Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,572 members, 7,958,775 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 11:35 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Isé Ni Òògùn Ìsé - Work Is The Antidote Of Poverty (736 Views)
Ogun Ti Afi Ngbe Aye Ni Irorun Ati Ogun Korikosun To Gbona Gan / Ebe Awon Agba Ti Eniyan Mafi Nri Aye Se Ni Irorun Lori Oun Gbogbo Taba Fe See / Perfection For Stroke :-ogun Ti Eniyan Kii Fi Ni Ropa- Rose (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Isé Ni Òògùn Ìsé - Work Is The Antidote Of Poverty by Nobody: 5:24pm On Mar 29, 2017 |
*AKOSORI YORUBA FUN GBOGBO OMO KAARO OOJIIRE* ENGLISH TRANSLATION *ISÉ NI ÒÒGÙN ÌSÉ* Work is the antidote for poverty. *MÚRA SÍ ISÉ RE, ÒRÉÈ MI* Work hard, my friend. *ISÉ NI A FI Í DI ENI GIGA* work is used to elevate one in respect and importance (Aspiring to higher height is fully dependent on hard work). *BÍ A KÒ BÁ RÉNI FÈYÌN TÌ, BÍ ÒLE LÀ Á RÍ* if we do not have anyone to lean on, we appear indolent. *BÍ A KO RÉNI GBÉKÈLÉ* if we do not have anyone to trust (we can depend on). *À A TERA MÓ ISÉ ENI* we simply work harder. *ÌYÁ RE LÈ LÓWÓ LÓWÓ* your mother may be wealthy. *BÀBÁ SÌ LÈ LÉSIN LÉÈKÀN* your father may have a ranch full of horses. *BÍ O BÁ GBÓJÚ LÉ WON* if you depend on their riches alone. *O TÉ TÁN NI MO SO FÚN O* you may end up in disgrace, I tell you. *OHUN TÍ A KÒ BA JÌYÀ FÚN* whatever gain one does not work hard to earn. *KÌ Í LÈ TÓJÓ* usually does not last. *OHUN TÍ A BÁ FARA SISÉ FÚN* whatever gain one works hard to earn. *NÍ Í PÉ LÓWÓ ENI* is the one that lasts in one's hands (while in ones possession). *APÁ LARÁ* the arm is a relative *ÌGÙNPÁ NÌYEKAN* the elbow is a sibling. *BÍ AYÉ N FÉ O LÓNÌÍ* you may be loved by all today. *BÍ O BÁ LÓWÓ LÓWÓ* it is when you have money. *NI WON Á MÁA FÉ O LÓLA* that they will love you tomorrow. *TÀBÍ TÍ O BÁ WÀ NÍ IPÒ ÀTÀTÀ* or when you are in a high position. *AYÉ Á YÉ O SÍ TÈRÍN-TÈRÍN* all will honor you with cheers and smiles. *JÉ KÍ O DI ENI N RÁÁGÓ* wait till you become poor or are struggling to get by. *KÍ O RÍ BÁYÉ TI Í SÍMÚ SÍ O* and you will see how all grimace at you as they pass you by. *ÈKÓ SÌ TÚN N SONI Í DÒGÁ* education also elevates one in position. *MÚRA KÍ O KÓ O DÁRADÁRA* work hard to acquire good education. *BÍ O SÌ RÍ ÒPÒ ÈNÌYÀN* and if you see a lot of people. *TÍ WÓN N FI ÈKÓ SE ÈRÍN RÍN* making education a laughing stock. *DÁKUN MÁ SE FARA WÉ WON* please do not emulate or keep their company. *ÌYÀ N BÒ FÓMO TÍ KÒ GBÓN* suffering is lying in wait for an unserious kid. *EKÚN N BE FÓMO TÓ N SÁ KIRI* sorrow is in the reserve for a truant kid. *MÁ FÒWÚRÒ SERÉ, ÒRÉÈ MI* do not play with your early years, my friend. *MÚRA SÍSÉ, OJÓ N LO* work harder; time and tide wait for no one. Let’s pass it on to our children. Original work by *J F Odunjo* |
Re: Isé Ni Òògùn Ìsé - Work Is The Antidote Of Poverty by AkinPhysicist: 5:52pm On Mar 31, 2017 |
1 Like |
(1) (Reply)
Why Do Some Nigerians Say Bless Me/bless You After Sneezing / Reno Omokri Writes Special Tributes To Yoruba In Nigeria / Wallabies Vs All Blacks
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 10 |