Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,130 members, 7,818,388 topics. Date: Sunday, 05 May 2024 at 02:10 PM

Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. - Politics (2) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. (10868 Views)

2019: Atiku Meets With Leaders Of Arewa, Yoruba And Ohanaeze Youth Groups (PICS) / The Hausa Fulani, The Yoruba And The Slaughter In Ile Ife (1) By Fani-kayode / Ile Ife Crisis: Security Operatives Commence Evacuation Of Hausas -channelsTv (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (Reply) (Go Down)

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by raumdeuter: 4:55pm On Mar 31, 2016
Ogbeni Lawani

E ku ise opolo. Awon alaale ile yi a gbe wa

Ohun ti emi faramo ni wipe ki gbogbo eya ti o wa loride ede Naijiriya ki gbogbo won pin yeleyele

Ko si ona abayori mo. Okete ti to si Gbegiri, ki eleko ko eko re lowo

Gbogbo eya ti o wa lorile ede naijeriya lo le da duro. Ko si ija nibe. Awa ko se mo ni

5 Likes

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by raumdeuter: 4:57pm On Mar 31, 2016
Movic1:

Oro wahala koni eleyi. if we gain secession today,shea ama fi awon eniyan wa to wa ni kwara and part of kogi si Northern Nigeria??

Awon eniyan to wa ni Kwara ati Kogi lo ma so ibi ti won fe faramo. Sugbon mo ni igbagbo wipe won o fe ba awon Omo iya won ni ile kaaro oojire lo
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by juman(m): 5:00pm On Mar 31, 2016
The kind of unseriousness and mindset of todays "leaders", it appears that one nigeria can never work well. It is just waste of time for common man.
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by lawani: 5:14pm On Mar 31, 2016
Movic1:

Oro wahala koni eleyi. if we gain secession today,shea ama fi awon eniyan wa to wa ni kwara and part of kogi si Northern Nigeria??

No Yoruba group, city, town or village will join another group of course, unless forced, which no one will want to do and there are non Yoruba groups like Bariba, even Tapa that may want to be part of the new nation but no one should be forced and it is infact good for all to determine their destinies by themselves as independent nations where interests are easily alligned with their own police, army, economy and etc. The Yoruba will not say Asaba should join us just because they were in the Western region. The Igala will prefer to have their own nation rather hyan be a minority anywhere, so far they are not going to be open to any disadvantage whatsoever.

A o le fi awon eniyan wa si le lo o. nitori wipe ero loja. Ti o ba si eniyan ahoro lasan ni ilu.
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Dansiki1: 6:51pm On Mar 31, 2016
lawani:

Ooto oro gbaa le so iya wa, sugbon a ko ni laati ba awon Gambari ja rara. Awa naa ni awon ti o gba esin odi [/b]laarin was, awon onisumomi po laarin Yoruba paapaa. [b]Sugbon a si ni anfaani ju awon Gambari lati da owo ibi duro ti a ba tete bere. Awon Baba wa ti igba laelae ko gba Olorun eke ti fun ni lase lati pa eniyan bi eni pa esinsin. A ko ni lati ba enikeni ja. Tiwa ni wipe a ko se mo. O to gee. Ki onikaluku o da omu iya re gbe. Ohun ti Boko Haram naa nfe kuku ni eyi. Ohun gbogbo nsise po fun rere ni.
Lawani, what's the meaning of the bolded words? If you are talking about Muslims, you are definitely making the same mistake as the biafrans.
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by oyinkinola: 7:08pm On Mar 31, 2016
igi worokoti da na ru,aro kaaro ti dobenu, kini isoro yoruba lorile ede yi loni, bi iya ba njomo yoruba bo tele lorile ede yi , iya ti dopin, asi ti ni aeyori oun akoile rere lorile ede yi, gbogbo aye lo mo pe ijoba tinlo lode yi ijoba yoruba ni, olori ijoba yi olooto eyan ni, gogbo aye lo sijeri si iwa oo re , ni bo lote eyi ti wa, nigba tawon ole nselu, omo yoruba o keko tie lowo, ese to je pe lasiko yi lo ye ka lo? bi eyan ba mo nkan pamo ko ranti eni moo wa! nigba ti yoruba si ipokini, taa si nipo keji, taa si nipo keta, taa si ni po kerin taa si nipo karun gaan paapaa laye jonathan ki lo se ti yoruba yari!
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by lawani: 8:36pm On Mar 31, 2016
oyinkinola:
igi worokoti da na ru,aro kaaro ti dobenu, kini isoro yoruba lorile ede yi loni, bi iya ba njomo yoruba bo tele lorile ede yi , iya ti dopin, asi ti ni aeyori oun akoile rere lorile ede yi, gbogbo aye lo mo pe ijoba tinlo lode yi ijoba yoruba ni, olori ijoba yi olooto eyan ni, gogbo aye lo sijeri si iwa oo re , ni bo lote eyi ti wa, nigba tawon ole nselu, omo yoruba o keko tie lowo, ese to je pe lasiko yi lo ye ka lo? bi eyan ba mo nkan pamo ko ranti eni moo wa! nigba ti yoruba si ipokini, taa si nipo keji, taa si nipo keta, taa si ni po kerin taa si nipo karun gaan paapaa laye jonathan ki lo se ti yoruba yari!

