Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,156,400 members, 7,830,029 topics. Date: Thursday, 16 May 2024 at 03:15 PM

Oduduwa Nation: Gani Adams Ní Àìmọ Ìtàn Ló Ń Mú Kí Oluwo Máa Tako Ìpè Fún Ìyapa - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Oduduwa Nation: Gani Adams Ní Àìmọ Ìtàn Ló Ń Mú Kí Oluwo Máa Tako Ìpè Fún Ìyapa (246 Views)

Sat Guru Maharaji Supports Sunday Igboho, Oduduwa Nation / BBC NEWS: No Going Back On Call For Oduduwa Nation- Gani Adams / Operation Paramole: Oduduwa Nation Security Force Launched In Ogun (Photos) (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Oduduwa Nation: Gani Adams Ní Àìmọ Ìtàn Ló Ń Mú Kí Oluwo Máa Tako Ìpè Fún Ìyapa by Habsonflow(m): 4:59pm On Apr 01, 2021
Aarẹ Ọna Kakanfo fun ilẹ Yoruba, Iba Gani Adams ti ranṣẹ si Oluwo ti Ilu Iwo, lori bo ṣe n ta ko ọrọ idaduro ilẹ Yoruba, o ni ko lọ ranti pe bi wọn ba ran ọmọ ni iṣẹ ẹru, a fi tọmọ jẹ ẹ.

Iba Gani Adams sọ ọrọ yii ninu ifọrọwerọ rẹ pẹlu BBC News Yoruba lọjọbọ.

O ni pẹlu bi ọrọ abo, eto ẹkọ, ilera ati igbayegbadun araalu ṣe ri ni Naijiria bayii, ilẹ Yoruba ko lee tẹsiwaju ati maa sinru nibi to yẹ ko ti lẹnu
Gani Adams ni lootọ oun ko lee yọ ẹrẹkẹ ṣuti tabi eebu si ọba kankan ni ilẹ Yoruba, ṣugbọn o wa rọ awọn ọba Yoruba lati fi ara wọn sipo ọwọ, ki wọn si maa tẹ sibi tawọn ọmọ Yoruba ba tẹ si.

"Oluwo ṣẹṣẹ jẹ Ọba ni, ko mọ itan Yoruba lo fi n ṣe gbogbo ohun to n ṣe lori oye, ko mọ pe ọba ti ko ba se ifẹ araalu maa n kabamọ gbẹyin ni."

Kaa siwaju si: https://bbc.in/31BJTiz
Re: Oduduwa Nation: Gani Adams Ní Àìmọ Ìtàn Ló Ń Mú Kí Oluwo Máa Tako Ìpè Fún Ìyapa by BERNIMOORE: 5:24pm On Apr 01, 2021
Bawo ni oluwo se dé ori oyè gan an? Alainitiju eyan ati alailarojinle eyan bi Oba Abdulrasheed yen jé eni abámò ti kò ye rara lati je oba ni ilè Yoruba ...,irú u won kò lè wá ilosiwaju omo oodua ....awon Arije ní modàrú niwon...ko sí nkan tí wón nfi isokan yorúbá se, kakà bée ijegaba, alatakò iwà bí elénini ni iru won a ma a hù...irinsé ni wón tún jé fún awon árèwá ki won ba le maa jegaba lori iran Yoruba afi igba ti a bá rò wón loyè nikan...

(1) (Reply)

Chibok Abduction: What Buhari Told Me About Missing Girls – Zulum / Politicians Need You Badly / IGP Baba, Police Trust Fund, And Battle Against Insecurity

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.