di ayo. Ni osan ana ni Ifeleke dede pe mi si ori aago ilewo mi (GSM) ti o si bere si nbe mi ti o si ntoro idariji ni odo mi. Oro yi je kayefi si mi, ni mo wa bii pe kilo sele. Lo ba ni ki nma binu pe ohun nba mi du iyawo pe ohun si ti jawo ninu iwa buruku bee. Iyalenu ni eleyi je fun mi, ni mo ba bii pe kilo ri ninu obe ti o fi wa iru sowo. Gbara to maa dahun, o ni awon agba meta kan ni won yo si ohun ni oju orun ti won si ki ohun nilo gidigidi pe ki nba mi du iyawo o. Ni oju orun yii ni won ti naa ni egba meje Won si so siwaju sii pe bi o ba jawo, bi yio se maa je egba awon aye ni ojoojumo niyen. E jowo e ba mi dupe lowo baba Goodu |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 9:49am On Jul 21, 2009 |
topsy25:tope-lobi, awe, ye'e tanrora e je, we e se lasan ni!. ati ki oje'e toyin bo'oloosha emi ifeleke lo wo o ku baba n la eni keni to ma a bo!, risika ni ko lo ma a ka gbogbo ewi ati atotonu to n se yi si. Emi o ki n paruwo rara, olorun ti fi ere si ise takun takun mi lori toyin pelu oyun ibeji lanti lanti to wa ninu aayo mi. E pa'a re o gboro mo, toyin ti di temi titi lai,jawo lori owo ti o ni pe e! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 10:16am On Jul 21, 2009 |
Gbogbo ile, se dada l'ewa? Debo, ololufe mi se dada lo wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 10:41am On Jul 21, 2009 |
topsy25:;DErin e n pami sha Ore, gbogbo ala ko lo ma n se(not all dreams come true and definately not this one of yours). Mo mo wipe nkan gidi wu e, sugbon to o ba na owo sori risika to'o fun loyun wa'a ri pe omo na daa di e instead to fi n fi iyawo oniyawo lala (instead of dreaming about another man's property) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 11:09am On Jul 21, 2009 |
FL Gators:iyawo mi atata,adumaradan,eleyin ege,aayo ifeleke bawo ni? se alaafia lo wa? awon ibeji mi nko? se won kick? ma da ogbeni tope yen lohun joo, o n se lasan ni. FL Gators:I opened it 6 yrs ago and it was love in the air then(or rather lust in the air) @Gbogbo Ile(toyin,ajenti,debo,tope,pafati, et al) In Okun O, Aba Rin A Gbe 'In O (Ekiti) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:26am On Jul 21, 2009 |
IFELEKE: Se eri oju aye abi e ri Otito ti nfara han die die. Eboni mi, se o ri nkan ti o jamo lowo Ifelepon "ohun ini" lasan lasan Shio!!! Se o wa ri pe omo yen kan ri e gege bi ohun ini ("puropati" abi kinni eleebo npe) ni. Nipa temi o, o ju ohun ini lo. Iwo ni eni bi okan mi, ilaji mi ti o dara ju (my better half), oluranlowo mi, angeli mi, iyun mi, alabaro mi, eni ti okan mi fe, abbl (ati bee bee lo) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 11:58am On Jul 21, 2009 |
topsy25:Gbenu so hun awe!, ye e pami lohun da! mo ti so fun e pe o kan n se lasan ni, pabo ni gbogbo kurukere e ma jasi, ko si eni to le ya emi ati aayo ati iyaafin ifeleke. oro ti mo so ti ye toyin temi nikan,iwo le ma gbiyanju asan. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:56pm On Jul 21, 2009 |
********** |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 5:36pm On Jul 21, 2009 |
faakay:ore, yoruba la n so nibi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 9:39pm On Jul 22, 2009 |
topsy25, awe mi, mii ke binu si o rara. emi nan moh pe okurin meta ni o. ku ise o @IFELEKE Mi ran message kan si o lori YIM, se o ri? Dude, you don't know how much I reallllly wanna learn my lang Eyin nule, se dede le wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 2:06am On Jul 23, 2009 |
oga oh i can barely read most of what y'all r writing ejo ta lo ma ko mi ni yooba? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 7:09am On Jul 23, 2009 |