Yoruba ti po to lati dawa, Igbo naa po to, Gambari po to, Tapa po to, Agatu po to abbl. Ki onikaluku da duro pelu awon ajagun ati olopa ti won lo dara. Ki enikeni ma di enikeni lowo mu. Ki Yoruba ma le parapo da wahala sile ni ile Gambari nitori awon lo wa nijoba. Ko nikaluku mu ogbon ori won lo fun ilosiwaju awon eniyan won. Bo se Sharia ni won fe, ki won o bere ni pereu. Bo ti ye ko ri niyen o. Ko ju bee lo.

Aare orile ede yii kiise olooto eniyan. O nmu iro ni aaye ni, ko pa rara. Ko si ni eje omoluwabi kankan lara bo ti le wu ko kere mo. Emi o mo ohun ti e ri ti e fi pe Aare Buhari ni eniyan gidi. Okunrin naa kiise eniyan gidi rara o. Bo ti le je eniyan gidi paapaa, Yoruba ti po to, awa omo ile kaaro o jiire ti po to lati daduro ni aye ara wa gegebi okan ninu awon ilu olominira agbaye. A o ma pade awon Igbo, Gambari ati awon to ku ni ECOWAS ati UN ti ise ajo isokan agbaye.

Kini ohun ti e ri ti e fi ro wipe o ye ki Nigeria ma pin?

1 Like

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by baby124: 8:41pm On Mar 31, 2016
Leyin Ijooba yi, o ti to ijo ki naija tun ro oro naija. Wahala ti poju. Regional focus lo sure ju. E ma tie wo awon agbaya bi ObJ ati awon afenifere, ti a ba fi sowo wan, bayi lo de ma ri titi lai lai. Awon youth lo le she
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by raumdeuter: 8:42pm On Mar 31, 2016
Dansiki1:
Lawani, what's the meaning of the bolded words? If you are talking about Muslims, you are definitely making the same mistake as the biafrans.

The OP is against all form of Middle eastern religion be it Xtianity or Islam

The only religion he supports is Yoruba traditional religion

I would translate what he said

" We dont need to demonize Hausas as terrorists that we have terrorists among even Southerners even in Yorubaland. And we can have the advantage if we start on time to stop the evil of terrorism unlike societies who wait until its too late"

Our forefathers do not support any foreign mischievous god that permit people to commit mass murder

3 Likes 1 Share

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by lawani: 8:46pm On Mar 31, 2016
Dansiki1:
Lawani, what's the meaning of the bolded words? If you are talking about Muslims, you are definitely making the same mistake as the biafrans.

Aborisha ni emi gegebi Olorun Oba Olodumare Agotun ateni ola legelege se fi le le fun awon babanla wa fun won lati wa ni ibarepo pelu ohun gbogbo. Mo mo wipe awon elesin igbagbo ati imale nwa lati gbe mi pa nitori mo duro si ilana Olodumare gegebi Aborisha, sugbon emi naa ko si duro. Mi o si lara awon ti o nso wipe ki won ofi onikaluku sile lati ma ba oruko Olorun Olodumare je kiri bi o ba ti wu won ni abe ofin freedom of religion. Temi ni wipe ki ijoba fagile awon onigbagbo ati imale ti won nba oruko Olorun je kaakiri gegebi toogi ti njo awa Aborisa ninu ina lorun apadi. Nitori kini? Olodumare temi ko so bee rara. Sugbon emi ko ni ede aiyede pelu awon elesin abalaiye, ibi yoo wu ki won ti wa, ibaa se Japan India, China abbl. Ti won ba ti bu owo fun mi, emi naa yio bu owo fun won. Ngo fi ori bale fun won pelu. Sugbon ti awon igbagbo ati imale ko ri ibe. Awon irunmale ajogun ni won nsise fun.
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by oyinkinola: 9:00pm On Mar 31, 2016
lawani:

