Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,790 members, 7,810,051 topics. Date: Friday, 26 April 2024 at 07:35 PM

Pastor Adeboye's Son: Ṣé Lóòtọ́ Ni Pasítọ̀ Dare, Ọmọ́ Pásítọ̀ Adeboye Ti Dágbéré - Nairaland / General - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Pastor Adeboye's Son: Ṣé Lóòtọ́ Ni Pasítọ̀ Dare, Ọmọ́ Pásítọ̀ Adeboye Ti Dágbéré (146 Views)

Islamic Group Give Reason For Adeboye Son's Death / Pastor Adeboye, Oyedepo & Kumuyi Will Die And Go To Hell Fire – A / My Successor Is Still A Sinner But Decided To Choose Another. Pastor Adeboye (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Pastor Adeboye's Son: Ṣé Lóòtọ́ Ni Pasítọ̀ Dare, Ọmọ́ Pásítọ̀ Adeboye Ti Dágbéré by Habsonflow(m): 9:49am On May 06, 2021
Iroyin to n tẹ wa lọwọ ni yajoyajo sọ pe Pasitọ Dare Adeboye to jẹ ọmọ oludari ijọ Redeemed Christian Church of God, Pasitọ Adejare Adeboye ti jade laye.

Ọkan lara awọn Pasitọ agba ijọ RCCG to tun eeyan to ṣee fọkan tan ni ijọ naa sọ fun BBC Yoruba pe lootọ ni awọn ti gbọ iroyin naa.

Ko fẹ ki awọn oniroyin maa gbe idi ti ko jẹ ootọ nipa iṣẹlẹ yii amọ o fi aridaju ọrọ naa mulẹ fun BBC Yoruba pe lootọ ni Pasitọ Dare dagbere faye lalẹ Ọjọru.

Ṣugbọn o ni adura ni ki gbogbo eeyan maa gba fun mọlẹbi Adeboye ki wọn ri itunu ati okun Ọlọrun.

Kaa siwaju sí: https://bbc.in/3vOo5No
Re: Pastor Adeboye's Son: Ṣé Lóòtọ́ Ni Pasítọ̀ Dare, Ọmọ́ Pásítọ̀ Adeboye Ti Dágbéré by peteregwu(m): 9:57am On May 06, 2021
This guy ehh...whicb one be this na?

May his soul rest in peace.
Re: Pastor Adeboye's Son: Ṣé Lóòtọ́ Ni Pasítọ̀ Dare, Ọmọ́ Pásítọ̀ Adeboye Ti Dágbéré by IjapaTiroko: 10:02am On May 06, 2021
Àwon ìròhìn búburú màá n tètè tàn ká. Òpòlopò Blogger ni won ò kín farabalé láti se ìwádí bóyá òótó ni ìròhìn tí won n tàn ká

(1) (Reply)

Common Oral Health Care Myths / A Woman That Suffered With You Or The One Who Helped You Become Someone – Who Wi / NCC Warns Nigerians Of SIM-NIN Linkage Deadline

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 14
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.