Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,140,477 members, 7,770,169 topics. Date: Tuesday, 19 March 2024 at 06:31 AM

The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo (3796 Views)

Tension As Traditionalists Boycott Rites For New King Appointed By Adeleke Govt / Fact About Oduduwa The Ancestor Of Yoruba.history. / Ekiti: 3 Killed, Oba Bobade Adeleke Chased Out Over Ogun Festival (Photos) (2) (3) (4)

(1) (2) (Reply) (Go Down)

The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 8:19am On Jul 11, 2018
It is opportunity for me to be alive and showing this. It all began last year March as I went to Igbajo for rememberance rite of my grandpa. Grandpa was not good in English but he can write Yoruba. He does not practise Christian orMuslim, not even devoted to any religion as at when I know. Grandpa likes us all, did not care about material things as such.
My daddy and mummy have told grandpa to come and be living with us in Osogbo he refuse. He said who will take care of the house in Igbajo? I remember grandpa use to boast of coming from a family that fight in the Kiriji War, but unlike many Igbajo people, he does not hate people from Imesi Ile. One baba Fadiji of Imesi Ile was even his friend, according to what he told us.
Baba use to talk about peace of mind to us his grandchildren. He use to emphasize fearlessness. Baba said that God has been left out of all religious books. That's where my father disagrees with him in those days: my dad said that God can only be found in the Quran.
Because of different religion or let me say the non-concern nature of Grandpa, our dad did not use to visit him in the village again till he died in 2002. We went to grandpa's house last year, it was in shamble, look like chicken house.
My dad still believe that he did not commit any offence for neglecting grandpa since 1998. When I searched into grandpa's document, that was when I knew the reason that old man did all the things he has been doing.

Grandpa has exercise books, dirty and old ones. Funny thing about the handwritings in the books is that some of them have big writings written on three rows of exercise book lines at once but some have tiny handwritings so small five to six lines can enter inside one row of exercise book lines. A change must have happened in grandpa's life. Yes and the change can be noticed in the content of the texts.
Since last year I have been looking for how to make it public, no way. I don't have money and all the public websites i know want money. I eventually find nairaland just last month.

The story I have is very long, all found inside my late grandpa's house. The latest date of the writing was in 1979 far before I was born but what amaze me is that some things inside the story look like recent events. His predictions happen in many instances.

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 8:22am On Jul 11, 2018
First before I post the content of the very long story i will post the pictures I took. I snapped few of the pages of the book, they are in my phone. I will post pictures of my grandpa's house in Igbajo.

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 8:26am On Jul 11, 2018
Picture of a page in the book

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 8:27am On Jul 11, 2018
Picture of another page in the book

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 8:28am On Jul 11, 2018
Other pages

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 8:29am On Jul 11, 2018
More

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 8:33am On Jul 11, 2018
More

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by RedboneSmith(m): 12:10pm On Jul 11, 2018
Soooo tiny. What is it about?

4 Likes

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MetaPhysical: 3:52pm On Jul 11, 2018
May his soul rest in peace!

4 Likes

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by vonxe: 9:22pm On Jul 11, 2018
Summary of what was written
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 6:19am On Jul 12, 2018
vonxe:
Summary of what was written
The summary is we yoruba are not from bible or quran. We have our own origin from our lands.

2 Likes

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 6:19am On Jul 12, 2018
RedboneSmith:
Soooo tiny. What is it about?
full history of yoruba ancestors... more than 200 thousand years ago.

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 6:22am On Jul 12, 2018
MetaPhysical:
May his soul rest in peace!
Ase waa!!

2 Likes

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 6:38am On Jul 12, 2018
Orin Baba Agba (

Mo roun to yami lenu de gongo
Mo ranju, mo moju, mo wa fowo kan gogongo
Itumo aye fagere sese sa koja loja Igbajo
Ko ye mi boya ki n di igbagbo mu tabi ki n gbajo
Iro laye n ba yi ninu okunkun dudu
A n gegi nigbo bi afoju age gedu
A n foribale fawon orisa to ti re koja
A wa n ba ara wa jija a si n deja

Eniyan lorisa eniyan lesu eniyan laseda ohun gbogbo
Eniyan ki n ku ki won ma seku sorile aye
Eni ba le se ohun ogunnagbongbo ni n di orisa

Bi ina ba ku a fi eeru boju
Bi ogede ba ku a fi omo re ropo
Bi fitila ba padanu ina ori re, afi ki a tun tan
Sugbon bi eniyan ba ku egbeegbewa eniyan yio dipo re

1 Like 1 Share

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 9:21pm On Jul 22, 2018
N'o kuku ni oju to ja geere.
Iriri oju mi, afi bi i ti afoju ti n fi fitila kawe.
Bi okele eba ara abule ni ikowesi owo mi ri o.
Ki n to le ri leta, ayafi ti n ba fi dingi oju wo o.