Yoruba ti po to lati dawa, Igbo naa po to, Gambari po to, Tapa po to, Agatu po to abbl. Ki onikaluku da duro pelu awon ajagun ati olopa ti won lo dara. Ki enikeni ma di enikeni lowo mu. Ki Yoruba ma le parapo da wahala sile ni ile Gambari nitori awon lo wa nijoba. Ko nikaluku mu ogbon ori won lo fun ilosiwaju awon eniyan won. Bo se Sharia ni won fe, ki won o bere ni pereu. Bo ti ye ko ri niyen o. Ko ju bee lo.

Aare orile ede yii kiise olooto eniyan. O nmu iro ni aaye ni, ko pa rara. Ko si ni eje omoluwabi kankan lara bo ti le wu ko kere mo. Emi o mo ohun ti e ri ti e fi pe Aare Buhari ni eniyan gidi. Okunrin naa kiise eniyan gidi rara o. Bo ti le je eniyan gidi paapaa, Yoruba ti po to, awa omo ile kaaro o jiire ti po to lati daduro ni aye ara wa gegebi okan ninu awon ilu olominira agbaye. A o ma pade awon Igbo, Gambari ati awon to ku ni ECOWAS ati UN ti ise ajo isokan agbaye.

Kini ohun ti e ri ti e fi ro wipe o ye ki Nigeria ma pin?
kini di ti buhari o fi joloodo, ejo laa ko kato leja, se bomo 'ya yin losibanjo, omo yoruba sinin saraki, omo yoruba ni fashola, omo yoruba ni tinubu, taa bapin orile ede nigeria lojule sojule, seyan loni kisoro wa o yanju,
se bi odidi ni molebi wa tele nile yoruba nigba aye daa, toje pe baale kan soso la nsin, nigba taye dojuru taapin yeleyele, saa rojutu ara wa mo, s ba a pin nigeria yeleyele saa tun ni asepopo po mo awon ti kii seran wa mo ni, aye daba oko,gbo omoeniyan si wa ona biwon se pa alaa le re eyin tiun gbiyanju ati maa faala le saarin wa, loni bi mo ba gbera lateko lo si kano de pota, omo nigeria nimi,
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by lawani: 9:08pm On Mar 31, 2016
raumdeuter:
Ogbeni Lawani

E ku ise opolo. Awon alaale ile yi a gbe wa

Ohun ti emi faramo ni wipe ki gbogbo eya ti o wa loride ede Naijiriya ki gbogbo won pin yeleyele

Ko si ona abayori mo. Okete ti to si Gbegiri, ki eleko ko eko re lowo

Gbogbo eya ti o wa lorile ede naijeriya lo le da duro. Ko si ija nibe. Awa ko se mo ni

Olodumare lo fi si yin lokan bee. Ohun to wa lokan Olodumare gaan le wi jade yen. Eni to ba fe lo ko lo. Eni to ba fe duro ko duro. Ko si agidi kankan loro Olodumare rara. Ko sisi imunisin kankan.

Awon alale a ma gbe yin. Owo yin a ma roke. Ogun o ni feje wa we o!

Ase Edumare.
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by scholes0(m): 9:22pm On Mar 31, 2016
lawani:

No Yoruba group, city, town or village will join another group of course, unless forced, which no one will want to do and there are non Yoruba groups like Bariba, even Tapa that may want to be part of the new nation but no one should be forced and it is infact good for all to determine their destinies by themselves as independent nations where interests are easily alligned with their own police, army, economy and etc. The Yoruba will not say Asaba should join us just because they were in the Western region. The Igala will prefer to have their own nation rather hyan be a minority anywhere, so far they are not going to be open to any disadvantage whatsoever.

A o le fi awon eniyan wa si le lo o. nitori wipe ero loja. Ti o ba si eniyan ahoro lasan ni ilu.

E ku ise opolo ti e n se.
Sugbon mo fe so wipe oro "Ero l'oja" ko ni o wanile yi......

Infact, the smaller the better.
Ao le so wipe nitori wipe a n wa ero pupo l'oja, ki a lo pe awon were sinu e.

