Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,205,793 members, 7,993,753 topics. Date: Monday, 04 November 2024 at 05:56 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Oluwa Mi, Emi O Jebi O....Ni Orin Ti Saraki Fi S'enu Ni Ile Igbejo (1467 Views)
Oba Orin Juju Pe Omo Odun Mokandinlaadorin (69 Years) Lonii / Oba Orin Juju Pe Omo Odun Mokandinlaadorin (69 Years) Lonii / Awon Olorin Naijiria O Ni Agbekale Ohun To Yato - Paul Play Dairo (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Oluwa Mi, Emi O Jebi O....Ni Orin Ti Saraki Fi S'enu Ni Ile Igbejo by SisiGbeborun(f): 12:48pm On Sep 22, 2015 |
Ni nkan bii deede aago mokanla koja iseju meedogbon laaro yi ni Bukola Saraki wo inu ibi iduro ni ile igbejo to ti n dahun si awon esun onigun metala ti won fi kan-an. O wo inu ibi iduro leyin ti agbejoro e, Joseph Daudu ku'na lati ri ogbon e da, ko ma baa wo'be. Loro kan sa, Saraki ti be'be pe oun o jebi si awon esun ti won fi kan oun o. E fo'ju so'na. Gbogbo bi o ba se n lo ni SisiGbeborun a maa fi to yin l'eti... http://www.sisigbeborun.com/2015/09/oluwa-mi-emi-o-jebi-oni-orin-ti-saraki.html |
(1) (Reply)
Why Do Most Hausa Men Bend Like Women When urinating? / STREET LAMPPOST ADVERTISING IN LAGOS, ABUJA & PH / Whose Name Should Be Our Surname?
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 5 |