Tani yio wa ya mi loju ti kii wami?
Ta ni yio fi oju jinki mi bii oju iya mi?
Oju ti n sepin, imu ti n fararo yo kun;
O su mi, n'o mogba aye mi yio dekun.

Agba n de, odun n gori odun bi eegun
Ewu ori n sokale si mi lori bii ti igunnugun
Asiko ati re iwale asa n fojojumo sunmo
Sugbon mi o mo wipe n'o sese bere aye oloyinmomo.
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 4:16pm On Jul 27, 2018
Latinu okunkun oju orun ni imole ti tayo
Ni mo ba ri emi kan bi omiran to funfun bi eyo
Iberu bojo, ki ni oju mi tun fi agba ara ri yi?
Sugbon n'o mo wipe iriri yi a le gbe mi niyi.

Oruko baba so mi ni Adeleke
N'o ma bori, n'o si maa fojojumo leke
Oruko baba nla mi a ma je Adeyemo
E ba n gbade ki n fi maa se 'demo'.
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by Olu317(m): 10:47am On Jul 28, 2018
MysteryFinder:
Latinu okunkun oju orun ni imole ti tayo
Ni mo ba ri emi kan bi omiran to funfun bi eyo
Iberu bojo, ki ni oju mi tun fi agba ara ri yi?
Sugbon n'o mo wipe iriri yi a le gbe mi niyi.

Oruko baba so mi ni Adeleke
N'o ma bori, n'o si maa fojojumo leke
Oruko baba nla mi a ma je Adeyemo
E ba n gbade ki n fi maa se 'demo'.

Your baba's story is more or less his family background and experience on earth. Is there any part of it that really deal precisely on Yoruba history? Perhaps, you can shed more light on it.

2 Likes

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by bluke(m): 5:57pm On Aug 05, 2018
your grand dad discovered himself, realised what life and humanity is all about, so refused to follow your dad to town to enjoy eureka time in the village

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by bluke(m): 5:59pm On Aug 05, 2018
please enlarge the write up and p[ost.
i enjoyed reading the poetry

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 3:53pm On Aug 07, 2018
Olu317:
Your baba's story is more or less his family background and experience on earth. Is there any part of it that really deal precisely on Yoruba history? Perhaps, you can shed more light on it.
Be patient and see, the pictures I pasted are histories of Yoruba. Am not good in typing. Am typing them, I will post them.
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 9:41am On Oct 18, 2018
Eni wo agbada gbodo sora fun agbada omi
Oloja to juko saarin oja ye ki o sora fori omo re
Oun a gbe ko soke ni n duro soke
Ohun a ri bole ile naa ni yio wa
Ohun aye ba gbe gege ni n di orisa lailai
Ohun a si ko sile ni n di ohun igbagbe

Aye o ri bi won ti so o si
Sugbon bi won se fe o ri ni n ri
Ologbon kan ki binu faye ko fori sopon
Oloye kan ki i titori baye se ri dagbere faye
Ohun a fe faye la a ponle
Ohun a o fe faye la a ba jijakadi

Se aye bi o se fe o ri
Orisa kan o dorisa lai gbiyanju
Eni lasan lo n wa saye lai yi aye pada
Iyipada gbogbo mirofa ni Olurofa n wa
Aimoye lorisa, okansoso ni Olurofa
Atinu Olurofa ni ohun gbogbo ti se wa

Asiko kan n bo ko i ti de
Asiko ti awon Orisa rere yi o gbe orisa nla kan dide
Olu omo ilu Naijiria ni Orisa naa yi o je
Ohun yio si wa fun aye ati gbogbo mirofa ni itunmo kikun
Ohun yio tan imole si gbogbo ohun ti o sokunkun dudu
Ko si si orisa kan ti yio le di i lowo ise ti yio waye wa se

Asiko ojo ibi Orisa rere yi yio di asiko tuntun
Ojo, osu, odun ati igba yio je onka lati asiko naa wa
Ijoba okan awon orisa yio di ohun afiseyin
Awon orisa ti a n gbe gege yio di afesetegun
Onikaluku yio maa bo ara re dipo awon orisa
Idagbasoke ti o ja gere yio si de ba ile aye

