Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,825 members, 7,956,119 topics. Date: Monday, 23 September 2024 at 03:23 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / O Ni Fete Competition! (3259 Views)
Oluwa Mi, Emi O Jebi O....Ni Orin Ti Saraki Fi S'enu Ni Ile Igbejo / Awon Olorin Naijiria O Ni Agbekale Ohun To Yato - Paul Play Dairo / Eko O Ni Baje (2) (3) (4)
Re: O Ni Fete Competition! by mrofficial(m): 5:46pm On Dec 29, 2009 |
cool. Oni fe te ko fi posi se closet Oni fe te ko fi bentiro(petrol) din dodo Oni fe te ko fi yinka ayefele se striker Oni fe se IT lodo baba alawo Oni fe gbe malu fo fence Oni fe fi omi gbona tamba Oni fe fi odo se helmet Oni fe fi omo ori odo ta eyin Oni fe kiri gala ninu BRT That's all for now, I'll come back with more. |
Re: O Ni Fete Competition! by vero4oau: 10:54am On Dec 30, 2009 |
o ni fete o de ni fe fi spermu je buredi |
Re: O Ni Fete Competition! by thweraja10: 6:46pm On Jan 02, 2010 |
You guys are funny but check this out O ni fete o ni fe fi kirikiri se prison break oni fe fi okija shrine se lost O ni fe iru se button o ni fe fi condom se blon blow o ni fe pe monkey ni fine girl Oni fe pe Yaradua ni super man Oni fe fi okun indomie pokun so |
Re: O Ni Fete Competition! by hauler: 8:03pm On Feb 10, 2010 |
:-x |
Re: O Ni Fete Competition! by Nobody: 7:58pm On Feb 16, 2010 |
LWKMD O ni fete, o ni fe fi generator se pendant o ni fe de pampers fejo(snake) o ni fe kiri gala niwaju BRT o ni fe fi peppersoup tamba o ni fe fi ejo de Tie o ni fe fi ata gigun se powder o ni fe pe mummy e ni virgin |
Re: O Ni Fete Competition! by dominique(f): 9:23pm On Feb 16, 2010 |
o ni fe fi acid fo eyin o ni fe fi petrol din akara o ni fe wa moto lori ategun o ni fe fi bamboo se toothpick |
Re: O Ni Fete Competition! by SHADE85: 6:03pm On Oct 11, 2010 |
O NI FE TE KO FI AKI AND PAWPAW SE P SQUARE, O DE NI FE TE KO LO FI STEVE WONDER SE VAN DER SAR, O NI FE TE KO MA WA ABIJA LORI GOOGLE. |
Represent Where You Are From / Life In A Muslim House / List Of Languages In Nigeria.
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 21 |