1 Like

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by babyfaceafrica: 9:41pm On Mar 31, 2016
Hmmmm.....
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by oyinkinola: 10:18pm On Mar 31, 2016
....e ma je a paro fun ra wa, gbogbo awon ti fe ki nigeria o daru lo ni awon jegudujera oselu ana ni, awon ni won gbe awuyeuye kale nile ibo, awon naa ni wontun bere nile yoruba yi, iro tiile yooba oni pepin, tori iran yoruba o fara mo le, gbogbo omo yoruba to ba kowo ilu je, ko loo da wo 'lu sile,
gbayi laaro tarugbo soge!
isokan ile nigeria ni baba awolowo di mu titi ojo ku e, iro ki le kan fe pa fun wa!
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by lawani: 12:50am On Apr 01, 2016
oyinkinola:
....e ma je a paro fun ra wa, gbogbo awon ti fe ki nigeria o daru lo ni awon jegudujera oselu ana ni, awon ni won gbe awuyeuye kale nile ibo, awon naa ni wontun bere nile yoruba yi, iro tiile yooba oni pepin, tori iran yoruba o fara mo le, gbogbo omo yoruba to ba kowo ilu je, ko loo da wo 'lu sile,
gbayi laaro tarugbo soge!
isokan ile nigeria ni baba awolowo di mu titi ojo ku e, iro ki le kan fe pa fun wa!

Ki ise oro Awolowo mo. Awolowo ti ba ti e lo. Herbert Macaulay paapaa lo bere oro Nigeria, oun naa ti lo. Awa to ku sile ni ki awa kun irin ese wa o.

Alagemo ti bimo e sile, aimojo o ku sowo omo alagemo.
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by 0YorubaParapo0: 1:18am On Apr 01, 2016
tobimillar:
Omo yoruba atata ni mi sugbon ikokuko ni writer yi ko. A n bu enu ate lu awon omo yiibo tori won n ja fun ominira ilu biafra, a si wa fe Maa ja fun tiwa. Iwa mimo tara Eni nikan leyi (selfishness)

This is the type of useless, afonjanistic Yorubas Yorubaland needs to get rid of. So, kini ikokuko ni gbogbo nkan ti ogbeni yen ko?

How is the current state of Yorubaland satisfactory to you and your future generation?

You have foreign particles coming to your land and attacking you in your land, calling your land and heritage no man's land and you're own forming boss. Fun tani? Se ko se pe won ti fi eleda e se akara?

I'm not saying Yorubas should fight Igbo's battle for them, because this is what Igbos want; a by force support from Yorubas. However, Yorubas should forget about regionalism and start their own fight for a republic state. Send everyone that isn't Yoruba back to their caves.

3 Likes

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Nobody: 1:22am On Apr 01, 2016
0YorubaParapo0:

This is the type of useless, afonjanistic Yorubas Yorubaland needs to get rid of. So, kini ikokuko ni gbogbo nkan ti ogbeni yen ko?

How is the current state of Yorubaland satisfactory to you and your future generation?

You have foreign particles coming to your land and attacking you in your land, calling your land and heritage no man's land and you're own forming boss. Fun tani? Se ko se pe won ti fi eleda e se akara?

I'm not saying Yorubas should fight Igbo's battle for them, because this is what Igbos want; a by force support from Yorubas. However, Yorubas should forget about regionalism and start their own fight for a republic state. Send everyone that isn't Yoruba back to their caves.

Ewo wa ni to epe? Op gan o sepe fun mi!! Oga fun awon omo yoruba ode isin!! Did u read my subsequent interaction with the op... sincerely I am not surprised just disappointed...

1 Like

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by 0YorubaParapo0: 1:24am On Apr 01, 2016
oyinkinola:
....e ma je a paro fun ra wa, gbogbo awon ti fe ki nigeria o daru lo ni awon jegudujera oselu ana ni, awon ni won gbe awuyeuye kale nile ibo, awon naa ni wontun bere nile yoruba yi, iro tiile yooba oni pepin, tori iran yoruba o fara mo le, gbogbo omo yoruba to ba kowo ilu je, ko loo da wo 'lu sile,
gbayi laaro tarugbo soge!
isokan ile nigeria ni baba awolowo di mu titi ojo ku e, iro ki le kan fe pa fun wa!

Ma paro fun ra re.

E duro na, ki lo n ba eyin Yoruba leru? Ki lo de to je pe eyin nikan le fe Nigeria? Eyin nikan ni e ki n support ara yin. Ewo lo kan yin ti awon oloshi ba fe ko eru won kuro l'oja?

