Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,715 members, 7,837,609 topics. Date: Thursday, 23 May 2024 at 08:13 AM

Itan Opolo - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Itan Opolo (1957 Views)

Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? / Itan Eye Odidere / Itan Ilorin Laderin (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Itan Opolo by gawab: 4:29pm On May 16, 2015
Opolo je okan ninu eranko to mo ngbe ori ile ati inu omi ti irawe ba wa dada, sugbon o feran ibi tuntun pupo, o si po lorile aye dada papa ni’le Yoruba to je pe igbo ati koko tuntun po nibe. Opolo ki i rin be ni ki i fi aya fa bi ti opo awon eranko afayafa Opolo mo nto ni nipa pe yio mo fo siwaju niwon ese bata meta si meje bi yio se mo to niyi ti yio fi de ibi to nlo.

Sugbon emo po lara Opolo lara emo ara Opolo ni pe
Ejo ki i je Olopo, ojo ti ejo ba je ni o gba ojo iku e
Enia naa ki i je Opolo, ewo ni jije re boya iru ohun ti yio se ejo naa ni yio se enia.
Sugbon eye asa mo nje Opolo ti nkankan ko si ni mu
Ti Opolo ba ku ki i jera bi ti gbogbo eranko to ku ati awa enia
Idin kii jade lara oku Opolo yio ka gbe ni .
Iwadi ijinle ti ise nlo lowo lori re je ka mo pe, ti Opolo ba ku ti o siwa ni odidi ti eya ara re ko ge ti ojo odun keji ba ro si nibi to ku si Opolo yio tu ji si aye pada ti Alafia ara re yio si pe pada.
Eyin mejilegbon ti o wa lenu enia naa lo wa lenu Opolo
Bi ikun enia se ri naa ni ti Opolo ri
Opolo mo ni ajose po larin ako ati abo ni ki abo to le loyun eyin ni yio si fi oyun re ye, inu omi ti irawe wa lo mo nye si niotri inu irawe naa lo mo ngbe kiise agbami. Eyin Opolo ni yio wa di omo sugbon Opolo tun mo njabo lati orun ti ojo ba nro. Orisiri ni Opolo irisi won mo nyato loju diedie lati agbegbe kan si agbegbe keji a mo ti enia ba ti ri yio ti mo pe Opolo ni oun ri.

Yara lo ka orisirisi itan ni: www.itanyoruba.com
Re: Itan Opolo by cirmuell(m): 5:01pm On May 16, 2015
Nice work, keep it up.
Re: Itan Opolo by scholes0(m): 5:53pm On May 16, 2015
Ki ni iyato ti o wa laarin Opolo, Akere ati Oyo?

(1) (Reply)

The Great Benin Kingdom (historical Analogy Of The Binis) / Youtube Spirituality Teaching--herbs And Mystics. Solutions To Life Problems / What Do You Think?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.