Lati ile ibi ipade odo oya ati odo binuwe ni olugbala okan yio ti wa
Eni ti gbogbo awon orisa rere ti n reti
Olugbala okan kuro ninu gbogbo onde esin ilu ajoji
Alagbara nla ti ko se e da
Onirawo titan bi orun osan gangan
Omo itan repete ti o fitan somi we

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 1:50am On May 13, 2019
Yoruba

Ori Kini

Aye kan ti re koja, aye miran ti wole wa.
Oduduwa ni o ba ara re ni ori apata ni igba ti awon eniyan tuntun bere si i se awari ara won lori apata ati lori ile ati iyanrin aye.
Oun mo wipe oruko oun ni o n je Oduduwa, sibe ko so enikeni ti o so fun un.

Nigba ti Oduduwa fi egbe apata se akaso wa si orile aye, oun ri awon eniyan eleran ara bi i tire lori iyanrin. Oun si so wipe, "awon eniyan eleran ara bi i temi re." Nigba ti won ri i, gbogbo won doju bole, won si n bo o.

Nigba ti oun si n so oro lo, eniyan kan ti n se Obatala naa bere si i so kale lori apata naa. Awon eniyan ile si ri i gege bi orisa oke.

Nigba ti Obatala ati Oduduwa fohun laarin a won eniyan toku, awon eniyan naa yanu, nitori wipe awon ko le fohun, won ko si ni oye ede kankan.

Bayii ni Oduduwa ati Obatala se gun ori apata naa pada, won si bere si i iroro i ji. Won si so fun ara won wipe, "Bawo ni awa se de orile aye? Ki lo sele ti awon ara ile ko le fohun bi awa mejeji?"

Nigba ti awon ko ri idahun si awon ibeere won, won boju wo osumare ati awon irawo. Nigbose ni won ba sun lo fonfon.

Nigba ti awon ti n fa orun lo, won bere si i ala ila. Ala ti won si n la si je okan naa. Awon eniyan meji bi tiwon si farahan ninu ala won. Awon mejeeji si so wipe, "Bawo ni eyin se je?" Awon ajoji naa si so wipe, "Awa ni oluwa yin. Awa ni atoka yin. Awa si ni asona fun yin. Aye kan ti re koja, aye tuntun si ti wa bayii. Awa si ran yi lo si aye tuntun yi ki eyin le ni iriri awon omo eniyan.

Omo orisa ti n se Olorun ni eyin i se ninu aye ti o ti re koja, sugbon eyin beere lowo Imole Mirofa wipe ki o fun yin ni anfani ati ni iriri tuntun ninu aye tuntun. Nitorina ni a se fi yin si ori apata. A si fun un yin ni anfani ti o ju ti awon eniyan ti won se awari ara won ni petele lo."

"A fun un yin ni ede Yoruba lati so. A fun un yin ni ogbon ti o tayo ti awon elegbe yin ti o n be ni petele. A si tun fun un yin ni ase lati salaye bi ile aye ati awon eda inu re se di alaye lona titi yin."

"A da yin ki e le pon apata kiya kiya, ki e si tun le sokale kiya kiya. A si tun si opolo yin ju ti awon eniyan ti won sese n to aye wo nigba akoko. A se eyi ki eyin le he asiwaju nigba ti awon eniyan ori ile yio ma je olutele yin."

"Amo ni bi egbegberun odun si asiko yi, orisa otito yio wa si aye, oun yio si tan imole si gbogbo oun ti i se otito inu aye. Okunkun iro yio si wo kuro."

Nigba ti awon eniyan ajoji naa fi Oduduwa ati Obatala sile lo, awon taji kuro ninu ala won. O si ya won lenu pupo. Awon si bere si I so kale.

Oduduwa ni o koko so kale. Oun si mu ikarahun igbin ti oun ri ninu iyanrin, oun si bu erupe sinu re. Oun si lo sinu igbe, o si ri awon adiye inu igbe ti won n fara pamo. Nigba ti won si fi oju ba a, won bere si i wo tele e.

Oduduwa si bere mu okan ninu a won adiye naa, awon iyoku si n tele e.

Nigba ti Oduduwa si rin jade kuro ninu igbe, oun ri awon eniyan. O si je iyalenu fun won wipe Oduduwa n rin laarin awon adiye repete ti won ko si sa fun un.

Nigba naa ni awon eniyan naa doju bole, won si n bo o. So si si enikeni ninu won ti o le fohun.

Bayii ni Oduduwa se ko won ni ede Yoruba i so. Oun si n gbe laarin awon eniyan naa.