Ko ye mi. Oroi yin ti fe ma su mi.

Yoruba, igba wo le ma joko lati ronu?
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by 0YorubaParapo0: 1:28am On Apr 01, 2016
tobimillar:

Ewo wa ni to epe? Op gan o sepe fun mi!! Oga fun awon omo yoruba ode isin!! Did u read my subsequent interaction with the op... sincerely I am not surprised just disappointed...

Ogbeni, e ma binu. Sugbon, ko ye ki eyan f'ata s'enu ko s'oro. Ito enu yin to fo simi loju lo n je ki n binu.

Oya, kini ikokuko ti OP ko?
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Nobody: 1:44am On Apr 01, 2016
0YorubaParapo0:

Ogbeni, e ma binu. Sugbon, ko ye ki eyan f'ata s'enu ko s'oro. Ito enu yin to fo simi loju lo n je ki n binu.

Oya, kini ikokuko ti OP ko?

On page zero I have highlighted my point to the Op. I totally support a yoruba Republic as it were, but let's face facts, with our Abuja politicians, how is it feasible? Bi o tile je pe mi o fi tara tara gba ti awon omo yiibo, I still believe a southern unity is the only way to break away from the Northern hegemony. Nkan ti o bi mi ninu ni pe, 95% awa omo yoruba ni a n bu enu ate lu awon omo yiibo ti won jija ominira, awa na si re ni a n soro ominira fun Ile yoruba. At least, enu ni awon omo yiibo ni, won san ju awon omo arewa (Northerners) , ti won ko ni value fun human lifes. Their herdsmen come to our lands to rape our daughters, sisters and mothers, they kill at will. I strongly believe the igbo's and Yorubas are victims and they must unite at least to achieve a common goal, after which we both can go our separate ways

1 Like 1 Share

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by macof(m): 8:24am On Apr 01, 2016
Movic1:

Correct !
Once the southerners are United automatically the Northerners are in trouble, but the question is are we ready to Unite?

this is what I've been saying.
The south needs to be United, Awolowo was on this path until he let his presidential ambition set Yorubas back

1 Like

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by macof(m): 8:27am On Apr 01, 2016
Yoruba, a ti n'ronu bayi.... o ti pe ti mo ti n'so
Ominira Oodua!
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Agbaletu: 9:22am On Apr 01, 2016
tobimillar:

On page zero I have highlighted my point to the Op. I totally support a yoruba Republic as it were, but let's face facts, with our Abuja politicians, how is it feasible? Bi o tile je pe mi o fi tara tara gba ti awon omo yiibo, I still believe a southern unity is the only way to break away from the Northern hegemony. Nkan ti o bi mi ninu ni pe, 95% awa omo yoruba ni a n bu enu ate lu awon omo yiibo ti won jija ominira, awa na si re ni a n soro ominira fun Ile yoruba. At least, enu ni awon omo yiibo ni, won san ju awon omo arewa (Northerners) , ti won ko ni value fun human lifes. Their herdsmen come to our lands to rape our daughters, sisters and mothers, they kill at will. I strongly believe the igbo's and Yorubas are victims and they must unite at least to achieve a common goal, after which we both can go our separate ways

Mo fara mo nkan ti Ogbeni tobimillar so yii, sugbon o ma soro lati unite pelu awon omo Igbo nitori awa mejeji ko trust ara wa. Ti o ba sese ki a le pari awo to wa larin awa ati awon omo Igbo, iba dara. Sugbon mo duro lori ki awa omo Yoruba da duro.
Aye a ye gbogbo awa omo Oodua o!
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Originality007: 9:28am On Apr 01, 2016
omo yoruba ni mi oo
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Nobody: 9:34am On Apr 01, 2016
Agbaletu:

Mo fara mo nkan ti Ogbeni tobimillar so yii, sugbon o ma soro lati unite pelu awon omo Igbo nitori awa mejeji ko trust ara wa. Ti o ba sese ki a le pari awo to wa larin awa ati awon omo Igbo, iba dara. Sugbon mo duro lori ki awa omo Yoruba da duro.
Aye a ye gbogbo awa omo Oodua o!