GRIRAMA NI EDE YORUBA Akeem: Oga ooo!! Semiu wa wo nkan oo!! ha america yi afi bi ile ni ose ri oo! afi bi idi-araba ati ajegunle, e be nikan ni oti ma ri awon aafokoko ti awon eniyan da si oju titi bayi. O gbo? Ede yankee gan gan ni wan so yen oo, ********************************************************* (Ohun awon eniyan ti wan soro) Femi: Titi ti o ma fi ku! iru nkan be yen ole sele mo Shipulu: [/b]O da O da! John Lucy nko? [b]Jagunlabi: haaaaaa! John Lucifer! Elese buruku ni yen oo! Shipulu: ehen! se otan! Femi: Gbogbo yin oti e soro pa teshin clin! teshin clin yen gan! Ija ni! Shipulu: ehen o le soro pa teshin clin lo to! sugbo se nkan ti teshin clin acheieve, se mohammed ali o achieve ju be lo ni? Jagunlabi: heee! Mohammed Ali achieve ju teshin clin loto! sugbo sho mo wipe ti mohammed ali ki oto achieve nkan ti o achieve yen, ikunmu otun e fe bosi tosi. Abi iwo ro wipe lasan ni? se oro wipe oju lasan se were ni? mohammed ali ti o je elese ti o ni agabara gan! se omo nkan ni omo buruku yen ti fa si opolo ni ki oto ma lu everybody pa ni! Femi: [/b]E ta ayo ti e ma ta jor! [b]Jagunlabi: ehen, se emi ni efin pa abi? hen? eyin meteta! e pa arayin po ki e wa ta draft yi! ma fe naa yin pa ni! ************************************************************** Back to Akeem Scenerio: Akeem ko lekun! ko ko ko! Baba LandLordu: ehen? kini e fe? Akeem: E jo! A need ile ni Baba LandLordu: E ma fi ti yin dami duro! se eni owo lowo sha? Semiu: Owo wa! ($$$$) Baba LandLordu: ehen, e wo ile! iru eniyan ti yin bayi ni emi wa! Ema binu! awon eniyan jakujaku ni mo gba si ile yi tele, sugbon bi mo se ri oju ti yin, oju ti yin farabale di e, E jo! E ma binu, iru ile wo gan gan ni e fe bayi? Akeem: Ejo! Ile face me and face you ni afe! Baba LandLordu: hen? mi gboooooo? Akeem: ani ile ti owo e kani lara pupoju ******************************************************************* (Omuti subu ni ori staircase) Baba LandLordu: Oloshi ara e ori owo ile san! ti oba ti lo mu oti! gbogbo awon lonbo YAHOO nkankan ati awon GIN yen! wa ama subu kakiri gbogbo staircase. Ti o ba ku lasan? sa ra ni oku ee ooo! Olofo! ********************************************************************* E be ni ade yi ooo (Yanmu Yanmu fo kiri! hmmmmmm, hmmmmmmmm, ) Baba LandLordu: Ileyi, shalanga kan pere ni owa ni ile yi ooo Owun ni yii! e be ni e ma ma lo ooo Awon ayan ati idun nkankan wa ni ibi bayi oo, sugbon eyin ti e wa lati AFRICA, o je ki oti mo yin lara. E de ma lo gun lift oo! ti e ba gun lasan? e ma payin si be ni ooo Akeem: [/b]A gba be! ************************************************************************ (Akeem ni balcony wo aworan New York) [b]Akeem Pariwo!!!!!!!!!!: America!!!!!!!! America! America!! America ilu ola! America Ilu oro! America ibi ti gbogbo aiye pin si! haa! America! America!! E ka ro eyin ara AMERICA!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!! Semiu: Ori FOKA!!!!!!!! Akeem: beni! Ori ti ena FOKASIBE!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!! IBI NI O PARI SI NI YI!! Emi Faakay lati ilu awon omo changpin lu |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 8:55am On Jul 23, 2009 |
faakay: Fakaay, o ri ti fokasibe |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 1:41pm On Jul 23, 2009 |
argent: Ooto ni o so iyawo mi, ori e ti fokasibe pata pata. Daa daa ni mo wa aya mi owon, eleyinju eke, adumaradan, orekelewa, ololufe mi. Se wahala ise ko poju fun e sa? Mo ni ebun nla kan fun e (surprise) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:39pm On Jul 23, 2009 |