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 9:10pm On Jun 13, 2019
Ori Keji
Nigbana ni awon olutele Oduduwa bere si i bi i lere nipa bi aye ti n he aye. Ede Yoruba ti oun ko won si no won fi n bi i.
Bayii ni Oduduwa si bere si i so fun won wipe, "Olorun ni o ran mi lati wa da aye lati ori oke ti a n pe ni Orun. O si fun mi ni ikarahun igbin ti erupe n be ninu re. O si tun fun mi ni adiye funfun yi.
Ibu si ni gbogbo aye je nigba ti mo sokale wa. Mo si da erupe inu ikarahun igbin naa si ori ibu, ile si wa."
"Mo si gbe adiye funfun yii sokale sori iyanrin naa, oun si n fi ese re fe iyanrin naa. Gbogbo ibi ti ile si fe de ni a n pe ni Ile-i-fesi. Adiye funfun yii ni o si maa se agba gbogbo adiye inu aye nitori wipe oun ni o fe ile loju aye."

"Awon iyanrin ile-i-fesi si wu eyin eniyan jade ki e le maa gbe ori iyanrin titi ti eyin yio fi lo si orun."

Bayii ni awon eniyan Ile-i-fesi se bere si i gba itan iseda aye ati awon eniyan ti Oduduwa so fun won gbo.
Nigbose, leyin igba ti Oduduwa ti se alaye iseda aye lona tire, Obatala ni o dede yo de. Oun si gbe akengbe emu lowo ti oun si n ta goo goo bi eni ti o ti mu oti yo bamu bamu.
Nigba ti oun si wo aarin awon eniyan wa, oun bere si i fohun bi oloti. Awon eniyan si n beru re. Won si lo fi ejo sun Oduduwa olori won.
Nigbana ni Oduduwa ro won ki won ma se foya, nitori wipe ibeji oun ni Obatala i se.
Oduduwa si so wipe, "Emi pelu Obatala ni Olorun bi si orun. O si ran wa sokale wa ki a wa se iseda aye. Obatala si ri igi ope ti o wu si isale apata, o si gun igi naa lo.
Oun si bere si i emu i da. Oun si mu emu gbagbe ise iseda aye ti Olorun ran an wa se.
Bayii ni awon eniyan se bere si i ri Obatala gege bii ibeji Oduduwa. Awon kan si n bo o. Oun si bere si i ko won bi won se n da emu, nitori wipe oun ni o koko da emu ni ile Yoruba.

2 Likes

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by dazzlingd(m): 6:43am On Sep 08, 2020
Otematum come and see the yoruba version of your book
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by OtemAtum: 11:25am On Sep 09, 2020
dazzlingd:
Otematum come and see the yoruba version of your book
I checked last week or so. I've been waiting for a time like this long before now. I'm keeping my fingers crossed.
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 1:55pm On Sep 09, 2020
Am back. I wil reopen this thread in Religion section for a more viewers.
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by Djamel(m): 2:13pm On Sep 09, 2020
Can you translate them to English?

2 Likes

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by MysteryFinder: 2:26pm On Sep 09, 2020
Djamel:
Can you translate them to English?

Yes I will try.

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by dazzlingd(m): 11:01pm On Sep 09, 2020
MysteryFinder:
Am back. I wil reopen this thread in Religion section for a more viewers.

I read it all, pls can I have a copy..
It is same story line with otems book.
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by dazzlingd(m): 8:50am On Sep 10, 2020
OtemAtum:
I checked last week or so. I've been waiting for a time like this long before now. I'm keeping my fingers crossed.

See your prediction o grin


Lati ile ibi ipade odo oya ati odo binuwe ni olugbala okan yio ti wa
Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by Proanalyst(m): 5:38pm On Sep 12, 2020
MysteryFinder:


Yes I will try.


How was it written?
Was it copied from another book or something. I understand you said it's for your grandpa but I believe that book is not too old.

Or is it that your grandpa got the information lately? Was it passed to him?

Thanks.

Also, if you find it difficult to write them as I have tired waiting, can you help by snapping them but this time around, clearly.

Thanks once again.

1 Like

Re: The Yoruba History Of My Grandfather-by Adeleke Adeyemo by ogyunging(m): 4:30am On Sep 15, 2020
Wow. That's Gold right there. Translating it to English would give some of us joy. Your gramps discovered himself. Fulfilled man.

(1) (2) (Reply)

The Ibibio Origins Of The Okonko Cult / All Spanish Learners / The Origins Of White People According To Ifa (odu Ifa Eji Ogbe)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 56
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.