Enu awon omo yiibo yen ko da rara... abi kini itunmo "Lagos is a no man's land"? Haven said that, awa na gege bi omo yoruba, we should be diplomatic. We should support them wholeheartedly to have their biafra, and as soon as they do, Lagos becomes a foreign land that they will require visa to come to... I still wonder why 95% of Nairalander Yoruba's are against biafra. If they can fight for their biafra, and have it, automatically yoruba becomes an independent Nation too. I wish yoruba can ronu jinle

4 Likes

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by zimoni(f): 9:38am On Apr 01, 2016
Nice one.

The forced-marriage will never be successful till we go our separate ways.

1 Like

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Movic1(m): 9:41am On Apr 01, 2016
tobimillar:

On page zero I have highlighted my point to the Op. I totally support a yoruba Republic as it were, but let's face facts, with our Abuja politicians, how is it feasible? Bi o tile je pe mi o fi tara tara gba ti awon omo yiibo, I still believe a southern unity is the only way to break away from the Northern hegemony. Nkan ti o bi mi ninu ni pe, 95% awa omo yoruba ni a n bu enu ate lu awon omo yiibo ti won jija ominira, awa na si re ni a n soro ominira fun Ile yoruba. At least, enu ni awon omo yiibo ni, won san ju awon omo arewa (Northerners) , ti won ko ni value fun human lifes. Their herdsmen come to our lands to rape our daughters, sisters and mothers, they kill at will. I strongly believe the igbo's and Yorubas are victims and they must unite at least to achieve a common goal, after which we both can go our separate ways

That's exactly what i meant by southern unity that many fails to understand. Unite to achieve a common goal,then go your separate ways after the achievement.
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Agbaletu: 9:48am On Apr 01, 2016
tobimillar:

Enu awon omo yiibo yen ko da rara... abi kini itunmo "Lagos is a no man's land"? Haven said that, awa na gege bi omo yoruba, we should be diplomatic. We should support them wholeheartedly to have their biafra, and as soon as they do, Lagos becomes a foreign land that they will require visa to come to... I still wonder why 95% of Nairalander Yoruba's are against biafra. If they can fight for their biafra, and have it, automatically yoruba becomes an independent Nation too. I wish yoruba can ronu jinle

Awon kan wa lara awon omo Igbo ti ori won pe ti won sin ni opolo ti mo ni gbagbo wipe ale ba soro ti won sin ma relay si awon toku. I quite agree that we need to support the Igbo to get their Biafra but Igbo people should stop calling us unsavoury names. I for one has never been against Biafra. I will always wish they get it. Igbo people need to reach out to Yoruba or we reach out to them and not calling us names. Akoko to lati pin orile ede yii. Awa omo Yoruba ani lati ronu jinle gidi gan.
Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by napoleonbaba(m): 10:01am On Apr 01, 2016
Akowe Lawani o ku ise opolo
Inu mi dun gan si aroko yi

1 Like

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by Nobody: 10:01am On Apr 01, 2016
Agbaletu:

Awon kan wa lara awon omo Igbo ti ori won pe ti won sin ni opolo ti mo ni gbagbo wipe ale ba soro ti won sin ma relay si awon toku. I quite agree that we need to support the Igbo to get their Biafra but Igbo people should stop calling us unsavoury names. I for one has never been against Biafra. I will always wish they get it. [b] Igbo people need to reach out to Yoruba or we reach out to them [/b]and not calling us names. Akoko to lati pin orile ede yii. Awa omo Yoruba ani lati ronu jinle gidi gan.

The igbo's call us names, and that's all they do.. they are chest beaters... awon arewa, they don't call us names, they kill us.

At bolded who will bell the cat, pride won't make the yoruba's online admit that ipob is fighting a just cause albeit wrongly. And awon chest beater gan o ni gba pe they are wrong for their annoying comments and land grabbing instincts. So what's the solution? Because truthfully, our Abuja politicians won't help us.. we need to create a better future for our kids... we need a yoruba Republic

1 Like

Re: Ile Kaaro Ojiire (the Yoruba) And Nigeria. by zimoni(f): 10:08am On Apr 01, 2016
Abi ooooooo

Igbo's call us various unsavoury and derogatory names, yet they have never attacked our people physically. They beat their chests and run their mouths yet they will never lay their hands on you.

I prefer to be insulted than to be slaughtered.

It's just a matter of time. The Unholy Forced-Marriage shall come to an end.

2 Likes 1 Share

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (Reply)

More Debt For Nigeria, As FG Seeks $100 Million Broadband Loan From India / Oshiomhole Acknowledges Cheers From Security Officials At ICC, Abuja (Video) / 2 Feared Dead As Gunmen Rain Bullets In Yenagoa

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 85
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.