Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,827 members, 7,813,745 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 05:30 PM

Iyonu Olorun Logajulo Oun Sini Ejawa - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Iyonu Olorun Logajulo Oun Sini Ejawa (3800 Views)

Asiri Ijinle Olorun Pelu Awon Woli Re / To The Yorubas "Stop Praising Olorun, He Is Not The Christian God" / Iyin Ye, Olorun Wa, Oba To Ngbo Adura, Ogo Ye, Olorun, Oba To Ngbo Adura (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Iyonu Olorun Logajulo Oun Sini Ejawa by kadunasouth(m): 9:20pm On Jul 01, 2015
Bi eniyan bari iyonu oloun gbogbo aye ni ma yonu si iru enibe
Ki oloun eledumare yonu si eni kokan wa kama se dede ibinu re lai lai ati awa ati aromodoma wa Amin ase

Sugbon onawo lalegba ri iyonu olorun oba?
Akoko ipa ofin re ma ati ti tele gbogbo nto ba pawalase.
IWa aforijin lori asise wa lai fi jafara
Ima so ebi po
Itore anu fun awon alaini
Imalosi ile ijosin lorekore latilo josin fun oluwa oba ati bebelo
Kini idahun tire lori ibere yi?

1 Like 1 Share

Re: Iyonu Olorun Logajulo Oun Sini Ejawa by libertyfather(m): 9:35pm On Jul 01, 2015
kadunasouth:
Bi eniyan bari iyonu oloun gbogbo aye ni ma yonu si iru enibe
Ki oloun eledumare yonu si eni kokan wa kama se dede ibinu re lai lai ati awa ati aromodoma wa Amin ase

Sugbon onawo lalegba ri iyonu olorun oba?
Akoko ipa ofin re ma ati ti tele gbogbo nto ba pawalase.
IWa aforijin lori asise wa lai fi jafara
Ima so ebi po
Itore anu fun awon alaini
Imalosi ile ijosin lorekore latilo josin fun oluwa oba etc
Kini idahun tire lori ibere yi?

Why nah? Dunt you know etc in yoruba ni?
Re: Iyonu Olorun Logajulo Oun Sini Ejawa by kadunasouth(m): 11:43am On Dec 26, 2015
libertyfather:

Why nah? Dunt you know etc in yoruba ni?
Alaylorun oun lanabiwa muhammadu ki ike ati ola oloun koma ba ohun sini oloun feran ju oun si loni agbega julo ninu gbogbo eda ti oloun da, oloun oba kokin fi oro anabi sere rara, anabi loloun nife si ju, ninu gbogbo eda ti oloun da patapata yala ninu malaika re ati awan alujannu, kosi alafiwe anabi ninu gbogbo eda ti oloun da,
Ona ti eyan le gba ri iyonu oloun ni kia kia ni koyan anabi muhammad ni ore ati ayo re.
Onawo lale gba yan anabi lore ati ayo?
Oun nani kani ifere ju arawa lo ju omowa lo ju ayawa lo ati sise asalatu fun ni gbogbo igba, anabi yi nikan sini ko je awokose funwa, walai eni bale se eleyi oloun yio da oju ife ko enina lesekese, eni ti oloun ba doju ife ko, gbogbo nkan loma di irorun fun iru eni be, gbogbo nti iru enina bafe yio si tolowo yio di eni iyi lawujo, gbogbo eda ti oloun da ni wan yio ma sikere, nitorina odi owo wa kani ife anabi kasi ma tele ilanare adua wayio gba

2 Likes

Re: Iyonu Olorun Logajulo Oun Sini Ejawa by skamo74: 9:59am On Apr 27, 2016
salam aleykum Baba kadunasourh. iyonu Olohun yio ma ba yin gbe lailai laye you ati ni ojo alikiyaoma.
Sir, egbami ooo awon enia kan ma lo ji oja mi ko nibi ti mo man ko si. kini mo le se si aye naa Baba

ma salam

kadunasouth:
Bi eniyan bari iyonu oloun gbogbo aye ni ma yonu si iru enibe
Ki oloun eledumare yonu si eni kokan wa kama se dede ibinu re lai lai ati awa ati aromodoma wa Amin ase

Sugbon onawo lalegba ri iyonu olorun oba?
Akoko ipa ofin re ma ati ti tele gbogbo nto ba pawalase.
IWa aforijin lori asise wa lai fi jafara
Ima so ebi po
Itore anu fun awon alaini
Imalosi ile ijosin lorekore latilo josin fun oluwa oba ati bebelo
Kini idahun tire lori ibere yi?
Re: Iyonu Olorun Logajulo Oun Sini Ejawa by kadunasouth(m): 10:46pm On Apr 28, 2016
skamo74:

salam aleykum Baba kadunasourh. iyonu Olohun yio ma ba yin gbe lailai laye you ati ni ojo alikiyaoma.
Sir, egbami ooo awon enia kan ma lo ji oja mi ko nibi ti mo man ko si. kini mo le se si aye naa Baba

ma salam

Eko oruko awan eru oloun ti wan sasi nu apata (Ashabul kaff) awan mejo ni ki eko kurisiyu si isale re ki efi ko sibe yala eniyan ni tabi Alujannu koni ni agbara lati ji nkan kan ko nibe, ti eko bamo oruko na eto awan alufa lo kiwan bayin han sinu pepa fun fun ki wan bayin we ni tira Adua wa yio gba

2 Likes

(1) (Reply)

The Concept Of God Is Absurd / Capela Dose Ossos; A Church Entirely Built With Skulls And Skeletons Of Muslims / Over Coming Fornication Is Not By Prayers Alone, Its Not The Sin The Sin Is Lust

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 16
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.