Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,796 members, 7,851,682 topics. Date: Thursday, 06 June 2024 at 05:23 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (96) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377468 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (93) (94) (95) (96) (97) (98) (99) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by damsol(f): 8:23pm On Aug 08, 2007
mi ko gbagbo pe o gbo yoruba
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 8:33pm On Aug 08, 2007
oodua ni mi tokan-tokan.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by damsol(f): 8:34pm On Aug 08, 2007
se loooooooooto?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 8:37pm On Aug 08, 2007
beeni, omo gbadamosi, e ku igbaladun. se ariya nlo ni gbogbo igba.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 8:56pm On Aug 08, 2007
e rora ko won je o tafari, ema je ki erekere lo di oyunkoyun, nitori awon iru won ni o maan d'omokomo grin grin grin

Omidan Iseju mo ti gbo tie. mo de wa pa naa wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 9:04pm On Aug 08, 2007
ko si wahala, to ba di oyun agbara olorun ka gbogbo e.
awon omoge kan waa ti eniyan ko gbodo ma jee nibe. awon apon bi epo, oreke lewa, ibadi aran ati beebee loo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 9:08pm On Aug 08, 2007
Ope ni f'Oluwa fun okun ati agbara lati ka gbogbo e

sugbon e gbodo sora fun awon apon bi epo o, iroyin miran ti mo tun gbo so wipe emi kemi maan gbe ninu won.

emi o de fe ki e darapo pelu emi biburu o, esi wulo gaan fun wa ni aafin.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 9:12pm On Aug 08, 2007
gbogbo ejo jije ni. wiwo ni gbogbo omoge. owo wa, ogun si wa pelu lipsrsealed
ko si nkan ti emi esu ma fi mi se. mo ti baa esu jeun lorita. padi mi ni emi okunkun.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 2:23am On Aug 09, 2007
shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 3:03am On Aug 09, 2007
Baale gbodo gbo eyi o!

ogbeni Tafari je padi pelu emi okunkun! shocked

Iru asiko ti a nilo Pastor haywhy ni yi o, lati se itusile pelu igbale gigun ati atorin elenu mefa grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 5:34am On Aug 09, 2007
ni badan ni won bi mi si o
ni badan ni wan bi mi si
baba wa pelu wa lonileX 2
ni badan eeeeee ni badan ni won bi mi si cheesy cheesy cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 6:01am On Aug 09, 2007
Debosky: Fi Tafari sile o, emi na ti n wo be tele. A se padi ni ohun ati emi okunkun. Abajo ti o fi fe je oye ki o ba le wa da ilu ru. Agbedo ki a mariĀ  shocked
Minute : Okan re bale o, se o ranti wipe mo ti so wipe emi ko ni tii igba kan bo ikan ninu! O didan ki a too ka to taa , a i jebe yio di eran idin.
Mishoo : Se oro ti wa ye o wayi, n je o ranti odu ti a ki fun Oba olufimo ninu Ayeyewontan?

Ayeyewontan iwa ibaje ni won n hu
A difa fun Olufimo Apopo ti o faya re moro
A pe 'je , ije o je o
A p'oro , Oro o mi titi o
E je a ye nu apeere oba wo.

Emi o ni se oro temi loro olufimo Apopo o.

Aloib: Pele omo Ibadan tooto, orin re yen de dun gan , o mu mi ranti iya mi Omoladun ( ki Olorun fi orun ke) . Awon ogidi omo Ibadan nu.
Iyalode Ika: Eyin na be ju wole, o da be. A bi emi Okunkun na ni o le yin pada ni. Tafari ti da nkan le o.
Tafari: Wahala wa o. eyi ti o tun so yi tun kamomo die o. O ti wa fihan wipe iwo ko ni fi okan awon omidan ati olomoge ilu yi bale pelu owo ati ogun re nu o. Ipade ilu ya, Baale stands up and leave for the palace meeting room
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 6:03am On Aug 09, 2007
ibadan ni wan bi mi si sugbon, ife ni mi, oduduwa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:26am On Aug 09, 2007
E karo o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 11:17am On Aug 09, 2007
Alaafia fun yin labule yio
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 12:22pm On Aug 09, 2007
Alaafia fun o o Ayanjide
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 1:28pm On Aug 09, 2007
Paga !!!
Kilati gbo si !!
Pe tafari n ba ebora muti yangan, o n be esu je efo riro lori okuta yangi lorita mefa !!

Ha oro re di inu ipade oo.
Je n sare loba Baale laafin !!

Ti a sese ngbimo ati fi o je oye !!
A si ni ao fe esu labule !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 1:35pm On Aug 09, 2007
E kuu kale eyin janmoo.
Ode o daa bi?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 1:51pm On Aug 09, 2007
Bolarge:

E kuu kale eyin janmoo.
Ode o daa bi?
Awon janmo n ja mon
Ode daa !
Se ile ti yin na daa??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 3:03pm On Aug 09, 2007
A dupe l'owo Olorun.
Kilo wa n sele lori thread yi bayi?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 3:10pm On Aug 09, 2007
ko si laburu kankan lori tiredi yii
ko baa le ni 'yanju naa la n seto
o si di dandan ko daa.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 3:13pm On Aug 09, 2007
Mo ki onile,mo ki alejo. Mo ki ara oko,mo ki ero ona.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 3:14pm On Aug 09, 2007
O daa naa mo wa leyin gbogbo yin oh.
Awon obinrin to rewa da? Abi omo nna ni gbogbo won ni? undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 3:16pm On Aug 09, 2007
nana:

Mo ki onile,mo ki alejo. Mo ki ara oko,mo ki ero ona.
Afi bi eni pe mo fi nkan senu soro.
Kaabo omo daadaa. Iwo naa la nduro de. cool grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NiteAngel(m): 3:27pm On Aug 09, 2007
E ki le o. Angeli Oru rin losan, ire ni o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 3:30pm On Aug 09, 2007
Ekaro ooo grin

gbe mi o, gbe mi o
ori mi gbemi lo ke oo

cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 3:52pm On Aug 09, 2007
@mishoo, eku ojometa se abule ti nfi araro. Mokoja si amuloko nigbati moriwipe ijongbon po nio. Boni nkan.
@aloib, omo Ibadan ni ile oluyole, irenakukale.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 3:54pm On Aug 09, 2007
Moki gbogbo awon ojogbon tiwondi abule imu. oroyin konisu Obaloke, kosinisu omo araye naa.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyalaje(m): 3:56pm On Aug 09, 2007
@ tafari, salam alykum o
se emo Alhaji sambaqi omowon ni ilu Iwo. Okeyin nikoje ki ari oke oun o. Emabinu pe opemidie.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NiteAngel(m): 4:44pm On Aug 09, 2007
Omoge, so wa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by deejay1(m): 5:41pm On Aug 09, 2007
ibaa gbogbo yin ooo boni nkan? se ojo oni mu oyin wa sha?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NiteAngel(m): 5:44pm On Aug 09, 2007
baa wa

(1) (2) (3) ... (93) (94) (95) (96) (97) (98) (99) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 20
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.