FL Gators:Ololufe mi,aaayo temi nikan, iyaafin IFELEKE bawo ni? se alaafia lo wa gege bi emi se wa nibi? awon ibeji mi nko? mo lero pe wahala yen o poju sha? ile-iwe e n ko, se o n lo deede? i'll check your message up and holla back, trust me, you'll learn @faakay Dude, you are off da hook! that is the yoruba version of eddie murphy's Coming To America. . .right? @Gbogbo Ile E n le oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 2:56pm On Jul 23, 2009 |
faakay o gbadun rara eyin ile e tie da mi lohun sha ani ta lo ma ko mi no yooba? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:16pm On Jul 23, 2009 |
@bluespice Maa ko e ni yoruba, while am learning ekiti B.T.W, gbe oju e yen kuro lodo IFELEKE. abi se oro pe mi ke ri o ni? Find debosky or faakay to teach you "yooba" . Our sistership no reach that level o IFELEKE:awww, all that for me?! Orimi ti wu well, alafia ni mi a, sugbon se ni mo n ni backpain and awan ibeji wa n ja bii pe jackie chan ni un. Okiez, holla back. Howzzzzzzzzzzzzz everyone (topsy25, ife, bluespice, argent, deboskey et all). Good morning o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 3:33pm On Jul 23, 2009 |
debosky: sweets mi mo se fe so wipe ki won ba mi wa e lo ni Ise fe shake mi die, but love e ni o je ki ma feel e rara Ebun wo niyen oh, je ki gbo bluespice: Mo ma ko e ni yoruba Bawo ni, se o wa dada? FL Gators: Why debosky ma je ki binu si e oh . O ti like ko ma pull legs mi ju @ bluespice ma da toyin lohun, ma ko e ni yoruba for free or to ba je wipe o prefer okunrin Ifeleke is readily available IFELEKE:Ifeleke, ba iyawo e soro, ki o de kilo fun gan ni. Mi o fi Debo mi se ere rara |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:52pm On Jul 23, 2009 |
IFELEKE:Beni ooo sugbon emi na tun fi awon ajasa si! bluespice: Mo gbadun oo!! ara mi ya gaga Bawo ni! emi o mo wipe omo oodua ni iwo naa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:29pm On Jul 23, 2009 |
faakay:Okare lai! Mo ri awon ajasa ti o fi kun, ogbon gidi wa lori e. argent:Mabinu aya mi, ise naa ni o mu mi jina si tireedi yii, sugbon ti mo ba tun ronu ife e si mi, mo ma sare pada ni. Ma je ki ise yen gbo e rara, ma ronu ife ti ajo ni ati ere ife ti ama se ti a ba dele. Mo ni ebun nla fun e, oruka ati ileke nla ti won fi wura (gold) da ni mo ti ra fun e lati ilu oyinbo. Mi o fi Debo mi se ere raraDaju daju oro ti o so yii oje ki ori mi wu. Ko si aya miran to dara to e ni ilu nairaland yii, ojojumo ni mo ndupe lowo Eledumare to so wa po. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:17pm On Jul 23, 2009 |
argent: looll, ori gbogbo wa ni owa foka bayi ooo argent: Argentina abi aje buredi la gege ni oruko re Ere gele wo ni e ta pelu ologbeni Debosky! debosky: Egbon mi tide!! Ekare layi!! Olori ebi! Eyin ni mo fi jo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:28pm On Jul 23, 2009 |
@argent hahaha Jor ma binu si mi. emi ke moh pe o lufe debosky beyi. mee binu si mi IFELEKE is not ready available. He's now a father to be @@post A saying goes like this "You never know what you ave until you lose it". Now I know, where's topsy25 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 7:53pm On Jul 23, 2009 |
FL Gators:Kini itumo oro ti o jabo lenu e yii? Se o ti ko ifeleke sile ni abi bawo ni o se je?? Ifeleke sure wa o, gatoosi ti nfi obe je isu e leyin o!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 8:21pm On Jul 23, 2009 |
faakay:ose ma soro rada rada bayi? awa mejeji ko la wa ni kilassi oluko goodass ni? oti sare gbagbe abi? ma lo f'ejo e sun won, wa ri amosexy ati gators eyin mejeji fe ko mi? ase mo l'eyan pataki ni bibayi oya kila ma bere pelu? awon ojo to wa l'ose? t'abi osu l'odun? |
(1) (2) (3) ... (38) (39) (40) (41) (42) (43) (44) ... (100)
Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 130 |