Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,765 members, 7,817,107 topics. Date: Saturday, 04 May 2024 at 05:59 AM

Bii Aa See Loo Awon Asiri Kankan - Health - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Bii Aa See Loo Awon Asiri Kankan (785 Views)

Bii Aa See Loo Awon Oduu Ifa Kankan / Ise Osole Awon Babami Ayee Igba Nii Tii Won Fii Jehun / Eleyi Ni Awon Asiri Ewe Ati Egbo (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Bii Aa See Loo Awon Asiri Kankan by bullet001: 10:19am On Apr 23, 2021
EYONU AWON AGBA

AIDAN KAN
ODIDI ATARE KAN

LO KUNNA DADA AO TENI FA EJIOGBE AO PE GBOLOHUNRE SI ..

Ohunre:-

Elarowa3*
Ifa mope ejiogbe ni baba ifa
Emi l-l ni mo pe iwo ejiogbe baba ifa wele loru loruko tanpe iwo iku
Wele loruko tanpe iwo arun ,
Owele wele ni oruko tianpe iwo asasi , olokun emi loruko tianpe eyin iyami osoronga eyin leye soso ori oro eyin lejoko talakara maraeni ra akara , esi ni jeki alakara kota bi ale balee ,gbogbo eye ndarijo sorigi aidan ibe ni olodumare ti nran se siwon pekin lense lori igi aidan, eleyin koni bale igi ree keje eso ree emi l-l moje eso aidan loni yii ooo emase fi owo aburu yin kan mi mo kiesi ma ba nkan mije mo
Ao ma bu ebu sinu epo ogere fun lila ...
Lalalee

Eni toba fe koje fun kofi comment dupe oree

Dr ifa Lana awoyemi ogboni Ile Yoruba patapata08146664979 abii Koo add mii sii ori WhatsApp
Re: Bii Aa See Loo Awon Asiri Kankan by Babakolanut(m): 9:44pm On Mar 29, 2023
E se pupo sir,ejowo kini enia le lo fun Ipake (HERNIA)
Re: Bii Aa See Loo Awon Asiri Kankan by Babakolanut(m): 9:45pm On Mar 29, 2023
E se pupo sir,ejowo kini enia le lo fun Ipake (HERNIA) Whatsapp mi ni +2349034612092
Re: Bii Aa See Loo Awon Asiri Kankan by Marakeem: 11:10pm On Mar 29, 2023
OGUN HERNIA TODAJU BI IKU
E lo wa ESO BOMUBOMU to po daadaa, ao wa gun kunna daadaa, ao ko sinu ike table water, ao wa da oti Lord tabi Schnapp le lori, ao fi le fun ojo meji, ao ma wa mu ni gaasi kan laaro laaro ki a to jeun. Pelu ogo Olohun Oba, eniyen o ni gburo e mo. Odaju gan

(1) (Reply)

How 10 Pushups Every Day Will Completely Transform Your Body | Push Ups / Superlife Registration Package / Advice On A Drug Addict

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.