Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,788 members, 7,851,659 topics. Date: Thursday, 06 June 2024 at 04:07 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (95) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377466 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (92) (93) (94) (95) (96) (97) (98) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 12:57pm On Aug 08, 2007
Lol. . .alafia ni o.just tot i should stop saying it for now
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 12:57pm On Aug 08, 2007
E karo

una goodu morning

se dada le wa awon ara ile/ara cyber  smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 1:17pm On Aug 08, 2007
omoge:

E karo

una goodu morning

se dada le wa awon ara ile/ara cyber smiley


Erin pupo yanturu !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 1:25pm On Aug 08, 2007
Ki olorun ma binu si wa !!!!

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 2:09pm On Aug 08, 2007
Amin o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:52pm On Aug 08, 2007
e ku ikale o gbogb ara ile :-p
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 3:38pm On Aug 08, 2007
eku aro nibi leni gbogbo eyin ara ile.

she alafia nimo ba yin?

ajinde ara ama je fun gbogbo wa.amin.

@ richylaw------ur posts reminds me of someone whenever i read them ---KOLA OLOOTU,do u know him?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:43pm On Aug 08, 2007
grin Yeah I know Kola Olootu the presenter.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 3:51pm On Aug 08, 2007
yeah that is  him.

what was your major in coll, yoruba language?
the way u type is what i'll call GBANKOGBI!

AND IM LOVIN IT!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 3:54pm On Aug 08, 2007
minute:

what was your major in coll, yoruba language?
the way u type is what i'll call GBANKOGBI!
Oro kanti ni eleyi oo lati enu Iseju ni o ti wa!!
E ku ise opolo !!
Baale, bawo ni ??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 4:25pm On Aug 08, 2007
mio kuku paro ogbeni mishoo

boshe ri gele niyen,mio need lati fi mini pe meji

esha ku igbadun.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:28pm On Aug 08, 2007
Mishoo daadaa ni mo wa o. A dupe lowo Eledua wipe a si n fi olele je eko.

minute:

yeah that is  him.

what was your major in coll, yoruba language?
the way u type is what i'll call GBANKOGBI!

AND IM LOVIN IT!!
Minute I am an architect by profession and an animator/ modellist as specialization.
otooto laayo suku lara agbado
otooto la pa omo yo ninu awusa
otooto laayo igbin kuro ninu ikarahun
oto lede, oto lasa , oto si tun ni ki a le fi se gbajumo lawujo.
cheers.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 4:42pm On Aug 08, 2007
WOW!!! cheesy shocked cheesy shocked

im impressed.

tin kan ba dara eje ka so,eleyii dara


by the way,igbawo lama bere lesson yen ,mowa eager lati ko-im serious diz time.

kosi enitio gbe ori meji wa lati orun.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 4:44pm On Aug 08, 2007
E ku 'role o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 4:49pm On Aug 08, 2007
ekurole o.sisi nana

she laaafia ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:06pm On Aug 08, 2007
Arabinrin Nana , e ma wo le si ori okun yii o. Alaafia a ko bi?

Minute, ko si igba ti kukulaja ogun(war) de, ti iran(clan) eso Ikoyi o gbera nile , gbera e nija.
Ebe ba laa b'oke(mountain), kokoko laa ba ota (bullet), ninu oye ede ati ilera ti o peye ni mo wa.
O ti bere na niyen o. O le ko iwe ranse so wo si mi lori adiresi ori alantakun mi , iseabe@yahoo.com.
Ko si ewu legberun eko a fi aidun obe.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:22pm On Aug 08, 2007
Kaare Baale !!

e gbo na, eru ikoni (lesson) wo le fe se oo??
Nitori Iseju mo yoruba to.
Koda o mo ju awon kan lo lori okun yi !
Kini minute fe mo si oo??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:28pm On Aug 08, 2007
bo ya ki olorun fun rara re da o lohun.
A kii saju elee de p'eede
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 5:35pm On Aug 08, 2007
Eku ojo mewa nibibayi o,ewo lari gbo, se kosi ija rara?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 5:46pm On Aug 08, 2007
ogbeni mishoo-madasi o,big bros mi ni richylaw anyday anytime.

kode le shi funmi lailai,abi kini moti wi bros richy?lol.

mogbo yoruba-yes,laisi ani ani nibe-but mofe ko biwon shen pede bi ogbeni richy.

abi she iyen tun je  eewo ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:53pm On Aug 08, 2007
O DARA NIGBA NA
A BERE ORO KII SINA !!
MO KAN FE MO BOYA - - - - -
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 6:02pm On Aug 08, 2007
nkan mi wani be tabi oma teyin e yo??

kamarii!!! egbon mi ni richy so jaami nbe!!

abere ona ki shina not oro.


moripe eyin naa while away time on nairaland,odaa bee!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:22pm On Aug 08, 2007
Ki ni ka wa se?? Aa sa ni parawa !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 6:33pm On Aug 08, 2007
ogaju, irinkerindo omo eda laye, o kun fun orisirisi isele iyanu.

ogbeni mishoo, e ku atoto nu lati aro.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:50pm On Aug 08, 2007
Tafari okunrin meta !!
Eni ko oo mo .
Eni mo oo ko .
Kaabo !!


Eewo la tun ri gbo oo
Ki lemu bo lati irinkerindo??
Abi ogboju ode ni yin ni??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 7:16pm On Aug 08, 2007
ejowo e kilo fun omidan Iseju o, ki o ye pe Baale wa l'oruko bii ara ilu lasan

abi eko mo pe lehin Eledumare Oba Ogo, Baale wa ni o tun se pataki si ara ilu?

ogbeni tafari ati alagba mishoo, mo kii yin o, se gbogbo e nlo dede?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 7:19pm On Aug 08, 2007
Engr Debosky, e kaabo si agbeede ilu wa yio o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 7:32pm On Aug 08, 2007
ese o ekuu ikinni

se akitiyan ati lakaka yin ko poju ni ilu irawo dudu?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 7:44pm On Aug 08, 2007
debosky:

ese o ekuu ikinni

se akitiyan ati lakaka yin ko poju ni ilu irawo dudu?

ko si ewu ni egberun eko. ilu larubawa ndun ni gbogbo igba.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 7:52pm On Aug 08, 2007
Ki a fi ope fun Eledumare ni gba naa.

awon omidan nko? iroyin ti mo gbo nipe awon ara ilu yen nise ni won ma ge owo enikeni ti o ba fi owo kan awon omobirin won

e sora ki won ma ge yin lowo o, e si wulo dara dara fun wa ni aafin, Oluwa o ni se wa ni olowo kan abo o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 8:04pm On Aug 08, 2007
won ni ekaabo lan ki ero onaa ,eku ile lan ki ara ile.
ekaabo-----tafari and debosky.


@debo-----awon agba man paa lowe wipe omokekere to ba mowo we,odidandan ko ba agba jeun,baale ole lailai binu simi.

showa?  wink wink wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 8:07pm On Aug 08, 2007
iroyin iro ni yen o.
omidan poo yaa nturu ni ilu kuwait o.
koda, olomi lo ma re. se awon laruba le fe so ni, abi filipino, indians, pakistani.
gbogbo won ni a npa je nibi yii. ki olorun ko wa yo ni. cheesy cheesy

(1) (2) (3) ... (92) (93) (94) (95) (96) (97) (98) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.