Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,161,443 members, 7,846,831 topics. Date: Saturday, 01 June 2024 at 02:38 AM

Yoruba Ronu - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Ronu (530 Views)

Yoruba E Ronu (A Must Read)! / If Acting President Osinbajo Were Hausa Or Fulani... Yoruba Ronu / Yoruba E Ronu Yin O. (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Yoruba Ronu by otitokoroleti: 9:08pm On Sep 18, 2016
Mo wo Ile Aye o, aye sa malamala; Mo ma b’oju w’orun okunkun losu bo’le; Mo ni eri eyi o, kini sele si Yoruba omo Alade, kini sele si Yoruba omo Odua; Ye, ye, ye, yeye, ye awa mase hun, oro nla nbe; Yoruba nse r’awon nitori Owó, Yoruba jin r’awon l’ese nitori ipò; Won gbebi f’alare, won gba’re f’elebi; Won pe olè ko wa ja, won tun pe oloko wa mu; Ogbon ti won gbon lo gbe won de Ilé Olà, ogbon na lo tun padawa si tunde won mole; Awon ti won ti n s’Oga lojo to ti pe, tun pada wa d’eni a n f’owo ti s’eyin. Yo, yo, yo, Yoruba yo yo yo bi ina ale; Yoruba ru ru ru bi Omi Òkun; Yoruba baba nse…Yo yo Yoruba ronu o! Yoruba so’ra won di boolu f’araye gba; To n ba gba won soke, won a tun gba’won s’isale o; Eya ti o ti kere te le ni won ge kuru; Awon ti ale f’ejo sun, ti di eni ati jo; Yoruba joko sile regede, won fi owo l’owo; Bi Agutan ti Abore n bo orisa re o! Yo yo Yoruba r’onu o! Ori ki ma i buru titi, ko bu ogun odun; Leyin okunkun biribiri, Imole a tan; Ejeka pe Olodumare, ka pe Oba lu Aye; k’ayewa le dun ni igbehin, igbein lalayo; Ile mo pe o, Ile dakun gbawa o, Ile o; Ile ogere, a f’okó yeri…ile! Alapo Ìkà, o te rere ka ibi…ile! Ogba ragada bi eni yeye mi omo adaru pale Oge…Ile, dakun gba wa o…Ile! Ibi ti n pa Ika l’enu mo…ile! Aate i ka, o ko ti a pe Ile…Ile! Ogbamu, gbamu oju Eledumare ko mase gbamu lowo aye…Ile…dakungba wa o… Ile Ehen, ehen awa gbe ori ile yi pe o; Eni ba dale, a ba ile lo…peregede o… ehen ehen awa gbe ori ile yi pe o; Oduduwa bawa tun ile yi se o…to’wo, t’omo o…ehen…awa gbe ori ile yi pe o; Oduduwa da wa l’are o, kaa si maa r’ere je o…ehen awa gbe ori ile yi pe o! yo yo yo Yoruba ronu o!



if you have a working brain, you will understand the motives behind this thread
Re: Yoruba Ronu by HtwoOw: 12:01am On Sep 19, 2016
reaing later
Re: Yoruba Ronu by Toluwani113: 1:23am On Sep 19, 2016
HtwoOw:
reaing later
Summarize it for me!
grin

(1) (Reply)

Polymer Notes.. / You’re Respected Worldwide, Ban Ki-moon Tells Buhari / 'abdulmutallab, US Bomber To Vote In Edo

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.